1 Chronicles 25 (BOYCB)

1 Pẹ̀lúpẹ̀lú Dafidi àti àwọn olórí àwọn ọmọ-ogun, ó sì yà díẹ̀ sọ́tọ̀ lára àwọn ọmọ Asafu, Hemani àti Jedutuni fún ìsìn àsọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú dùùrù, ohun èlò orin olókùn àti kimbali. Èyí sì ní àwọn iye àwọn ọkùnrin ẹni tí ó ṣe oníṣẹ́ ìsìn yìí. 2 Nínú àwọn ọmọ Asafu:Sakkuri, Josẹfu, Netaniah àti Asarela, àwọn ọmọ Asafu ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó Asafu, ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀ lábẹ́ ìbojútó ọba. 3 Gẹ́gẹ́ bí ti Jedutuni, nínú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀:Gedaliah, Seri, Jeṣaiah, Ṣimei, Haṣabiah àti Mattitiah, mẹ́fà nínú gbogbo wọn, lábẹ́ ìbojútó baba wọn Jedutuni, ẹni tí ó sọtẹ́lẹ̀, ẹni tí ó lo dùùrù láti dúpẹ́ àti láti yin OLÚWA. 4 Gẹ́gẹ́ bí ti Hemani, nínú àwọn ọmọ rẹ̀:Bukkiah, Mattaniah, Usieli, Ṣubaeli àti Jerimoti; Hananiah, Hanani, Eliata, Giddalti, àti Romamtieseri, Joṣbekaṣa, Malloti, Hotiri, Mahasiotu. 5 Gbogbo àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Hemani àti wòlíì ọba. Wọ́n sì fi wọ́n fún nípa ìlérí Ọlọ́run láti máa gbé ìwo sókè. Ọlọ́run sì fún Hemani ní ọmọkùnrin mẹ́rìnlá àti àwọn ọmọbìnrin mẹ́ta. 6 Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ni wọ́n wà lábẹ́ ìbojútó àwọn baba wọn fún ohun èlò orin ilé OLÚWA, pẹ̀lú kimbali, ohun èlò orin olókùn àti dùùrù, fún ìsìn ilé Olúwa.Asafu, Jedutuni àti Hemani sì wà lábẹ́ ọba. 7 Àwọn ìdílé wọn pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó mòye àti àwọn tí a kọ́ ní ohun èlò orin fún OLÚWA, iye wọn sì jẹ́ ọ̀rìnlélúgba ó lé mẹ́jọ (288). 8 Kékeré àti àgbà bákan náà, olùkọ́ àti gẹ́gẹ́ bí ti akẹ́kọ̀ọ́, ṣẹ́ kèké fún iṣẹ́ wọn. 9 Kèké èkínní èyí tí ó jẹ́ ti Asafu, jáde sí Josẹfu, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìláèkejì sì ni Gedaliah, òun àti àwọn ìdílé rẹ̀ àti àwọn ọmọ rẹ̀, méjìlá 10 ẹlẹ́ẹ̀kẹta sí Sakkuri, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé, méjìlá 11 ẹlẹ́ẹ̀kẹrin sí Isiri, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 12 ẹlẹ́ẹ̀karùnún sí Netaniah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 13 ẹlẹ́ẹ̀kẹfà sí Bukkiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 14 ẹlẹ́ẹ̀keje sí Jasarela, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 15 ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ sí Jeṣaiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 16 ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn-án sí Mattaniah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 17 ẹlẹ́ẹ̀kẹwàá sí Ṣimei, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ jẹ́, méjìlá 18 ẹlẹ́ẹ̀kọkànlá sí Asareeli, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 19 ẹlẹ́ẹ̀kẹjìlá sí Haṣabiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 20 ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlá sí Ṣubaeli, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 21 ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlá sí Mattitiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 22 ẹlẹ́ẹ̀kẹẹ̀dógún sí Jerimoti, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 23 ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndínlógún sí Hananiah, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 24 ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínlógún sí Joṣbekaṣa, àwọn ọmọ rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 25 ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlógún sí Hanani, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 26 ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlógún sí Malloti, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 27 ogún sí Eliata, àwọn ọmọ rẹ̀ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 28 ẹlẹ́ẹ̀kọkànlélógún sí Hotiri, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 29 ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún sí Giddalti, àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 30 ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlélógún sí Mahasiotu, àwọn ọmọ rẹ àti ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá 31 ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlélógún sí Romamtieseri àwọn ọmọ rẹ̀, àti àwọn ìdílé rẹ̀ sì jẹ́, méjìlá.

In Other Versions

1 Chronicles 25 in the ANGEFD

1 Chronicles 25 in the ANTPNG2D

1 Chronicles 25 in the AS21

1 Chronicles 25 in the BAGH

1 Chronicles 25 in the BBPNG

1 Chronicles 25 in the BBT1E

1 Chronicles 25 in the BDS

1 Chronicles 25 in the BEV

1 Chronicles 25 in the BHAD

1 Chronicles 25 in the BIB

1 Chronicles 25 in the BLPT

1 Chronicles 25 in the BNT

1 Chronicles 25 in the BNTABOOT

1 Chronicles 25 in the BNTLV

1 Chronicles 25 in the BOATCB

1 Chronicles 25 in the BOATCB2

1 Chronicles 25 in the BOBCV

1 Chronicles 25 in the BOCNT

1 Chronicles 25 in the BOECS

1 Chronicles 25 in the BOGWICC

1 Chronicles 25 in the BOHCB

1 Chronicles 25 in the BOHCV

1 Chronicles 25 in the BOHLNT

1 Chronicles 25 in the BOHNTLTAL

1 Chronicles 25 in the BOICB

1 Chronicles 25 in the BOILNTAP

1 Chronicles 25 in the BOITCV

1 Chronicles 25 in the BOKCV

1 Chronicles 25 in the BOKCV2

1 Chronicles 25 in the BOKHWOG

1 Chronicles 25 in the BOKSSV

1 Chronicles 25 in the BOLCB

1 Chronicles 25 in the BOLCB2

1 Chronicles 25 in the BOMCV

1 Chronicles 25 in the BONAV

1 Chronicles 25 in the BONCB

1 Chronicles 25 in the BONLT

1 Chronicles 25 in the BONUT2

1 Chronicles 25 in the BOPLNT

1 Chronicles 25 in the BOSCB

1 Chronicles 25 in the BOSNC

1 Chronicles 25 in the BOTLNT

1 Chronicles 25 in the BOVCB

1 Chronicles 25 in the BPBB

1 Chronicles 25 in the BPH

1 Chronicles 25 in the BSB

1 Chronicles 25 in the CCB

1 Chronicles 25 in the CUV

1 Chronicles 25 in the CUVS

1 Chronicles 25 in the DBT

1 Chronicles 25 in the DGDNT

1 Chronicles 25 in the DHNT

1 Chronicles 25 in the DNT

1 Chronicles 25 in the ELBE

1 Chronicles 25 in the EMTV

1 Chronicles 25 in the ESV

1 Chronicles 25 in the FBV

1 Chronicles 25 in the FEB

1 Chronicles 25 in the GGMNT

1 Chronicles 25 in the GNT

1 Chronicles 25 in the HARY

1 Chronicles 25 in the HNT

1 Chronicles 25 in the IRVA

1 Chronicles 25 in the IRVB

1 Chronicles 25 in the IRVG

1 Chronicles 25 in the IRVH

1 Chronicles 25 in the IRVK

1 Chronicles 25 in the IRVM

1 Chronicles 25 in the IRVM2

1 Chronicles 25 in the IRVO

1 Chronicles 25 in the IRVP

1 Chronicles 25 in the IRVT

1 Chronicles 25 in the IRVT2

1 Chronicles 25 in the IRVU

1 Chronicles 25 in the ISVN

1 Chronicles 25 in the JSNT

1 Chronicles 25 in the KAPI

1 Chronicles 25 in the KBT1ETNIK

1 Chronicles 25 in the KBV

1 Chronicles 25 in the KJV

1 Chronicles 25 in the KNFD

1 Chronicles 25 in the LBA

1 Chronicles 25 in the LBLA

1 Chronicles 25 in the LNT

1 Chronicles 25 in the LSV

1 Chronicles 25 in the MAAL

1 Chronicles 25 in the MBV

1 Chronicles 25 in the MBV2

1 Chronicles 25 in the MHNT

1 Chronicles 25 in the MKNFD

1 Chronicles 25 in the MNG

1 Chronicles 25 in the MNT

1 Chronicles 25 in the MNT2

1 Chronicles 25 in the MRS1T

1 Chronicles 25 in the NAA

1 Chronicles 25 in the NASB

1 Chronicles 25 in the NBLA

1 Chronicles 25 in the NBS

1 Chronicles 25 in the NBVTP

1 Chronicles 25 in the NET2

1 Chronicles 25 in the NIV11

1 Chronicles 25 in the NNT

1 Chronicles 25 in the NNT2

1 Chronicles 25 in the NNT3

1 Chronicles 25 in the PDDPT

1 Chronicles 25 in the PFNT

1 Chronicles 25 in the RMNT

1 Chronicles 25 in the SBIAS

1 Chronicles 25 in the SBIBS

1 Chronicles 25 in the SBIBS2

1 Chronicles 25 in the SBICS

1 Chronicles 25 in the SBIDS

1 Chronicles 25 in the SBIGS

1 Chronicles 25 in the SBIHS

1 Chronicles 25 in the SBIIS

1 Chronicles 25 in the SBIIS2

1 Chronicles 25 in the SBIIS3

1 Chronicles 25 in the SBIKS

1 Chronicles 25 in the SBIKS2

1 Chronicles 25 in the SBIMS

1 Chronicles 25 in the SBIOS

1 Chronicles 25 in the SBIPS

1 Chronicles 25 in the SBISS

1 Chronicles 25 in the SBITS

1 Chronicles 25 in the SBITS2

1 Chronicles 25 in the SBITS3

1 Chronicles 25 in the SBITS4

1 Chronicles 25 in the SBIUS

1 Chronicles 25 in the SBIVS

1 Chronicles 25 in the SBT

1 Chronicles 25 in the SBT1E

1 Chronicles 25 in the SCHL

1 Chronicles 25 in the SNT

1 Chronicles 25 in the SUSU

1 Chronicles 25 in the SUSU2

1 Chronicles 25 in the SYNO

1 Chronicles 25 in the TBIAOTANT

1 Chronicles 25 in the TBT1E

1 Chronicles 25 in the TBT1E2

1 Chronicles 25 in the TFTIP

1 Chronicles 25 in the TFTU

1 Chronicles 25 in the TGNTATF3T

1 Chronicles 25 in the THAI

1 Chronicles 25 in the TNFD

1 Chronicles 25 in the TNT

1 Chronicles 25 in the TNTIK

1 Chronicles 25 in the TNTIL

1 Chronicles 25 in the TNTIN

1 Chronicles 25 in the TNTIP

1 Chronicles 25 in the TNTIZ

1 Chronicles 25 in the TOMA

1 Chronicles 25 in the TTENT

1 Chronicles 25 in the UBG

1 Chronicles 25 in the UGV

1 Chronicles 25 in the UGV2

1 Chronicles 25 in the UGV3

1 Chronicles 25 in the VBL

1 Chronicles 25 in the VDCC

1 Chronicles 25 in the YALU

1 Chronicles 25 in the YAPE

1 Chronicles 25 in the YBVTP

1 Chronicles 25 in the ZBP