2 Corinthians 7 (BOYCB)

1 Nítorí náà, ẹ̀yin olùfẹ́, bí a ti ní àwọn ìlérí wọ̀nyí, ẹ jẹ́ kí a wẹ ara wá mọ́ kúrò nínú gbogbo ẹ̀gbin ti ara àti ti ẹ̀mí, kí a sọ ìwà mímọ́ dí pípé nínú ìbẹ̀rù Ọlọ́run. 2 Ẹ gbà wá tọkàntọkàn; a kò fi ibi ṣe ẹnikẹ́ni, a kò ba ẹnikẹ́ni jẹ́, a kò rẹ́ ẹnikẹ́ni jẹ. 3 Èmi kò sọ èyí láti dá a yín lẹ́bi; nítorí mo tí wí ṣáájú pé, ẹ̀yin wà nínú ọkàn wa kí a lè jùmọ̀ kú, àti kí a lè jùmọ̀ wà láààyè. 4 Mo ní ìgboyà ńlá láti bá yín sọ̀rọ̀; ìṣògo mí lórí yín pọ̀; mo kún fún ìtùnú, mo sì ń yọ̀ rékọjá nínú gbogbo ìpọ́njú wa. 5 Nítorí pé nígbà tí àwa tilẹ̀ dé Makedonia, ara wá kò balẹ̀, ṣùgbọ́n a ń pọ́n wá lójú níhà gbogbo, ìjà ń bẹ lóde, ẹ̀rù ń bẹ nínú. 6 Ṣùgbọ́n ẹni tí ń tu àwọn onírẹ̀lẹ̀ nínú, àní Ọlọ́run, ó tù wá nínú nípa dídé tí Titu dé, 7 kì í sì i ṣe nípa dídé rẹ̀ nìkan ṣùgbọ́n nípa ìtùnú náà pẹ̀lú tí ẹ ti tù ú nínú, nígbà tí ó ròyìn fún wa ìfẹ́ àtọkànwá yín, ìbànújẹ́ yín, àti ìtara yín fún mi; bẹ́ẹ̀ ní mo sì túbọ̀ yọ̀. 8 Nítorí pé, bí mo tilẹ̀ ba inú yín jẹ́ nípa ìwé tí mo kọ èmi kò kábámọ̀ mọ́, bí mo tilẹ̀ ti kábámọ̀ tẹ́lẹ̀ rí; nítorí tí mo wòye pé ìwé mi mú yín banújẹ́, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé fún ìgbà díẹ̀. 9 Èmi yọ̀ nísinsin yìí, kì í ṣe nítorí tí a mú inú yín bàjẹ́, ṣùgbọ́n nítorí tí a mú inú yín bàjẹ́ sí ìrònúpìwàdà: nítorí ti a mú inú yín bàjẹ́ bí ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run, kí ẹ̀yin má ṣe ti ipasẹ̀ wa pàdánù ní ohunkóhun. 10 Nítorí pé ìbànújẹ́ ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run máa ṣiṣẹ́ ìrònúpìwàdà sí ìgbàlà tí kì í mú àbámọ̀ wá, ṣùgbọ́n ìbànújẹ́ ti ayé a máa ṣiṣẹ́ ikú. 11 Kíyèsi i, nítorí ohun kan náà yìí tí a mú yin banújẹ́ fún bí ẹni ìwà-bí-Ọlọ́run, irú ìmúraṣíṣẹ́ tí ó mú jáde nínú yín, wíwẹ ara yín mọ́ ń kọ́, ìbànújẹ́ ń kọ́, ìpayà ń kọ́, ìfojúṣọ́nà ń kọ́, ìtara ń kọ́, ìjẹ́ni-níyà ń kọ́. Nínú ohun àmì kọ̀ọ̀kan yìí ni ẹ̀yin ti fi ara yín hàn bí aláìlẹ́bi nínú ọ̀ràn náà. 12 Nítorí náà, bí mo tilẹ̀ tí kọ̀wé sí yín, èmi kò kọ ọ́ nítorí ẹni tí ó ṣe ohun búburú náà tàbí nítorí ẹni ti a fi ohun búburú náà ṣe, ṣùgbọ́n kí àníyàn yín nítorí wá lè farahàn níwájú Ọlọ́run. 13 Nítorí náà, a tí fi ìtùnú yín tù wá nínú.Àti nínú ìtùnú wa, a yọ̀ gidigidi nítorí pé Titu ní ayọ̀, nítorí láti ọ̀dọ̀ gbogbo yín ni a ti tu ẹ̀mí rẹ̀ lára. 14 Bí mo tilẹ̀ ti lérí ohunkóhun fún ún nítorí yín, a kò dójútì mí; ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí àwa ti sọ ohun gbogbo fún yín ní òtítọ́, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ìlérí wá níwájú Titu sì jásí òtítọ́. 15 Ọkàn rẹ̀ sì fà gidigidi sí yín, bí òun ti ń rántí ìgbọ́ràn gbogbo yín, bí ẹ ti fi ìbẹ̀rù àti ìwárìrì tẹ́wọ́gbà á. 16 Mo yọ̀ nítorí pé ní ohun gbogbo, mo ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú yín.

In Other Versions

2 Corinthians 7 in the ANGEFD

2 Corinthians 7 in the ANTPNG2D

2 Corinthians 7 in the AS21

2 Corinthians 7 in the BAGH

2 Corinthians 7 in the BBPNG

2 Corinthians 7 in the BBT1E

2 Corinthians 7 in the BDS

2 Corinthians 7 in the BEV

2 Corinthians 7 in the BHAD

2 Corinthians 7 in the BIB

2 Corinthians 7 in the BLPT

2 Corinthians 7 in the BNT

2 Corinthians 7 in the BNTABOOT

2 Corinthians 7 in the BNTLV

2 Corinthians 7 in the BOATCB

2 Corinthians 7 in the BOATCB2

2 Corinthians 7 in the BOBCV

2 Corinthians 7 in the BOCNT

2 Corinthians 7 in the BOECS

2 Corinthians 7 in the BOGWICC

2 Corinthians 7 in the BOHCB

2 Corinthians 7 in the BOHCV

2 Corinthians 7 in the BOHLNT

2 Corinthians 7 in the BOHNTLTAL

2 Corinthians 7 in the BOICB

2 Corinthians 7 in the BOILNTAP

2 Corinthians 7 in the BOITCV

2 Corinthians 7 in the BOKCV

2 Corinthians 7 in the BOKCV2

2 Corinthians 7 in the BOKHWOG

2 Corinthians 7 in the BOKSSV

2 Corinthians 7 in the BOLCB

2 Corinthians 7 in the BOLCB2

2 Corinthians 7 in the BOMCV

2 Corinthians 7 in the BONAV

2 Corinthians 7 in the BONCB

2 Corinthians 7 in the BONLT

2 Corinthians 7 in the BONUT2

2 Corinthians 7 in the BOPLNT

2 Corinthians 7 in the BOSCB

2 Corinthians 7 in the BOSNC

2 Corinthians 7 in the BOTLNT

2 Corinthians 7 in the BOVCB

2 Corinthians 7 in the BPBB

2 Corinthians 7 in the BPH

2 Corinthians 7 in the BSB

2 Corinthians 7 in the CCB

2 Corinthians 7 in the CUV

2 Corinthians 7 in the CUVS

2 Corinthians 7 in the DBT

2 Corinthians 7 in the DGDNT

2 Corinthians 7 in the DHNT

2 Corinthians 7 in the DNT

2 Corinthians 7 in the ELBE

2 Corinthians 7 in the EMTV

2 Corinthians 7 in the ESV

2 Corinthians 7 in the FBV

2 Corinthians 7 in the FEB

2 Corinthians 7 in the GGMNT

2 Corinthians 7 in the GNT

2 Corinthians 7 in the HARY

2 Corinthians 7 in the HNT

2 Corinthians 7 in the IRVA

2 Corinthians 7 in the IRVB

2 Corinthians 7 in the IRVG

2 Corinthians 7 in the IRVH

2 Corinthians 7 in the IRVK

2 Corinthians 7 in the IRVM

2 Corinthians 7 in the IRVM2

2 Corinthians 7 in the IRVO

2 Corinthians 7 in the IRVP

2 Corinthians 7 in the IRVT

2 Corinthians 7 in the IRVT2

2 Corinthians 7 in the IRVU

2 Corinthians 7 in the ISVN

2 Corinthians 7 in the JSNT

2 Corinthians 7 in the KAPI

2 Corinthians 7 in the KBT1ETNIK

2 Corinthians 7 in the KBV

2 Corinthians 7 in the KJV

2 Corinthians 7 in the KNFD

2 Corinthians 7 in the LBA

2 Corinthians 7 in the LBLA

2 Corinthians 7 in the LNT

2 Corinthians 7 in the LSV

2 Corinthians 7 in the MAAL

2 Corinthians 7 in the MBV

2 Corinthians 7 in the MBV2

2 Corinthians 7 in the MHNT

2 Corinthians 7 in the MKNFD

2 Corinthians 7 in the MNG

2 Corinthians 7 in the MNT

2 Corinthians 7 in the MNT2

2 Corinthians 7 in the MRS1T

2 Corinthians 7 in the NAA

2 Corinthians 7 in the NASB

2 Corinthians 7 in the NBLA

2 Corinthians 7 in the NBS

2 Corinthians 7 in the NBVTP

2 Corinthians 7 in the NET2

2 Corinthians 7 in the NIV11

2 Corinthians 7 in the NNT

2 Corinthians 7 in the NNT2

2 Corinthians 7 in the NNT3

2 Corinthians 7 in the PDDPT

2 Corinthians 7 in the PFNT

2 Corinthians 7 in the RMNT

2 Corinthians 7 in the SBIAS

2 Corinthians 7 in the SBIBS

2 Corinthians 7 in the SBIBS2

2 Corinthians 7 in the SBICS

2 Corinthians 7 in the SBIDS

2 Corinthians 7 in the SBIGS

2 Corinthians 7 in the SBIHS

2 Corinthians 7 in the SBIIS

2 Corinthians 7 in the SBIIS2

2 Corinthians 7 in the SBIIS3

2 Corinthians 7 in the SBIKS

2 Corinthians 7 in the SBIKS2

2 Corinthians 7 in the SBIMS

2 Corinthians 7 in the SBIOS

2 Corinthians 7 in the SBIPS

2 Corinthians 7 in the SBISS

2 Corinthians 7 in the SBITS

2 Corinthians 7 in the SBITS2

2 Corinthians 7 in the SBITS3

2 Corinthians 7 in the SBITS4

2 Corinthians 7 in the SBIUS

2 Corinthians 7 in the SBIVS

2 Corinthians 7 in the SBT

2 Corinthians 7 in the SBT1E

2 Corinthians 7 in the SCHL

2 Corinthians 7 in the SNT

2 Corinthians 7 in the SUSU

2 Corinthians 7 in the SUSU2

2 Corinthians 7 in the SYNO

2 Corinthians 7 in the TBIAOTANT

2 Corinthians 7 in the TBT1E

2 Corinthians 7 in the TBT1E2

2 Corinthians 7 in the TFTIP

2 Corinthians 7 in the TFTU

2 Corinthians 7 in the TGNTATF3T

2 Corinthians 7 in the THAI

2 Corinthians 7 in the TNFD

2 Corinthians 7 in the TNT

2 Corinthians 7 in the TNTIK

2 Corinthians 7 in the TNTIL

2 Corinthians 7 in the TNTIN

2 Corinthians 7 in the TNTIP

2 Corinthians 7 in the TNTIZ

2 Corinthians 7 in the TOMA

2 Corinthians 7 in the TTENT

2 Corinthians 7 in the UBG

2 Corinthians 7 in the UGV

2 Corinthians 7 in the UGV2

2 Corinthians 7 in the UGV3

2 Corinthians 7 in the VBL

2 Corinthians 7 in the VDCC

2 Corinthians 7 in the YALU

2 Corinthians 7 in the YAPE

2 Corinthians 7 in the YBVTP

2 Corinthians 7 in the ZBP