1 Thessalonians 4 (BOYCB)

1 Ní ìparí, ará, a sọ fún un yín bí ẹ ti ń gbé láti wu Ọlọ́run, àní gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí ń ṣe. Nísinsin yìí, a béèrè, a sì ń rọ̀ yín nínú Jesu Olúwa láti ṣe bẹ́ẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ sí. 2 Nítorí pé, ẹ̀yin mọ àṣẹ tí a pa fún yín láti ọ̀dọ̀ Olúwa Jesu. 3 Nítorí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí ẹ jẹ́ mímọ́, kí ẹ sì yàgò kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè, 4 kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín kọ́ láti ṣàkóso ara rẹ̀ ní ọ̀nà mímọ́ àti pẹ̀lú ọlá, 5 kì í ṣe ní ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn aláìkọlà, ẹni tí kò mọ Ọlọ́run; 6 àti pé nínú ọ̀rọ̀ yìí, kí ẹnikẹ́ni nínú yín máa ṣe rẹ arákùnrin rẹ̀ jẹ nípa ohunkóhun. Olúwa yóò jẹ àwọn ènìyàn ní yà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn, gẹ́gẹ́ bí a ti ń sọ fún un yín tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀. 7 Nítorí Ọlọ́run kò pè wá sínú ìwà èérí, bí kò ṣe sínú ìgbé ayé mímọ́. 8 Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó kọ òfin yìí, kì í ṣe òfin ènìyàn ni ẹni náà kọ̀, bí kò ṣe òfin Ọlọ́run ẹni tí ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ fún ni. 9 Ṣùgbọ́n nípa ìfẹ́ ará, a kò ní láti tún kọ̀wé sí i yín, ìdí ni pé, Ọlọ́run pàápàá ń kọ́ yín láti fẹ́ràn ara yín. 10 Nítòótọ́, ẹ ní ìfẹ́ fún àwọn arákùnrin tí ó wà káàkiri Makedonia. Síbẹ̀síbẹ̀ àwa ń bẹ̀ yín, ará, pé kí ẹ̀yin kí ó máa tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. 11 Ẹ jẹ́ kí èyí jẹ́ ìfẹ́ ọkàn yín láti gbé jẹ́ẹ́ àti láti mọ ti ara yín àti kí olúkúlùkù kọjú sí iṣẹ́ rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí a ti wí fún yín. 12 Èyí yóò mú kí àwọn tí kì í ṣe onígbàgbọ́ gbẹ́kẹ̀lé yín àti láti bu ọlá fún yín pẹ̀lú. Bí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, ẹ kò ní máa wo ojú ẹnikẹ́ni láti fún yín ni owó tí ẹ ó fi san gbèsè. 13 Ẹ̀yin ará, àwa kò fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó jẹ́ òpè ní ti àwọn tí ó ti sùn, pé kí ẹ máa banújẹ́ gẹ́gẹ́ bí àwọn yòókù tí kò ní ìrètí. 14 A gbàgbọ́ pé, Jesu kú, ó sì tún jíǹde, àti pé Ọlọ́run yóò mú gbogbo àwọn tí ó ti sùn nínú rẹ̀ padà wá. 15 Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa, pé àwa tí ó wà láààyè, tí a sì kù lẹ́yìn de à ti wá Olúwa, bí ó ti wù kí ó rí, kì yóò ṣáájú àwọn tí ó sùn láti pàdé rẹ̀. 16 Nítorí pé, Olúwa fúnra rẹ̀ yóò sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá, pẹ̀lú ariwo àṣẹ ńlá àti ohùn àwọn angẹli ti àwọn angẹli ti àwọn ti ìpè Ọlọ́run, àwọn òkú nínú Kristi yóò sì kọ́kọ́ jíǹde. 17 Nígbà náà ni a ó gba àwa tí ó sì wà láààyè sókè nínú àwọsánmọ̀ láti ọwọ́ Olúwa. A ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀ títí láéláé. 18 Nítorí náà, ẹ tu ara yín nínú, kí ẹ sì máa gba ara yín níyànjú pẹ̀lú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.

In Other Versions

1 Thessalonians 4 in the ANGEFD

1 Thessalonians 4 in the ANTPNG2D

1 Thessalonians 4 in the AS21

1 Thessalonians 4 in the BAGH

1 Thessalonians 4 in the BBPNG

1 Thessalonians 4 in the BBT1E

1 Thessalonians 4 in the BDS

1 Thessalonians 4 in the BEV

1 Thessalonians 4 in the BHAD

1 Thessalonians 4 in the BIB

1 Thessalonians 4 in the BLPT

1 Thessalonians 4 in the BNT

1 Thessalonians 4 in the BNTABOOT

1 Thessalonians 4 in the BNTLV

1 Thessalonians 4 in the BOATCB

1 Thessalonians 4 in the BOATCB2

1 Thessalonians 4 in the BOBCV

1 Thessalonians 4 in the BOCNT

1 Thessalonians 4 in the BOECS

1 Thessalonians 4 in the BOGWICC

1 Thessalonians 4 in the BOHCB

1 Thessalonians 4 in the BOHCV

1 Thessalonians 4 in the BOHLNT

1 Thessalonians 4 in the BOHNTLTAL

1 Thessalonians 4 in the BOICB

1 Thessalonians 4 in the BOILNTAP

1 Thessalonians 4 in the BOITCV

1 Thessalonians 4 in the BOKCV

1 Thessalonians 4 in the BOKCV2

1 Thessalonians 4 in the BOKHWOG

1 Thessalonians 4 in the BOKSSV

1 Thessalonians 4 in the BOLCB

1 Thessalonians 4 in the BOLCB2

1 Thessalonians 4 in the BOMCV

1 Thessalonians 4 in the BONAV

1 Thessalonians 4 in the BONCB

1 Thessalonians 4 in the BONLT

1 Thessalonians 4 in the BONUT2

1 Thessalonians 4 in the BOPLNT

1 Thessalonians 4 in the BOSCB

1 Thessalonians 4 in the BOSNC

1 Thessalonians 4 in the BOTLNT

1 Thessalonians 4 in the BOVCB

1 Thessalonians 4 in the BPBB

1 Thessalonians 4 in the BPH

1 Thessalonians 4 in the BSB

1 Thessalonians 4 in the CCB

1 Thessalonians 4 in the CUV

1 Thessalonians 4 in the CUVS

1 Thessalonians 4 in the DBT

1 Thessalonians 4 in the DGDNT

1 Thessalonians 4 in the DHNT

1 Thessalonians 4 in the DNT

1 Thessalonians 4 in the ELBE

1 Thessalonians 4 in the EMTV

1 Thessalonians 4 in the ESV

1 Thessalonians 4 in the FBV

1 Thessalonians 4 in the FEB

1 Thessalonians 4 in the GGMNT

1 Thessalonians 4 in the GNT

1 Thessalonians 4 in the HARY

1 Thessalonians 4 in the HNT

1 Thessalonians 4 in the IRVA

1 Thessalonians 4 in the IRVB

1 Thessalonians 4 in the IRVG

1 Thessalonians 4 in the IRVH

1 Thessalonians 4 in the IRVK

1 Thessalonians 4 in the IRVM

1 Thessalonians 4 in the IRVM2

1 Thessalonians 4 in the IRVO

1 Thessalonians 4 in the IRVP

1 Thessalonians 4 in the IRVT

1 Thessalonians 4 in the IRVT2

1 Thessalonians 4 in the IRVU

1 Thessalonians 4 in the ISVN

1 Thessalonians 4 in the JSNT

1 Thessalonians 4 in the KAPI

1 Thessalonians 4 in the KBT1ETNIK

1 Thessalonians 4 in the KBV

1 Thessalonians 4 in the KJV

1 Thessalonians 4 in the KNFD

1 Thessalonians 4 in the LBA

1 Thessalonians 4 in the LBLA

1 Thessalonians 4 in the LNT

1 Thessalonians 4 in the LSV

1 Thessalonians 4 in the MAAL

1 Thessalonians 4 in the MBV

1 Thessalonians 4 in the MBV2

1 Thessalonians 4 in the MHNT

1 Thessalonians 4 in the MKNFD

1 Thessalonians 4 in the MNG

1 Thessalonians 4 in the MNT

1 Thessalonians 4 in the MNT2

1 Thessalonians 4 in the MRS1T

1 Thessalonians 4 in the NAA

1 Thessalonians 4 in the NASB

1 Thessalonians 4 in the NBLA

1 Thessalonians 4 in the NBS

1 Thessalonians 4 in the NBVTP

1 Thessalonians 4 in the NET2

1 Thessalonians 4 in the NIV11

1 Thessalonians 4 in the NNT

1 Thessalonians 4 in the NNT2

1 Thessalonians 4 in the NNT3

1 Thessalonians 4 in the PDDPT

1 Thessalonians 4 in the PFNT

1 Thessalonians 4 in the RMNT

1 Thessalonians 4 in the SBIAS

1 Thessalonians 4 in the SBIBS

1 Thessalonians 4 in the SBIBS2

1 Thessalonians 4 in the SBICS

1 Thessalonians 4 in the SBIDS

1 Thessalonians 4 in the SBIGS

1 Thessalonians 4 in the SBIHS

1 Thessalonians 4 in the SBIIS

1 Thessalonians 4 in the SBIIS2

1 Thessalonians 4 in the SBIIS3

1 Thessalonians 4 in the SBIKS

1 Thessalonians 4 in the SBIKS2

1 Thessalonians 4 in the SBIMS

1 Thessalonians 4 in the SBIOS

1 Thessalonians 4 in the SBIPS

1 Thessalonians 4 in the SBISS

1 Thessalonians 4 in the SBITS

1 Thessalonians 4 in the SBITS2

1 Thessalonians 4 in the SBITS3

1 Thessalonians 4 in the SBITS4

1 Thessalonians 4 in the SBIUS

1 Thessalonians 4 in the SBIVS

1 Thessalonians 4 in the SBT

1 Thessalonians 4 in the SBT1E

1 Thessalonians 4 in the SCHL

1 Thessalonians 4 in the SNT

1 Thessalonians 4 in the SUSU

1 Thessalonians 4 in the SUSU2

1 Thessalonians 4 in the SYNO

1 Thessalonians 4 in the TBIAOTANT

1 Thessalonians 4 in the TBT1E

1 Thessalonians 4 in the TBT1E2

1 Thessalonians 4 in the TFTIP

1 Thessalonians 4 in the TFTU

1 Thessalonians 4 in the TGNTATF3T

1 Thessalonians 4 in the THAI

1 Thessalonians 4 in the TNFD

1 Thessalonians 4 in the TNT

1 Thessalonians 4 in the TNTIK

1 Thessalonians 4 in the TNTIL

1 Thessalonians 4 in the TNTIN

1 Thessalonians 4 in the TNTIP

1 Thessalonians 4 in the TNTIZ

1 Thessalonians 4 in the TOMA

1 Thessalonians 4 in the TTENT

1 Thessalonians 4 in the UBG

1 Thessalonians 4 in the UGV

1 Thessalonians 4 in the UGV2

1 Thessalonians 4 in the UGV3

1 Thessalonians 4 in the VBL

1 Thessalonians 4 in the VDCC

1 Thessalonians 4 in the YALU

1 Thessalonians 4 in the YAPE

1 Thessalonians 4 in the YBVTP

1 Thessalonians 4 in the ZBP