Psalms 74 (BOYCB)

undefined Maskili ti Asafu. 1 Ọlọ́run, èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?Èéṣe tí ìbínú rẹ̀ fi dìde sí àwọn àgùntàn pápá rẹ? 2 Rántí àwọn ènìyàn tí ìwọ ti rà nígbà àtijọ́,ẹ̀yà ilẹ̀ ìní rẹ, tí ìwọ ti rà padà.Òkè Sioni, níbi tí ìwọ ń gbé. 3 Yí ẹsẹ̀ rẹ padà sí ìparun ayérayé wọn,gbogbo ìparun yìí tí ọ̀tá ti mú wá sí ibi mímọ́. 4 Àwọn ọ̀tá rẹ ń bú ramúramùláàrín ènìyàn rẹ,wọ́n ń gbé àsíá wọn sókè fún àmì. 5 Wọ́n ń rí bí ọkùnrin tí ó gbé àáké rẹ̀ sókèláti gé igi igbó dídí. 6 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, iṣẹ́ ọnà fínfín,ni wọ́n fi àáké wó lulẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀kan náà. 7 Wọ́n sun ibi mímọ́ rẹ lulẹ̀wọ́n ba ibùgbé orúkọ rẹ jẹ́. 8 Wọ́n wí ní ọkàn wọn. “Àwa ó run wọ́n pátápátá!”Wọ́n sun gbogbo ibi ìjọ́sìn Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà. 9 A kò fún wa ní àmì iṣẹ́ ìyanu kankan;kò sí wòlíì kankanẹnìkankan wa kò mọ ìgbà tí eléyìí yóò dà. 10 Àwọn ọ̀tá yóò ti kùn sí ọ pẹ́ tó, Ọlọ́run?Àwọn ọ̀tá yóò ha ba orúkọ rẹ jẹ́ títí láé? 11 Èéṣe tí ìwọ fi dá ọwọ́ rẹ dúró, ọwọ́ ọ̀tún rẹ?Mú un kúrò nínú ìṣẹ́po aṣọ rẹ kí o sì run wọ́n! 12 Ṣùgbọ́n ìwọ Ọlọ́run ni ọba mi láti ìgbà pípẹ́;Ó mú ìgbàlà wá sórí ilẹ̀ ayé. 13 Ìwọ ni ó la òkun sílẹ̀ nípa agbára rẹ;ìwọ fọ́ orí ẹ̀mí búburú nínú omi. 14 Ìwọ fọ́ orí Lefitani túútúú, o sì fi ṣe oúnjẹ fun àwọn ẹ̀dá tí ń gbé inú ijùtìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ sì ni alẹ́ pẹ̀lú;ìwọ fi ìdí oòrùn àti òṣùpá lélẹ̀. 15 Ìwọ ya orísun omi àti ìṣàn omi;Ìwọ mú kí odò tó ń sàn gbẹ. 16 Tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ ni òru pẹ̀lú;ìwọ yà oòrùn àti òṣùpá. 17 Ìwọ pààlà etí ayé;Ìwọ dá ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù. 18 Rántí bí àwọn ọ̀tá ń kẹ́gàn rẹ, OLÚWAbí àwọn aṣiwèrè ènìyàn ti ń ba orúkọ rẹ jẹ́. 19 Má ṣe fi ẹ̀mí àdàbà rẹ fún ẹranko igbó búburú;má ṣe gbàgbé ẹ̀mí àwọn ènìyàn rẹ tí a ń pọ́n lójú títí láé. 20 Bojú wo májẹ̀mú rẹ,nítorí ibi òkùnkùn ayé kún fún ibùgbé ìkà. 21 Má ṣe jẹ́ kí àwọn aninilára padà sẹ́yìn nínú ìtìjújẹ́ kí àwọn aláìní àti tálákà yin orúkọ rẹ. 22 Dìde, Ọlọ́run, gba ẹjọ́ ara rẹ rò;rántí bí àwọn aṣiwèrè ti ń kẹ́gàn rẹ ní gbogbo ọjọ́. 23 Má ṣe gbàgbé ohùn àwọn ọ̀tá rẹ,bíbú àwọn ọ̀tá rẹ, tí ó ń pọ̀ sí i nígbà gbogbo.

In Other Versions

Psalms 74 in the ANGEFD

Psalms 74 in the ANTPNG2D

Psalms 74 in the AS21

Psalms 74 in the BAGH

Psalms 74 in the BBPNG

Psalms 74 in the BBT1E

Psalms 74 in the BDS

Psalms 74 in the BEV

Psalms 74 in the BHAD

Psalms 74 in the BIB

Psalms 74 in the BLPT

Psalms 74 in the BNT

Psalms 74 in the BNTABOOT

Psalms 74 in the BNTLV

Psalms 74 in the BOATCB

Psalms 74 in the BOATCB2

Psalms 74 in the BOBCV

Psalms 74 in the BOCNT

Psalms 74 in the BOECS

Psalms 74 in the BOGWICC

Psalms 74 in the BOHCB

Psalms 74 in the BOHCV

Psalms 74 in the BOHLNT

Psalms 74 in the BOHNTLTAL

Psalms 74 in the BOICB

Psalms 74 in the BOILNTAP

Psalms 74 in the BOITCV

Psalms 74 in the BOKCV

Psalms 74 in the BOKCV2

Psalms 74 in the BOKHWOG

Psalms 74 in the BOKSSV

Psalms 74 in the BOLCB

Psalms 74 in the BOLCB2

Psalms 74 in the BOMCV

Psalms 74 in the BONAV

Psalms 74 in the BONCB

Psalms 74 in the BONLT

Psalms 74 in the BONUT2

Psalms 74 in the BOPLNT

Psalms 74 in the BOSCB

Psalms 74 in the BOSNC

Psalms 74 in the BOTLNT

Psalms 74 in the BOVCB

Psalms 74 in the BPBB

Psalms 74 in the BPH

Psalms 74 in the BSB

Psalms 74 in the CCB

Psalms 74 in the CUV

Psalms 74 in the CUVS

Psalms 74 in the DBT

Psalms 74 in the DGDNT

Psalms 74 in the DHNT

Psalms 74 in the DNT

Psalms 74 in the ELBE

Psalms 74 in the EMTV

Psalms 74 in the ESV

Psalms 74 in the FBV

Psalms 74 in the FEB

Psalms 74 in the GGMNT

Psalms 74 in the GNT

Psalms 74 in the HARY

Psalms 74 in the HNT

Psalms 74 in the IRVA

Psalms 74 in the IRVB

Psalms 74 in the IRVG

Psalms 74 in the IRVH

Psalms 74 in the IRVK

Psalms 74 in the IRVM

Psalms 74 in the IRVM2

Psalms 74 in the IRVO

Psalms 74 in the IRVP

Psalms 74 in the IRVT

Psalms 74 in the IRVT2

Psalms 74 in the IRVU

Psalms 74 in the ISVN

Psalms 74 in the JSNT

Psalms 74 in the KAPI

Psalms 74 in the KBT1ETNIK

Psalms 74 in the KBV

Psalms 74 in the KJV

Psalms 74 in the KNFD

Psalms 74 in the LBA

Psalms 74 in the LBLA

Psalms 74 in the LNT

Psalms 74 in the LSV

Psalms 74 in the MAAL

Psalms 74 in the MBV

Psalms 74 in the MBV2

Psalms 74 in the MHNT

Psalms 74 in the MKNFD

Psalms 74 in the MNG

Psalms 74 in the MNT

Psalms 74 in the MNT2

Psalms 74 in the MRS1T

Psalms 74 in the NAA

Psalms 74 in the NASB

Psalms 74 in the NBLA

Psalms 74 in the NBS

Psalms 74 in the NBVTP

Psalms 74 in the NET2

Psalms 74 in the NIV11

Psalms 74 in the NNT

Psalms 74 in the NNT2

Psalms 74 in the NNT3

Psalms 74 in the PDDPT

Psalms 74 in the PFNT

Psalms 74 in the RMNT

Psalms 74 in the SBIAS

Psalms 74 in the SBIBS

Psalms 74 in the SBIBS2

Psalms 74 in the SBICS

Psalms 74 in the SBIDS

Psalms 74 in the SBIGS

Psalms 74 in the SBIHS

Psalms 74 in the SBIIS

Psalms 74 in the SBIIS2

Psalms 74 in the SBIIS3

Psalms 74 in the SBIKS

Psalms 74 in the SBIKS2

Psalms 74 in the SBIMS

Psalms 74 in the SBIOS

Psalms 74 in the SBIPS

Psalms 74 in the SBISS

Psalms 74 in the SBITS

Psalms 74 in the SBITS2

Psalms 74 in the SBITS3

Psalms 74 in the SBITS4

Psalms 74 in the SBIUS

Psalms 74 in the SBIVS

Psalms 74 in the SBT

Psalms 74 in the SBT1E

Psalms 74 in the SCHL

Psalms 74 in the SNT

Psalms 74 in the SUSU

Psalms 74 in the SUSU2

Psalms 74 in the SYNO

Psalms 74 in the TBIAOTANT

Psalms 74 in the TBT1E

Psalms 74 in the TBT1E2

Psalms 74 in the TFTIP

Psalms 74 in the TFTU

Psalms 74 in the TGNTATF3T

Psalms 74 in the THAI

Psalms 74 in the TNFD

Psalms 74 in the TNT

Psalms 74 in the TNTIK

Psalms 74 in the TNTIL

Psalms 74 in the TNTIN

Psalms 74 in the TNTIP

Psalms 74 in the TNTIZ

Psalms 74 in the TOMA

Psalms 74 in the TTENT

Psalms 74 in the UBG

Psalms 74 in the UGV

Psalms 74 in the UGV2

Psalms 74 in the UGV3

Psalms 74 in the VBL

Psalms 74 in the VDCC

Psalms 74 in the YALU

Psalms 74 in the YAPE

Psalms 74 in the YBVTP

Psalms 74 in the ZBP