1 Corinthians 2 (BOYCB)
1 Nígbà tí èmí tọ̀ yín wá, ẹ̀yin ará, kì í ṣe nípa ọ̀rọ̀ gíga àti ọgbọ́n gíga ni mo fi bá yín sọ̀rọ̀, nígbà tí èmi ń sọ̀rọ̀ ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run fún un yín. 2 Èmi ti pinnu láti má mọ ohunkóhun nígbà ti mo wà láàrín yín bí kò ṣe Jesu Kristi, ẹni tí a kàn mọ́ àgbélébùú. 3 Èmi sì tọ̀ yín wá ni àìlera, àti ní ẹ̀rù, àti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwárìrì. 4 Ìwàásù mi àti ẹ̀kọ́ mi, kì í ṣe nípa ọgbọ́n ènìyàn àti ọ̀rọ̀ tí a fi ń yí ènìyàn lọ́kàn padà, bí kò ṣe nípa ìfihàn agbára Ẹ̀mí. 5 Kí ìgbàgbọ́ yín kí ó má ṣe dúró lórí ọgbọ́n ènìyàn, ṣùgbọ́n kí ó dúró lórí agbára Ọlọ́run. 6 Ṣùgbọ́n àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n láàrín àwọn tí a pè, ṣùgbọ́n kì í ṣe ọgbọ́n ti ayé yìí tàbí ti àwọn olórí ayé yìí, èyí tí yóò di asán. 7 Bẹ́ẹ̀ kọ́, àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n ti Ọlọ́run tó fi ara sin, ọgbọ́n tí ó ti fi ara pamọ́, èyí tí Ọlọ́run ti lànà sílẹ̀ ṣáájú ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé fún ògo wa. 8 Èyí ti ẹnikẹ́ni nínú àwọn aláṣẹ ayé yìí kò mọ̀. Ìbá ṣe pé wọ́n mọ̀ ọ́n, wọn kì bá tún kan Olúwa ògo mọ́ àgbélébùú. 9 Gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:“Ojú kò tí ì rí,etí kò tí í gbọ́,kò sì ọkàn ènìyàn tí ó tí í mọ̀ohun tí Ọlọ́run tí pèsè sílẹ̀ fún àwọn tí o fẹ́ ẹ.” 10 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ti fi í hàn fún wa nípasẹ̀ Ẹ̀mí rẹ̀.Ẹ̀mí á máa wádìí ohun gbogbo, kódà àwọn àṣírí Ọlọ́run tó jinlẹ̀ jùlọ. 11 Ta ni nínú ènìyàn tí ó mọ èrò ọkàn ènìyàn kan, bí kò ṣe ẹ̀mí ènìyàn tí ó wà nínú rẹ̀? Bákan náà, kò sí ẹni ti ó mọ àwọn èrò Ọlọ́run, bí kò ṣe Ẹ̀mí Ọlọ́run fúnra rẹ̀. 12 Àwa kò gbà ẹ̀mí ti ayé yìí, bí kò ṣe Ẹ̀mí ẹni tí ó ti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wa, kí a lè ní òye ohun tí Ọlọ́run fi fún wa lọ́fẹ̀ẹ́. 13 Èyí ni àwa ń wí, kì í ṣe èyí tí a ń kọ nípa ọ̀rọ̀ ọgbọ́n ènìyàn, ṣùgbọ́n èyí tí Ẹ̀mí Mímọ́ fi ń kọ ènìyàn, èyí tí a ń fi ohun Ẹ̀mí wé ohun Ẹ̀mí. 14 Ṣùgbọ́n ènìyàn nípa ti ara kò gba ohun ti Ẹ̀mí Ọlọ́run wọ̀n-ọn-nì, nítorí pé wèrè ni wọ́n jásí fún un, òun kò sì le mọ̀ wọ́n, nítorí nípa tí Ẹ̀mí ní a fi ń wádìí wọn. 15 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó wà nípa ti ẹ̀mí ń wádìí ohun gbogbo, ṣùgbọ́n kò sí ẹnikẹ́ni tí í wádìí rẹ̀. 16 “Nítorí ta ni ó mọ ọkàn Olúwa,ti yóò fi máa kọ́ Ọ?”Ṣùgbọ́n àwa ní inú Kristi.
In Other Versions
1 Corinthians 2 in the ANGEFD
1 Corinthians 2 in the ANTPNG2D
1 Corinthians 2 in the AS21
1 Corinthians 2 in the BAGH
1 Corinthians 2 in the BBPNG
1 Corinthians 2 in the BBT1E
1 Corinthians 2 in the BDS
1 Corinthians 2 in the BEV
1 Corinthians 2 in the BHAD
1 Corinthians 2 in the BIB
1 Corinthians 2 in the BLPT
1 Corinthians 2 in the BNT
1 Corinthians 2 in the BNTABOOT
1 Corinthians 2 in the BNTLV
1 Corinthians 2 in the BOATCB
1 Corinthians 2 in the BOATCB2
1 Corinthians 2 in the BOBCV
1 Corinthians 2 in the BOCNT
1 Corinthians 2 in the BOECS
1 Corinthians 2 in the BOGWICC
1 Corinthians 2 in the BOHCB
1 Corinthians 2 in the BOHCV
1 Corinthians 2 in the BOHLNT
1 Corinthians 2 in the BOHNTLTAL
1 Corinthians 2 in the BOICB
1 Corinthians 2 in the BOILNTAP
1 Corinthians 2 in the BOITCV
1 Corinthians 2 in the BOKCV
1 Corinthians 2 in the BOKCV2
1 Corinthians 2 in the BOKHWOG
1 Corinthians 2 in the BOKSSV
1 Corinthians 2 in the BOLCB
1 Corinthians 2 in the BOLCB2
1 Corinthians 2 in the BOMCV
1 Corinthians 2 in the BONAV
1 Corinthians 2 in the BONCB
1 Corinthians 2 in the BONLT
1 Corinthians 2 in the BONUT2
1 Corinthians 2 in the BOPLNT
1 Corinthians 2 in the BOSCB
1 Corinthians 2 in the BOSNC
1 Corinthians 2 in the BOTLNT
1 Corinthians 2 in the BOVCB
1 Corinthians 2 in the BPBB
1 Corinthians 2 in the BPH
1 Corinthians 2 in the BSB
1 Corinthians 2 in the CCB
1 Corinthians 2 in the CUV
1 Corinthians 2 in the CUVS
1 Corinthians 2 in the DBT
1 Corinthians 2 in the DGDNT
1 Corinthians 2 in the DHNT
1 Corinthians 2 in the DNT
1 Corinthians 2 in the ELBE
1 Corinthians 2 in the EMTV
1 Corinthians 2 in the ESV
1 Corinthians 2 in the FBV
1 Corinthians 2 in the FEB
1 Corinthians 2 in the GGMNT
1 Corinthians 2 in the GNT
1 Corinthians 2 in the HARY
1 Corinthians 2 in the HNT
1 Corinthians 2 in the IRVA
1 Corinthians 2 in the IRVB
1 Corinthians 2 in the IRVG
1 Corinthians 2 in the IRVH
1 Corinthians 2 in the IRVK
1 Corinthians 2 in the IRVM
1 Corinthians 2 in the IRVM2
1 Corinthians 2 in the IRVO
1 Corinthians 2 in the IRVP
1 Corinthians 2 in the IRVT
1 Corinthians 2 in the IRVT2
1 Corinthians 2 in the IRVU
1 Corinthians 2 in the ISVN
1 Corinthians 2 in the JSNT
1 Corinthians 2 in the KAPI
1 Corinthians 2 in the KBT1ETNIK
1 Corinthians 2 in the KBV
1 Corinthians 2 in the KJV
1 Corinthians 2 in the KNFD
1 Corinthians 2 in the LBA
1 Corinthians 2 in the LBLA
1 Corinthians 2 in the LNT
1 Corinthians 2 in the LSV
1 Corinthians 2 in the MAAL
1 Corinthians 2 in the MBV
1 Corinthians 2 in the MBV2
1 Corinthians 2 in the MHNT
1 Corinthians 2 in the MKNFD
1 Corinthians 2 in the MNG
1 Corinthians 2 in the MNT
1 Corinthians 2 in the MNT2
1 Corinthians 2 in the MRS1T
1 Corinthians 2 in the NAA
1 Corinthians 2 in the NASB
1 Corinthians 2 in the NBLA
1 Corinthians 2 in the NBS
1 Corinthians 2 in the NBVTP
1 Corinthians 2 in the NET2
1 Corinthians 2 in the NIV11
1 Corinthians 2 in the NNT
1 Corinthians 2 in the NNT2
1 Corinthians 2 in the NNT3
1 Corinthians 2 in the PDDPT
1 Corinthians 2 in the PFNT
1 Corinthians 2 in the RMNT
1 Corinthians 2 in the SBIAS
1 Corinthians 2 in the SBIBS
1 Corinthians 2 in the SBIBS2
1 Corinthians 2 in the SBICS
1 Corinthians 2 in the SBIDS
1 Corinthians 2 in the SBIGS
1 Corinthians 2 in the SBIHS
1 Corinthians 2 in the SBIIS
1 Corinthians 2 in the SBIIS2
1 Corinthians 2 in the SBIIS3
1 Corinthians 2 in the SBIKS
1 Corinthians 2 in the SBIKS2
1 Corinthians 2 in the SBIMS
1 Corinthians 2 in the SBIOS
1 Corinthians 2 in the SBIPS
1 Corinthians 2 in the SBISS
1 Corinthians 2 in the SBITS
1 Corinthians 2 in the SBITS2
1 Corinthians 2 in the SBITS3
1 Corinthians 2 in the SBITS4
1 Corinthians 2 in the SBIUS
1 Corinthians 2 in the SBIVS
1 Corinthians 2 in the SBT
1 Corinthians 2 in the SBT1E
1 Corinthians 2 in the SCHL
1 Corinthians 2 in the SNT
1 Corinthians 2 in the SUSU
1 Corinthians 2 in the SUSU2
1 Corinthians 2 in the SYNO
1 Corinthians 2 in the TBIAOTANT
1 Corinthians 2 in the TBT1E
1 Corinthians 2 in the TBT1E2
1 Corinthians 2 in the TFTIP
1 Corinthians 2 in the TFTU
1 Corinthians 2 in the TGNTATF3T
1 Corinthians 2 in the THAI
1 Corinthians 2 in the TNFD
1 Corinthians 2 in the TNT
1 Corinthians 2 in the TNTIK
1 Corinthians 2 in the TNTIL
1 Corinthians 2 in the TNTIN
1 Corinthians 2 in the TNTIP
1 Corinthians 2 in the TNTIZ
1 Corinthians 2 in the TOMA
1 Corinthians 2 in the TTENT
1 Corinthians 2 in the UBG
1 Corinthians 2 in the UGV
1 Corinthians 2 in the UGV2
1 Corinthians 2 in the UGV3
1 Corinthians 2 in the VBL
1 Corinthians 2 in the VDCC
1 Corinthians 2 in the YALU
1 Corinthians 2 in the YAPE
1 Corinthians 2 in the YBVTP
1 Corinthians 2 in the ZBP