Amos 6 (BOYCB)
1 Ègbé ni fún ẹ̀yin tí ará rọ̀ ní Sioniàti ẹ̀yin tí ẹ wà ní abẹ́ ààbò ní òkè Samariaàti ẹ̀yin olókìkí orílẹ̀-èdètí ẹ̀yin ènìyàn Israẹli máa ń tọ̀ ọ́ wá. 2 Ẹ lọ Kalne kí ẹ lọ wò ókí ẹ sí tí ibẹ̀ lọ sí Hamati ìlú ńlá a nì.Kí ẹ sì tún sọ̀kalẹ̀ lọ Gati ní ilẹ̀ Filistini.Ǹjẹ́ wọ́n ha dára ju ìpínlẹ̀ yín méjèèjì lọ?Ǹjẹ́ a ha rí ilẹ̀ tó tóbi ju tiyín lọ bí? 3 Ẹ̀yin sún ọjọ́ ibi síwájú,ẹ sì mú ìjọba òǹrorò súnmọ́ tòsí. 4 Ẹ̀yin sùn lé ibùsùn tí a fi eyín erin ṣeẹ sì tẹ́ ara sílẹ̀ ni orí àwọn ibùsùnẹyin pa èyí tí o dára nínú àwọn ọ̀dọ́-àgùntàn yín jẹẹ sì ń pa àwọn ọ̀dọ́ màlúù láàrín agbo wọn jẹ. 5 Ẹ̀yin ń lo ohun èlò orin bí i Dafidiẹ sì ń ṣe àwọn àpilẹ̀rọ àwọn ohun èlò orin. 6 Ẹ̀yin mu wáìnì ẹ̀kún ọpọ́n kanàti ìkunra tí o dára jùlọṣùgbọ́n ẹ̀yin kò káàánú ilé Josẹfu tí ó di ahoro. 7 Nítorí náà, àwọn ni yóò lọ sí ìgbèkùnpẹ̀lú àwọn tí ó ti kó lọ sí ìgbèkùnàsè àwọn tí ń ṣe àṣelékè ni a ó mú kúrò. 8 OLÚWA Olódùmarè ti búra fúnra rẹ̀, OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì ti wí pé:“Mo kórìíra ìgbéraga Jakọbun kò sì ní inú dídùn sí odi alágbára rẹ̀,Èmi yóò sì fa ìlú náà lé wọn lọ́wọ́àti ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀.” 9 Bí ọkùnrin mẹ́wàá bá ṣẹ́kù nínú ilé kan, àwọn náà yóò kú. 10 Bí ẹbí tí ó yẹ kí ó gbé òkú wọn jáde fún sínsin bá wọlé, bí o ba sì béèrè pé ǹjẹ́ ẹnìkan wa tí ó fi ara pamọ́ níbẹ̀, “Ǹjẹ́ ẹnìkankan wà lọ́dọ̀ yín?” tí ó bá sì dáhùn wí pé, “Rárá,” nígbà náà ni yóò wí pé, “Pa ẹnu rẹ mọ́ àwa kò gbọdọ̀ dárúkọ OLÚWA.” 11 Nítorí OLÚWA tí pa àṣẹ náà,Òun yóò sì wó ilé ńlá náà lulẹ̀ túútúú,àti àwọn ilé kéékèèké sí wẹ́wẹ́. 12 Ǹjẹ́ ẹṣin a máa sáré lórí àpáta bí?Ǹjẹ́ ènìyàn a máa fi akọ màlúù kọ ilẹ̀ níbẹ̀?Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ti yí òtítọ́ padà sí májèléẹ sì ti sọ èso òdodo di ìkorò. 13 Ẹ̀yin yọ̀ torí ìṣẹ́gun lórí Lo-Debari,ẹ̀yin sì wí pé, “Ṣé kì í ṣe agbára wa ni àwa fi gba Karnaimu?” 14 Nítorí OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí pé,“Èmi yóò gbé orílẹ̀-èdè kan dìde sí ọ ìwọ Israẹli,wọn yóò pọ́n yín lójú ní gbogbo ọ̀nà,láti Lebo-Hamati, títí dé pẹ̀tẹ́lẹ̀ Arabah.”
In Other Versions
Amos 6 in the ANGEFD
Amos 6 in the ANTPNG2D
Amos 6 in the AS21
Amos 6 in the BAGH
Amos 6 in the BBPNG
Amos 6 in the BBT1E
Amos 6 in the BDS
Amos 6 in the BEV
Amos 6 in the BHAD
Amos 6 in the BIB
Amos 6 in the BLPT
Amos 6 in the BNT
Amos 6 in the BNTABOOT
Amos 6 in the BNTLV
Amos 6 in the BOATCB
Amos 6 in the BOATCB2
Amos 6 in the BOBCV
Amos 6 in the BOCNT
Amos 6 in the BOECS
Amos 6 in the BOGWICC
Amos 6 in the BOHCB
Amos 6 in the BOHCV
Amos 6 in the BOHLNT
Amos 6 in the BOHNTLTAL
Amos 6 in the BOICB
Amos 6 in the BOILNTAP
Amos 6 in the BOITCV
Amos 6 in the BOKCV
Amos 6 in the BOKCV2
Amos 6 in the BOKHWOG
Amos 6 in the BOKSSV
Amos 6 in the BOLCB
Amos 6 in the BOLCB2
Amos 6 in the BOMCV
Amos 6 in the BONAV
Amos 6 in the BONCB
Amos 6 in the BONLT
Amos 6 in the BONUT2
Amos 6 in the BOPLNT
Amos 6 in the BOSCB
Amos 6 in the BOSNC
Amos 6 in the BOTLNT
Amos 6 in the BOVCB
Amos 6 in the BPBB
Amos 6 in the BPH
Amos 6 in the BSB
Amos 6 in the CCB
Amos 6 in the CUV
Amos 6 in the CUVS
Amos 6 in the DBT
Amos 6 in the DGDNT
Amos 6 in the DHNT
Amos 6 in the DNT
Amos 6 in the ELBE
Amos 6 in the EMTV
Amos 6 in the ESV
Amos 6 in the FBV
Amos 6 in the FEB
Amos 6 in the GGMNT
Amos 6 in the GNT
Amos 6 in the HARY
Amos 6 in the HNT
Amos 6 in the IRVA
Amos 6 in the IRVB
Amos 6 in the IRVG
Amos 6 in the IRVH
Amos 6 in the IRVK
Amos 6 in the IRVM
Amos 6 in the IRVM2
Amos 6 in the IRVO
Amos 6 in the IRVP
Amos 6 in the IRVT
Amos 6 in the IRVT2
Amos 6 in the IRVU
Amos 6 in the ISVN
Amos 6 in the JSNT
Amos 6 in the KAPI
Amos 6 in the KBT1ETNIK
Amos 6 in the KBV
Amos 6 in the KJV
Amos 6 in the KNFD
Amos 6 in the LBA
Amos 6 in the LBLA
Amos 6 in the LNT
Amos 6 in the LSV
Amos 6 in the MAAL
Amos 6 in the MBV
Amos 6 in the MBV2
Amos 6 in the MHNT
Amos 6 in the MKNFD
Amos 6 in the MNG
Amos 6 in the MNT
Amos 6 in the MNT2
Amos 6 in the MRS1T
Amos 6 in the NAA
Amos 6 in the NASB
Amos 6 in the NBLA
Amos 6 in the NBS
Amos 6 in the NBVTP
Amos 6 in the NET2
Amos 6 in the NIV11
Amos 6 in the NNT
Amos 6 in the NNT2
Amos 6 in the NNT3
Amos 6 in the PDDPT
Amos 6 in the PFNT
Amos 6 in the RMNT
Amos 6 in the SBIAS
Amos 6 in the SBIBS
Amos 6 in the SBIBS2
Amos 6 in the SBICS
Amos 6 in the SBIDS
Amos 6 in the SBIGS
Amos 6 in the SBIHS
Amos 6 in the SBIIS
Amos 6 in the SBIIS2
Amos 6 in the SBIIS3
Amos 6 in the SBIKS
Amos 6 in the SBIKS2
Amos 6 in the SBIMS
Amos 6 in the SBIOS
Amos 6 in the SBIPS
Amos 6 in the SBISS
Amos 6 in the SBITS
Amos 6 in the SBITS2
Amos 6 in the SBITS3
Amos 6 in the SBITS4
Amos 6 in the SBIUS
Amos 6 in the SBIVS
Amos 6 in the SBT
Amos 6 in the SBT1E
Amos 6 in the SCHL
Amos 6 in the SNT
Amos 6 in the SUSU
Amos 6 in the SUSU2
Amos 6 in the SYNO
Amos 6 in the TBIAOTANT
Amos 6 in the TBT1E
Amos 6 in the TBT1E2
Amos 6 in the TFTIP
Amos 6 in the TFTU
Amos 6 in the TGNTATF3T
Amos 6 in the THAI
Amos 6 in the TNFD
Amos 6 in the TNT
Amos 6 in the TNTIK
Amos 6 in the TNTIL
Amos 6 in the TNTIN
Amos 6 in the TNTIP
Amos 6 in the TNTIZ
Amos 6 in the TOMA
Amos 6 in the TTENT
Amos 6 in the UBG
Amos 6 in the UGV
Amos 6 in the UGV2
Amos 6 in the UGV3
Amos 6 in the VBL
Amos 6 in the VDCC
Amos 6 in the YALU
Amos 6 in the YAPE
Amos 6 in the YBVTP
Amos 6 in the ZBP