Titus 3 (BOYCB)
1 Rán àwọn ènìyàn náà létí láti máa tẹríba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ. Kí wọn ṣe ìgbọ́ràn nígbà gbogbo, kí wọn sì múra fún iṣẹ́ rere gbogbo. 2 Wọn kò gbọdọ̀ sọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni ní ibi, kí wọn jẹ́ ẹni àlàáfíà àti ẹni pẹ̀lẹ́, kí wọn sì máa fi ìwà tútù gbogbo hàn sí gbogbo ènìyàn. 3 Nígbà kan rí, àwa pàápàá jẹ́ òpè àti aláìgbọ́ràn, àti tàn wá jẹ, a sì ti sọ wá di ẹrú fún onírúurú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti adùn ayé. À ń gbé ìgbé ayé àrankàn àti owú kíkorò, a jẹ́ ẹni ìríra, a sì ń kórìíra ọmọ ẹnìkejì wa pẹ̀lú. 4 Ṣùgbọ́n nígbà tí inú rere àti ìfẹ́ Ọlọ́run Olùgbàlà wa farahàn, 5 o gbà wá là. Kì í ṣe nípa iṣẹ́ tí àwa ṣe nínú òdodo bí kò ṣe nítorí àánú rẹ̀. Ó gbà wá là, nípasẹ̀ ìwẹ̀nù àtúnbí àti ìsọdọ̀tun ti Ẹ̀mí Mímọ́, 6 èyí tí tú lé wa lórí ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípasẹ̀ Jesu Kristi Olùgbàlà wá. 7 Tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó jẹ́ wí pé lẹ́hìn tí a tí dá wa láre nípasẹ̀ oore-ọ̀fẹ́, kí a lè jẹ́ àjùmọ̀jogún ìrètí ìyè àìnípẹ̀kun. 8 Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ wọ̀nyí. Mo sì fẹ́ kí ó ṣe ìtẹnumọ́ rẹ̀ gidigidi, kí àwọn tí wọ́n ti gbàgbọ́ nínú Ọlọ́run le kíyèsi láti máa fi ara wọn jì fún iṣẹ́ rere. Nǹkan wọ̀nyí dára, wọ́n sì jẹ́ èrè fún gbogbo ènìyàn. 9 Ṣùgbọ́n yẹra kúrò nínú àwọn ìbéèrè òmùgọ̀, àti ìtàn ìran, àti àríyànjiyàn àti ìjà nípa ti òfin, nítorí pé àwọn nǹkan báyìí jẹ́ aláìlérè àti asán. 10 Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ dá ìyapa sílẹ̀ láàrín yín, ẹ bá a wí lẹ́ẹ̀kínní àti lẹ́ẹ̀kejì. Lẹ́yìn náà, ẹ má ṣe ní ohunkóhun í ṣe pẹ̀lú rẹ̀. 11 Kí ó dá ọ lójú wí pé irú ẹni bẹ́ẹ̀ ti yapa, ó jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀, ó sì dá ara rẹ̀ lẹ́bi. 12 Ní kété tí mo bá ti rán Artema tàbí Tikiku sí ọ, sa gbogbo ipá rẹ láti tọ̀ mí wá ní Nikopoli, nítorí mo ti pinnu láti lo ìgbà òtútù mi níbẹ̀. 13 Sa gbogbo agbára rẹ láti ran Senasi amòfin àti Apollo lọ́wọ́ nínú ìrìnàjò wọn. Rí i dájú pé wọ́n ní ohun gbogbo tí wọn nílò. 14 Àwọn ènìyàn nílò láti kọ́ bí a tí ń fi ara ẹni jì sí iṣẹ́ rere kí wọn ba à le pèsè ohun kòsémánìí fún ara wọn, nípa èyí, wọn kì yóò jẹ́ aláìléso. 15 Gbogbo àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ mi kí ọ.Bá mi kí àwọn tí ó fẹ́ wa nínú ìgbàgbọ́. Kí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú gbogbo yín.
In Other Versions
Titus 3 in the ANGEFD
Titus 3 in the ANTPNG2D
Titus 3 in the AS21
Titus 3 in the BAGH
Titus 3 in the BBPNG
Titus 3 in the BBT1E
Titus 3 in the BDS
Titus 3 in the BEV
Titus 3 in the BHAD
Titus 3 in the BIB
Titus 3 in the BLPT
Titus 3 in the BNT
Titus 3 in the BNTABOOT
Titus 3 in the BNTLV
Titus 3 in the BOATCB
Titus 3 in the BOATCB2
Titus 3 in the BOBCV
Titus 3 in the BOCNT
Titus 3 in the BOECS
Titus 3 in the BOGWICC
Titus 3 in the BOHCB
Titus 3 in the BOHCV
Titus 3 in the BOHLNT
Titus 3 in the BOHNTLTAL
Titus 3 in the BOICB
Titus 3 in the BOILNTAP
Titus 3 in the BOITCV
Titus 3 in the BOKCV
Titus 3 in the BOKCV2
Titus 3 in the BOKHWOG
Titus 3 in the BOKSSV
Titus 3 in the BOLCB
Titus 3 in the BOLCB2
Titus 3 in the BOMCV
Titus 3 in the BONAV
Titus 3 in the BONCB
Titus 3 in the BONLT
Titus 3 in the BONUT2
Titus 3 in the BOPLNT
Titus 3 in the BOSCB
Titus 3 in the BOSNC
Titus 3 in the BOTLNT
Titus 3 in the BOVCB
Titus 3 in the BPBB
Titus 3 in the BPH
Titus 3 in the BSB
Titus 3 in the CCB
Titus 3 in the CUV
Titus 3 in the CUVS
Titus 3 in the DBT
Titus 3 in the DGDNT
Titus 3 in the DHNT
Titus 3 in the DNT
Titus 3 in the ELBE
Titus 3 in the EMTV
Titus 3 in the ESV
Titus 3 in the FBV
Titus 3 in the FEB
Titus 3 in the GGMNT
Titus 3 in the GNT
Titus 3 in the HARY
Titus 3 in the HNT
Titus 3 in the IRVA
Titus 3 in the IRVB
Titus 3 in the IRVG
Titus 3 in the IRVH
Titus 3 in the IRVK
Titus 3 in the IRVM
Titus 3 in the IRVM2
Titus 3 in the IRVO
Titus 3 in the IRVP
Titus 3 in the IRVT
Titus 3 in the IRVT2
Titus 3 in the IRVU
Titus 3 in the ISVN
Titus 3 in the JSNT
Titus 3 in the KAPI
Titus 3 in the KBT1ETNIK
Titus 3 in the KBV
Titus 3 in the KJV
Titus 3 in the KNFD
Titus 3 in the LBA
Titus 3 in the LBLA
Titus 3 in the LNT
Titus 3 in the LSV
Titus 3 in the MAAL
Titus 3 in the MBV
Titus 3 in the MBV2
Titus 3 in the MHNT
Titus 3 in the MKNFD
Titus 3 in the MNG
Titus 3 in the MNT
Titus 3 in the MNT2
Titus 3 in the MRS1T
Titus 3 in the NAA
Titus 3 in the NASB
Titus 3 in the NBLA
Titus 3 in the NBS
Titus 3 in the NBVTP
Titus 3 in the NET2
Titus 3 in the NIV11
Titus 3 in the NNT
Titus 3 in the NNT2
Titus 3 in the NNT3
Titus 3 in the PDDPT
Titus 3 in the PFNT
Titus 3 in the RMNT
Titus 3 in the SBIAS
Titus 3 in the SBIBS
Titus 3 in the SBIBS2
Titus 3 in the SBICS
Titus 3 in the SBIDS
Titus 3 in the SBIGS
Titus 3 in the SBIHS
Titus 3 in the SBIIS
Titus 3 in the SBIIS2
Titus 3 in the SBIIS3
Titus 3 in the SBIKS
Titus 3 in the SBIKS2
Titus 3 in the SBIMS
Titus 3 in the SBIOS
Titus 3 in the SBIPS
Titus 3 in the SBISS
Titus 3 in the SBITS
Titus 3 in the SBITS2
Titus 3 in the SBITS3
Titus 3 in the SBITS4
Titus 3 in the SBIUS
Titus 3 in the SBIVS
Titus 3 in the SBT
Titus 3 in the SBT1E
Titus 3 in the SCHL
Titus 3 in the SNT
Titus 3 in the SUSU
Titus 3 in the SUSU2
Titus 3 in the SYNO
Titus 3 in the TBIAOTANT
Titus 3 in the TBT1E
Titus 3 in the TBT1E2
Titus 3 in the TFTIP
Titus 3 in the TFTU
Titus 3 in the TGNTATF3T
Titus 3 in the THAI
Titus 3 in the TNFD
Titus 3 in the TNT
Titus 3 in the TNTIK
Titus 3 in the TNTIL
Titus 3 in the TNTIN
Titus 3 in the TNTIP
Titus 3 in the TNTIZ
Titus 3 in the TOMA
Titus 3 in the TTENT
Titus 3 in the UBG
Titus 3 in the UGV
Titus 3 in the UGV2
Titus 3 in the UGV3
Titus 3 in the VBL
Titus 3 in the VDCC
Titus 3 in the YALU
Titus 3 in the YAPE
Titus 3 in the YBVTP
Titus 3 in the ZBP