Proverbs 29 (BOYCB)
1 Ẹni tí ó sì ń ṣorí kunkun lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìbáwíyóò parun lójijì láìsí àtúnṣe. 2 Nígbà tí olódodo bá ń gbilẹ̀, àwọn ènìyàn a yọ̀nígbà tí ènìyàn búburú ń ṣàkóso, àwọn ènìyàn ń kórìíra. 3 Ènìyàn tí ó fẹ́ràn ọgbọ́n mú kí baba rẹ̀ láyọ̀ṣùgbọ́n ẹni ti ń bá panṣágà kẹ́gbẹ́ ba ọrọ̀ ọ rẹ̀ jẹ́. 4 Nípa ìdájọ́ òdodo ni ọba fi í mú ìlú tòrò nini,ṣùgbọ́n èyí tí ń ṣe ojúkòkòrò àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fà á lulẹ̀. 5 Ẹnikẹ́ni tí ó bá tan aládùúgbò rẹ̀ó ń dẹ àwọ̀n de ẹsẹ̀ ẹ rẹ̀. 6 Ẹ̀ṣẹ̀ ènìyàn ibi ni ó jẹ́ ìdẹ̀kùn rẹ̀ṣùgbọ́n olódodo le è kọrin kí ó sì máa yọ̀. 7 Olódodo ń máa ro ọ̀rọ̀ tálákà,ṣùgbọ́n ènìyàn búburú kò sú sí i láti rò ó. 8 Àwọn ẹlẹ́yà a máa ru ìlú sókè,ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n ènìyàn máa ń mú ìbínú kúrò. 9 Bí ọlọ́gbọ́n ènìyàn bá lọ sí ilé ẹjọ́ pẹ̀lú aláìgbọ́naláìgbọ́n a máa bínú a sì máa jà, kò sì ní sí àlàáfíà. 10 Àwọn tí ó ń tàjẹ̀ sílẹ̀ kò rí ẹni dídúró ṣinṣinwọ́n sì ń wá ọ̀nà láti pa olódodo. 11 Aláìgbọ́n ènìyàn fi gbogbo ẹnu rẹ̀ bínúṣùgbọ́n ọlọ́gbọ́n ènìyàn a máa kó ìbínú rẹ̀ ní ìjánu. 12 Bí olórí bá fetí sí irọ́,gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ a di ènìyàn búburú lójú rẹ̀. 13 Tálákà ènìyàn àti aninilára jọ ní àbùdá yìí, OLÚWA jẹ́ kí ojú àwọn méjèèjì máa ríran. 14 Bí ọba kan bá ń ṣe ìdájọ́ tálákà pẹ̀lú òtítọ́ìtẹ́ ìjọba rẹ yóò fìdímúlẹ̀ nígbà gbogbo. 15 Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́nṣùgbọ́n ọmọ tí a fi sílẹ̀ fúnra rẹ̀ a dójútì ìyá rẹ̀. 16 Nígbà tí ènìyàn búburú ń gbilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀ṣẹ̀ ń gbilẹ̀ṣùgbọ́n olódodo yóò rí ìṣubú wọn. 17 Bá ọmọ rẹ wí, yóò sì fún ọ ní àlàáfíàyóò sì mú inú dídùn wá sí inú ọkàn rẹ. 18 Níbi tí kò ti sí ìfihàn, àwọn ènìyàn a gbé ìgbé ayé àìbìkítà,ṣùgbọ́n ìbùkún ní fún àwọn tí ń pa òfin mọ́. 19 A kò le fi ọ̀rọ̀ lásán kìlọ̀ fún ìránṣẹ́bí ó tilẹ̀ yé e, kò ní kọbi ara sí i. 20 Ǹjẹ́ ó rí ènìyàn tí ń kánjú sọ̀rọ̀?Ìrètí wà fún aláìgbọ́n jù ú lọ. 21 Bí ènìyàn kan bá kẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ lákẹ̀ẹ́jù láti kékeréyóò mú ìbànújẹ́ wá ní ìgbẹ̀yìn. 22 Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè,onínú-fùfù ènìyàn a sì máa dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀. 23 Ìgbéraga ènìyàn a máa sọ ọ́ di ẹni ilẹ̀ṣùgbọ́n onírẹ̀lẹ̀ ènìyàn a máa gba iyì kún iyì. 24 Ẹni tí ó ń kó ẹgbẹ́, olè kórìíra ọkàn ara rẹ̀,ó ń gbọ́ èpè olóhun kò sì le è fọhùn. 25 Ìbẹ̀rù ènìyàn kan yóò sì di ìdẹ̀kùnṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bẹ̀rù OLÚWA wà láìléwu. 26 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ń wá ojúrere alákòóso,ṣùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ OLÚWA ni ènìyàn tí ń gba ìdájọ́ òdodo. 27 Olódodo kórìíra àwọn aláìṣòótọ́:ènìyàn búburú kórìíra olódodo.
In Other Versions
Proverbs 29 in the ANGEFD
Proverbs 29 in the ANTPNG2D
Proverbs 29 in the AS21
Proverbs 29 in the BAGH
Proverbs 29 in the BBPNG
Proverbs 29 in the BBT1E
Proverbs 29 in the BDS
Proverbs 29 in the BEV
Proverbs 29 in the BHAD
Proverbs 29 in the BIB
Proverbs 29 in the BLPT
Proverbs 29 in the BNT
Proverbs 29 in the BNTABOOT
Proverbs 29 in the BNTLV
Proverbs 29 in the BOATCB
Proverbs 29 in the BOATCB2
Proverbs 29 in the BOBCV
Proverbs 29 in the BOCNT
Proverbs 29 in the BOECS
Proverbs 29 in the BOGWICC
Proverbs 29 in the BOHCB
Proverbs 29 in the BOHCV
Proverbs 29 in the BOHLNT
Proverbs 29 in the BOHNTLTAL
Proverbs 29 in the BOICB
Proverbs 29 in the BOILNTAP
Proverbs 29 in the BOITCV
Proverbs 29 in the BOKCV
Proverbs 29 in the BOKCV2
Proverbs 29 in the BOKHWOG
Proverbs 29 in the BOKSSV
Proverbs 29 in the BOLCB
Proverbs 29 in the BOLCB2
Proverbs 29 in the BOMCV
Proverbs 29 in the BONAV
Proverbs 29 in the BONCB
Proverbs 29 in the BONLT
Proverbs 29 in the BONUT2
Proverbs 29 in the BOPLNT
Proverbs 29 in the BOSCB
Proverbs 29 in the BOSNC
Proverbs 29 in the BOTLNT
Proverbs 29 in the BOVCB
Proverbs 29 in the BPBB
Proverbs 29 in the BPH
Proverbs 29 in the BSB
Proverbs 29 in the CCB
Proverbs 29 in the CUV
Proverbs 29 in the CUVS
Proverbs 29 in the DBT
Proverbs 29 in the DGDNT
Proverbs 29 in the DHNT
Proverbs 29 in the DNT
Proverbs 29 in the ELBE
Proverbs 29 in the EMTV
Proverbs 29 in the ESV
Proverbs 29 in the FBV
Proverbs 29 in the FEB
Proverbs 29 in the GGMNT
Proverbs 29 in the GNT
Proverbs 29 in the HARY
Proverbs 29 in the HNT
Proverbs 29 in the IRVA
Proverbs 29 in the IRVB
Proverbs 29 in the IRVG
Proverbs 29 in the IRVH
Proverbs 29 in the IRVK
Proverbs 29 in the IRVM
Proverbs 29 in the IRVM2
Proverbs 29 in the IRVO
Proverbs 29 in the IRVP
Proverbs 29 in the IRVT
Proverbs 29 in the IRVT2
Proverbs 29 in the IRVU
Proverbs 29 in the ISVN
Proverbs 29 in the JSNT
Proverbs 29 in the KAPI
Proverbs 29 in the KBT1ETNIK
Proverbs 29 in the KBV
Proverbs 29 in the KJV
Proverbs 29 in the KNFD
Proverbs 29 in the LBA
Proverbs 29 in the LBLA
Proverbs 29 in the LNT
Proverbs 29 in the LSV
Proverbs 29 in the MAAL
Proverbs 29 in the MBV
Proverbs 29 in the MBV2
Proverbs 29 in the MHNT
Proverbs 29 in the MKNFD
Proverbs 29 in the MNG
Proverbs 29 in the MNT
Proverbs 29 in the MNT2
Proverbs 29 in the MRS1T
Proverbs 29 in the NAA
Proverbs 29 in the NASB
Proverbs 29 in the NBLA
Proverbs 29 in the NBS
Proverbs 29 in the NBVTP
Proverbs 29 in the NET2
Proverbs 29 in the NIV11
Proverbs 29 in the NNT
Proverbs 29 in the NNT2
Proverbs 29 in the NNT3
Proverbs 29 in the PDDPT
Proverbs 29 in the PFNT
Proverbs 29 in the RMNT
Proverbs 29 in the SBIAS
Proverbs 29 in the SBIBS
Proverbs 29 in the SBIBS2
Proverbs 29 in the SBICS
Proverbs 29 in the SBIDS
Proverbs 29 in the SBIGS
Proverbs 29 in the SBIHS
Proverbs 29 in the SBIIS
Proverbs 29 in the SBIIS2
Proverbs 29 in the SBIIS3
Proverbs 29 in the SBIKS
Proverbs 29 in the SBIKS2
Proverbs 29 in the SBIMS
Proverbs 29 in the SBIOS
Proverbs 29 in the SBIPS
Proverbs 29 in the SBISS
Proverbs 29 in the SBITS
Proverbs 29 in the SBITS2
Proverbs 29 in the SBITS3
Proverbs 29 in the SBITS4
Proverbs 29 in the SBIUS
Proverbs 29 in the SBIVS
Proverbs 29 in the SBT
Proverbs 29 in the SBT1E
Proverbs 29 in the SCHL
Proverbs 29 in the SNT
Proverbs 29 in the SUSU
Proverbs 29 in the SUSU2
Proverbs 29 in the SYNO
Proverbs 29 in the TBIAOTANT
Proverbs 29 in the TBT1E
Proverbs 29 in the TBT1E2
Proverbs 29 in the TFTIP
Proverbs 29 in the TFTU
Proverbs 29 in the TGNTATF3T
Proverbs 29 in the THAI
Proverbs 29 in the TNFD
Proverbs 29 in the TNT
Proverbs 29 in the TNTIK
Proverbs 29 in the TNTIL
Proverbs 29 in the TNTIN
Proverbs 29 in the TNTIP
Proverbs 29 in the TNTIZ
Proverbs 29 in the TOMA
Proverbs 29 in the TTENT
Proverbs 29 in the UBG
Proverbs 29 in the UGV
Proverbs 29 in the UGV2
Proverbs 29 in the UGV3
Proverbs 29 in the VBL
Proverbs 29 in the VDCC
Proverbs 29 in the YALU
Proverbs 29 in the YAPE
Proverbs 29 in the YBVTP
Proverbs 29 in the ZBP