Deuteronomy 13 (BOYCB)
1 Bí wòlíì tàbí alásọtẹ́lẹ̀ nípa àlá lílá bá farahàn láàrín yín, tí ó sì ń kéde iṣẹ́ àmì tàbí iṣẹ́ ìyanu, 2 bí iṣẹ́ àmì tàbí iṣẹ́ ìyanu tí ó sọ̀rọ̀ rẹ̀ bá ṣẹ tí òun sì wí pé, “ẹ wá ẹ jẹ́ kí a tẹ̀lé ọlọ́run mìíràn” (àwọn ọlọ́run tí ẹ kò mọ̀ rí) “kí ẹ sì jẹ́ kí a máa sìn wọ́n,” 3 ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ wòlíì tàbí àlá náà, OLÚWA Ọlọ́run yín ń dán an yín wò ni, láti mọ̀ bóyá ẹ fẹ́ràn rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àyà yín àti gbogbo ọkàn an yín. 4 OLÚWA Ọlọ́run yín ni kí ẹ tẹ̀lé, Òun ni kí ẹ bu ọlá fún, ẹ pa òfin rẹ̀ mọ́ kí ẹ sì gbọ́ tirẹ̀, ẹ sìn ín, kí ẹ sì dìímú ṣinṣin. 5 Wòlíì náà tàbí alálàá náà ni kí ẹ pa, nítorí pé wàásù ìṣọ̀tẹ̀ sí OLÚWA Ọlọ́run yín, tí ó mú yín jáde láti Ejibiti wá, tí ó sì rà yín padà lóko ẹrú. Ó ti gbìyànjú láti fà yín kúrò lójú ọ̀nà tí OLÚWA Ọlọ́run yín ti pàṣẹ fún un yín láti máa rìn. Ẹ gbọdọ̀ yọ ibi náà kúrò láàrín yín. 6 Bí arákùnrin tìrẹ gan an ọmọ ìyá rẹ tàbí ọmọ rẹ ọkùnrin tàbí obìnrin, aya tí o fẹ́ràn jù, tàbí ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ bá tàn ọ́ jẹ níkọ̀kọ̀ wí pé, “Jẹ́ kí a lọ sin ọlọ́run mìíràn” (ọlọ́run tí ìwọ tàbí baba rẹ kò mọ̀, 7 ọlọ́run àwọn tí ó wà láyìíká yín, yálà wọ́n jìnnà tàbí wọ́n wà nítòsí, láti òpin ilẹ̀ kan dé òmíràn), 8 má ṣe fetí sí i, má sì dá sí i, má ṣe dáàbò bò ó. 9 Ṣùgbọ́n pípa ni kí o pa á. Ọwọ́ rẹ ni yóò kọ́kọ́ wà lára rẹ̀ láti pa á, lẹ́yìn náà ọwọ́ gbogbo ènìyàn. 10 Sọ ọ́ ní òkúta pa nítorí pé ó gbìyànjú láti fà ọ́ kúrò lẹ́yìn OLÚWA Ọlọ́run rẹ, tí ó mú ọ jáde ti Ejibiti wá kúrò ní oko ẹrú. 11 Gbogbo Israẹli yóò sì gbọ́, ẹ̀rù yóò sì bà wọ́n, kò sì sí ẹnikẹ́ni nínú yín tí yóò dán irú ibi bẹ́ẹ̀ wò mọ́. 12 Bí ẹ̀yin bá gbọ́ tí a sọ nípa èyíkéyìí nínú àwọn ìlú u yín tí OLÚWA Ọlọ́run yín fún un yín láti máa gbé, 13 pé àwọn ènìyàn búburú, ti farahàn láàrín yín, tí ó sì ti mú kí àwọn ènìyàn ìlú wọn ṣìnà lọ, tí wọ́n wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a lọ sin ọlọ́run mìíràn.” (àwọn ọlọ́run tí ẹ kò mọ̀.) 14 Kí ẹ wádìí, ẹ béèrè, kí ẹ sì tọpinpin ọ̀rọ̀ náà dájúṣáká, bí ó bá jẹ́ òtítọ́ ni, tí ó sì hàn dájú pé ìwà ìríra yìí ti ṣẹlẹ̀ láàrín yín. 15 Gbogbo àwọn tí ó ń gbé ìlú náà ni kí ẹ fi idà run pátápátá. Ẹ run ún pátápátá, àti ènìyàn àti ẹran ọ̀sìn inú rẹ̀. 16 Ẹ kó gbogbo ìkógun ìlú náà, sí àárín gbogbo ènìyàn, kí ẹ sun ìlú náà àti gbogbo ìkógun rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun sí OLÚWA Ọlọ́run rẹ. Ó gbọdọ̀ wà ní píparun láéláé, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ tún un kọ. 17 A kò gbọdọ̀ rí ọ̀kan nínú àwọn ohun ìyàsọ́tọ̀ fún ìparun wọ̀n-ọn-nì lọ́wọ́ yín, kí OLÚWA ba à le yípadà kúrò nínú ìbínú gbígbóná rẹ̀, yóò sì ṣàánú fún un yín, yóò sì bá a yín kẹ́dùn, yóò sì mú kí ẹ pọ̀ sí i, bí ó ti fì búra ṣèlérí fún àwọn baba ńlá yín. 18 Nítorí pé ẹ̀yin gbọ́rọ̀ sí OLÚWA Ọlọ́run yín, tí ẹ̀yin sì ń pa òfin rẹ̀ mọ́, tí mo ń fún un yín lónìí yìí, tí ẹ̀yin sì ń ṣe ohun tí ó tọ́ lójú rẹ̀.
In Other Versions
Deuteronomy 13 in the ANGEFD
Deuteronomy 13 in the ANTPNG2D
Deuteronomy 13 in the AS21
Deuteronomy 13 in the BAGH
Deuteronomy 13 in the BBPNG
Deuteronomy 13 in the BBT1E
Deuteronomy 13 in the BDS
Deuteronomy 13 in the BEV
Deuteronomy 13 in the BHAD
Deuteronomy 13 in the BIB
Deuteronomy 13 in the BLPT
Deuteronomy 13 in the BNT
Deuteronomy 13 in the BNTABOOT
Deuteronomy 13 in the BNTLV
Deuteronomy 13 in the BOATCB
Deuteronomy 13 in the BOATCB2
Deuteronomy 13 in the BOBCV
Deuteronomy 13 in the BOCNT
Deuteronomy 13 in the BOECS
Deuteronomy 13 in the BOGWICC
Deuteronomy 13 in the BOHCB
Deuteronomy 13 in the BOHCV
Deuteronomy 13 in the BOHLNT
Deuteronomy 13 in the BOHNTLTAL
Deuteronomy 13 in the BOICB
Deuteronomy 13 in the BOILNTAP
Deuteronomy 13 in the BOITCV
Deuteronomy 13 in the BOKCV
Deuteronomy 13 in the BOKCV2
Deuteronomy 13 in the BOKHWOG
Deuteronomy 13 in the BOKSSV
Deuteronomy 13 in the BOLCB
Deuteronomy 13 in the BOLCB2
Deuteronomy 13 in the BOMCV
Deuteronomy 13 in the BONAV
Deuteronomy 13 in the BONCB
Deuteronomy 13 in the BONLT
Deuteronomy 13 in the BONUT2
Deuteronomy 13 in the BOPLNT
Deuteronomy 13 in the BOSCB
Deuteronomy 13 in the BOSNC
Deuteronomy 13 in the BOTLNT
Deuteronomy 13 in the BOVCB
Deuteronomy 13 in the BPBB
Deuteronomy 13 in the BPH
Deuteronomy 13 in the BSB
Deuteronomy 13 in the CCB
Deuteronomy 13 in the CUV
Deuteronomy 13 in the CUVS
Deuteronomy 13 in the DBT
Deuteronomy 13 in the DGDNT
Deuteronomy 13 in the DHNT
Deuteronomy 13 in the DNT
Deuteronomy 13 in the ELBE
Deuteronomy 13 in the EMTV
Deuteronomy 13 in the ESV
Deuteronomy 13 in the FBV
Deuteronomy 13 in the FEB
Deuteronomy 13 in the GGMNT
Deuteronomy 13 in the GNT
Deuteronomy 13 in the HARY
Deuteronomy 13 in the HNT
Deuteronomy 13 in the IRVA
Deuteronomy 13 in the IRVB
Deuteronomy 13 in the IRVG
Deuteronomy 13 in the IRVH
Deuteronomy 13 in the IRVK
Deuteronomy 13 in the IRVM
Deuteronomy 13 in the IRVM2
Deuteronomy 13 in the IRVO
Deuteronomy 13 in the IRVP
Deuteronomy 13 in the IRVT
Deuteronomy 13 in the IRVT2
Deuteronomy 13 in the IRVU
Deuteronomy 13 in the ISVN
Deuteronomy 13 in the JSNT
Deuteronomy 13 in the KAPI
Deuteronomy 13 in the KBT1ETNIK
Deuteronomy 13 in the KBV
Deuteronomy 13 in the KJV
Deuteronomy 13 in the KNFD
Deuteronomy 13 in the LBA
Deuteronomy 13 in the LBLA
Deuteronomy 13 in the LNT
Deuteronomy 13 in the LSV
Deuteronomy 13 in the MAAL
Deuteronomy 13 in the MBV
Deuteronomy 13 in the MBV2
Deuteronomy 13 in the MHNT
Deuteronomy 13 in the MKNFD
Deuteronomy 13 in the MNG
Deuteronomy 13 in the MNT
Deuteronomy 13 in the MNT2
Deuteronomy 13 in the MRS1T
Deuteronomy 13 in the NAA
Deuteronomy 13 in the NASB
Deuteronomy 13 in the NBLA
Deuteronomy 13 in the NBS
Deuteronomy 13 in the NBVTP
Deuteronomy 13 in the NET2
Deuteronomy 13 in the NIV11
Deuteronomy 13 in the NNT
Deuteronomy 13 in the NNT2
Deuteronomy 13 in the NNT3
Deuteronomy 13 in the PDDPT
Deuteronomy 13 in the PFNT
Deuteronomy 13 in the RMNT
Deuteronomy 13 in the SBIAS
Deuteronomy 13 in the SBIBS
Deuteronomy 13 in the SBIBS2
Deuteronomy 13 in the SBICS
Deuteronomy 13 in the SBIDS
Deuteronomy 13 in the SBIGS
Deuteronomy 13 in the SBIHS
Deuteronomy 13 in the SBIIS
Deuteronomy 13 in the SBIIS2
Deuteronomy 13 in the SBIIS3
Deuteronomy 13 in the SBIKS
Deuteronomy 13 in the SBIKS2
Deuteronomy 13 in the SBIMS
Deuteronomy 13 in the SBIOS
Deuteronomy 13 in the SBIPS
Deuteronomy 13 in the SBISS
Deuteronomy 13 in the SBITS
Deuteronomy 13 in the SBITS2
Deuteronomy 13 in the SBITS3
Deuteronomy 13 in the SBITS4
Deuteronomy 13 in the SBIUS
Deuteronomy 13 in the SBIVS
Deuteronomy 13 in the SBT
Deuteronomy 13 in the SBT1E
Deuteronomy 13 in the SCHL
Deuteronomy 13 in the SNT
Deuteronomy 13 in the SUSU
Deuteronomy 13 in the SUSU2
Deuteronomy 13 in the SYNO
Deuteronomy 13 in the TBIAOTANT
Deuteronomy 13 in the TBT1E
Deuteronomy 13 in the TBT1E2
Deuteronomy 13 in the TFTIP
Deuteronomy 13 in the TFTU
Deuteronomy 13 in the TGNTATF3T
Deuteronomy 13 in the THAI
Deuteronomy 13 in the TNFD
Deuteronomy 13 in the TNT
Deuteronomy 13 in the TNTIK
Deuteronomy 13 in the TNTIL
Deuteronomy 13 in the TNTIN
Deuteronomy 13 in the TNTIP
Deuteronomy 13 in the TNTIZ
Deuteronomy 13 in the TOMA
Deuteronomy 13 in the TTENT
Deuteronomy 13 in the UBG
Deuteronomy 13 in the UGV
Deuteronomy 13 in the UGV2
Deuteronomy 13 in the UGV3
Deuteronomy 13 in the VBL
Deuteronomy 13 in the VDCC
Deuteronomy 13 in the YALU
Deuteronomy 13 in the YAPE
Deuteronomy 13 in the YBVTP
Deuteronomy 13 in the ZBP