Joshua 12 (BOYCB)
1 Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí àwọn ará Israẹli ṣẹ́gun, tí wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn ní ìlà-oòrùn Jordani, láti odò Arnoni dé òkè Hermoni, pẹ̀lú gbogbo ìhà ìlà-oòrùn aginjù: 2 Sihoni ọba àwọn Amori, tí ó jẹ ọba ní Heṣboni.Ó ṣe àkóso láti Aroeri tí ń bẹ ní etí odò Arnoni, láti ìlú tó wà ní àárín àfonífojì náà dé odò Jabbok, èyí tí ó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ Ammoni. Pẹ̀lú ìdajì àwọn ará Gileadi. 3 Ó sì ṣe àkóso ní orí ìlà-oòrùn aginjù láti Òkun Kinnereti sí ìhà Òkun ti aginjù (ti o túmọ̀ sí Òkun Iyọ̀), sí Beti-Jeṣimoti, àti láti gúúsù lọ dé ìsàlẹ̀ ẹsẹ̀ òkè Pisga. 4 Àti agbègbè Ogu ọba Baṣani, ọ̀kan nínú àwọn tí ó kù nínú àwọn ará Refaimu, ẹni tí ó jẹ ọba ní Aṣtarotu àti Edrei. 5 Ó ṣe àkóso ní orí òkè Hermoni, Saleka, Baṣani títí dé ààlà àwọn ènìyàn Geṣuri àti Maakati, àti ìdajì Gileadi dé ààlà Sihoni ọba Heṣboni. 6 Mose ìránṣẹ́ OLÚWA àti àwọn ọmọ Israẹli sì borí wọn. Mose ìránṣẹ́ OLÚWA sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Reubeni, àwọn ẹ̀yà Gadi àti ìdajì ẹ̀yà Manase kí ó jẹ́ ohun ìní wọn. 7 Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí Joṣua àti àwọn ọmọ Israẹli ṣẹ́gun ní ìhà ìwọ̀-oòrùn Jordani, láti Baali-Gadi ní àfonífojì Lebanoni sí òkè Halaki, èyí tí o lọ sí ọ̀nà Seiri (Joṣua sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Israẹli ní ilẹ̀ ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín ẹ̀yà wọn: 8 ilẹ̀ òkè, ní ẹsẹ̀ òkè ní ìhà ìwọ̀-oòrùn òkè aginjù, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè, ní aginjù àti nì gúúsù ilẹ̀ àwọn ará: Hiti, Amori, Kenaani, Peresi, Hifi àti àwọn ará Jebusi). 9 Ọba Jeriko, ọ̀kanọba Ai (tí ó wà nítòsí Beteli), ọ̀kan 10 ọba Jerusalẹmu, ọ̀kanọba Hebroni, ọ̀kan 11 ọba Jarmatu, ọ̀kanọba Lakiṣi, ọ̀kan 12 ọba Egloni, ọ̀kanọba Geseri, ọ̀kan 13 ọba Debiri, ọ̀kanọba Gederi, ọ̀kan 14 ọba Horma, ọ̀kanọba Aradi, ọ̀kan 15 ọba Libina, ọ̀kanọba Adullamu, ọ̀kan 16 ọba Makkeda, ọ̀kanọba Beteli, ọ̀kan 17 ọba Tapua, ọ̀kanọba Heferi, ọ̀kan 18 ọba Afeki, ọ̀kanọba Laṣaroni, ọ̀kan 19 ọba Madoni, ọ̀kanọba Hasori, ọ̀kan 20 ọba Ṣimroni-Meroni, ọ̀kanọba Akṣafu, ọ̀kan 21 ọba Taanaki, ọ̀kanọba Megido, ọ̀kan 22 ọba Kedeṣi, ọ̀kanọba Jokneamu ni Karmeli, ọ̀kan 23 ọba Dori (ní Nafoti Dori), ọ̀kanọba Goyimu ní Gilgali, ọ̀kan 24 ọba Tirsa, ọ̀kan. Gbogbo àwọn ọba náà jẹ́ mọ́kànlélọ́gbọ̀n.
In Other Versions
Joshua 12 in the ANGEFD
Joshua 12 in the ANTPNG2D
Joshua 12 in the AS21
Joshua 12 in the BAGH
Joshua 12 in the BBPNG
Joshua 12 in the BBT1E
Joshua 12 in the BDS
Joshua 12 in the BEV
Joshua 12 in the BHAD
Joshua 12 in the BIB
Joshua 12 in the BLPT
Joshua 12 in the BNT
Joshua 12 in the BNTABOOT
Joshua 12 in the BNTLV
Joshua 12 in the BOATCB
Joshua 12 in the BOATCB2
Joshua 12 in the BOBCV
Joshua 12 in the BOCNT
Joshua 12 in the BOECS
Joshua 12 in the BOGWICC
Joshua 12 in the BOHCB
Joshua 12 in the BOHCV
Joshua 12 in the BOHLNT
Joshua 12 in the BOHNTLTAL
Joshua 12 in the BOICB
Joshua 12 in the BOILNTAP
Joshua 12 in the BOITCV
Joshua 12 in the BOKCV
Joshua 12 in the BOKCV2
Joshua 12 in the BOKHWOG
Joshua 12 in the BOKSSV
Joshua 12 in the BOLCB
Joshua 12 in the BOLCB2
Joshua 12 in the BOMCV
Joshua 12 in the BONAV
Joshua 12 in the BONCB
Joshua 12 in the BONLT
Joshua 12 in the BONUT2
Joshua 12 in the BOPLNT
Joshua 12 in the BOSCB
Joshua 12 in the BOSNC
Joshua 12 in the BOTLNT
Joshua 12 in the BOVCB
Joshua 12 in the BPBB
Joshua 12 in the BPH
Joshua 12 in the BSB
Joshua 12 in the CCB
Joshua 12 in the CUV
Joshua 12 in the CUVS
Joshua 12 in the DBT
Joshua 12 in the DGDNT
Joshua 12 in the DHNT
Joshua 12 in the DNT
Joshua 12 in the ELBE
Joshua 12 in the EMTV
Joshua 12 in the ESV
Joshua 12 in the FBV
Joshua 12 in the FEB
Joshua 12 in the GGMNT
Joshua 12 in the GNT
Joshua 12 in the HARY
Joshua 12 in the HNT
Joshua 12 in the IRVA
Joshua 12 in the IRVB
Joshua 12 in the IRVG
Joshua 12 in the IRVH
Joshua 12 in the IRVK
Joshua 12 in the IRVM
Joshua 12 in the IRVM2
Joshua 12 in the IRVO
Joshua 12 in the IRVP
Joshua 12 in the IRVT
Joshua 12 in the IRVT2
Joshua 12 in the IRVU
Joshua 12 in the ISVN
Joshua 12 in the JSNT
Joshua 12 in the KAPI
Joshua 12 in the KBT1ETNIK
Joshua 12 in the KBV
Joshua 12 in the KJV
Joshua 12 in the KNFD
Joshua 12 in the LBA
Joshua 12 in the LBLA
Joshua 12 in the LNT
Joshua 12 in the LSV
Joshua 12 in the MAAL
Joshua 12 in the MBV
Joshua 12 in the MBV2
Joshua 12 in the MHNT
Joshua 12 in the MKNFD
Joshua 12 in the MNG
Joshua 12 in the MNT
Joshua 12 in the MNT2
Joshua 12 in the MRS1T
Joshua 12 in the NAA
Joshua 12 in the NASB
Joshua 12 in the NBLA
Joshua 12 in the NBS
Joshua 12 in the NBVTP
Joshua 12 in the NET2
Joshua 12 in the NIV11
Joshua 12 in the NNT
Joshua 12 in the NNT2
Joshua 12 in the NNT3
Joshua 12 in the PDDPT
Joshua 12 in the PFNT
Joshua 12 in the RMNT
Joshua 12 in the SBIAS
Joshua 12 in the SBIBS
Joshua 12 in the SBIBS2
Joshua 12 in the SBICS
Joshua 12 in the SBIDS
Joshua 12 in the SBIGS
Joshua 12 in the SBIHS
Joshua 12 in the SBIIS
Joshua 12 in the SBIIS2
Joshua 12 in the SBIIS3
Joshua 12 in the SBIKS
Joshua 12 in the SBIKS2
Joshua 12 in the SBIMS
Joshua 12 in the SBIOS
Joshua 12 in the SBIPS
Joshua 12 in the SBISS
Joshua 12 in the SBITS
Joshua 12 in the SBITS2
Joshua 12 in the SBITS3
Joshua 12 in the SBITS4
Joshua 12 in the SBIUS
Joshua 12 in the SBIVS
Joshua 12 in the SBT
Joshua 12 in the SBT1E
Joshua 12 in the SCHL
Joshua 12 in the SNT
Joshua 12 in the SUSU
Joshua 12 in the SUSU2
Joshua 12 in the SYNO
Joshua 12 in the TBIAOTANT
Joshua 12 in the TBT1E
Joshua 12 in the TBT1E2
Joshua 12 in the TFTIP
Joshua 12 in the TFTU
Joshua 12 in the TGNTATF3T
Joshua 12 in the THAI
Joshua 12 in the TNFD
Joshua 12 in the TNT
Joshua 12 in the TNTIK
Joshua 12 in the TNTIL
Joshua 12 in the TNTIN
Joshua 12 in the TNTIP
Joshua 12 in the TNTIZ
Joshua 12 in the TOMA
Joshua 12 in the TTENT
Joshua 12 in the UBG
Joshua 12 in the UGV
Joshua 12 in the UGV2
Joshua 12 in the UGV3
Joshua 12 in the VBL
Joshua 12 in the VDCC
Joshua 12 in the YALU
Joshua 12 in the YAPE
Joshua 12 in the YBVTP
Joshua 12 in the ZBP