1 Samuel 21 (BOYCB)

1 Dafidi sì wá sí Nobu sọ́dọ̀ Ahimeleki àlùfáà, Ahimeleki sì bẹ̀rù láti pàdé Dafidi, ó sì wí fún un pé, “Èéha ti rí tí o fi ṣe ìwọ nìkan, àti tí kò sì sí ọkùnrin kan tí ó pẹ̀lú rẹ?” 2 Dafidi sì wí fún Ahimeleki àlùfáà pé, “Ọba pàṣẹ iṣẹ́ kan fún mi, ó sì wí fún mi pé, ‘Má ṣe jẹ́ kí ẹnìkan mọ ìdí iṣẹ́ náà ti mo rán ọ, àti èyí tí èmi ti pàṣẹ fún ọ.’ Èmi sì yan àwọn ìránṣẹ́ mi sí ibí báyìí. 3 Ǹjẹ́ kín ni ó wà ní ọwọ́ rẹ̀? Fún mi ni ìṣù àkàrà márùn-ún tàbí ohunkóhun tí o bá rí.” 4 Àlùfáà náà sí dá Dafidi lóhùn ó sì wí pé, “Kò sí àkàrà mìíràn lọ́wọ́ mi bí kò ṣe àkàrà mímọ́. Kìkì pé bi àwọn ọmọkùnrin bá ti pa ara wọn mọ́ kúrò lọ́dọ̀ obìnrin!” 5 Dafidi sì dá àlùfáà náà lóhùn, ó sì wí fún un pé, “Nítòótọ́ ni a tí ń pa ara wá mọ́ kúrò lọ́dọ̀ obìnrin láti ìwọ̀n ọjọ́ mẹ́ta wá, tí èmí ti jáde. Gbogbo nǹkan àwọn ọmọkùnrin náà ni ó mọ́, àti àkàrà náà sì wá dàbí àkàrà mìíràn, pàápàá nígbà tí ó jẹ́ pé òmíràn wà tí a yà sí mímọ́ lónìí nínú ohun èlò náà!” 6 Bẹ́ẹ̀ ni àlùfáà náà sì fi àkàrà mímọ́ fún un; nítorí tí kò sí àkàrà mìíràn níbẹ̀ bí kò ṣe àkàrà ìfihàn tí a ti kó kúrò níwájú OLÚWA, láti fi àkàrà gbígbóná síbẹ̀ ní ọjọ́ tí a kó o kúrò. 7 Ọkùnrin kan nínú àwọn ìránṣẹ́ Saulu sì ń bẹ níbẹ̀ lọ́jọ́ náà, tí a tí dádúró síwájú OLÚWA; orúkọ rẹ̀ sì ń jẹ́ Doegi, ará Edomu olórí nínú àwọn darandaran Saulu. 8 Dafidi sì tún wí fún Ahimeleki pé, “Kò sí ọ̀kọ̀ tàbí idà lọ́wọ́ rẹ níhìn-ín? Nítorí tí èmi kò mú idà mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò mú nǹkan ìjà mi lọ́wọ́, nítorí pé iṣẹ́ ọba náà jẹ́ iṣẹ́ ìkánjú.” 9 Àlùfáà náà sì wí pé, “Idà Goliati ará Filistini tí ó pa ní àfonífojì Ela ní ń bẹ, wò ó, a fi aṣọ kan wé e lẹ́yìn efodu; bí ìwọ yóò bá mú èyí, mú un; kò sì sí òmíràn níhìn-ín mọ́ bí kò ṣe ọ̀kan náà.”Dafidi sì wí pé, “Kò sí èyí tí ó dàbí rẹ̀ fún mi.” 10 Dafidi sì dìde, o sì sá ni ọjọ́ náà níwájú Saulu, ó sì lọ sọ́dọ̀ Akiṣi, ọba Gati. 11 Àwọn ìránṣẹ́ Akiṣi sì wí fún un pé, “Èyí ha kọ́ ní Dafidi ọba ilẹ̀ náà? Ǹjẹ́ wọn kò ha ti dárin ti wọ́n sì gbe orin nítorí rẹ̀, tí wọ́n sì jó pé,“ ‘Saulu pa ẹgbẹ̀rún tirẹ̀.Dafidi sì pa ẹgbàárùn-ún tirẹ̀’?” 12 Dafidi sì pa ọ̀rọ̀ wọ̀nyí í mọ́ ni ọkàn rẹ̀, ó sì bẹ̀rù Akiṣi ọba Gati gidigidi. 13 Òun sì pa ìṣe rẹ̀ dà níwájú wọn, ó sì sọ ara rẹ̀ di aṣiwèrè ní ọwọ́ wọn, ó sì ń fi ọwọ́ rẹ̀ ha ìlẹ̀kùn ojú ọ̀nà, ó sì ń wá itọ́ sí irùngbọ̀n rẹ̀. 14 Nígbà náà ni Akiṣi wí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Wó o, nítorí kín ni ẹ̀yin ṣe mú un tọ̀ mí wá. 15 Mo ha ni un fi aṣiwèrè ṣe? Tí ẹ̀yin fi mú èyí tọ̀ mí wá láti hu ìwà aṣiwèrè níwájú mi? Eléyìí yóò ha wọ inú ilé mi?”

In Other Versions

1 Samuel 21 in the ANGEFD

1 Samuel 21 in the ANTPNG2D

1 Samuel 21 in the AS21

1 Samuel 21 in the BAGH

1 Samuel 21 in the BBPNG

1 Samuel 21 in the BBT1E

1 Samuel 21 in the BDS

1 Samuel 21 in the BEV

1 Samuel 21 in the BHAD

1 Samuel 21 in the BIB

1 Samuel 21 in the BLPT

1 Samuel 21 in the BNT

1 Samuel 21 in the BNTABOOT

1 Samuel 21 in the BNTLV

1 Samuel 21 in the BOATCB

1 Samuel 21 in the BOATCB2

1 Samuel 21 in the BOBCV

1 Samuel 21 in the BOCNT

1 Samuel 21 in the BOECS

1 Samuel 21 in the BOGWICC

1 Samuel 21 in the BOHCB

1 Samuel 21 in the BOHCV

1 Samuel 21 in the BOHLNT

1 Samuel 21 in the BOHNTLTAL

1 Samuel 21 in the BOICB

1 Samuel 21 in the BOILNTAP

1 Samuel 21 in the BOITCV

1 Samuel 21 in the BOKCV

1 Samuel 21 in the BOKCV2

1 Samuel 21 in the BOKHWOG

1 Samuel 21 in the BOKSSV

1 Samuel 21 in the BOLCB

1 Samuel 21 in the BOLCB2

1 Samuel 21 in the BOMCV

1 Samuel 21 in the BONAV

1 Samuel 21 in the BONCB

1 Samuel 21 in the BONLT

1 Samuel 21 in the BONUT2

1 Samuel 21 in the BOPLNT

1 Samuel 21 in the BOSCB

1 Samuel 21 in the BOSNC

1 Samuel 21 in the BOTLNT

1 Samuel 21 in the BOVCB

1 Samuel 21 in the BPBB

1 Samuel 21 in the BPH

1 Samuel 21 in the BSB

1 Samuel 21 in the CCB

1 Samuel 21 in the CUV

1 Samuel 21 in the CUVS

1 Samuel 21 in the DBT

1 Samuel 21 in the DGDNT

1 Samuel 21 in the DHNT

1 Samuel 21 in the DNT

1 Samuel 21 in the ELBE

1 Samuel 21 in the EMTV

1 Samuel 21 in the ESV

1 Samuel 21 in the FBV

1 Samuel 21 in the FEB

1 Samuel 21 in the GGMNT

1 Samuel 21 in the GNT

1 Samuel 21 in the HARY

1 Samuel 21 in the HNT

1 Samuel 21 in the IRVA

1 Samuel 21 in the IRVB

1 Samuel 21 in the IRVG

1 Samuel 21 in the IRVH

1 Samuel 21 in the IRVK

1 Samuel 21 in the IRVM

1 Samuel 21 in the IRVM2

1 Samuel 21 in the IRVO

1 Samuel 21 in the IRVP

1 Samuel 21 in the IRVT

1 Samuel 21 in the IRVT2

1 Samuel 21 in the IRVU

1 Samuel 21 in the ISVN

1 Samuel 21 in the JSNT

1 Samuel 21 in the KAPI

1 Samuel 21 in the KBT1ETNIK

1 Samuel 21 in the KBV

1 Samuel 21 in the KJV

1 Samuel 21 in the KNFD

1 Samuel 21 in the LBA

1 Samuel 21 in the LBLA

1 Samuel 21 in the LNT

1 Samuel 21 in the LSV

1 Samuel 21 in the MAAL

1 Samuel 21 in the MBV

1 Samuel 21 in the MBV2

1 Samuel 21 in the MHNT

1 Samuel 21 in the MKNFD

1 Samuel 21 in the MNG

1 Samuel 21 in the MNT

1 Samuel 21 in the MNT2

1 Samuel 21 in the MRS1T

1 Samuel 21 in the NAA

1 Samuel 21 in the NASB

1 Samuel 21 in the NBLA

1 Samuel 21 in the NBS

1 Samuel 21 in the NBVTP

1 Samuel 21 in the NET2

1 Samuel 21 in the NIV11

1 Samuel 21 in the NNT

1 Samuel 21 in the NNT2

1 Samuel 21 in the NNT3

1 Samuel 21 in the PDDPT

1 Samuel 21 in the PFNT

1 Samuel 21 in the RMNT

1 Samuel 21 in the SBIAS

1 Samuel 21 in the SBIBS

1 Samuel 21 in the SBIBS2

1 Samuel 21 in the SBICS

1 Samuel 21 in the SBIDS

1 Samuel 21 in the SBIGS

1 Samuel 21 in the SBIHS

1 Samuel 21 in the SBIIS

1 Samuel 21 in the SBIIS2

1 Samuel 21 in the SBIIS3

1 Samuel 21 in the SBIKS

1 Samuel 21 in the SBIKS2

1 Samuel 21 in the SBIMS

1 Samuel 21 in the SBIOS

1 Samuel 21 in the SBIPS

1 Samuel 21 in the SBISS

1 Samuel 21 in the SBITS

1 Samuel 21 in the SBITS2

1 Samuel 21 in the SBITS3

1 Samuel 21 in the SBITS4

1 Samuel 21 in the SBIUS

1 Samuel 21 in the SBIVS

1 Samuel 21 in the SBT

1 Samuel 21 in the SBT1E

1 Samuel 21 in the SCHL

1 Samuel 21 in the SNT

1 Samuel 21 in the SUSU

1 Samuel 21 in the SUSU2

1 Samuel 21 in the SYNO

1 Samuel 21 in the TBIAOTANT

1 Samuel 21 in the TBT1E

1 Samuel 21 in the TBT1E2

1 Samuel 21 in the TFTIP

1 Samuel 21 in the TFTU

1 Samuel 21 in the TGNTATF3T

1 Samuel 21 in the THAI

1 Samuel 21 in the TNFD

1 Samuel 21 in the TNT

1 Samuel 21 in the TNTIK

1 Samuel 21 in the TNTIL

1 Samuel 21 in the TNTIN

1 Samuel 21 in the TNTIP

1 Samuel 21 in the TNTIZ

1 Samuel 21 in the TOMA

1 Samuel 21 in the TTENT

1 Samuel 21 in the UBG

1 Samuel 21 in the UGV

1 Samuel 21 in the UGV2

1 Samuel 21 in the UGV3

1 Samuel 21 in the VBL

1 Samuel 21 in the VDCC

1 Samuel 21 in the YALU

1 Samuel 21 in the YAPE

1 Samuel 21 in the YBVTP

1 Samuel 21 in the ZBP