Job 18 (BOYCB)
1 Ìgbà náà ni Bilidadi, ará Ṣuhi, dáhùn, ó sì wí pé, 2 “Nígbà wo ni ẹ̀yin yóò tó fi ìdí ọ̀rọ̀ tì;ẹ rò ó, nígbẹ̀yìn rẹ̀ ni àwa ó tó máa sọ. 3 Nítorí kí ni a ṣe ń kà wá sí bí ẹranko,tí a sì ń kà wá si bí ẹni ẹ̀gàn ní ojú yín? 4 Ìwọ fa ara rẹ ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ nínú ìbínú rẹ̀;kí a ha kọ ayé sílẹ̀ nítorí rẹ̀ bi?Tàbí kí a sí àpáta kúrò ní ipò rẹ̀? 5 “Nítòótọ́ ìmọ́lẹ̀ ènìyàn búburú ni a ó pa kúrò,ọ̀wọ́-iná rẹ̀ kì yóò sì tan ìmọ́lẹ̀. 6 Ìmọ́lẹ̀ yóò di òkùnkùn nínú àgọ́ rẹ̀,fìtílà ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni a ó sì pa pẹ̀lú. 7 Ìrìn ẹsẹ̀ agbára rẹ̀ yóò di fífọ;ète òun tìkára rẹ̀ ni yóò bí i ṣubú. 8 Nípa ẹ̀ṣẹ̀ òun tìkára rẹ̀ ó ti bọ́ sínú àwọ̀n,ó sì rìn lórí okùn dídẹ. 9 Tàkúté ni yóò mú un ní gìgísẹ̀,àwọn àwọ̀n tí a dẹ yóò sì ṣẹ́gun rẹ̀. 10 A dẹkùn sílẹ̀ fún un lórí ilẹ̀,a sì wà ọ̀fìn fún un lójú ọ̀nà. 11 Ẹ̀rù ńlá yóò bà á ní ìhà gbogbo,yóò sì lé e dé ẹsẹ̀ rẹ̀. 12 Àìlera rẹ̀ yóò di púpọ̀ fún ebi,ìparun yóò dìde dúró sí i nígbà tí ó bá ṣubú. 13 Yóò jẹ ẹ̀yà ara rẹ̀;ikú àkọ́bí ni yóò jẹ agbára rẹ̀ run. 14 A ó fà á tu kúrò nínú àgọ́ tí ó gbẹ́kẹ̀lé,a ó sì mú un tọ ọba ẹ̀rù ńlá nì lọ. 15 Yóò sì máa jókòó nínú àgọ́ rẹ̀ èyí tí í ṣe tirẹ̀;sulfuru ti o jóná ni a ó fún káàkiri ibùgbé rẹ̀. 16 Gbòǹgbò rẹ̀ yóò gbẹ níṣàlẹ̀,a ó sì ké ẹ̀ka rẹ̀ kúrò lókè. 17 Ìrántí rẹ̀ yóò parun kúrò ni ayé,kì yóò sí orúkọ rẹ̀ ní ìgboro ìlú. 18 A ó sì lé e láti inú ìmọ́lẹ̀ sí inú òkùnkùn,a ó sì lé e kúrò ní ayé. 19 Kì yóò ní ọmọ tàbí ọmọ ọmọ nínú àwọn ènìyàn rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnikẹ́ni tí yóò kù nínú agbo ilé rẹ̀. 20 Ẹnu yóò ya àwọn ìran ti ìwọ̀-oòrùn sí ìgbà ọjọ́ rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rù ìwárìrì ti í bá àwọn ìran ti ìlà-oòrùn. 21 Nítòótọ́ irú bẹ́ẹ̀ ni ibùgbé àwọnènìyàn búburú, èyí sì ni ipò ẹni tí kò mọ̀ Ọlọ́run.”
In Other Versions
Job 18 in the ANGEFD
Job 18 in the ANTPNG2D
Job 18 in the AS21
Job 18 in the BAGH
Job 18 in the BBPNG
Job 18 in the BBT1E
Job 18 in the BDS
Job 18 in the BEV
Job 18 in the BHAD
Job 18 in the BIB
Job 18 in the BLPT
Job 18 in the BNT
Job 18 in the BNTABOOT
Job 18 in the BNTLV
Job 18 in the BOATCB
Job 18 in the BOATCB2
Job 18 in the BOBCV
Job 18 in the BOCNT
Job 18 in the BOECS
Job 18 in the BOGWICC
Job 18 in the BOHCB
Job 18 in the BOHCV
Job 18 in the BOHLNT
Job 18 in the BOHNTLTAL
Job 18 in the BOICB
Job 18 in the BOILNTAP
Job 18 in the BOITCV
Job 18 in the BOKCV
Job 18 in the BOKCV2
Job 18 in the BOKHWOG
Job 18 in the BOKSSV
Job 18 in the BOLCB
Job 18 in the BOLCB2
Job 18 in the BOMCV
Job 18 in the BONAV
Job 18 in the BONCB
Job 18 in the BONLT
Job 18 in the BONUT2
Job 18 in the BOPLNT
Job 18 in the BOSCB
Job 18 in the BOSNC
Job 18 in the BOTLNT
Job 18 in the BOVCB
Job 18 in the BPBB
Job 18 in the BPH
Job 18 in the BSB
Job 18 in the CCB
Job 18 in the CUV
Job 18 in the CUVS
Job 18 in the DBT
Job 18 in the DGDNT
Job 18 in the DHNT
Job 18 in the DNT
Job 18 in the ELBE
Job 18 in the EMTV
Job 18 in the ESV
Job 18 in the FBV
Job 18 in the FEB
Job 18 in the GGMNT
Job 18 in the GNT
Job 18 in the HARY
Job 18 in the HNT
Job 18 in the IRVA
Job 18 in the IRVB
Job 18 in the IRVG
Job 18 in the IRVH
Job 18 in the IRVK
Job 18 in the IRVM
Job 18 in the IRVM2
Job 18 in the IRVO
Job 18 in the IRVP
Job 18 in the IRVT
Job 18 in the IRVT2
Job 18 in the IRVU
Job 18 in the ISVN
Job 18 in the JSNT
Job 18 in the KAPI
Job 18 in the KBT1ETNIK
Job 18 in the KBV
Job 18 in the KJV
Job 18 in the KNFD
Job 18 in the LBA
Job 18 in the LBLA
Job 18 in the LNT
Job 18 in the LSV
Job 18 in the MAAL
Job 18 in the MBV
Job 18 in the MBV2
Job 18 in the MHNT
Job 18 in the MKNFD
Job 18 in the MNG
Job 18 in the MNT
Job 18 in the MNT2
Job 18 in the MRS1T
Job 18 in the NAA
Job 18 in the NASB
Job 18 in the NBLA
Job 18 in the NBS
Job 18 in the NBVTP
Job 18 in the NET2
Job 18 in the NIV11
Job 18 in the NNT
Job 18 in the NNT2
Job 18 in the NNT3
Job 18 in the PDDPT
Job 18 in the PFNT
Job 18 in the RMNT
Job 18 in the SBIAS
Job 18 in the SBIBS
Job 18 in the SBIBS2
Job 18 in the SBICS
Job 18 in the SBIDS
Job 18 in the SBIGS
Job 18 in the SBIHS
Job 18 in the SBIIS
Job 18 in the SBIIS2
Job 18 in the SBIIS3
Job 18 in the SBIKS
Job 18 in the SBIKS2
Job 18 in the SBIMS
Job 18 in the SBIOS
Job 18 in the SBIPS
Job 18 in the SBISS
Job 18 in the SBITS
Job 18 in the SBITS2
Job 18 in the SBITS3
Job 18 in the SBITS4
Job 18 in the SBIUS
Job 18 in the SBIVS
Job 18 in the SBT
Job 18 in the SBT1E
Job 18 in the SCHL
Job 18 in the SNT
Job 18 in the SUSU
Job 18 in the SUSU2
Job 18 in the SYNO
Job 18 in the TBIAOTANT
Job 18 in the TBT1E
Job 18 in the TBT1E2
Job 18 in the TFTIP
Job 18 in the TFTU
Job 18 in the TGNTATF3T
Job 18 in the THAI
Job 18 in the TNFD
Job 18 in the TNT
Job 18 in the TNTIK
Job 18 in the TNTIL
Job 18 in the TNTIN
Job 18 in the TNTIP
Job 18 in the TNTIZ
Job 18 in the TOMA
Job 18 in the TTENT
Job 18 in the UBG
Job 18 in the UGV
Job 18 in the UGV2
Job 18 in the UGV3
Job 18 in the VBL
Job 18 in the VDCC
Job 18 in the YALU
Job 18 in the YAPE
Job 18 in the YBVTP
Job 18 in the ZBP