Job 20 (BOYCB)
1 Ìgbà náà ní Sofari, ará Naama dáhùn, ó sì wí pé, 2 “Nítorí náà ní ìrò inú mi dá mi lóhùn,àti nítorí èyí náà ní mo sì yára si gidigidi. 3 Mo ti gbọ́ ẹ̀san ẹ̀gàn mi,ẹ̀mí òye mi sì dá mi lóhùn. 4 “Ìwọ kò mọ̀ èyí rí ní ìgbà àtijọ́,láti ìgbà tí a sọ ènìyàn lọ́jọ̀ sílé ayé, 5 pé, orin ayọ̀ ènìyàn búburú, ìgbà kúkúrú ni,àti pé, ní ìṣẹ́jú kan ní ayọ̀ àgàbàgebè? 6 Bí ọláńlá rẹ̀ tilẹ̀ gòkè dé ọ̀run,ti orí rẹ̀ sì kan àwọsánmọ̀; 7 ṣùgbọ́n yóò ṣègbé láéláé bí ìgbẹ́ ara rẹ̀;àwọn tí ó ti rí i rí yóò wí pé, ‘Òun ha dà?’ 8 Yóò fò lọ bí àlá, a kì yóò sì rí i,àní a ó lé e lọ bi ìran òru. 9 Ojú tí ó ti rí i rí kì yóò sì rí i mọ́,bẹ́ẹ̀ ni ibùjókòó rẹ̀ kì yóò sì ri i mọ́. 10 Àwọn ọmọ rẹ̀ yóò máa wá àti rí ojúrere lọ́dọ̀ tálákà,ọwọ́ rẹ̀ yóò sì kó ọrọ̀ wọn padà. 11 Egungun rẹ̀ kún fún agbára ìgbà èwe rẹ̀,tí yóò bá a dùbúlẹ̀ nínú erùpẹ̀. 12 “Bí ìwà búburú tilẹ̀ dún ní ẹnu rẹ̀,bí ó tilẹ̀ pa á mọ́ nísàlẹ̀ ahọ́n rẹ̀, 13 bí ó tilẹ̀ dá a sì, tí kò si kọ̀ ọ́ sílẹ̀,tí ó pa á mọ́ síbẹ̀ ní ẹnu rẹ̀, 14 ṣùgbọ́n oúnjẹ rẹ̀ nínú ikùn rẹ̀ ti yípadà,ó jásí òróró paramọ́lẹ̀ nínú rẹ̀; 15 Ó ti gbé ọrọ̀ mì, yóò sì tún bí i jáde;Ọlọ́run yóò pọ̀ ọ́ yọ jáde láti inú rẹ̀ wá. 16 Ó ti fà oró paramọ́lẹ̀ mú;ahọ́n ejò olóró ní yóò pa á. 17 Kì yóò rí odò wọ̀n-ọn-nì,ìṣàn omi, odò tí ń ṣàn fún oyin àti ti òrí-àmọ́. 18 Ohun tí ó ṣiṣẹ́ fún ni yóò mú un padà, kí yóò sì gbé e mì;gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ tí ó ní, kì yóò sì ìgbádùn nínú rẹ̀. 19 Nítorí tí ó fi owó rẹ̀ ni tálákà lára, ó sì ti pẹ̀yìndà si wọ́n;nítorí ti ó fi agbára gbé ilé tí òun kò kọ́. 20 “Nítorí òun kò mọ̀ ìwà pẹ̀lẹ́ nínú ara rẹ̀,kì yóò sì gbà nínú èyí tí ọkàn rẹ̀ fẹ́ sílẹ̀. 21 Ohun kan kò kù fún jíjẹ́ rẹ̀;nítorí náà ọ̀rọ̀ rẹ̀ kì yóò dúró pẹ́. 22 Nínú ànító rẹ̀, ìdààmú yóò dé bá a;àwọn ènìyàn búburú yóò dáwọ́jọ lé e lórí. 23 Yóò sì ṣe, nígbà tí ó bá fẹ́ jẹun,Ọlọ́run yóò fà ríru ìbínú rẹ̀ sí í lórí, nígbà tó bá ń jẹun lọ́wọ́,yóò sì rọ òjò ìbínú rẹ̀ lé e lórí. 24 Bi o tilẹ̀ sá kúrò lọ́wọ́ ohun ìjà ìrìn;ọrun akọ irin ní yóò ta a po yọ. 25 O fà á yọ, ó sì jáde kúrò lára;idà dídán ní ń jáde láti inú òróòro wá.Ẹ̀rù ńlá ń bẹ ní ara rẹ̀; 26 òkùnkùn biribiri ní a ti pamọ́ fún ìṣúra rẹ̀.Iná ti a kò fẹ́ ní yóò jó o runyóò sì jẹ èyí tí ó kù nínú àgọ́ rẹ̀ run. 27 Ọ̀run yóò fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ hàn,ayé yóò sì dìde dúró sí i. 28 Ìbísí ilé rẹ̀ yóò kọjá lọ,àti ohun ìní rẹ̀ yóò sàn dànù lọ ni ọjọ́ ìbínú Ọlọ́run. 29 Èyí ni ìpín ènìyàn búburú láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá,àti ogún tí a yàn sílẹ̀ fún un láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run.”
In Other Versions
Job 20 in the ANGEFD
Job 20 in the ANTPNG2D
Job 20 in the AS21
Job 20 in the BAGH
Job 20 in the BBPNG
Job 20 in the BBT1E
Job 20 in the BDS
Job 20 in the BEV
Job 20 in the BHAD
Job 20 in the BIB
Job 20 in the BLPT
Job 20 in the BNT
Job 20 in the BNTABOOT
Job 20 in the BNTLV
Job 20 in the BOATCB
Job 20 in the BOATCB2
Job 20 in the BOBCV
Job 20 in the BOCNT
Job 20 in the BOECS
Job 20 in the BOGWICC
Job 20 in the BOHCB
Job 20 in the BOHCV
Job 20 in the BOHLNT
Job 20 in the BOHNTLTAL
Job 20 in the BOICB
Job 20 in the BOILNTAP
Job 20 in the BOITCV
Job 20 in the BOKCV
Job 20 in the BOKCV2
Job 20 in the BOKHWOG
Job 20 in the BOKSSV
Job 20 in the BOLCB
Job 20 in the BOLCB2
Job 20 in the BOMCV
Job 20 in the BONAV
Job 20 in the BONCB
Job 20 in the BONLT
Job 20 in the BONUT2
Job 20 in the BOPLNT
Job 20 in the BOSCB
Job 20 in the BOSNC
Job 20 in the BOTLNT
Job 20 in the BOVCB
Job 20 in the BPBB
Job 20 in the BPH
Job 20 in the BSB
Job 20 in the CCB
Job 20 in the CUV
Job 20 in the CUVS
Job 20 in the DBT
Job 20 in the DGDNT
Job 20 in the DHNT
Job 20 in the DNT
Job 20 in the ELBE
Job 20 in the EMTV
Job 20 in the ESV
Job 20 in the FBV
Job 20 in the FEB
Job 20 in the GGMNT
Job 20 in the GNT
Job 20 in the HARY
Job 20 in the HNT
Job 20 in the IRVA
Job 20 in the IRVB
Job 20 in the IRVG
Job 20 in the IRVH
Job 20 in the IRVK
Job 20 in the IRVM
Job 20 in the IRVM2
Job 20 in the IRVO
Job 20 in the IRVP
Job 20 in the IRVT
Job 20 in the IRVT2
Job 20 in the IRVU
Job 20 in the ISVN
Job 20 in the JSNT
Job 20 in the KAPI
Job 20 in the KBT1ETNIK
Job 20 in the KBV
Job 20 in the KJV
Job 20 in the KNFD
Job 20 in the LBA
Job 20 in the LBLA
Job 20 in the LNT
Job 20 in the LSV
Job 20 in the MAAL
Job 20 in the MBV
Job 20 in the MBV2
Job 20 in the MHNT
Job 20 in the MKNFD
Job 20 in the MNG
Job 20 in the MNT
Job 20 in the MNT2
Job 20 in the MRS1T
Job 20 in the NAA
Job 20 in the NASB
Job 20 in the NBLA
Job 20 in the NBS
Job 20 in the NBVTP
Job 20 in the NET2
Job 20 in the NIV11
Job 20 in the NNT
Job 20 in the NNT2
Job 20 in the NNT3
Job 20 in the PDDPT
Job 20 in the PFNT
Job 20 in the RMNT
Job 20 in the SBIAS
Job 20 in the SBIBS
Job 20 in the SBIBS2
Job 20 in the SBICS
Job 20 in the SBIDS
Job 20 in the SBIGS
Job 20 in the SBIHS
Job 20 in the SBIIS
Job 20 in the SBIIS2
Job 20 in the SBIIS3
Job 20 in the SBIKS
Job 20 in the SBIKS2
Job 20 in the SBIMS
Job 20 in the SBIOS
Job 20 in the SBIPS
Job 20 in the SBISS
Job 20 in the SBITS
Job 20 in the SBITS2
Job 20 in the SBITS3
Job 20 in the SBITS4
Job 20 in the SBIUS
Job 20 in the SBIVS
Job 20 in the SBT
Job 20 in the SBT1E
Job 20 in the SCHL
Job 20 in the SNT
Job 20 in the SUSU
Job 20 in the SUSU2
Job 20 in the SYNO
Job 20 in the TBIAOTANT
Job 20 in the TBT1E
Job 20 in the TBT1E2
Job 20 in the TFTIP
Job 20 in the TFTU
Job 20 in the TGNTATF3T
Job 20 in the THAI
Job 20 in the TNFD
Job 20 in the TNT
Job 20 in the TNTIK
Job 20 in the TNTIL
Job 20 in the TNTIN
Job 20 in the TNTIP
Job 20 in the TNTIZ
Job 20 in the TOMA
Job 20 in the TTENT
Job 20 in the UBG
Job 20 in the UGV
Job 20 in the UGV2
Job 20 in the UGV3
Job 20 in the VBL
Job 20 in the VDCC
Job 20 in the YALU
Job 20 in the YAPE
Job 20 in the YBVTP
Job 20 in the ZBP