Hebrews 5 (BOYCB)
1 Nítorí olórí àlùfáà kọ̀ọ̀kan tí a yàn nínú àwọn ènìyàn, ní a fi jẹ nítorí iṣẹ́ ìsìn àwọn ènìyàn sí Ọlọ́run láti máa mú ẹ̀bùn àti ẹbọ wá nítorí ẹ̀ṣẹ̀. 2 Ẹni tí ó lè ṣe jẹ́ẹ́jẹ́ pẹ̀lú àwọn aláìmòye, tí ó sì lé bá àwọn tí ó ti yapa kẹ́dùn, nítorí a fi àìlera yí òun náà ká pẹ̀lú. 3 Nítorí ìdí èyí ni ó ṣe yẹ, bí ó ti ń rú ẹbọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ fún àwọn ènìyàn rẹ̀, bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ní ń ṣe fún ara rẹ̀ náà. 4 Kọ sí ẹni tí o gba ọlá yìí fún ara rẹ̀, bí kò ṣe ẹni tí a pè láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá gẹ́gẹ́ bí a ti pe Aaroni. 5 Bẹ́ẹ̀ ni Kristi pẹ̀lú kò sì ṣe ara rẹ̀ lógo láti jẹ́ olórí àlùfáà; bí kò ṣe ẹni tí o wí fún ún pé,“Ìwọ ni ọmọ mi,lónìí ni mo bí ọ.” 6 Bí ó ti wí pẹ̀lú ní ibòmíràn pé,“Ìwọ ni àlùfáà títí láéní ipasẹ̀ Melkisedeki.” 7 Ní ìgbà ọjọ́ Jesu nínú ayé, ó fi ìkérora rara àti omijé gbàdúrà, tí ó sì bẹ̀bẹ̀ lọ́dọ̀ ẹni tí ó lè gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ ikú, a sì gbóhùn rẹ̀ nítorí ó ní ẹ̀mí ìbẹ̀rù Ọlọ́run rẹ̀. 8 Bí òun tilẹ̀ ń ṣe Ọmọ Ọlọ́run, síbẹ̀ ó kọ́ ìgbọ́ran nípa ohun tí ó jìyà rẹ̀. 9 Bí a sì ti sọ ọ di pípé, o wa di orísun ìgbàlà àìnípẹ̀kun fún gbogbo àwọn tí ó ń gbọ́ tirẹ̀, 10 tí a yàn ní olórí àlùfáà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá ní ipasẹ̀ Melkisedeki. 11 Nípa èyí àwa ní ohun púpọ̀ láti sọ, tí ó sì ṣòro láti túmọ̀, nítorí pé ẹ yigbì ní gbígbọ́. 12 Nítorí pé báyìí ó ti yẹ kí ẹ jẹ́ olùkọ́ni, ẹ tún wà ní ẹni tí ẹnìkan yóò máa kọ́ ni ìbẹ̀rẹ̀ ìpìlẹ̀ ẹ̀kọ́ àwọn ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, ẹ sì tún di irú àwọn tí ó mu wàrà, tí wọn kò sì fẹ́ oúnjẹ líle. 13 Nítorí olúkúlùkù ẹni tí ń mu wàrà jẹ́ aláìlóye ọ̀rọ̀ òdodo, nítorí ọmọ ọwọ́ ni. 14 Ṣùgbọ́n oúnjẹ líle wà fún àwọn tí ó dàgbà, àwọn ẹni nípa ìrírí, tí wọn ń lo ọgbọ́n wọn láti fi ìyàtọ̀ sáàrín rere àti búburú.
In Other Versions
Hebrews 5 in the ANGEFD
Hebrews 5 in the ANTPNG2D
Hebrews 5 in the AS21
Hebrews 5 in the BAGH
Hebrews 5 in the BBPNG
Hebrews 5 in the BBT1E
Hebrews 5 in the BDS
Hebrews 5 in the BEV
Hebrews 5 in the BHAD
Hebrews 5 in the BIB
Hebrews 5 in the BLPT
Hebrews 5 in the BNT
Hebrews 5 in the BNTABOOT
Hebrews 5 in the BNTLV
Hebrews 5 in the BOATCB
Hebrews 5 in the BOATCB2
Hebrews 5 in the BOBCV
Hebrews 5 in the BOCNT
Hebrews 5 in the BOECS
Hebrews 5 in the BOGWICC
Hebrews 5 in the BOHCB
Hebrews 5 in the BOHCV
Hebrews 5 in the BOHLNT
Hebrews 5 in the BOHNTLTAL
Hebrews 5 in the BOICB
Hebrews 5 in the BOILNTAP
Hebrews 5 in the BOITCV
Hebrews 5 in the BOKCV
Hebrews 5 in the BOKCV2
Hebrews 5 in the BOKHWOG
Hebrews 5 in the BOKSSV
Hebrews 5 in the BOLCB
Hebrews 5 in the BOLCB2
Hebrews 5 in the BOMCV
Hebrews 5 in the BONAV
Hebrews 5 in the BONCB
Hebrews 5 in the BONLT
Hebrews 5 in the BONUT2
Hebrews 5 in the BOPLNT
Hebrews 5 in the BOSCB
Hebrews 5 in the BOSNC
Hebrews 5 in the BOTLNT
Hebrews 5 in the BOVCB
Hebrews 5 in the BPBB
Hebrews 5 in the BPH
Hebrews 5 in the BSB
Hebrews 5 in the CCB
Hebrews 5 in the CUV
Hebrews 5 in the CUVS
Hebrews 5 in the DBT
Hebrews 5 in the DGDNT
Hebrews 5 in the DHNT
Hebrews 5 in the DNT
Hebrews 5 in the ELBE
Hebrews 5 in the EMTV
Hebrews 5 in the ESV
Hebrews 5 in the FBV
Hebrews 5 in the FEB
Hebrews 5 in the GGMNT
Hebrews 5 in the GNT
Hebrews 5 in the HARY
Hebrews 5 in the HNT
Hebrews 5 in the IRVA
Hebrews 5 in the IRVB
Hebrews 5 in the IRVG
Hebrews 5 in the IRVH
Hebrews 5 in the IRVK
Hebrews 5 in the IRVM
Hebrews 5 in the IRVM2
Hebrews 5 in the IRVO
Hebrews 5 in the IRVP
Hebrews 5 in the IRVT
Hebrews 5 in the IRVT2
Hebrews 5 in the IRVU
Hebrews 5 in the ISVN
Hebrews 5 in the JSNT
Hebrews 5 in the KAPI
Hebrews 5 in the KBT1ETNIK
Hebrews 5 in the KBV
Hebrews 5 in the KJV
Hebrews 5 in the KNFD
Hebrews 5 in the LBA
Hebrews 5 in the LBLA
Hebrews 5 in the LNT
Hebrews 5 in the LSV
Hebrews 5 in the MAAL
Hebrews 5 in the MBV
Hebrews 5 in the MBV2
Hebrews 5 in the MHNT
Hebrews 5 in the MKNFD
Hebrews 5 in the MNG
Hebrews 5 in the MNT
Hebrews 5 in the MNT2
Hebrews 5 in the MRS1T
Hebrews 5 in the NAA
Hebrews 5 in the NASB
Hebrews 5 in the NBLA
Hebrews 5 in the NBS
Hebrews 5 in the NBVTP
Hebrews 5 in the NET2
Hebrews 5 in the NIV11
Hebrews 5 in the NNT
Hebrews 5 in the NNT2
Hebrews 5 in the NNT3
Hebrews 5 in the PDDPT
Hebrews 5 in the PFNT
Hebrews 5 in the RMNT
Hebrews 5 in the SBIAS
Hebrews 5 in the SBIBS
Hebrews 5 in the SBIBS2
Hebrews 5 in the SBICS
Hebrews 5 in the SBIDS
Hebrews 5 in the SBIGS
Hebrews 5 in the SBIHS
Hebrews 5 in the SBIIS
Hebrews 5 in the SBIIS2
Hebrews 5 in the SBIIS3
Hebrews 5 in the SBIKS
Hebrews 5 in the SBIKS2
Hebrews 5 in the SBIMS
Hebrews 5 in the SBIOS
Hebrews 5 in the SBIPS
Hebrews 5 in the SBISS
Hebrews 5 in the SBITS
Hebrews 5 in the SBITS2
Hebrews 5 in the SBITS3
Hebrews 5 in the SBITS4
Hebrews 5 in the SBIUS
Hebrews 5 in the SBIVS
Hebrews 5 in the SBT
Hebrews 5 in the SBT1E
Hebrews 5 in the SCHL
Hebrews 5 in the SNT
Hebrews 5 in the SUSU
Hebrews 5 in the SUSU2
Hebrews 5 in the SYNO
Hebrews 5 in the TBIAOTANT
Hebrews 5 in the TBT1E
Hebrews 5 in the TBT1E2
Hebrews 5 in the TFTIP
Hebrews 5 in the TFTU
Hebrews 5 in the TGNTATF3T
Hebrews 5 in the THAI
Hebrews 5 in the TNFD
Hebrews 5 in the TNT
Hebrews 5 in the TNTIK
Hebrews 5 in the TNTIL
Hebrews 5 in the TNTIN
Hebrews 5 in the TNTIP
Hebrews 5 in the TNTIZ
Hebrews 5 in the TOMA
Hebrews 5 in the TTENT
Hebrews 5 in the UBG
Hebrews 5 in the UGV
Hebrews 5 in the UGV2
Hebrews 5 in the UGV3
Hebrews 5 in the VBL
Hebrews 5 in the VDCC
Hebrews 5 in the YALU
Hebrews 5 in the YAPE
Hebrews 5 in the YBVTP
Hebrews 5 in the ZBP