Psalms 45 (BOYCB)

undefined Fún adarí orin. Tí ohun orin “Lílì.” Ti orin àwọn ọmọ Kora. Maskili. Orin ìgbéyàwó. 1 Ọkàn mi mọ ọ̀rọ̀ reregẹ́gẹ́ bí mo ṣe ń sọ ohun tí mo ti ṣe fún ọbaahọ́n mi ni kálámù ayára kọ̀wé. 2 Ìwọ yanjú ju àwọn ọmọ ènìyàn lọ:a da oore-ọ̀fẹ́ sí ọ ní ètè:nítorí náà ni Ọlọ́run ṣe bùkún fún ọ láéláé. 3 Gba idà rẹ mọ́ ìhà rẹ, ìwọ alágbára jùlọwọ ara rẹ ní ògo àti ọláńlá. 4 Nínú ọláńlá rẹ, máa gẹṣin lọ ní àlàáfíà lórí òtítọ́,ìwà tútù àti òtítọ́;jẹ́ kí ọwọ́ ọ̀tún rẹ ṣe ohun ẹ̀rù. 5 Jẹ́ kí ọfà mímú rẹ̀ dá ọkàn àwọn ọ̀tá ọba lujẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè ṣubú sí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀. 6 Ọlọ́run láé, àti láéláé ni ìtẹ́ rẹ,ọ̀pá aládé ìjọba rẹ, ọ̀pá aládé òtítọ́ ni. 7 Ìwọ fẹ́ olódodo, ìwọ sì kórìíra ìwà búburúnígbà náà Ọlọ́run, Ọlọ́run rẹ ti yàn ọ́ ṣe olórí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ,nípa fífi àmì òróró ayọ̀ kùn ọ́. 8 Gbogbo aṣọ rẹ̀ ni ó ń rùn pẹ̀lú òjìá àti aloe àti kasia;láti inú ààfin tí a fi eyín erin ṣeorin olókùn tẹ́ẹ́rẹ́ mú inú rẹ̀ dùn. 9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọbawà nínú àwọn àyànfẹ́ rẹ̀,ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ ni ayaba náà gbé dúrónínú wúrà Ofiri. 10 Gbọ́ ìwọ ọmọbìnrin, ronú kí o sì dẹtí rẹ sí migbàgbé àwọn ènìyàn rẹ àti ilé baba rẹ. 11 Bẹ́ẹ̀ ni ọba yóò fẹ́ ẹwà rẹ gidigidinítorí òun ni olúwa rẹkí ìwọ sì máa tẹríba fún un. 12 Ọmọbìnrin ọba Tire yóò wá pẹ̀lú ẹ̀bùnàwọn ọkùnrin ọlọ́rọ̀ yóò máa wá ojúrere rẹ̀. 13 Gbogbo ògo ni ti ọmọbìnrin ọba ní àárín ilé rẹ̀,iṣẹ́ wúrà ọnà abẹ́rẹ́ ní aṣọ rẹ̀. 14 Nínú aṣọ olówó iyebíye ni a mú un tọ́ ọba wá,àwọn wúńdíá ẹgbẹ́ rẹ̀ tẹ̀lé e, wọ́n sí mú un tọ̀ ọ́ wá. 15 Wọ́n sì mú un wá pẹ̀lú ayọ̀ àti inú dídùnwọ́n sì wọ ààfin ọba. 16 Ọmọ rẹ̀ ni yóò gba ipò baba rẹ̀ìwọ yóò sì fi wọ́n joyè lórí ilẹ̀ gbogbo. 17 Èmí yóò máa rántí orúkọ rẹ̀ ní ìran gbogbo,nígbà náà ni orílẹ̀-èdè yóò yìn ọ́ láé àti láéláé.

In Other Versions

Psalms 45 in the ANGEFD

Psalms 45 in the ANTPNG2D

Psalms 45 in the AS21

Psalms 45 in the BAGH

Psalms 45 in the BBPNG

Psalms 45 in the BBT1E

Psalms 45 in the BDS

Psalms 45 in the BEV

Psalms 45 in the BHAD

Psalms 45 in the BIB

Psalms 45 in the BLPT

Psalms 45 in the BNT

Psalms 45 in the BNTABOOT

Psalms 45 in the BNTLV

Psalms 45 in the BOATCB

Psalms 45 in the BOATCB2

Psalms 45 in the BOBCV

Psalms 45 in the BOCNT

Psalms 45 in the BOECS

Psalms 45 in the BOGWICC

Psalms 45 in the BOHCB

Psalms 45 in the BOHCV

Psalms 45 in the BOHLNT

Psalms 45 in the BOHNTLTAL

Psalms 45 in the BOICB

Psalms 45 in the BOILNTAP

Psalms 45 in the BOITCV

Psalms 45 in the BOKCV

Psalms 45 in the BOKCV2

Psalms 45 in the BOKHWOG

Psalms 45 in the BOKSSV

Psalms 45 in the BOLCB

Psalms 45 in the BOLCB2

Psalms 45 in the BOMCV

Psalms 45 in the BONAV

Psalms 45 in the BONCB

Psalms 45 in the BONLT

Psalms 45 in the BONUT2

Psalms 45 in the BOPLNT

Psalms 45 in the BOSCB

Psalms 45 in the BOSNC

Psalms 45 in the BOTLNT

Psalms 45 in the BOVCB

Psalms 45 in the BPBB

Psalms 45 in the BPH

Psalms 45 in the BSB

Psalms 45 in the CCB

Psalms 45 in the CUV

Psalms 45 in the CUVS

Psalms 45 in the DBT

Psalms 45 in the DGDNT

Psalms 45 in the DHNT

Psalms 45 in the DNT

Psalms 45 in the ELBE

Psalms 45 in the EMTV

Psalms 45 in the ESV

Psalms 45 in the FBV

Psalms 45 in the FEB

Psalms 45 in the GGMNT

Psalms 45 in the GNT

Psalms 45 in the HARY

Psalms 45 in the HNT

Psalms 45 in the IRVA

Psalms 45 in the IRVB

Psalms 45 in the IRVG

Psalms 45 in the IRVH

Psalms 45 in the IRVK

Psalms 45 in the IRVM

Psalms 45 in the IRVM2

Psalms 45 in the IRVO

Psalms 45 in the IRVP

Psalms 45 in the IRVT

Psalms 45 in the IRVT2

Psalms 45 in the IRVU

Psalms 45 in the ISVN

Psalms 45 in the JSNT

Psalms 45 in the KAPI

Psalms 45 in the KBT1ETNIK

Psalms 45 in the KBV

Psalms 45 in the KJV

Psalms 45 in the KNFD

Psalms 45 in the LBA

Psalms 45 in the LBLA

Psalms 45 in the LNT

Psalms 45 in the LSV

Psalms 45 in the MAAL

Psalms 45 in the MBV

Psalms 45 in the MBV2

Psalms 45 in the MHNT

Psalms 45 in the MKNFD

Psalms 45 in the MNG

Psalms 45 in the MNT

Psalms 45 in the MNT2

Psalms 45 in the MRS1T

Psalms 45 in the NAA

Psalms 45 in the NASB

Psalms 45 in the NBLA

Psalms 45 in the NBS

Psalms 45 in the NBVTP

Psalms 45 in the NET2

Psalms 45 in the NIV11

Psalms 45 in the NNT

Psalms 45 in the NNT2

Psalms 45 in the NNT3

Psalms 45 in the PDDPT

Psalms 45 in the PFNT

Psalms 45 in the RMNT

Psalms 45 in the SBIAS

Psalms 45 in the SBIBS

Psalms 45 in the SBIBS2

Psalms 45 in the SBICS

Psalms 45 in the SBIDS

Psalms 45 in the SBIGS

Psalms 45 in the SBIHS

Psalms 45 in the SBIIS

Psalms 45 in the SBIIS2

Psalms 45 in the SBIIS3

Psalms 45 in the SBIKS

Psalms 45 in the SBIKS2

Psalms 45 in the SBIMS

Psalms 45 in the SBIOS

Psalms 45 in the SBIPS

Psalms 45 in the SBISS

Psalms 45 in the SBITS

Psalms 45 in the SBITS2

Psalms 45 in the SBITS3

Psalms 45 in the SBITS4

Psalms 45 in the SBIUS

Psalms 45 in the SBIVS

Psalms 45 in the SBT

Psalms 45 in the SBT1E

Psalms 45 in the SCHL

Psalms 45 in the SNT

Psalms 45 in the SUSU

Psalms 45 in the SUSU2

Psalms 45 in the SYNO

Psalms 45 in the TBIAOTANT

Psalms 45 in the TBT1E

Psalms 45 in the TBT1E2

Psalms 45 in the TFTIP

Psalms 45 in the TFTU

Psalms 45 in the TGNTATF3T

Psalms 45 in the THAI

Psalms 45 in the TNFD

Psalms 45 in the TNT

Psalms 45 in the TNTIK

Psalms 45 in the TNTIL

Psalms 45 in the TNTIN

Psalms 45 in the TNTIP

Psalms 45 in the TNTIZ

Psalms 45 in the TOMA

Psalms 45 in the TTENT

Psalms 45 in the UBG

Psalms 45 in the UGV

Psalms 45 in the UGV2

Psalms 45 in the UGV3

Psalms 45 in the VBL

Psalms 45 in the VDCC

Psalms 45 in the YALU

Psalms 45 in the YAPE

Psalms 45 in the YBVTP

Psalms 45 in the ZBP