Genesis 10 (BOYCB)

1 Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi. 2 Àwọn ọmọ Jafeti ni:Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi. 3 Àwọn ọmọ Gomeri ni:Aṣkenasi, Rifati àti Togarma. 4 Àwọn ọmọ Jafani ni:Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu. 5 (Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀). 6 Àwọn ọmọ Hamu ni:Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani. 7 Àwọn ọmọ Kuṣi ni:Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.Àwọn ọmọ Raama ni:Ṣeba àti Dedani. 8 Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé. 9 Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú OLÚWA; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú OLÚWA.” 10 Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni Babeli, Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari. 11 Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala, 12 àti Resini, tí ó wà ní àárín Ninefe àti Kala, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí. 13 Ejibiti sì bíLudimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu. 14 Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu. 15 Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀,àti Heti. 16 Àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi, 17 àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini, 18 àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati.Lẹ́yìn èyí ni àwọn ẹ̀yà Kenaani tànkálẹ̀. 19 Ààlà ilẹ̀ àwọn ará Kenaani sì dé Sidoni, lọ sí Gerari títí dé Gasa, lọ sí Sodomu, Gomorra, Adma àti Seboimu, títí dé Laṣa. 20 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Hamu, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, àti èdè wọn, ní ìpínlẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn. 21 A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí Jafeti jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ Eberi. 22 Àwọn ọmọ Ṣemu ni:Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. 23 Àwọn ọmọ Aramu ni:Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki. 24 Arfakṣadi sì bí Ṣela,Ṣela sì bí Eberi. 25 Eberi sì bí ọmọ méjì:ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani. 26 Joktani sì bíAlmodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. 27 Hadoramu, Usali, Dikla, 28 Obali, Abimaeli, Ṣeba. 29 Ofiri, Hafila àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani. 30 Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Meṣa títí dé Sefari, ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà-oòrùn. 31 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Ṣemu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, ní èdè wọn, ní ilẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn. 32 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Noa gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, ní orílẹ̀-èdè wọn. Ní ipasẹ̀ wọn ni àwọn ènìyàn ti tàn ká ilẹ̀ ayé lẹ́yìn ìkún omi.

In Other Versions

Genesis 10 in the ANGEFD

Genesis 10 in the ANTPNG2D

Genesis 10 in the AS21

Genesis 10 in the BAGH

Genesis 10 in the BBPNG

Genesis 10 in the BBT1E

Genesis 10 in the BDS

Genesis 10 in the BEV

Genesis 10 in the BHAD

Genesis 10 in the BIB

Genesis 10 in the BLPT

Genesis 10 in the BNT

Genesis 10 in the BNTABOOT

Genesis 10 in the BNTLV

Genesis 10 in the BOATCB

Genesis 10 in the BOATCB2

Genesis 10 in the BOBCV

Genesis 10 in the BOCNT

Genesis 10 in the BOECS

Genesis 10 in the BOGWICC

Genesis 10 in the BOHCB

Genesis 10 in the BOHCV

Genesis 10 in the BOHLNT

Genesis 10 in the BOHNTLTAL

Genesis 10 in the BOICB

Genesis 10 in the BOILNTAP

Genesis 10 in the BOITCV

Genesis 10 in the BOKCV

Genesis 10 in the BOKCV2

Genesis 10 in the BOKHWOG

Genesis 10 in the BOKSSV

Genesis 10 in the BOLCB

Genesis 10 in the BOLCB2

Genesis 10 in the BOMCV

Genesis 10 in the BONAV

Genesis 10 in the BONCB

Genesis 10 in the BONLT

Genesis 10 in the BONUT2

Genesis 10 in the BOPLNT

Genesis 10 in the BOSCB

Genesis 10 in the BOSNC

Genesis 10 in the BOTLNT

Genesis 10 in the BOVCB

Genesis 10 in the BPBB

Genesis 10 in the BPH

Genesis 10 in the BSB

Genesis 10 in the CCB

Genesis 10 in the CUV

Genesis 10 in the CUVS

Genesis 10 in the DBT

Genesis 10 in the DGDNT

Genesis 10 in the DHNT

Genesis 10 in the DNT

Genesis 10 in the ELBE

Genesis 10 in the EMTV

Genesis 10 in the ESV

Genesis 10 in the FBV

Genesis 10 in the FEB

Genesis 10 in the GGMNT

Genesis 10 in the GNT

Genesis 10 in the HARY

Genesis 10 in the HNT

Genesis 10 in the IRVA

Genesis 10 in the IRVB

Genesis 10 in the IRVG

Genesis 10 in the IRVH

Genesis 10 in the IRVK

Genesis 10 in the IRVM

Genesis 10 in the IRVM2

Genesis 10 in the IRVO

Genesis 10 in the IRVP

Genesis 10 in the IRVT

Genesis 10 in the IRVT2

Genesis 10 in the IRVU

Genesis 10 in the ISVN

Genesis 10 in the JSNT

Genesis 10 in the KAPI

Genesis 10 in the KBT1ETNIK

Genesis 10 in the KBV

Genesis 10 in the KJV

Genesis 10 in the KNFD

Genesis 10 in the LBA

Genesis 10 in the LBLA

Genesis 10 in the LNT

Genesis 10 in the LSV

Genesis 10 in the MAAL

Genesis 10 in the MBV

Genesis 10 in the MBV2

Genesis 10 in the MHNT

Genesis 10 in the MKNFD

Genesis 10 in the MNG

Genesis 10 in the MNT

Genesis 10 in the MNT2

Genesis 10 in the MRS1T

Genesis 10 in the NAA

Genesis 10 in the NASB

Genesis 10 in the NBLA

Genesis 10 in the NBS

Genesis 10 in the NBVTP

Genesis 10 in the NET2

Genesis 10 in the NIV11

Genesis 10 in the NNT

Genesis 10 in the NNT2

Genesis 10 in the NNT3

Genesis 10 in the PDDPT

Genesis 10 in the PFNT

Genesis 10 in the RMNT

Genesis 10 in the SBIAS

Genesis 10 in the SBIBS

Genesis 10 in the SBIBS2

Genesis 10 in the SBICS

Genesis 10 in the SBIDS

Genesis 10 in the SBIGS

Genesis 10 in the SBIHS

Genesis 10 in the SBIIS

Genesis 10 in the SBIIS2

Genesis 10 in the SBIIS3

Genesis 10 in the SBIKS

Genesis 10 in the SBIKS2

Genesis 10 in the SBIMS

Genesis 10 in the SBIOS

Genesis 10 in the SBIPS

Genesis 10 in the SBISS

Genesis 10 in the SBITS

Genesis 10 in the SBITS2

Genesis 10 in the SBITS3

Genesis 10 in the SBITS4

Genesis 10 in the SBIUS

Genesis 10 in the SBIVS

Genesis 10 in the SBT

Genesis 10 in the SBT1E

Genesis 10 in the SCHL

Genesis 10 in the SNT

Genesis 10 in the SUSU

Genesis 10 in the SUSU2

Genesis 10 in the SYNO

Genesis 10 in the TBIAOTANT

Genesis 10 in the TBT1E

Genesis 10 in the TBT1E2

Genesis 10 in the TFTIP

Genesis 10 in the TFTU

Genesis 10 in the TGNTATF3T

Genesis 10 in the THAI

Genesis 10 in the TNFD

Genesis 10 in the TNT

Genesis 10 in the TNTIK

Genesis 10 in the TNTIL

Genesis 10 in the TNTIN

Genesis 10 in the TNTIP

Genesis 10 in the TNTIZ

Genesis 10 in the TOMA

Genesis 10 in the TTENT

Genesis 10 in the UBG

Genesis 10 in the UGV

Genesis 10 in the UGV2

Genesis 10 in the UGV3

Genesis 10 in the VBL

Genesis 10 in the VDCC

Genesis 10 in the YALU

Genesis 10 in the YAPE

Genesis 10 in the YBVTP

Genesis 10 in the ZBP