Amos 4 (BOYCB)
1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin màlúù Baṣani lórí òkè Samaria,ẹ̀yin obìnrin tí ó ń ni tálákà lára,tí ó ń tẹ aláìní mọ́lẹ̀, tí ó wí fún ọkọ rẹ̀, “Gbé wá kí a sì mu!” 2 OLÚWA Olódùmarè ti fi ìwà mímọ́ rẹ̀ búra:“Àkókò náà yóò dé nítòótọ́nígbà tí a ó fi ìwọ̀ mú un yín lọ,ẹni tí ó kẹ́yìn pẹ̀lú ìwọ̀ ẹja. 3 Ẹni kọ̀ọ̀kan yín yóò jáde lọgba àárín odi yíyaa ó sì lé e yín sí Harmoni,”ni OLÚWA wí. 4 “Ẹ lọ sí Beteli láti dẹ́ṣẹ̀;ẹ lọ sí Gilgali kí ẹ sì dẹ́ṣẹ̀ sí i.Ẹ mú ẹbọ sísun yín láràárọ̀ wá,ìdámẹ́wàá yín ní ọdọọdún mẹ́ta. 5 Kí ẹ mú ọ̀rẹ́ ìdúpẹ́ ìyẹ̀fun ìwúkàrà ti a sunkí ẹ sì mú ọrẹ àtinúwálọ fi wọ́n yangàn, ẹ̀yin ènìyàn Israẹli,nítorí èyí ni ẹ fẹ́ láti ṣe,”ni OLÚWA Olódùmarè wí. 6 “Èmi fún un yín ní mímọ́ eyín ní gbogbo ìlú yín,àti àìní oúnjẹ ní gbogbo ibùgbé yín,síbẹ̀, ẹ̀yin kò yípadà sọ́dọ̀ mi,”ni OLÚWA wí. 7 “Àti pẹ̀lú mo mú òjò dúrónígbà tí ìkórè ku oṣù mẹ́ta.Mo rán òjò sí ibùgbé kanṣùgbọ́n kò rọ̀ sí ìlú mìíràn.Oko kan ní òjò;àwọn mìíràn kò ní ó sì gbẹ. 8 Àwọn ènìyàn ń rìn láti ìlú kan sí ìlú mìíràn fún omiwọn kò rí mu tẹ́ wọn lọ́rùn,síbẹ̀ ẹ̀yin kò padà sí ọ̀dọ̀ mi,”ni OLÚWA wí. 9 “Lọ́pọ̀ ìgbà ni mo kọlu ọgbà àti ọgbà àjàrà yínmo fi ìrẹ̀dànù àti ìmúwòdù lù wọ́n.Eṣú sì jẹ igi ọ̀pọ̀tọ́ àti igi olifi yín,síbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni OLÚWA wí. 10 “Mo rán àjàkálẹ̀-ààrùn sí i yínbí mo ti ṣe sí Ejibiti.Mo fi idà pa àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin yín.Pẹ̀lú àwọn ẹṣin tí a kó ní ìgbèkùn.Mo kún imú yín fún òórùn ibùdó yín,síbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni OLÚWA wí. 11 “Mo ti bì ṣubú nínú yín,bí Ọlọ́run ti bi Sodomu àti Gomorra ṣubúẹ̀yin sì dàbí ògúnná tí a fa yọ kúrò nínú iná,síbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni OLÚWA wí. 12 “Nítorí náà, èyí ni ohun tí èmi yóò ṣe sí i yín, Israẹli,àti nítorí tí èmi ó ṣe èyí sí i yín,ẹ múra láti pàdé Ọlọ́run yín, ẹ̀yin Israẹli.” 13 Ẹni tí ó dá àwọn òkètí ó dá afẹ́fẹ́tí ó sì fi èrò rẹ̀ hàn sí ènìyàn,ẹni tí ó yípadà sí òkùnkùntí ó sì tẹ ibi gíga ayé. OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀.
In Other Versions
Amos 4 in the ANGEFD
Amos 4 in the ANTPNG2D
Amos 4 in the AS21
Amos 4 in the BAGH
Amos 4 in the BBPNG
Amos 4 in the BBT1E
Amos 4 in the BDS
Amos 4 in the BEV
Amos 4 in the BHAD
Amos 4 in the BIB
Amos 4 in the BLPT
Amos 4 in the BNT
Amos 4 in the BNTABOOT
Amos 4 in the BNTLV
Amos 4 in the BOATCB
Amos 4 in the BOATCB2
Amos 4 in the BOBCV
Amos 4 in the BOCNT
Amos 4 in the BOECS
Amos 4 in the BOGWICC
Amos 4 in the BOHCB
Amos 4 in the BOHCV
Amos 4 in the BOHLNT
Amos 4 in the BOHNTLTAL
Amos 4 in the BOICB
Amos 4 in the BOILNTAP
Amos 4 in the BOITCV
Amos 4 in the BOKCV
Amos 4 in the BOKCV2
Amos 4 in the BOKHWOG
Amos 4 in the BOKSSV
Amos 4 in the BOLCB
Amos 4 in the BOLCB2
Amos 4 in the BOMCV
Amos 4 in the BONAV
Amos 4 in the BONCB
Amos 4 in the BONLT
Amos 4 in the BONUT2
Amos 4 in the BOPLNT
Amos 4 in the BOSCB
Amos 4 in the BOSNC
Amos 4 in the BOTLNT
Amos 4 in the BOVCB
Amos 4 in the BPBB
Amos 4 in the BPH
Amos 4 in the BSB
Amos 4 in the CCB
Amos 4 in the CUV
Amos 4 in the CUVS
Amos 4 in the DBT
Amos 4 in the DGDNT
Amos 4 in the DHNT
Amos 4 in the DNT
Amos 4 in the ELBE
Amos 4 in the EMTV
Amos 4 in the ESV
Amos 4 in the FBV
Amos 4 in the FEB
Amos 4 in the GGMNT
Amos 4 in the GNT
Amos 4 in the HARY
Amos 4 in the HNT
Amos 4 in the IRVA
Amos 4 in the IRVB
Amos 4 in the IRVG
Amos 4 in the IRVH
Amos 4 in the IRVK
Amos 4 in the IRVM
Amos 4 in the IRVM2
Amos 4 in the IRVO
Amos 4 in the IRVP
Amos 4 in the IRVT
Amos 4 in the IRVT2
Amos 4 in the IRVU
Amos 4 in the ISVN
Amos 4 in the JSNT
Amos 4 in the KAPI
Amos 4 in the KBT1ETNIK
Amos 4 in the KBV
Amos 4 in the KJV
Amos 4 in the KNFD
Amos 4 in the LBA
Amos 4 in the LBLA
Amos 4 in the LNT
Amos 4 in the LSV
Amos 4 in the MAAL
Amos 4 in the MBV
Amos 4 in the MBV2
Amos 4 in the MHNT
Amos 4 in the MKNFD
Amos 4 in the MNG
Amos 4 in the MNT
Amos 4 in the MNT2
Amos 4 in the MRS1T
Amos 4 in the NAA
Amos 4 in the NASB
Amos 4 in the NBLA
Amos 4 in the NBS
Amos 4 in the NBVTP
Amos 4 in the NET2
Amos 4 in the NIV11
Amos 4 in the NNT
Amos 4 in the NNT2
Amos 4 in the NNT3
Amos 4 in the PDDPT
Amos 4 in the PFNT
Amos 4 in the RMNT
Amos 4 in the SBIAS
Amos 4 in the SBIBS
Amos 4 in the SBIBS2
Amos 4 in the SBICS
Amos 4 in the SBIDS
Amos 4 in the SBIGS
Amos 4 in the SBIHS
Amos 4 in the SBIIS
Amos 4 in the SBIIS2
Amos 4 in the SBIIS3
Amos 4 in the SBIKS
Amos 4 in the SBIKS2
Amos 4 in the SBIMS
Amos 4 in the SBIOS
Amos 4 in the SBIPS
Amos 4 in the SBISS
Amos 4 in the SBITS
Amos 4 in the SBITS2
Amos 4 in the SBITS3
Amos 4 in the SBITS4
Amos 4 in the SBIUS
Amos 4 in the SBIVS
Amos 4 in the SBT
Amos 4 in the SBT1E
Amos 4 in the SCHL
Amos 4 in the SNT
Amos 4 in the SUSU
Amos 4 in the SUSU2
Amos 4 in the SYNO
Amos 4 in the TBIAOTANT
Amos 4 in the TBT1E
Amos 4 in the TBT1E2
Amos 4 in the TFTIP
Amos 4 in the TFTU
Amos 4 in the TGNTATF3T
Amos 4 in the THAI
Amos 4 in the TNFD
Amos 4 in the TNT
Amos 4 in the TNTIK
Amos 4 in the TNTIL
Amos 4 in the TNTIN
Amos 4 in the TNTIP
Amos 4 in the TNTIZ
Amos 4 in the TOMA
Amos 4 in the TTENT
Amos 4 in the UBG
Amos 4 in the UGV
Amos 4 in the UGV2
Amos 4 in the UGV3
Amos 4 in the VBL
Amos 4 in the VDCC
Amos 4 in the YALU
Amos 4 in the YAPE
Amos 4 in the YBVTP
Amos 4 in the ZBP