Job 32 (BOYCB)
1 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí dákẹ́ láti dá Jobu lóhùn, nítorí ó ṣe olódodo lójú ara rẹ̀. 2 Nígbà náà ni inú bí Elihu ọmọ Barakeli ará Busi, láti ìbátan ìdílé Ramu; ó bínú si Jobu nítorí ti ó dá ara rẹ̀ láre kàkà ki ó dá Ọlọ́run láre. 3 Inú sì bí i sí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, nítorí tí wọn kò rí ọ̀nà láti dá Jobu lóhùn bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dá Jobu lẹ́bi. 4 Ǹjẹ́ Elihu ti dúró títí tí Jobu fi sọ̀rọ̀ tán nítorí tí àwọn wọ̀nyí dàgbà ju òun lọ ní ọjọ́ orí. 5 Nígbà tí Elihu rí i pé ìdáhùn ọ̀rọ̀ kò sí ní ẹnu àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí nígbà náà ni ó bínú. 6 Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, dáhùn ó sì wí pé,“Ọmọdé ni èmi,àgbà sì ní ẹ̀yin;ǹjẹ́ nítorí náà ní mo dúró,mo sì ń bẹ̀rù láti fi ìmọ̀ mi hàn yin. 7 Èmi wí pé ọjọ́ orí ni ìbá sọ̀rọ̀,àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní ìbá kọ́ ni ní ọgbọ́n. 8 Ṣùgbọ́n ẹ̀mí kan ní ó wà nínú ènìyànàti ìmísí Olódùmarè ní ì sì máa fún wọn ní òye. 9 Ènìyàn ńlá ńlá kì í ṣe ọlọ́gbọ́n,bẹ́ẹ̀ ni àwọn àgbà ní òye ẹ̀tọ́ kò yé. 10 “Nítorí náà ní èmí ṣe wí pé, ẹ dẹtí sílẹ̀ sí mi;èmí pẹ̀lú yóò fi ìmọ̀ mi hàn. 11 Kíyèsi i, èmí ti dúró de ọ̀rọ̀ yín;èmi fetísí àròyé yín,nígbà tí ẹ̀yin ń wá ọ̀rọ̀ ti ẹ̀yin yóò sọ; 12 àní, mo fiyèsí yín tinútinú.Sì kíyèsi i, kò sí ẹnìkan nínú yín tí ó le já Jobu ní irọ́;tàbí tí ó lè dá a lóhùn àríyànjiyàn rẹ̀! 13 Kí ẹ̀yin kí ó má ṣe wí pé, ‘Àwa wá ọgbọ́n ní àwárí;Ọlọ́run ni ó lè bì í ṣubú kì í ṣe ènìyàn.’ 14 Bí òun kò ti sọ̀rọ̀ sí mi,bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò fi ọ̀rọ̀ yín dá a lóhùn. 15 “Ẹnu sì yà wọ́n, wọn kò sì dáhùn mọ́,wọ́n ṣíwọ́ ọ̀rọ̀ í sọ. 16 Mo sì retí, nítorí wọn kò sì fọhùn, wọ́n dákẹ́ jẹ́ẹ́;wọn kò sì dáhùn mọ́. 17 Bẹ́ẹ̀ ni èmí ó sì dáhùn nípa ti èmi,èmí pẹ̀lú yóò sì fi ìmọ̀ mi hàn. 18 Nítorí pé èmi kún fún ọ̀rọ̀ sísọ,ẹ̀mí ń rọ̀ mi ni inú mi. 19 Kíyèsi i, ikùn mi dàbí ọtí wáìnì, tí kò ní ojú-ìhò;ó múra tán láti bẹ́ bí ìgò-awọ tuntun. 20 Èmí ó sọ, kí ara kí ó le rọ̀ mí,èmí ó sí ètè mi, èmí ó sì dáhùn. 21 Lóòtítọ́ èmi kì yóò ṣe ojúsàájú sí ẹnìkankan,bẹ́ẹ̀ ni èmí kì yóò sì ṣe ìpọ́nni fún ẹnìkan. 22 Nítorí pé èmí kò mọ̀ ọ̀rọ̀ ìpọ́nni í sọ ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀,ẹlẹ́dàá mi yóò mú mi kúrò lọ́gán.
In Other Versions
Job 32 in the ANGEFD
Job 32 in the ANTPNG2D
Job 32 in the AS21
Job 32 in the BAGH
Job 32 in the BBPNG
Job 32 in the BBT1E
Job 32 in the BDS
Job 32 in the BEV
Job 32 in the BHAD
Job 32 in the BIB
Job 32 in the BLPT
Job 32 in the BNT
Job 32 in the BNTABOOT
Job 32 in the BNTLV
Job 32 in the BOATCB
Job 32 in the BOATCB2
Job 32 in the BOBCV
Job 32 in the BOCNT
Job 32 in the BOECS
Job 32 in the BOGWICC
Job 32 in the BOHCB
Job 32 in the BOHCV
Job 32 in the BOHLNT
Job 32 in the BOHNTLTAL
Job 32 in the BOICB
Job 32 in the BOILNTAP
Job 32 in the BOITCV
Job 32 in the BOKCV
Job 32 in the BOKCV2
Job 32 in the BOKHWOG
Job 32 in the BOKSSV
Job 32 in the BOLCB
Job 32 in the BOLCB2
Job 32 in the BOMCV
Job 32 in the BONAV
Job 32 in the BONCB
Job 32 in the BONLT
Job 32 in the BONUT2
Job 32 in the BOPLNT
Job 32 in the BOSCB
Job 32 in the BOSNC
Job 32 in the BOTLNT
Job 32 in the BOVCB
Job 32 in the BPBB
Job 32 in the BPH
Job 32 in the BSB
Job 32 in the CCB
Job 32 in the CUV
Job 32 in the CUVS
Job 32 in the DBT
Job 32 in the DGDNT
Job 32 in the DHNT
Job 32 in the DNT
Job 32 in the ELBE
Job 32 in the EMTV
Job 32 in the ESV
Job 32 in the FBV
Job 32 in the FEB
Job 32 in the GGMNT
Job 32 in the GNT
Job 32 in the HARY
Job 32 in the HNT
Job 32 in the IRVA
Job 32 in the IRVB
Job 32 in the IRVG
Job 32 in the IRVH
Job 32 in the IRVK
Job 32 in the IRVM
Job 32 in the IRVM2
Job 32 in the IRVO
Job 32 in the IRVP
Job 32 in the IRVT
Job 32 in the IRVT2
Job 32 in the IRVU
Job 32 in the ISVN
Job 32 in the JSNT
Job 32 in the KAPI
Job 32 in the KBT1ETNIK
Job 32 in the KBV
Job 32 in the KJV
Job 32 in the KNFD
Job 32 in the LBA
Job 32 in the LBLA
Job 32 in the LNT
Job 32 in the LSV
Job 32 in the MAAL
Job 32 in the MBV
Job 32 in the MBV2
Job 32 in the MHNT
Job 32 in the MKNFD
Job 32 in the MNG
Job 32 in the MNT
Job 32 in the MNT2
Job 32 in the MRS1T
Job 32 in the NAA
Job 32 in the NASB
Job 32 in the NBLA
Job 32 in the NBS
Job 32 in the NBVTP
Job 32 in the NET2
Job 32 in the NIV11
Job 32 in the NNT
Job 32 in the NNT2
Job 32 in the NNT3
Job 32 in the PDDPT
Job 32 in the PFNT
Job 32 in the RMNT
Job 32 in the SBIAS
Job 32 in the SBIBS
Job 32 in the SBIBS2
Job 32 in the SBICS
Job 32 in the SBIDS
Job 32 in the SBIGS
Job 32 in the SBIHS
Job 32 in the SBIIS
Job 32 in the SBIIS2
Job 32 in the SBIIS3
Job 32 in the SBIKS
Job 32 in the SBIKS2
Job 32 in the SBIMS
Job 32 in the SBIOS
Job 32 in the SBIPS
Job 32 in the SBISS
Job 32 in the SBITS
Job 32 in the SBITS2
Job 32 in the SBITS3
Job 32 in the SBITS4
Job 32 in the SBIUS
Job 32 in the SBIVS
Job 32 in the SBT
Job 32 in the SBT1E
Job 32 in the SCHL
Job 32 in the SNT
Job 32 in the SUSU
Job 32 in the SUSU2
Job 32 in the SYNO
Job 32 in the TBIAOTANT
Job 32 in the TBT1E
Job 32 in the TBT1E2
Job 32 in the TFTIP
Job 32 in the TFTU
Job 32 in the TGNTATF3T
Job 32 in the THAI
Job 32 in the TNFD
Job 32 in the TNT
Job 32 in the TNTIK
Job 32 in the TNTIL
Job 32 in the TNTIN
Job 32 in the TNTIP
Job 32 in the TNTIZ
Job 32 in the TOMA
Job 32 in the TTENT
Job 32 in the UBG
Job 32 in the UGV
Job 32 in the UGV2
Job 32 in the UGV3
Job 32 in the VBL
Job 32 in the VDCC
Job 32 in the YALU
Job 32 in the YAPE
Job 32 in the YBVTP
Job 32 in the ZBP