1 Chronicles 24 (BOYCB)

1 Àwọn wọ̀nyí sì ni pínpín àwọn ọmọ Aaroni.Àwọn ọmọ Aaroni ni Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari. 2 Ṣùgbọ́n Nadabu àti Abihu kú kí ó tó di wí pé baba wọn kú, wọn kò sì ní àwọn ọmọ; bẹ́ẹ̀ ni Eleasari àti Itamari sì ṣe gẹ́gẹ́ bí àlùfáà. 3 Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Sadoku ọmọ Eleasari àti Ahimeleki ọmọ Itamari, Dafidi sì yà wọ́n nípa nínú ìpín fún ìyàsọ́tọ̀ àwọn iṣẹ́ ìsìn wọn. 4 A rí ọ̀pọ̀ àwọn olórí lára àwọn ọmọ Eleasari ju lára àwọn ọmọ Itamari lọ, wọ́n sì pín wọn lẹ́sẹ lẹ́sẹ: mẹ́rìndínlógún olórí láti ìdílé ọmọ Eleasari ìran wọn àti olórí méjọ ìdílé láti ara àwọn ọmọ Itamari. 5 Wọ́n sì pín wọn láìṣègbè nípa yíya ìpín, nítorí àwọn olórí ibi mímọ́ àti àwọn olórí ilé Ọlọ́run wà láàrín àwọn ọmọ méjèèjì Eleasari àti Itamari. 6 Ṣemaiah ọmọ Netaneli, akọ̀wé ọ̀kan lára àwọn ọmọ Lefi sì kọ orúkọ wọn níwájú ọba àti àwọn ìjòyè: Sadoku àlùfáà, Ahimeleki ọmọ Abiatari àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà tí a mú láti ọ̀dọ̀ Eleasari àti ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ Itamari. 7 Ìpín èkínní jáde sí Jehoiaribu,èkejì sí Jedaiah, 8 ẹlẹ́ẹ̀kẹta sì ni Harimu,ẹ̀kẹrin sì ní Seorimu, 9 ẹ̀karùnún sì ni Malkiah,ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sì ni Mijamini, 10 èkeje sì ni Hakosi,ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí ni Abijah, 11 ẹ̀kẹsànán sì ni Jeṣua,ẹ̀kẹwàá sì ni Ṣekaniah, 12 ẹ̀kọkànlá sì ni Eliaṣibu,ẹlẹ́ẹ̀kẹjìlá sì ni Jakimu, 13 ẹ̀kẹtàlá sì ni Hupa,ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá sì ni Jeṣebeabu, 14 ẹ̀kẹdógún sì ni Bilgah,ẹ̀kẹrìndínlógún sì ni Immeri, 15 ẹ̀kẹtàdínlógún sì ni Hesiri,èkejìdínlógún sì ni Hafisesi, 16 ẹ̀kọkàndínlógún sì ni Petahiah,ogún sì ni Jeheskeli, 17 ẹ̀kọkànlélógún sì ni Jakini,ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Gamuli, 18 ẹ̀kẹtàlélógún sì ni Delaiah,ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Maasiah. 19 Àwọn wọ̀nyí ni a yàn fún iṣẹ́ ìsìn nígbà tí wọ́n wọ ilé OLÚWA, gẹ́gẹ́ bí ìlànà àti àṣẹ tí a ti fi fún wọn láti ọwọ́ baba ńlá wọn Aaroni gẹ́gẹ́ bí OLÚWA, Ọlọ́run Israẹli, tí pàṣẹ fun un. 20 Ìyókù àwọn ọmọ Lefi. Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Amramu: Ṣubaeliláti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣubaeli; Jehdeiah. 21 Àti gẹ́gẹ́ bí Rehabiah, láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Rehabiah, Iṣiah sì ni alákọ́kọ́. 22 Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Isari: Ṣelomiti;láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣelomoti: Jahati. 23 Àwọn ọmọ Hebroni:Jeriah alákọ́kọ́, Amariah ẹlẹ́ẹ̀kejì, Jahasieli ẹlẹ́ẹ̀kẹta àti Jekameamu ẹlẹ́ẹ̀kẹrin. 24 Àwọn ọmọ Usieli: Mika;nínú àwọn ọmọ Mika: Ṣamiri. 25 Àwọn arákùnrin Mika: Iṣi;nínú àwọn ọmọ Iṣiah: Sekariah. 26 Àwọn ọmọ Merari: Mahili àti Muṣi.Àwọn ọmọ Jaasiah: Beno. 27 Àwọn ọmọ Merari.Láti Jaasiah: Beno, Ṣohamu, Sakkuri àti Ibri. 28 Láti Mahili: Eleasari, ẹni tí kò ni àwọn ọmọ. 29 Láti Kiṣi. Àwọn ọmọ Kiṣi: Jerahmeeli. 30 Àti àwọn ọmọ Muṣi: Mahili, Ederi àti Jerimoti. Èyí ni àwọn ọmọ Lefi, gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. 31 Wọ́n sì ṣé kèké gẹ́gẹ́ bí àwọn arákùnrin wọn àwọn ọmọ Aaroni ṣe ṣẹ́, níwájú ọba Dafidi àti Sadoku, Ahimeleki, àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Lefi. Àwọn ìdílé àgbàgbà arákùnrin wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀ lórí àwọn arákùnrin wọn kéékèèké.

In Other Versions

1 Chronicles 24 in the ANGEFD

1 Chronicles 24 in the ANTPNG2D

1 Chronicles 24 in the AS21

1 Chronicles 24 in the BAGH

1 Chronicles 24 in the BBPNG

1 Chronicles 24 in the BBT1E

1 Chronicles 24 in the BDS

1 Chronicles 24 in the BEV

1 Chronicles 24 in the BHAD

1 Chronicles 24 in the BIB

1 Chronicles 24 in the BLPT

1 Chronicles 24 in the BNT

1 Chronicles 24 in the BNTABOOT

1 Chronicles 24 in the BNTLV

1 Chronicles 24 in the BOATCB

1 Chronicles 24 in the BOATCB2

1 Chronicles 24 in the BOBCV

1 Chronicles 24 in the BOCNT

1 Chronicles 24 in the BOECS

1 Chronicles 24 in the BOGWICC

1 Chronicles 24 in the BOHCB

1 Chronicles 24 in the BOHCV

1 Chronicles 24 in the BOHLNT

1 Chronicles 24 in the BOHNTLTAL

1 Chronicles 24 in the BOICB

1 Chronicles 24 in the BOILNTAP

1 Chronicles 24 in the BOITCV

1 Chronicles 24 in the BOKCV

1 Chronicles 24 in the BOKCV2

1 Chronicles 24 in the BOKHWOG

1 Chronicles 24 in the BOKSSV

1 Chronicles 24 in the BOLCB

1 Chronicles 24 in the BOLCB2

1 Chronicles 24 in the BOMCV

1 Chronicles 24 in the BONAV

1 Chronicles 24 in the BONCB

1 Chronicles 24 in the BONLT

1 Chronicles 24 in the BONUT2

1 Chronicles 24 in the BOPLNT

1 Chronicles 24 in the BOSCB

1 Chronicles 24 in the BOSNC

1 Chronicles 24 in the BOTLNT

1 Chronicles 24 in the BOVCB

1 Chronicles 24 in the BPBB

1 Chronicles 24 in the BPH

1 Chronicles 24 in the BSB

1 Chronicles 24 in the CCB

1 Chronicles 24 in the CUV

1 Chronicles 24 in the CUVS

1 Chronicles 24 in the DBT

1 Chronicles 24 in the DGDNT

1 Chronicles 24 in the DHNT

1 Chronicles 24 in the DNT

1 Chronicles 24 in the ELBE

1 Chronicles 24 in the EMTV

1 Chronicles 24 in the ESV

1 Chronicles 24 in the FBV

1 Chronicles 24 in the FEB

1 Chronicles 24 in the GGMNT

1 Chronicles 24 in the GNT

1 Chronicles 24 in the HARY

1 Chronicles 24 in the HNT

1 Chronicles 24 in the IRVA

1 Chronicles 24 in the IRVB

1 Chronicles 24 in the IRVG

1 Chronicles 24 in the IRVH

1 Chronicles 24 in the IRVK

1 Chronicles 24 in the IRVM

1 Chronicles 24 in the IRVM2

1 Chronicles 24 in the IRVO

1 Chronicles 24 in the IRVP

1 Chronicles 24 in the IRVT

1 Chronicles 24 in the IRVT2

1 Chronicles 24 in the IRVU

1 Chronicles 24 in the ISVN

1 Chronicles 24 in the JSNT

1 Chronicles 24 in the KAPI

1 Chronicles 24 in the KBT1ETNIK

1 Chronicles 24 in the KBV

1 Chronicles 24 in the KJV

1 Chronicles 24 in the KNFD

1 Chronicles 24 in the LBA

1 Chronicles 24 in the LBLA

1 Chronicles 24 in the LNT

1 Chronicles 24 in the LSV

1 Chronicles 24 in the MAAL

1 Chronicles 24 in the MBV

1 Chronicles 24 in the MBV2

1 Chronicles 24 in the MHNT

1 Chronicles 24 in the MKNFD

1 Chronicles 24 in the MNG

1 Chronicles 24 in the MNT

1 Chronicles 24 in the MNT2

1 Chronicles 24 in the MRS1T

1 Chronicles 24 in the NAA

1 Chronicles 24 in the NASB

1 Chronicles 24 in the NBLA

1 Chronicles 24 in the NBS

1 Chronicles 24 in the NBVTP

1 Chronicles 24 in the NET2

1 Chronicles 24 in the NIV11

1 Chronicles 24 in the NNT

1 Chronicles 24 in the NNT2

1 Chronicles 24 in the NNT3

1 Chronicles 24 in the PDDPT

1 Chronicles 24 in the PFNT

1 Chronicles 24 in the RMNT

1 Chronicles 24 in the SBIAS

1 Chronicles 24 in the SBIBS

1 Chronicles 24 in the SBIBS2

1 Chronicles 24 in the SBICS

1 Chronicles 24 in the SBIDS

1 Chronicles 24 in the SBIGS

1 Chronicles 24 in the SBIHS

1 Chronicles 24 in the SBIIS

1 Chronicles 24 in the SBIIS2

1 Chronicles 24 in the SBIIS3

1 Chronicles 24 in the SBIKS

1 Chronicles 24 in the SBIKS2

1 Chronicles 24 in the SBIMS

1 Chronicles 24 in the SBIOS

1 Chronicles 24 in the SBIPS

1 Chronicles 24 in the SBISS

1 Chronicles 24 in the SBITS

1 Chronicles 24 in the SBITS2

1 Chronicles 24 in the SBITS3

1 Chronicles 24 in the SBITS4

1 Chronicles 24 in the SBIUS

1 Chronicles 24 in the SBIVS

1 Chronicles 24 in the SBT

1 Chronicles 24 in the SBT1E

1 Chronicles 24 in the SCHL

1 Chronicles 24 in the SNT

1 Chronicles 24 in the SUSU

1 Chronicles 24 in the SUSU2

1 Chronicles 24 in the SYNO

1 Chronicles 24 in the TBIAOTANT

1 Chronicles 24 in the TBT1E

1 Chronicles 24 in the TBT1E2

1 Chronicles 24 in the TFTIP

1 Chronicles 24 in the TFTU

1 Chronicles 24 in the TGNTATF3T

1 Chronicles 24 in the THAI

1 Chronicles 24 in the TNFD

1 Chronicles 24 in the TNT

1 Chronicles 24 in the TNTIK

1 Chronicles 24 in the TNTIL

1 Chronicles 24 in the TNTIN

1 Chronicles 24 in the TNTIP

1 Chronicles 24 in the TNTIZ

1 Chronicles 24 in the TOMA

1 Chronicles 24 in the TTENT

1 Chronicles 24 in the UBG

1 Chronicles 24 in the UGV

1 Chronicles 24 in the UGV2

1 Chronicles 24 in the UGV3

1 Chronicles 24 in the VBL

1 Chronicles 24 in the VDCC

1 Chronicles 24 in the YALU

1 Chronicles 24 in the YAPE

1 Chronicles 24 in the YBVTP

1 Chronicles 24 in the ZBP