2 Chronicles 22 (BOYCB)
1 Àwọn ènìyàn Jerusalẹmu mú Ahasiah, ọmọ Jehoramu tí ó kéré jùlọ, jẹ ọba ní ipò rẹ̀, láti ìgbà tí àwọn onísùnmọ̀mí, tí ó wá pẹ̀lú àwọn ará Arabia sínú ibùdó, tí wọn sì ti pa àwọn ọmọkùnrin àgbà. Bẹ́ẹ̀ ni Ahasiah ọmọ Jehoramu ọba Juda bẹ̀rẹ̀ sí ní jẹ ọba. 2 Ahasiah jẹ́ ẹni ọdún méjìlélógún nígbà tí ó di ọba. Ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún kan. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Ataliah, ọmọ ọmọbìnrin Omri. 3 Ó mú ìrìn ní ọ̀nà ilé Ahabu. Nítorí tí ìyá rẹ̀ kì í láyà nínú ṣíṣe búburú. 4 Ó ṣe búburú ní ojú OLÚWA, gẹ́gẹ́ bí ilé Ahabu ti ṣe, nítorí lẹ́yìn ikú baba a rẹ̀, wọ́n di olùgbani nímọ̀ràn rẹ̀ sí ṣíṣe rẹ̀. 5 Ó tẹ̀lé ìgbìmọ̀ wọn nígbà tí ó lọ pẹ̀lú Joramu ọmọ Ahabu ọba Israẹli láti gbógun ti Hasaeli ọba Aramu ní Ramoti Gileadi. Àwọn ará Aramu ṣá Joramu ní ọgbẹ́; 6 bẹ́ẹ̀ ni ó padà sí Jesreeli láti wo ọgbẹ́ rẹ̀ sàn tí wọ́n ti dá sí i lára ní Rama ní ojú ogun rẹ̀ pẹ̀lú Hasaeli ọba Siria.Nígbà náà, Ahasiah, ọmọ Jehoramu ọba Juda lọ sí Jesreeli láti lọ rí Joramu ọmọ Ahabu nítorí a ti ṣá a lọ́gbẹ́. 7 Ní gbogbo ìgbà ìbẹ̀wò Ahasiah sí Joramu, Ọlọ́run mú ìṣubú Ahasiah wá. Nígbà tí Ahasiah dé, ó jáde lọ pẹ̀lú Jehoramu láti lọ bá Jehu ọmọ Nimṣi, ẹni tí OLÚWA ti fi àmì òróró yàn láti pa ìdílé Ahabu run. 8 Nígbà tí Jehu ń ṣe ìdájọ́ lórí ilé Ahabu, ó rí àwọn ọmọbìnrin ọba ti Juda àti àwọn ọmọkùnrin ìbátan Ahasi, tí ó ń tọ́jú Ahasiah, ó sì pa wọ́n. 9 Ó lọ láti wá Ahasiah, àti àwọn ọkùnrin rẹ̀. Àwọn arákùnrin rẹ̀ ṣẹ́gun rẹ̀ nígbà tí ó sá pamọ́ ní Samaria. A gbé e wá sí ọ̀dọ̀ Jehu, a sì pa á. Wọ́n sin ín nítorí wọ́n wí pé, “Ọmọkùnrin Jehoṣafati ni, ẹni tí ó wá OLÚWA pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹnìkan ní ilé Ahasiah tí ó lágbára láti gbé ìjọba náà dúró. 10 Nígbà tí Ataliah ìyá Ahasiah rí i wí pé ọmọkùnrin rẹ̀ ti kú, ó tẹ̀síwájú láti pa gbogbo ìdílé ọba ti ilẹ̀ Juda run. 11 Ṣùgbọ́n Jehoṣeba ọmọbìnrin ọba Jehoramu mú Joaṣi, ọmọkùnrin Ahasiah ó sì jí gbé lọ kúrò láàrín àwọn ọmọbìnrin ọba, àwọn tí ó kù díẹ̀ kí wọn pa. Wọn gbé òun àti olùtọ́jú rẹ̀ sínú ìyẹ̀wù. Nítorí Jehoṣeba ọmọbìnrin ọba Jehoramu àti ìyàwó àlùfáà Jehoiada jẹ́ arábìnrin Ahasiah. Ó fi ọmọ náà pamọ́ kúrò fún Ataliah, kí ó má ba à pa á. 12 Ó wà ní ìpamọ́ pẹ̀lú wọn ni ilé Ọlọ́run fún ọdún mẹ́fà nígbà tí Ataliah ṣàkóso ilẹ̀ náà.
In Other Versions
2 Chronicles 22 in the ANGEFD
2 Chronicles 22 in the ANTPNG2D
2 Chronicles 22 in the AS21
2 Chronicles 22 in the BAGH
2 Chronicles 22 in the BBPNG
2 Chronicles 22 in the BBT1E
2 Chronicles 22 in the BDS
2 Chronicles 22 in the BEV
2 Chronicles 22 in the BHAD
2 Chronicles 22 in the BIB
2 Chronicles 22 in the BLPT
2 Chronicles 22 in the BNT
2 Chronicles 22 in the BNTABOOT
2 Chronicles 22 in the BNTLV
2 Chronicles 22 in the BOATCB
2 Chronicles 22 in the BOATCB2
2 Chronicles 22 in the BOBCV
2 Chronicles 22 in the BOCNT
2 Chronicles 22 in the BOECS
2 Chronicles 22 in the BOGWICC
2 Chronicles 22 in the BOHCB
2 Chronicles 22 in the BOHCV
2 Chronicles 22 in the BOHLNT
2 Chronicles 22 in the BOHNTLTAL
2 Chronicles 22 in the BOICB
2 Chronicles 22 in the BOILNTAP
2 Chronicles 22 in the BOITCV
2 Chronicles 22 in the BOKCV
2 Chronicles 22 in the BOKCV2
2 Chronicles 22 in the BOKHWOG
2 Chronicles 22 in the BOKSSV
2 Chronicles 22 in the BOLCB
2 Chronicles 22 in the BOLCB2
2 Chronicles 22 in the BOMCV
2 Chronicles 22 in the BONAV
2 Chronicles 22 in the BONCB
2 Chronicles 22 in the BONLT
2 Chronicles 22 in the BONUT2
2 Chronicles 22 in the BOPLNT
2 Chronicles 22 in the BOSCB
2 Chronicles 22 in the BOSNC
2 Chronicles 22 in the BOTLNT
2 Chronicles 22 in the BOVCB
2 Chronicles 22 in the BPBB
2 Chronicles 22 in the BPH
2 Chronicles 22 in the BSB
2 Chronicles 22 in the CCB
2 Chronicles 22 in the CUV
2 Chronicles 22 in the CUVS
2 Chronicles 22 in the DBT
2 Chronicles 22 in the DGDNT
2 Chronicles 22 in the DHNT
2 Chronicles 22 in the DNT
2 Chronicles 22 in the ELBE
2 Chronicles 22 in the EMTV
2 Chronicles 22 in the ESV
2 Chronicles 22 in the FBV
2 Chronicles 22 in the FEB
2 Chronicles 22 in the GGMNT
2 Chronicles 22 in the GNT
2 Chronicles 22 in the HARY
2 Chronicles 22 in the HNT
2 Chronicles 22 in the IRVA
2 Chronicles 22 in the IRVB
2 Chronicles 22 in the IRVG
2 Chronicles 22 in the IRVH
2 Chronicles 22 in the IRVK
2 Chronicles 22 in the IRVM
2 Chronicles 22 in the IRVM2
2 Chronicles 22 in the IRVO
2 Chronicles 22 in the IRVP
2 Chronicles 22 in the IRVT
2 Chronicles 22 in the IRVT2
2 Chronicles 22 in the IRVU
2 Chronicles 22 in the ISVN
2 Chronicles 22 in the JSNT
2 Chronicles 22 in the KAPI
2 Chronicles 22 in the KBT1ETNIK
2 Chronicles 22 in the KBV
2 Chronicles 22 in the KJV
2 Chronicles 22 in the KNFD
2 Chronicles 22 in the LBA
2 Chronicles 22 in the LBLA
2 Chronicles 22 in the LNT
2 Chronicles 22 in the LSV
2 Chronicles 22 in the MAAL
2 Chronicles 22 in the MBV
2 Chronicles 22 in the MBV2
2 Chronicles 22 in the MHNT
2 Chronicles 22 in the MKNFD
2 Chronicles 22 in the MNG
2 Chronicles 22 in the MNT
2 Chronicles 22 in the MNT2
2 Chronicles 22 in the MRS1T
2 Chronicles 22 in the NAA
2 Chronicles 22 in the NASB
2 Chronicles 22 in the NBLA
2 Chronicles 22 in the NBS
2 Chronicles 22 in the NBVTP
2 Chronicles 22 in the NET2
2 Chronicles 22 in the NIV11
2 Chronicles 22 in the NNT
2 Chronicles 22 in the NNT2
2 Chronicles 22 in the NNT3
2 Chronicles 22 in the PDDPT
2 Chronicles 22 in the PFNT
2 Chronicles 22 in the RMNT
2 Chronicles 22 in the SBIAS
2 Chronicles 22 in the SBIBS
2 Chronicles 22 in the SBIBS2
2 Chronicles 22 in the SBICS
2 Chronicles 22 in the SBIDS
2 Chronicles 22 in the SBIGS
2 Chronicles 22 in the SBIHS
2 Chronicles 22 in the SBIIS
2 Chronicles 22 in the SBIIS2
2 Chronicles 22 in the SBIIS3
2 Chronicles 22 in the SBIKS
2 Chronicles 22 in the SBIKS2
2 Chronicles 22 in the SBIMS
2 Chronicles 22 in the SBIOS
2 Chronicles 22 in the SBIPS
2 Chronicles 22 in the SBISS
2 Chronicles 22 in the SBITS
2 Chronicles 22 in the SBITS2
2 Chronicles 22 in the SBITS3
2 Chronicles 22 in the SBITS4
2 Chronicles 22 in the SBIUS
2 Chronicles 22 in the SBIVS
2 Chronicles 22 in the SBT
2 Chronicles 22 in the SBT1E
2 Chronicles 22 in the SCHL
2 Chronicles 22 in the SNT
2 Chronicles 22 in the SUSU
2 Chronicles 22 in the SUSU2
2 Chronicles 22 in the SYNO
2 Chronicles 22 in the TBIAOTANT
2 Chronicles 22 in the TBT1E
2 Chronicles 22 in the TBT1E2
2 Chronicles 22 in the TFTIP
2 Chronicles 22 in the TFTU
2 Chronicles 22 in the TGNTATF3T
2 Chronicles 22 in the THAI
2 Chronicles 22 in the TNFD
2 Chronicles 22 in the TNT
2 Chronicles 22 in the TNTIK
2 Chronicles 22 in the TNTIL
2 Chronicles 22 in the TNTIN
2 Chronicles 22 in the TNTIP
2 Chronicles 22 in the TNTIZ
2 Chronicles 22 in the TOMA
2 Chronicles 22 in the TTENT
2 Chronicles 22 in the UBG
2 Chronicles 22 in the UGV
2 Chronicles 22 in the UGV2
2 Chronicles 22 in the UGV3
2 Chronicles 22 in the VBL
2 Chronicles 22 in the VDCC
2 Chronicles 22 in the YALU
2 Chronicles 22 in the YAPE
2 Chronicles 22 in the YBVTP
2 Chronicles 22 in the ZBP