Psalms 50 (BOYCB)
undefined Saamu ti Asafu. 1 OLÚWA, Ọlọ́run alágbára,sọ̀rọ̀ kí o sì pe ayé jọláti ìlà-oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀. 2 Láti Sioni wá, pípé ni ẹwà,Ọlọ́run tí ń tan ìmọ́lẹ̀ 3 Ọlọ́run ń bọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kì yóò dákẹ́,iná yóò máa jó níwájú rẹ̀,àti ní àyíká rẹ̀ ni ẹ̀fúùfù líle yóò ti máa jà ká. 4 Yóò sì pe àwọn ọ̀run láti òkè wá jọ àti ayé,kí o le máa ṣe ìdárò àwọn ènìyàn rẹ̀. 5 “Kó àwọn ènìyàn mímọ́ jọ fún miàwọn tí wọn fi ẹbọ dá májẹ̀mú fún mi.” 6 Àwọn ọ̀run yóò sì sọ̀rọ̀ òdodo rẹ̀,nítorí Ọlọ́run fúnra rẹ̀ ni onídàájọ́. 7 “Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ènìyàn mi, èmi yóò si sọ̀rọ̀, ìwọ Israẹli, èmi yóò jẹ́rìí sí ọ:èmi ní Ọlọ́run, àní Ọlọ́run rẹ. 8 Èmi kí yóò bá ọ wínítorí àwọn ìrúbọ rẹ,tàbí ọrẹ ẹbọ sísun rẹ, èyí tí ó wà níwájú miní ìgbà gbogbo. 9 Èmí kò fẹ́ kí ó mú akọ màlúù láti inú ilé tí o kọ́ fún un,tàbí kí o mú òbúkọ látiinú agbo ẹran rẹ̀ 10 nítorí gbogbo ẹran igbó ni tèmiàti ẹran ọ̀sìn lórí ẹgbẹ̀rún (1,000) òkè. 11 Èmi mọ gbogbo ẹyẹ ní orí àwọn òkè ńláàti gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ó wà ní orí ilẹ̀ ni tèmi. 12 Bí ebi tilẹ̀ ń pa mí, èmi kì yóò sọ fún ọ,nítorí ayé ni tèmi àti ohun gbogbotí ó wa ní inú rẹ̀. 13 Ǹjẹ́ èmi yóò ha jẹ ẹran akọ màlúù tàbímú ẹ̀jẹ̀ òbúkọ? 14 “Rú ẹbọ ọpẹ́ sí Ọlọ́run,kí o sì san ẹ̀jẹ́ rẹ fún Ọ̀gá-ògo. 15 Kí o sì pè mí ní ọjọ́ ìpọ́njú,èmi yóò gbà ọ́, ìwọ yóò sì bu ọlá fún mi.” 16 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run sọ fún àwọn, ènìyàn búburú:“Kí ní ẹ̀tọ́ tí o ní tí ìwọ fi ń tún àwọn ìlànà mi sọ,tàbí tí ìwọ sì ń sọ májẹ̀mú mi ní ẹnu rẹ? 17 Ìwọ kórìíra àṣẹ mi,ìwọ sì ṣá ọ̀rọ̀ mí tì sí apá kan. 18 Nígbà tí ìwọ rí olè, ìwọ dára pọ̀ mọ́ ọn,ìwọ sì da ara rẹ dé àwọn alágbèrè. 19 Ìwọ lo ẹnu rẹ fún aburú,ìwọ sì ń fi ahọ́n rẹ pète ẹ̀tàn. 20 Ní ìgbà gbogbo ìwọ ń sọ̀rọ̀ sí arákùnrin rẹ,ìwọ sì ń ba orúkọ ọmọ ìyá rẹ jẹ́. 21 Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ ti ṣe, mo sì dákẹ́;ìwọ rò pé mo jẹ́ irú kan náà bí ìrẹ,ṣùgbọ́n èmi yóò bá ọ wí,èmi yóò sì fi ẹ̀sùn kàn ọ́ ní ojú ara rẹ. 22 “Ǹjẹ́ ìwọ ro èyí wò, ẹ̀yin tí ó gbàgbé Ọlọ́run.Bí bẹ́ẹ̀ kọ́ èmi yóò fa yin ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, láìsí ẹni tí yóò gbà yin sílẹ̀. 23 Ẹni tí ó ba ní ẹbọ ọrẹ-ọpẹ́ bu ọlá fún mi; kí ó sì tún ọ̀nà rẹ̀ ṣe,kí èmi kí ó le fi ìgbàlà Ọlọ́run hàn án.”
In Other Versions
Psalms 50 in the ANGEFD
Psalms 50 in the ANTPNG2D
Psalms 50 in the AS21
Psalms 50 in the BAGH
Psalms 50 in the BBPNG
Psalms 50 in the BBT1E
Psalms 50 in the BDS
Psalms 50 in the BEV
Psalms 50 in the BHAD
Psalms 50 in the BIB
Psalms 50 in the BLPT
Psalms 50 in the BNT
Psalms 50 in the BNTABOOT
Psalms 50 in the BNTLV
Psalms 50 in the BOATCB
Psalms 50 in the BOATCB2
Psalms 50 in the BOBCV
Psalms 50 in the BOCNT
Psalms 50 in the BOECS
Psalms 50 in the BOGWICC
Psalms 50 in the BOHCB
Psalms 50 in the BOHCV
Psalms 50 in the BOHLNT
Psalms 50 in the BOHNTLTAL
Psalms 50 in the BOICB
Psalms 50 in the BOILNTAP
Psalms 50 in the BOITCV
Psalms 50 in the BOKCV
Psalms 50 in the BOKCV2
Psalms 50 in the BOKHWOG
Psalms 50 in the BOKSSV
Psalms 50 in the BOLCB
Psalms 50 in the BOLCB2
Psalms 50 in the BOMCV
Psalms 50 in the BONAV
Psalms 50 in the BONCB
Psalms 50 in the BONLT
Psalms 50 in the BONUT2
Psalms 50 in the BOPLNT
Psalms 50 in the BOSCB
Psalms 50 in the BOSNC
Psalms 50 in the BOTLNT
Psalms 50 in the BOVCB
Psalms 50 in the BPBB
Psalms 50 in the BPH
Psalms 50 in the BSB
Psalms 50 in the CCB
Psalms 50 in the CUV
Psalms 50 in the CUVS
Psalms 50 in the DBT
Psalms 50 in the DGDNT
Psalms 50 in the DHNT
Psalms 50 in the DNT
Psalms 50 in the ELBE
Psalms 50 in the EMTV
Psalms 50 in the ESV
Psalms 50 in the FBV
Psalms 50 in the FEB
Psalms 50 in the GGMNT
Psalms 50 in the GNT
Psalms 50 in the HARY
Psalms 50 in the HNT
Psalms 50 in the IRVA
Psalms 50 in the IRVB
Psalms 50 in the IRVG
Psalms 50 in the IRVH
Psalms 50 in the IRVK
Psalms 50 in the IRVM
Psalms 50 in the IRVM2
Psalms 50 in the IRVO
Psalms 50 in the IRVP
Psalms 50 in the IRVT
Psalms 50 in the IRVT2
Psalms 50 in the IRVU
Psalms 50 in the ISVN
Psalms 50 in the JSNT
Psalms 50 in the KAPI
Psalms 50 in the KBT1ETNIK
Psalms 50 in the KBV
Psalms 50 in the KJV
Psalms 50 in the KNFD
Psalms 50 in the LBA
Psalms 50 in the LBLA
Psalms 50 in the LNT
Psalms 50 in the LSV
Psalms 50 in the MAAL
Psalms 50 in the MBV
Psalms 50 in the MBV2
Psalms 50 in the MHNT
Psalms 50 in the MKNFD
Psalms 50 in the MNG
Psalms 50 in the MNT
Psalms 50 in the MNT2
Psalms 50 in the MRS1T
Psalms 50 in the NAA
Psalms 50 in the NASB
Psalms 50 in the NBLA
Psalms 50 in the NBS
Psalms 50 in the NBVTP
Psalms 50 in the NET2
Psalms 50 in the NIV11
Psalms 50 in the NNT
Psalms 50 in the NNT2
Psalms 50 in the NNT3
Psalms 50 in the PDDPT
Psalms 50 in the PFNT
Psalms 50 in the RMNT
Psalms 50 in the SBIAS
Psalms 50 in the SBIBS
Psalms 50 in the SBIBS2
Psalms 50 in the SBICS
Psalms 50 in the SBIDS
Psalms 50 in the SBIGS
Psalms 50 in the SBIHS
Psalms 50 in the SBIIS
Psalms 50 in the SBIIS2
Psalms 50 in the SBIIS3
Psalms 50 in the SBIKS
Psalms 50 in the SBIKS2
Psalms 50 in the SBIMS
Psalms 50 in the SBIOS
Psalms 50 in the SBIPS
Psalms 50 in the SBISS
Psalms 50 in the SBITS
Psalms 50 in the SBITS2
Psalms 50 in the SBITS3
Psalms 50 in the SBITS4
Psalms 50 in the SBIUS
Psalms 50 in the SBIVS
Psalms 50 in the SBT
Psalms 50 in the SBT1E
Psalms 50 in the SCHL
Psalms 50 in the SNT
Psalms 50 in the SUSU
Psalms 50 in the SUSU2
Psalms 50 in the SYNO
Psalms 50 in the TBIAOTANT
Psalms 50 in the TBT1E
Psalms 50 in the TBT1E2
Psalms 50 in the TFTIP
Psalms 50 in the TFTU
Psalms 50 in the TGNTATF3T
Psalms 50 in the THAI
Psalms 50 in the TNFD
Psalms 50 in the TNT
Psalms 50 in the TNTIK
Psalms 50 in the TNTIL
Psalms 50 in the TNTIN
Psalms 50 in the TNTIP
Psalms 50 in the TNTIZ
Psalms 50 in the TOMA
Psalms 50 in the TTENT
Psalms 50 in the UBG
Psalms 50 in the UGV
Psalms 50 in the UGV2
Psalms 50 in the UGV3
Psalms 50 in the VBL
Psalms 50 in the VDCC
Psalms 50 in the YALU
Psalms 50 in the YAPE
Psalms 50 in the YBVTP
Psalms 50 in the ZBP