2 Corinthians 3 (BOYCB)
1 Àwa ha tún bẹ̀rẹ̀ láti máa yín ara wá bí? Tàbí àwa ha ń fẹ́ ìwé ìyìn sọ́dọ̀ yín, tàbí láti ọ̀dọ̀ yín gẹ́gẹ́ bí ẹlòmíràn tí ń ṣe? 2 Ẹ̀yin fúnra yín ni ìwé ìyìn wa, tí a ti kọ sí yín ní ọkàn, ti gbogbo ènìyàn mọ̀, tí wọ́n sì ń kà. 3 Ẹ̀yin sì ń fihàn pé ìwé tí a gbà sílẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Kristi ni yín, kì í ṣe èyí tí a sì fi jẹ́lú kọ, bí kò sẹ Ẹ̀mí Ọlọ́run alààyè, kì í ṣe nínú wàláà òkúta bí kò ṣe nínú wàláà ọkàn ẹran. 4 Irú ìgbẹ́kẹ̀lé yìí ni àwa ní nípasẹ̀ Kristi sọ́dọ̀ Ọlọ́run, 5 kì í ṣe pé àwa tó fún ara wa láti ṣírò ohunkóhun bí ẹni pé láti ọ̀dọ̀ àwa tìkára wa; ṣùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ní tító wà, 6 Ẹni tí ó mú wa yẹ bí ìránṣẹ́ májẹ̀mú tuntun; kì í ṣe ní ti ìwé àkọsílẹ̀ ṣùgbọ́n ní ti ẹ̀mí, nítorí ìwé a máa pa ni, ṣùgbọ́n ẹ̀mí a máa sọ ní di ààyè. 7 Ṣùgbọ́n bí iṣẹ́ ìránṣẹ́ tí ikú, tí a tí kọ tí a sì ti gbẹ́ sí ara òkúta bá jẹ́ ológo tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ọmọ Israẹli kò lè tẹjúmọ́ wíwo ojú Mose nítorí ògo ojú rẹ̀ (ògo ti ń kọjá lọ); 8 yóò ha ti rí tí iṣẹ́ ìránṣẹ́ ti ẹ̀mí kì yóò kúkú jẹ́ ògo jù? 9 Nítorí pé bi iṣẹ́ ìránṣẹ́ ìdálẹ́bi bá jẹ́ ológo, mélòó mélòó ni iṣẹ́ ìránṣẹ́ òdodo yóò tayọ jù ú ní ògo. 10 Nítorí, èyí tí a tí ṣe lógo rí, kó lógo mọ́ báyìí, nítorí ògo tí ó tayọ. 11 Nítorí pé bí èyí ti ń kọjá lọ bá lógo, mélòó mélòó ni èyí tí ó dúró kí yóò ní ògo! 12 Ǹjẹ́ nítorí náà bí a tí ní irú ìrètí bí èyí, àwa ń fi ìgboyà púpọ̀ sọ̀rọ̀. 13 Kì í sì í ṣe bí Mose, ẹni tí ó fi ìbòjú bo ojú rẹ̀, ki àwọn ọmọ Israẹli má ba à lè tẹjúmọ́ wíwo òpin èyí tí ń kọjá lọ. 14 Ṣùgbọ́n ojú inú wọn fọ́; nítorí pé títí fi di òní olónìí nípa kíka májẹ̀mú láéláé, ìbòjú kan náà ṣì wà láìká kúrò; nítorí pé nínú Kristi ni a tí lè mú ìbòjú náà kúrò. 15 Ṣùgbọ́n títí di òní olónìí, nígbàkígbà ti a bá ń ka Mose, ìbòjú náà ń bẹ lọ́kàn wọn. 16 Ṣùgbọ́n nígbà ti òun bá yípadà sí Olúwa, a ó mú ìbòjú náà kúrò. 17 Ǹjẹ́ Olúwa ni Ẹ̀mí náà: níbi tí Ẹ̀mí Olúwa bá sì wà, níbẹ̀ ni òmìnira gbé wà. 18 Ṣùgbọ́n gbogbo wa ń wo ògo Olúwa láìsí ìbòjú bí ẹni pé nínú àwòjìji, a sì ń pa wa dà sí àwòrán kan náà láti ògo dé ògo, àní bí láti ọ̀dọ̀ Olúwa tí í ṣe Ẹ̀mí.
In Other Versions
2 Corinthians 3 in the ANGEFD
2 Corinthians 3 in the ANTPNG2D
2 Corinthians 3 in the AS21
2 Corinthians 3 in the BAGH
2 Corinthians 3 in the BBPNG
2 Corinthians 3 in the BBT1E
2 Corinthians 3 in the BDS
2 Corinthians 3 in the BEV
2 Corinthians 3 in the BHAD
2 Corinthians 3 in the BIB
2 Corinthians 3 in the BLPT
2 Corinthians 3 in the BNT
2 Corinthians 3 in the BNTABOOT
2 Corinthians 3 in the BNTLV
2 Corinthians 3 in the BOATCB
2 Corinthians 3 in the BOATCB2
2 Corinthians 3 in the BOBCV
2 Corinthians 3 in the BOCNT
2 Corinthians 3 in the BOECS
2 Corinthians 3 in the BOGWICC
2 Corinthians 3 in the BOHCB
2 Corinthians 3 in the BOHCV
2 Corinthians 3 in the BOHLNT
2 Corinthians 3 in the BOHNTLTAL
2 Corinthians 3 in the BOICB
2 Corinthians 3 in the BOILNTAP
2 Corinthians 3 in the BOITCV
2 Corinthians 3 in the BOKCV
2 Corinthians 3 in the BOKCV2
2 Corinthians 3 in the BOKHWOG
2 Corinthians 3 in the BOKSSV
2 Corinthians 3 in the BOLCB
2 Corinthians 3 in the BOLCB2
2 Corinthians 3 in the BOMCV
2 Corinthians 3 in the BONAV
2 Corinthians 3 in the BONCB
2 Corinthians 3 in the BONLT
2 Corinthians 3 in the BONUT2
2 Corinthians 3 in the BOPLNT
2 Corinthians 3 in the BOSCB
2 Corinthians 3 in the BOSNC
2 Corinthians 3 in the BOTLNT
2 Corinthians 3 in the BOVCB
2 Corinthians 3 in the BPBB
2 Corinthians 3 in the BPH
2 Corinthians 3 in the BSB
2 Corinthians 3 in the CCB
2 Corinthians 3 in the CUV
2 Corinthians 3 in the CUVS
2 Corinthians 3 in the DBT
2 Corinthians 3 in the DGDNT
2 Corinthians 3 in the DHNT
2 Corinthians 3 in the DNT
2 Corinthians 3 in the ELBE
2 Corinthians 3 in the EMTV
2 Corinthians 3 in the ESV
2 Corinthians 3 in the FBV
2 Corinthians 3 in the FEB
2 Corinthians 3 in the GGMNT
2 Corinthians 3 in the GNT
2 Corinthians 3 in the HARY
2 Corinthians 3 in the HNT
2 Corinthians 3 in the IRVA
2 Corinthians 3 in the IRVB
2 Corinthians 3 in the IRVG
2 Corinthians 3 in the IRVH
2 Corinthians 3 in the IRVK
2 Corinthians 3 in the IRVM
2 Corinthians 3 in the IRVM2
2 Corinthians 3 in the IRVO
2 Corinthians 3 in the IRVP
2 Corinthians 3 in the IRVT
2 Corinthians 3 in the IRVT2
2 Corinthians 3 in the IRVU
2 Corinthians 3 in the ISVN
2 Corinthians 3 in the JSNT
2 Corinthians 3 in the KAPI
2 Corinthians 3 in the KBT1ETNIK
2 Corinthians 3 in the KBV
2 Corinthians 3 in the KJV
2 Corinthians 3 in the KNFD
2 Corinthians 3 in the LBA
2 Corinthians 3 in the LBLA
2 Corinthians 3 in the LNT
2 Corinthians 3 in the LSV
2 Corinthians 3 in the MAAL
2 Corinthians 3 in the MBV
2 Corinthians 3 in the MBV2
2 Corinthians 3 in the MHNT
2 Corinthians 3 in the MKNFD
2 Corinthians 3 in the MNG
2 Corinthians 3 in the MNT
2 Corinthians 3 in the MNT2
2 Corinthians 3 in the MRS1T
2 Corinthians 3 in the NAA
2 Corinthians 3 in the NASB
2 Corinthians 3 in the NBLA
2 Corinthians 3 in the NBS
2 Corinthians 3 in the NBVTP
2 Corinthians 3 in the NET2
2 Corinthians 3 in the NIV11
2 Corinthians 3 in the NNT
2 Corinthians 3 in the NNT2
2 Corinthians 3 in the NNT3
2 Corinthians 3 in the PDDPT
2 Corinthians 3 in the PFNT
2 Corinthians 3 in the RMNT
2 Corinthians 3 in the SBIAS
2 Corinthians 3 in the SBIBS
2 Corinthians 3 in the SBIBS2
2 Corinthians 3 in the SBICS
2 Corinthians 3 in the SBIDS
2 Corinthians 3 in the SBIGS
2 Corinthians 3 in the SBIHS
2 Corinthians 3 in the SBIIS
2 Corinthians 3 in the SBIIS2
2 Corinthians 3 in the SBIIS3
2 Corinthians 3 in the SBIKS
2 Corinthians 3 in the SBIKS2
2 Corinthians 3 in the SBIMS
2 Corinthians 3 in the SBIOS
2 Corinthians 3 in the SBIPS
2 Corinthians 3 in the SBISS
2 Corinthians 3 in the SBITS
2 Corinthians 3 in the SBITS2
2 Corinthians 3 in the SBITS3
2 Corinthians 3 in the SBITS4
2 Corinthians 3 in the SBIUS
2 Corinthians 3 in the SBIVS
2 Corinthians 3 in the SBT
2 Corinthians 3 in the SBT1E
2 Corinthians 3 in the SCHL
2 Corinthians 3 in the SNT
2 Corinthians 3 in the SUSU
2 Corinthians 3 in the SUSU2
2 Corinthians 3 in the SYNO
2 Corinthians 3 in the TBIAOTANT
2 Corinthians 3 in the TBT1E
2 Corinthians 3 in the TBT1E2
2 Corinthians 3 in the TFTIP
2 Corinthians 3 in the TFTU
2 Corinthians 3 in the TGNTATF3T
2 Corinthians 3 in the THAI
2 Corinthians 3 in the TNFD
2 Corinthians 3 in the TNT
2 Corinthians 3 in the TNTIK
2 Corinthians 3 in the TNTIL
2 Corinthians 3 in the TNTIN
2 Corinthians 3 in the TNTIP
2 Corinthians 3 in the TNTIZ
2 Corinthians 3 in the TOMA
2 Corinthians 3 in the TTENT
2 Corinthians 3 in the UBG
2 Corinthians 3 in the UGV
2 Corinthians 3 in the UGV2
2 Corinthians 3 in the UGV3
2 Corinthians 3 in the VBL
2 Corinthians 3 in the VDCC
2 Corinthians 3 in the YALU
2 Corinthians 3 in the YAPE
2 Corinthians 3 in the YBVTP
2 Corinthians 3 in the ZBP