2 Samuel 4 (BOYCB)

1 Nígbà tí ọmọ Saulu sì gbọ́ pé, Abneri kú ní Hebroni, ọwọ́ rẹ̀ sì rọ, gbogbo Israẹli sì rẹ̀wẹ̀sì. 2 Ọmọ Saulu sì ní ọkùnrin méjì tí í ṣe olórí ẹgbẹ́ ogun: a ń pe orúkọ ọ̀kan ní Baanah, àti orúkọ èkejì ní Rekabu, àwọn ọmọ Rimoni ará Beeroti ti àwọn ọmọ Benjamini (nítorí pé a sì ka Beeroti pẹ̀lú Benjamini). 3 Àwọn ará Beeroti sì ti sálọ sí Gittaimu, wọ́n sì ṣe àtìpó níbẹ̀ títí ó fi di ọjọ́ òní yìí. 4 (Jonatani ọmọ Saulu sì ti bí ọmọkùnrin kan tí ẹsẹ̀ rẹ̀ rọ, òun sì jẹ́ ọdún márùn-ún, nígbà tí ìròyìn dé ní ti Saulu àti Jonatani láti Jesreeli wá, olùtọ́ rẹ̀ sì gbé e, o sì sálọ, ó sì ṣe, bí ó sì ti ń yára láti sálọ, òun sì ṣubú, ó sì ya arọ. Orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Mefiboṣeti.) 5 Àwọn ọmọ Rimoni, ará Beeroti, Rekabu àti Baanah sì lọ wọ́n sì wá síh ilé Iṣboṣeti ní ọ̀sán gangan, òun sì sinmi lórí ibùsùn kan ní ọjọ́-kanrí. 6 Sì wò ó, bí olùṣọ́ ẹnu-ọ̀nà ilé náà ti ń gbọn àwọn pàǹtí, ó tòògbé ó sì sùn lọ, wọ́n sì wá sí àárín ilé náà, wọ́n sì ṣe bí ẹni pé wọ́n ń fẹ́ mú alikama; wọ́n sì gún un lábẹ́ inú. Rekabu àti Baanah arákùnrin rẹ̀ sì sálọ. 7 Nígbà tí wọ́n wọ ilé náà lọ, òun sì dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀ nínú iyàrá rẹ̀, wọ́n sì pa á, wọ́n sì bẹ́ ẹ lórí, wọ́n gbé orí sálọ, wọ́n sì fi gbogbo òru rìn ni pẹ̀tẹ́lẹ̀ náà. 8 Wọ́n sì gbé orí Iṣboṣeti tọ Dafidi wá ní Hebroni, wọ́n sì wí fún ọba pé, “Wò ó, orí Iṣboṣeti ọmọ Saulu ọ̀tá rẹ, tí ó ti ń wá ẹ̀mí rẹ kiri, OLÚWA ti gbẹ̀san fún ọba olúwa mi lónìí lára Saulu àti lára irú-ọmọ rẹ̀.” 9 Dafidi sì dá Rekabu àti Baanah arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rimoni ará Beeroti lóhùn, ó sì wí fún wọn pé, “Bí OLÚWA ti ń bẹ, ẹni tí ó gba ẹ̀mí mi lọ́wọ́ gbogbo ìpọ́njú. 10 Nígbà tí ẹnìkan rò fún mi pé, ‘Wò ó, Saulu ti kú,’ lójú ara rẹ̀ òun sì jásí ẹni tí ó mú ìyìnrere wá, èmi sì mú un, mo sì pa á ní Siklagi, ẹni tí ó ṣe bí òun ó rí nǹkan gbà nítorí ìròyìn rere rẹ̀. 11 Mélòó mélòó ni, nígbà tí àwọn ìkà ènìyàn pa olódodo ènìyàn kan ni ilé rẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀—ǹjẹ́ èmi ha sì lè ṣe aláìbéèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ yín bí? Kí èmi sì mú yín kúrò láààyè.” 12 Dafidi sì fi àṣẹ fún àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ̀, wọ́n sì pa wọ́n, wọ́n sì gé ọwọ́ àti ẹsẹ̀ wọn, a sì fi wọ́n há lórí igi ní Hebroni. Ṣùgbọ́n wọ́n mú orí Iṣboṣeti, wọ́n sì sin ín ní ibojì Abneri ní Hebroni.

In Other Versions

2 Samuel 4 in the ANGEFD

2 Samuel 4 in the ANTPNG2D

2 Samuel 4 in the AS21

2 Samuel 4 in the BAGH

2 Samuel 4 in the BBPNG

2 Samuel 4 in the BBT1E

2 Samuel 4 in the BDS

2 Samuel 4 in the BEV

2 Samuel 4 in the BHAD

2 Samuel 4 in the BIB

2 Samuel 4 in the BLPT

2 Samuel 4 in the BNT

2 Samuel 4 in the BNTABOOT

2 Samuel 4 in the BNTLV

2 Samuel 4 in the BOATCB

2 Samuel 4 in the BOATCB2

2 Samuel 4 in the BOBCV

2 Samuel 4 in the BOCNT

2 Samuel 4 in the BOECS

2 Samuel 4 in the BOGWICC

2 Samuel 4 in the BOHCB

2 Samuel 4 in the BOHCV

2 Samuel 4 in the BOHLNT

2 Samuel 4 in the BOHNTLTAL

2 Samuel 4 in the BOICB

2 Samuel 4 in the BOILNTAP

2 Samuel 4 in the BOITCV

2 Samuel 4 in the BOKCV

2 Samuel 4 in the BOKCV2

2 Samuel 4 in the BOKHWOG

2 Samuel 4 in the BOKSSV

2 Samuel 4 in the BOLCB

2 Samuel 4 in the BOLCB2

2 Samuel 4 in the BOMCV

2 Samuel 4 in the BONAV

2 Samuel 4 in the BONCB

2 Samuel 4 in the BONLT

2 Samuel 4 in the BONUT2

2 Samuel 4 in the BOPLNT

2 Samuel 4 in the BOSCB

2 Samuel 4 in the BOSNC

2 Samuel 4 in the BOTLNT

2 Samuel 4 in the BOVCB

2 Samuel 4 in the BPBB

2 Samuel 4 in the BPH

2 Samuel 4 in the BSB

2 Samuel 4 in the CCB

2 Samuel 4 in the CUV

2 Samuel 4 in the CUVS

2 Samuel 4 in the DBT

2 Samuel 4 in the DGDNT

2 Samuel 4 in the DHNT

2 Samuel 4 in the DNT

2 Samuel 4 in the ELBE

2 Samuel 4 in the EMTV

2 Samuel 4 in the ESV

2 Samuel 4 in the FBV

2 Samuel 4 in the FEB

2 Samuel 4 in the GGMNT

2 Samuel 4 in the GNT

2 Samuel 4 in the HARY

2 Samuel 4 in the HNT

2 Samuel 4 in the IRVA

2 Samuel 4 in the IRVB

2 Samuel 4 in the IRVG

2 Samuel 4 in the IRVH

2 Samuel 4 in the IRVK

2 Samuel 4 in the IRVM

2 Samuel 4 in the IRVM2

2 Samuel 4 in the IRVO

2 Samuel 4 in the IRVP

2 Samuel 4 in the IRVT

2 Samuel 4 in the IRVT2

2 Samuel 4 in the IRVU

2 Samuel 4 in the ISVN

2 Samuel 4 in the JSNT

2 Samuel 4 in the KAPI

2 Samuel 4 in the KBT1ETNIK

2 Samuel 4 in the KBV

2 Samuel 4 in the KJV

2 Samuel 4 in the KNFD

2 Samuel 4 in the LBA

2 Samuel 4 in the LBLA

2 Samuel 4 in the LNT

2 Samuel 4 in the LSV

2 Samuel 4 in the MAAL

2 Samuel 4 in the MBV

2 Samuel 4 in the MBV2

2 Samuel 4 in the MHNT

2 Samuel 4 in the MKNFD

2 Samuel 4 in the MNG

2 Samuel 4 in the MNT

2 Samuel 4 in the MNT2

2 Samuel 4 in the MRS1T

2 Samuel 4 in the NAA

2 Samuel 4 in the NASB

2 Samuel 4 in the NBLA

2 Samuel 4 in the NBS

2 Samuel 4 in the NBVTP

2 Samuel 4 in the NET2

2 Samuel 4 in the NIV11

2 Samuel 4 in the NNT

2 Samuel 4 in the NNT2

2 Samuel 4 in the NNT3

2 Samuel 4 in the PDDPT

2 Samuel 4 in the PFNT

2 Samuel 4 in the RMNT

2 Samuel 4 in the SBIAS

2 Samuel 4 in the SBIBS

2 Samuel 4 in the SBIBS2

2 Samuel 4 in the SBICS

2 Samuel 4 in the SBIDS

2 Samuel 4 in the SBIGS

2 Samuel 4 in the SBIHS

2 Samuel 4 in the SBIIS

2 Samuel 4 in the SBIIS2

2 Samuel 4 in the SBIIS3

2 Samuel 4 in the SBIKS

2 Samuel 4 in the SBIKS2

2 Samuel 4 in the SBIMS

2 Samuel 4 in the SBIOS

2 Samuel 4 in the SBIPS

2 Samuel 4 in the SBISS

2 Samuel 4 in the SBITS

2 Samuel 4 in the SBITS2

2 Samuel 4 in the SBITS3

2 Samuel 4 in the SBITS4

2 Samuel 4 in the SBIUS

2 Samuel 4 in the SBIVS

2 Samuel 4 in the SBT

2 Samuel 4 in the SBT1E

2 Samuel 4 in the SCHL

2 Samuel 4 in the SNT

2 Samuel 4 in the SUSU

2 Samuel 4 in the SUSU2

2 Samuel 4 in the SYNO

2 Samuel 4 in the TBIAOTANT

2 Samuel 4 in the TBT1E

2 Samuel 4 in the TBT1E2

2 Samuel 4 in the TFTIP

2 Samuel 4 in the TFTU

2 Samuel 4 in the TGNTATF3T

2 Samuel 4 in the THAI

2 Samuel 4 in the TNFD

2 Samuel 4 in the TNT

2 Samuel 4 in the TNTIK

2 Samuel 4 in the TNTIL

2 Samuel 4 in the TNTIN

2 Samuel 4 in the TNTIP

2 Samuel 4 in the TNTIZ

2 Samuel 4 in the TOMA

2 Samuel 4 in the TTENT

2 Samuel 4 in the UBG

2 Samuel 4 in the UGV

2 Samuel 4 in the UGV2

2 Samuel 4 in the UGV3

2 Samuel 4 in the VBL

2 Samuel 4 in the VDCC

2 Samuel 4 in the YALU

2 Samuel 4 in the YAPE

2 Samuel 4 in the YBVTP

2 Samuel 4 in the ZBP