Isaiah 55 (BOYCB)
1 “Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin tí òǹgbẹ ń gbẹ,ẹ wá sí ibi omi;àti ẹ̀yin tí kò ní owó;ẹ wá, ẹ rà kí ẹ sì jẹ!Ẹ wá ra wáìnì àti wàràláìsí owó àti láìdíyelé. 2 Èéṣe tí ẹ fi ń ná owó fún èyí tí kì í ṣe àkàrààti làálàá yín lórí ohun tí kì í tẹ́nilọ́rùn?Tẹ́tí sílẹ̀, tẹ́tí sí mi, kí ẹ sì jẹ èyí tí ó dára,bẹ́ẹ̀ ni ọkàn yín yóò láyọ̀ nínú ọrọ̀ tí ó bójúmu. 3 Tẹ́tí sílẹ̀ kí o sì wá sọ́dọ̀ mi;gbọ́ tèmi, kí ọkàn rẹ lè wà láààyè.Èmi yóò dá májẹ̀mú ayérayé pẹ̀lú rẹ,ìfẹ́ òtítọ́ tí mo ṣèlérí fún Dafidi. 4 Kíyèsi i, mo ti fi òun ṣe ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn,olórí àti apàṣẹ fún àwọn ènìyàn. 5 Lóòtítọ́ ìwọ yóò ké sí àwọn orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀àti orílẹ̀-èdè tí ìwọ kò mọ̀ ni yóò sáré tọ̀ ọ́ wá,nítorí OLÚWA Ọlọ́run rẹẸni Mímọ́ Israẹlinítorí pé ó ti fi ohun dídára dá ọ lọ́lá.” 6 Ẹ wá OLÚWA nígbà tí ẹ lè rí i;ẹ pè é nígbà tí ó wà nítòsí. 7 Jẹ́ kí ìkà kí ó kọ ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀àti ènìyàn búburú èrò rẹ̀.Jẹ́ kí ó yípadà sí OLÚWA, Òun yóò sì ṣàánú fún un,àti sí Ọlọ́run wa, nítorí Òun yóò sì dáríjì. 8 “Nítorí èrò mi kì í ṣe èrò yín,tàbí ọ̀nà yín a ha máa ṣe ọ̀nà mi,”ni OLÚWA wí. 9 “Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ,bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín lọàti èrò mi ju èrò yín lọ. 10 Gẹ́gẹ́ bí òjò àti yìnyínti wálẹ̀ láti ọ̀runtí kì í sì padà sí ibẹ̀láì bomirin ilẹ̀kí ó sì mú kí ó tanná kí ó sì rudi,tó bẹ́ẹ̀ tí yóò fi mú irúgbìn fún afúnrúgbìnàti àkàrà fún ọ̀jẹun, 11 bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá;kì yóò padà sọ́dọ̀ mi lọ́wọ́ òfo,ṣùgbọ́n yóò ṣe ohun tí mo fẹ́,yóò sì mú ète mi tí mo fi rán an wá sí ìmúṣẹ. 12 Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀a ó sì darí i yín lọ ní àlàáfíà;òkè ńlá ńlá àti kéékèèkéyóò bú sí orin níwájú yínàti gbogbo igi inú pápáyóò máa pàtẹ́wọ́. 13 Dípò igi ẹ̀gún ni igi junifa yóò máa dàgbà,àti dípò ẹ̀wọ̀n, maritili ni yóò yọ.Èyí yóò wà fún òkìkí OLÚWA,fún àmì ayérayé,tí a kì yóò lè parun.”
In Other Versions
Isaiah 55 in the ANGEFD
Isaiah 55 in the ANTPNG2D
Isaiah 55 in the AS21
Isaiah 55 in the BAGH
Isaiah 55 in the BBPNG
Isaiah 55 in the BBT1E
Isaiah 55 in the BDS
Isaiah 55 in the BEV
Isaiah 55 in the BHAD
Isaiah 55 in the BIB
Isaiah 55 in the BLPT
Isaiah 55 in the BNT
Isaiah 55 in the BNTABOOT
Isaiah 55 in the BNTLV
Isaiah 55 in the BOATCB
Isaiah 55 in the BOATCB2
Isaiah 55 in the BOBCV
Isaiah 55 in the BOCNT
Isaiah 55 in the BOECS
Isaiah 55 in the BOGWICC
Isaiah 55 in the BOHCB
Isaiah 55 in the BOHCV
Isaiah 55 in the BOHLNT
Isaiah 55 in the BOHNTLTAL
Isaiah 55 in the BOICB
Isaiah 55 in the BOILNTAP
Isaiah 55 in the BOITCV
Isaiah 55 in the BOKCV
Isaiah 55 in the BOKCV2
Isaiah 55 in the BOKHWOG
Isaiah 55 in the BOKSSV
Isaiah 55 in the BOLCB
Isaiah 55 in the BOLCB2
Isaiah 55 in the BOMCV
Isaiah 55 in the BONAV
Isaiah 55 in the BONCB
Isaiah 55 in the BONLT
Isaiah 55 in the BONUT2
Isaiah 55 in the BOPLNT
Isaiah 55 in the BOSCB
Isaiah 55 in the BOSNC
Isaiah 55 in the BOTLNT
Isaiah 55 in the BOVCB
Isaiah 55 in the BPBB
Isaiah 55 in the BPH
Isaiah 55 in the BSB
Isaiah 55 in the CCB
Isaiah 55 in the CUV
Isaiah 55 in the CUVS
Isaiah 55 in the DBT
Isaiah 55 in the DGDNT
Isaiah 55 in the DHNT
Isaiah 55 in the DNT
Isaiah 55 in the ELBE
Isaiah 55 in the EMTV
Isaiah 55 in the ESV
Isaiah 55 in the FBV
Isaiah 55 in the FEB
Isaiah 55 in the GGMNT
Isaiah 55 in the GNT
Isaiah 55 in the HARY
Isaiah 55 in the HNT
Isaiah 55 in the IRVA
Isaiah 55 in the IRVB
Isaiah 55 in the IRVG
Isaiah 55 in the IRVH
Isaiah 55 in the IRVK
Isaiah 55 in the IRVM
Isaiah 55 in the IRVM2
Isaiah 55 in the IRVO
Isaiah 55 in the IRVP
Isaiah 55 in the IRVT
Isaiah 55 in the IRVT2
Isaiah 55 in the IRVU
Isaiah 55 in the ISVN
Isaiah 55 in the JSNT
Isaiah 55 in the KAPI
Isaiah 55 in the KBT1ETNIK
Isaiah 55 in the KBV
Isaiah 55 in the KJV
Isaiah 55 in the KNFD
Isaiah 55 in the LBA
Isaiah 55 in the LBLA
Isaiah 55 in the LNT
Isaiah 55 in the LSV
Isaiah 55 in the MAAL
Isaiah 55 in the MBV
Isaiah 55 in the MBV2
Isaiah 55 in the MHNT
Isaiah 55 in the MKNFD
Isaiah 55 in the MNG
Isaiah 55 in the MNT
Isaiah 55 in the MNT2
Isaiah 55 in the MRS1T
Isaiah 55 in the NAA
Isaiah 55 in the NASB
Isaiah 55 in the NBLA
Isaiah 55 in the NBS
Isaiah 55 in the NBVTP
Isaiah 55 in the NET2
Isaiah 55 in the NIV11
Isaiah 55 in the NNT
Isaiah 55 in the NNT2
Isaiah 55 in the NNT3
Isaiah 55 in the PDDPT
Isaiah 55 in the PFNT
Isaiah 55 in the RMNT
Isaiah 55 in the SBIAS
Isaiah 55 in the SBIBS
Isaiah 55 in the SBIBS2
Isaiah 55 in the SBICS
Isaiah 55 in the SBIDS
Isaiah 55 in the SBIGS
Isaiah 55 in the SBIHS
Isaiah 55 in the SBIIS
Isaiah 55 in the SBIIS2
Isaiah 55 in the SBIIS3
Isaiah 55 in the SBIKS
Isaiah 55 in the SBIKS2
Isaiah 55 in the SBIMS
Isaiah 55 in the SBIOS
Isaiah 55 in the SBIPS
Isaiah 55 in the SBISS
Isaiah 55 in the SBITS
Isaiah 55 in the SBITS2
Isaiah 55 in the SBITS3
Isaiah 55 in the SBITS4
Isaiah 55 in the SBIUS
Isaiah 55 in the SBIVS
Isaiah 55 in the SBT
Isaiah 55 in the SBT1E
Isaiah 55 in the SCHL
Isaiah 55 in the SNT
Isaiah 55 in the SUSU
Isaiah 55 in the SUSU2
Isaiah 55 in the SYNO
Isaiah 55 in the TBIAOTANT
Isaiah 55 in the TBT1E
Isaiah 55 in the TBT1E2
Isaiah 55 in the TFTIP
Isaiah 55 in the TFTU
Isaiah 55 in the TGNTATF3T
Isaiah 55 in the THAI
Isaiah 55 in the TNFD
Isaiah 55 in the TNT
Isaiah 55 in the TNTIK
Isaiah 55 in the TNTIL
Isaiah 55 in the TNTIN
Isaiah 55 in the TNTIP
Isaiah 55 in the TNTIZ
Isaiah 55 in the TOMA
Isaiah 55 in the TTENT
Isaiah 55 in the UBG
Isaiah 55 in the UGV
Isaiah 55 in the UGV2
Isaiah 55 in the UGV3
Isaiah 55 in the VBL
Isaiah 55 in the VDCC
Isaiah 55 in the YALU
Isaiah 55 in the YAPE
Isaiah 55 in the YBVTP
Isaiah 55 in the ZBP