Isaiah 56 (BOYCB)

1 Èyí ni ohun ti OLÚWA sọ:“Ẹ pa ìdájọ́ mọ́ẹ sì ṣe ohun tí ó tọ̀nà,nítorí ìgbàlà mi súnmọ́ tòsíàti òdodo mi ni a ó fihàn láìpẹ́ jọjọ. 2 Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ó ṣe èyí,àti fún ọmọ ènìyàn tí ó dìímú ṣinṣin,tí ó pa ọjọ́ ìsinmi mọ́ láì bà á jẹ́,tí ó sì pa ọwọ́ rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ibi ṣíṣe.” 3 Má ṣe jẹ́ kí àjèjì kan tí ó ti di ara rẹ̀mọ́ OLÚWA sọ wí pé,“OLÚWA yóò yà mí sọ́tọ̀ kúrò nínú àwọn ènìyàn rẹ̀.”Àti kí ìwẹ̀fà kan ṣe àròyé pé,“Igi gbígbẹ lásán ni mí.” 4 Nítorí pé báyìí ni OLÚWA wí:“Sí àwọn ìwẹ̀fà yìí tí ó pa ọjọ́ ìsinmi mi mọ́,tí wọ́n yan ohun tí ó dùn mọ́ mití wọ́n sì di májẹ̀mú mi mú ṣinṣin 5 fún wọn ni Èmi yóò fún nínú tẹmpili àti àgbàlá rẹ̀ìrántí kan àti orúkọ kantí ó sàn ju àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrin,Èmi yóò fún wọn ní orúkọ ayérayétí a kì yóò ké kúrò. 6 Àti àwọn àjèjì tí ó so ara wọn mọ́ OLÚWAláti sìn ín,láti fẹ́ orúkọ OLÚWAàti láti foríbalẹ̀ fún ungbogbo àwọn tí ń pa ọjọ́ ìsinmi mọ́ láì bà á jẹ́àti tí wọ́n sì di májẹ̀mú mi mú ṣinṣin— 7 àwọn wọ̀nyí ni èmi yóò mú wá òkè mímọ́ mi,èmi ó sì fún wọn ní ayọ̀ nínú ilé àdúrà mi.Ẹbọ sísun wọn àti ìrúbọ wọn,ni a ó tẹ́wọ́gbà lórí i pẹpẹ mi;nítorí a ó máa pe ilé mi níilé àdúrà fún gbogbo orílẹ̀-èdè.” 8 OLÚWA Olódùmarè sọ wí pé—ẹni tí ó kó àwọn àtìpó Israẹli jọ:“Èmi yóò kó àwọn mìíràn jọ pẹ̀lú wọnyàtọ̀ sí àwọn tí a ti kójọ.” 9 Ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin ẹranko inú pápá,ẹ wá jẹ àwọn ẹranko inú igbó run! 10 Àwọn olùṣọ́ Israẹli fọ́jú,gbogbo wọn ṣe aláìní ìmọ̀;gbogbo wọn jẹ́ adití ajá,wọn kò lè gbó;wọ́n sùn sílẹ̀ wọ́n ń lálàá,wọ́n fẹ́ràn láti máa sùn. 11 Wọ́n jẹ́ àwọn ajá tí ó kúndùn púpọ̀;wọn kì í ní ànító.Wọ́n jẹ́ olùṣọ́-àgùntàn tí kò ní òye;olúkúlùkù ń yà ṣọ́nà ara rẹ̀,ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn sì wá ère tirẹ̀. 12 Igbe ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ni wí pé, “Wá, fún mi ní ọtí wáìnì!Jẹ́ kí a mu ọtí líle wa lámu yóọ̀la yóò sì dàbí òní,tàbí kí ó dára jù bẹ́ẹ̀ lọ.”

In Other Versions

Isaiah 56 in the ANGEFD

Isaiah 56 in the ANTPNG2D

Isaiah 56 in the AS21

Isaiah 56 in the BAGH

Isaiah 56 in the BBPNG

Isaiah 56 in the BBT1E

Isaiah 56 in the BDS

Isaiah 56 in the BEV

Isaiah 56 in the BHAD

Isaiah 56 in the BIB

Isaiah 56 in the BLPT

Isaiah 56 in the BNT

Isaiah 56 in the BNTABOOT

Isaiah 56 in the BNTLV

Isaiah 56 in the BOATCB

Isaiah 56 in the BOATCB2

Isaiah 56 in the BOBCV

Isaiah 56 in the BOCNT

Isaiah 56 in the BOECS

Isaiah 56 in the BOGWICC

Isaiah 56 in the BOHCB

Isaiah 56 in the BOHCV

Isaiah 56 in the BOHLNT

Isaiah 56 in the BOHNTLTAL

Isaiah 56 in the BOICB

Isaiah 56 in the BOILNTAP

Isaiah 56 in the BOITCV

Isaiah 56 in the BOKCV

Isaiah 56 in the BOKCV2

Isaiah 56 in the BOKHWOG

Isaiah 56 in the BOKSSV

Isaiah 56 in the BOLCB

Isaiah 56 in the BOLCB2

Isaiah 56 in the BOMCV

Isaiah 56 in the BONAV

Isaiah 56 in the BONCB

Isaiah 56 in the BONLT

Isaiah 56 in the BONUT2

Isaiah 56 in the BOPLNT

Isaiah 56 in the BOSCB

Isaiah 56 in the BOSNC

Isaiah 56 in the BOTLNT

Isaiah 56 in the BOVCB

Isaiah 56 in the BPBB

Isaiah 56 in the BPH

Isaiah 56 in the BSB

Isaiah 56 in the CCB

Isaiah 56 in the CUV

Isaiah 56 in the CUVS

Isaiah 56 in the DBT

Isaiah 56 in the DGDNT

Isaiah 56 in the DHNT

Isaiah 56 in the DNT

Isaiah 56 in the ELBE

Isaiah 56 in the EMTV

Isaiah 56 in the ESV

Isaiah 56 in the FBV

Isaiah 56 in the FEB

Isaiah 56 in the GGMNT

Isaiah 56 in the GNT

Isaiah 56 in the HARY

Isaiah 56 in the HNT

Isaiah 56 in the IRVA

Isaiah 56 in the IRVB

Isaiah 56 in the IRVG

Isaiah 56 in the IRVH

Isaiah 56 in the IRVK

Isaiah 56 in the IRVM

Isaiah 56 in the IRVM2

Isaiah 56 in the IRVO

Isaiah 56 in the IRVP

Isaiah 56 in the IRVT

Isaiah 56 in the IRVT2

Isaiah 56 in the IRVU

Isaiah 56 in the ISVN

Isaiah 56 in the JSNT

Isaiah 56 in the KAPI

Isaiah 56 in the KBT1ETNIK

Isaiah 56 in the KBV

Isaiah 56 in the KJV

Isaiah 56 in the KNFD

Isaiah 56 in the LBA

Isaiah 56 in the LBLA

Isaiah 56 in the LNT

Isaiah 56 in the LSV

Isaiah 56 in the MAAL

Isaiah 56 in the MBV

Isaiah 56 in the MBV2

Isaiah 56 in the MHNT

Isaiah 56 in the MKNFD

Isaiah 56 in the MNG

Isaiah 56 in the MNT

Isaiah 56 in the MNT2

Isaiah 56 in the MRS1T

Isaiah 56 in the NAA

Isaiah 56 in the NASB

Isaiah 56 in the NBLA

Isaiah 56 in the NBS

Isaiah 56 in the NBVTP

Isaiah 56 in the NET2

Isaiah 56 in the NIV11

Isaiah 56 in the NNT

Isaiah 56 in the NNT2

Isaiah 56 in the NNT3

Isaiah 56 in the PDDPT

Isaiah 56 in the PFNT

Isaiah 56 in the RMNT

Isaiah 56 in the SBIAS

Isaiah 56 in the SBIBS

Isaiah 56 in the SBIBS2

Isaiah 56 in the SBICS

Isaiah 56 in the SBIDS

Isaiah 56 in the SBIGS

Isaiah 56 in the SBIHS

Isaiah 56 in the SBIIS

Isaiah 56 in the SBIIS2

Isaiah 56 in the SBIIS3

Isaiah 56 in the SBIKS

Isaiah 56 in the SBIKS2

Isaiah 56 in the SBIMS

Isaiah 56 in the SBIOS

Isaiah 56 in the SBIPS

Isaiah 56 in the SBISS

Isaiah 56 in the SBITS

Isaiah 56 in the SBITS2

Isaiah 56 in the SBITS3

Isaiah 56 in the SBITS4

Isaiah 56 in the SBIUS

Isaiah 56 in the SBIVS

Isaiah 56 in the SBT

Isaiah 56 in the SBT1E

Isaiah 56 in the SCHL

Isaiah 56 in the SNT

Isaiah 56 in the SUSU

Isaiah 56 in the SUSU2

Isaiah 56 in the SYNO

Isaiah 56 in the TBIAOTANT

Isaiah 56 in the TBT1E

Isaiah 56 in the TBT1E2

Isaiah 56 in the TFTIP

Isaiah 56 in the TFTU

Isaiah 56 in the TGNTATF3T

Isaiah 56 in the THAI

Isaiah 56 in the TNFD

Isaiah 56 in the TNT

Isaiah 56 in the TNTIK

Isaiah 56 in the TNTIL

Isaiah 56 in the TNTIN

Isaiah 56 in the TNTIP

Isaiah 56 in the TNTIZ

Isaiah 56 in the TOMA

Isaiah 56 in the TTENT

Isaiah 56 in the UBG

Isaiah 56 in the UGV

Isaiah 56 in the UGV2

Isaiah 56 in the UGV3

Isaiah 56 in the VBL

Isaiah 56 in the VDCC

Isaiah 56 in the YALU

Isaiah 56 in the YAPE

Isaiah 56 in the YBVTP

Isaiah 56 in the ZBP