Psalms 55 (BOYCB)
undefined Fún adarí orin. Pẹ̀lú ohun èlò orin olókùn. Maskili ti Dafidi. 1 Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run,má ṣe fi ojú pa ẹ̀bẹ̀ mi rẹ́: 2 gbọ́ mi kí o sì dá mi lóhùn.Èrò mi ń dà mí láàmú, èmi sì ń pariwo. 3 Sí ohùn àwọn ọ̀tá ni,nítorí igbe àwọn ènìyàn búburú;nítorí wọ́n mú ìjìyà wá sórí mi,wọ́n sì kẹ́gàn mi nínú ìbínú wọn. 4 Ọkàn mi wà nínú ìrora pẹ̀lú;ẹ̀rù ikú kọjú ìjà sí mi. 5 Ìbẹ̀rù àti ìwárìrì wa sí ara mi;ìbẹ̀rù ti bò mí mọ́lẹ̀. 6 Èmi sọ pé, “Èmi ìbá ní ìyẹ́ bí àdàbà!Èmi ìbá fò lọ kí n sì sinmi. 7 Èmi ìbá sálọ, jìnnà réré,kí ń sì dúró sí aginjù; 8 èmi ìbá yára lọ́ si ibùgbé mi ní ibi ààbò,jìnnà kúrò nínú ìjì àti ẹ̀fúùfù líle.” 9 Da àwọn ẹni búburú láàmú, OLÚWA, da ahọ́n wọn rú,nítorí èmi rí ìwà agbára àti ìjà ní ìlú náà. 10 Ọ̀sán àti òru ni wọ́n fi ń rìn gbogbo odi kiri;ìwà ìkà àti èébú wà láàrín rẹ̀. 11 Ìwà búburú ń bẹ ní àárín rẹ̀;ẹ̀tàn àti èké kò kúrò ní ìgboro rẹ̀. 12 Tí ọ̀tá bá tàbùkù mi,èmi yóò fi ara mọ́ ọn;tí ọ̀tá bá gbé ara rẹ̀ ga sí mi,èmi ìbá sá pamọ́ fún un. 13 Ṣùgbọ́n tí ó bá ṣe ìwọ, ọkùnrin bí ẹgbẹ́ mi,ẹlẹgbẹ́ mi, àti ọ̀rẹ́ tí ó súnmọ́ mi, 14 pẹ̀lú ẹni tí èmi ti jẹ ìgbádùn adùn ìdàpọ̀,bí a ṣe ń rìn pẹ̀lú àwùjọ ní ilé Ọlọ́run. 15 Kí ikú kí ó dé bá wọn,kí wọn ó lọ láààyè sí isà òkú,jẹ́ kí wọn ó sọ̀kalẹ̀ sí ibojì pẹ̀lú ìpayà,nítorí tí ìwà búburú ń bẹ ní ibùjókòó wọn, àti nínú wọn. 16 Ṣùgbọ́n èmi pe Ọlọ́run; OLÚWA yóò sì gbà mí. 17 Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sánèmi sọkún jáde nínú ìpọ́njú,o sì gbọ́ ohùn mi. 18 Ó rà mí padà láìléwukúrò nínú ogun tí ó dìde sí mi,nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó dìde sí mi. 19 Ọlọ́run yóò gbọ́, yóò sì pọ́n wọn lójú àní,ẹni tí ó ti jókòó láti ìgbàanì Sela,nítorí tí wọn kò ní àyípadà,tí wọn kò sì bẹ̀rù Ọlọ́run. 20 Ọ̀rẹ́ mi yìí ti dalẹ̀ èmi ọ̀rẹ́ rẹ̀;ó ti ba májẹ̀mú rẹ̀ jẹ́. 21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ kúnná ju òrí-àmọ́,ṣùgbọ́n ogun wà ni àyà rẹ̀;ọ̀rọ̀ rẹ̀ fẹ́lẹ́ ju òróró lọ,ṣùgbọ́n idà fífàyọ ní wọn. 22 Gbé ẹrù rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ OLÚWAyóò sì mú ọ dúró;òun kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú. 23 Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni yóò mu àwọn ọ̀tá miwá sí ihò ìparun;àwọn ẹni tí òǹgbẹ ẹ̀jẹ̀ ń gbẹ àti ẹni ẹ̀tàn,kì yóò gbé ààbọ̀ ọjọ́ wọn. Ṣùgbọ́n fún èmi, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ.
In Other Versions
Psalms 55 in the ANGEFD
Psalms 55 in the ANTPNG2D
Psalms 55 in the AS21
Psalms 55 in the BAGH
Psalms 55 in the BBPNG
Psalms 55 in the BBT1E
Psalms 55 in the BDS
Psalms 55 in the BEV
Psalms 55 in the BHAD
Psalms 55 in the BIB
Psalms 55 in the BLPT
Psalms 55 in the BNT
Psalms 55 in the BNTABOOT
Psalms 55 in the BNTLV
Psalms 55 in the BOATCB
Psalms 55 in the BOATCB2
Psalms 55 in the BOBCV
Psalms 55 in the BOCNT
Psalms 55 in the BOECS
Psalms 55 in the BOGWICC
Psalms 55 in the BOHCB
Psalms 55 in the BOHCV
Psalms 55 in the BOHLNT
Psalms 55 in the BOHNTLTAL
Psalms 55 in the BOICB
Psalms 55 in the BOILNTAP
Psalms 55 in the BOITCV
Psalms 55 in the BOKCV
Psalms 55 in the BOKCV2
Psalms 55 in the BOKHWOG
Psalms 55 in the BOKSSV
Psalms 55 in the BOLCB
Psalms 55 in the BOLCB2
Psalms 55 in the BOMCV
Psalms 55 in the BONAV
Psalms 55 in the BONCB
Psalms 55 in the BONLT
Psalms 55 in the BONUT2
Psalms 55 in the BOPLNT
Psalms 55 in the BOSCB
Psalms 55 in the BOSNC
Psalms 55 in the BOTLNT
Psalms 55 in the BOVCB
Psalms 55 in the BPBB
Psalms 55 in the BPH
Psalms 55 in the BSB
Psalms 55 in the CCB
Psalms 55 in the CUV
Psalms 55 in the CUVS
Psalms 55 in the DBT
Psalms 55 in the DGDNT
Psalms 55 in the DHNT
Psalms 55 in the DNT
Psalms 55 in the ELBE
Psalms 55 in the EMTV
Psalms 55 in the ESV
Psalms 55 in the FBV
Psalms 55 in the FEB
Psalms 55 in the GGMNT
Psalms 55 in the GNT
Psalms 55 in the HARY
Psalms 55 in the HNT
Psalms 55 in the IRVA
Psalms 55 in the IRVB
Psalms 55 in the IRVG
Psalms 55 in the IRVH
Psalms 55 in the IRVK
Psalms 55 in the IRVM
Psalms 55 in the IRVM2
Psalms 55 in the IRVO
Psalms 55 in the IRVP
Psalms 55 in the IRVT
Psalms 55 in the IRVT2
Psalms 55 in the IRVU
Psalms 55 in the ISVN
Psalms 55 in the JSNT
Psalms 55 in the KAPI
Psalms 55 in the KBT1ETNIK
Psalms 55 in the KBV
Psalms 55 in the KJV
Psalms 55 in the KNFD
Psalms 55 in the LBA
Psalms 55 in the LBLA
Psalms 55 in the LNT
Psalms 55 in the LSV
Psalms 55 in the MAAL
Psalms 55 in the MBV
Psalms 55 in the MBV2
Psalms 55 in the MHNT
Psalms 55 in the MKNFD
Psalms 55 in the MNG
Psalms 55 in the MNT
Psalms 55 in the MNT2
Psalms 55 in the MRS1T
Psalms 55 in the NAA
Psalms 55 in the NASB
Psalms 55 in the NBLA
Psalms 55 in the NBS
Psalms 55 in the NBVTP
Psalms 55 in the NET2
Psalms 55 in the NIV11
Psalms 55 in the NNT
Psalms 55 in the NNT2
Psalms 55 in the NNT3
Psalms 55 in the PDDPT
Psalms 55 in the PFNT
Psalms 55 in the RMNT
Psalms 55 in the SBIAS
Psalms 55 in the SBIBS
Psalms 55 in the SBIBS2
Psalms 55 in the SBICS
Psalms 55 in the SBIDS
Psalms 55 in the SBIGS
Psalms 55 in the SBIHS
Psalms 55 in the SBIIS
Psalms 55 in the SBIIS2
Psalms 55 in the SBIIS3
Psalms 55 in the SBIKS
Psalms 55 in the SBIKS2
Psalms 55 in the SBIMS
Psalms 55 in the SBIOS
Psalms 55 in the SBIPS
Psalms 55 in the SBISS
Psalms 55 in the SBITS
Psalms 55 in the SBITS2
Psalms 55 in the SBITS3
Psalms 55 in the SBITS4
Psalms 55 in the SBIUS
Psalms 55 in the SBIVS
Psalms 55 in the SBT
Psalms 55 in the SBT1E
Psalms 55 in the SCHL
Psalms 55 in the SNT
Psalms 55 in the SUSU
Psalms 55 in the SUSU2
Psalms 55 in the SYNO
Psalms 55 in the TBIAOTANT
Psalms 55 in the TBT1E
Psalms 55 in the TBT1E2
Psalms 55 in the TFTIP
Psalms 55 in the TFTU
Psalms 55 in the TGNTATF3T
Psalms 55 in the THAI
Psalms 55 in the TNFD
Psalms 55 in the TNT
Psalms 55 in the TNTIK
Psalms 55 in the TNTIL
Psalms 55 in the TNTIN
Psalms 55 in the TNTIP
Psalms 55 in the TNTIZ
Psalms 55 in the TOMA
Psalms 55 in the TTENT
Psalms 55 in the UBG
Psalms 55 in the UGV
Psalms 55 in the UGV2
Psalms 55 in the UGV3
Psalms 55 in the VBL
Psalms 55 in the VDCC
Psalms 55 in the YALU
Psalms 55 in the YAPE
Psalms 55 in the YBVTP
Psalms 55 in the ZBP