Ecclesiastes 3 (BOYCB)
1 Àsìkò wà fún ohun gbogbo,àti ìgbà fún gbogbo nǹkan ní abẹ́ ọ̀run. 2 Ìgbà láti bí àti ìgbà kíkú,ìgbà láti gbìn àti ìgbà láti fàtu. 3 Ìgbà láti pa àti ìgbà láti mú láradáìgbà láti wó lulẹ̀ àti ìgbà láti kọ́. 4 Ìgbà láti sọkún àti ìgbà láti rín ẹ̀rínìgbà láti ṣọ̀fọ̀ àti ìgbà láti jó, 5 ìgbà láti tú òkúta ká àti ìgbà láti ṣà wọ́n jọìgbà láti súnmọ́ àti ìgbà láti fàsẹ́yìn, 6 ìgbà láti wá kiri àti ìgbà láti ṣàì wá kiriìgbà láti pamọ́ àti ìgbà láti jù nù, 7 ìgbà láti ya àti ìgbà láti ránìgbà láti dákẹ́ àti ìgbà láti sọ̀rọ̀, 8 ìgbà láti ní ìfẹ́ àti ìgbà láti kórìíraìgbà fún ogun àti ìgbà fún àlàáfíà. 9 Kí ni òṣìṣẹ́ jẹ ní èrè nínú wàhálà rẹ̀? 10 Mo ti rí àjàgà tí Ọlọ́run gbé lé ọmọ ènìyàn. 11 Ó ti ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀, ó sì ti fi èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn, síbẹ̀, wọn kò le ṣe àwárí ìdí ohun tí Ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin. 12 Mo mọ̀ wí pé kò sí ohun tí ó dára fún ènìyàn ju pé kí inú wọn dùn kí wọn sì ṣe rere níwọ̀n ìgbà tí wọ́n sì wà láààyè. 13 Wí pé: kí olúkúlùkù le è jẹ, kí wọn sì mu, kí wọn sì rí ìtẹ́lọ́rùn nínú gbogbo iṣẹ́ wọn ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí jẹ́. 14 Mo mọ̀ wí pé ohun gbogbo tí Ọlọ́run ṣe ni yóò wà títí láé, kò sí ohun tí a lè fi kún un tàbí kí a yọ kúrò nínú rẹ̀. Ọlọ́run ṣe èyí kí ènìyàn le è ní ìbẹ̀rù rẹ̀ ni. 15 Ohun tí ó wà ti wà tẹ́lẹ̀,ohun tí ó ń bọ̀ wá ti wà tẹ́lẹ̀,Ọlọ́run yóò sì mú kí àwọn ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn tún ṣẹlẹ̀. 16 Mo sì tún rí ohun mìíràn níabẹ́ ọ̀run dípò ìdájọ́,òdodo ni ó wà níbẹ̀ dípò ètò òtítọ́, ẹ̀ṣẹ̀ ni o wà níbẹ̀. 17 Mo wí nínú ọkàn mi,“Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́olódodo àti ènìyàn búburú,nítorí pé àsìkò yóò wà fún gbogbo iṣẹ́,àti àsìkò ṣe ìdájọ́ gbogbo ìṣe.” 18 Mo tún rò pé “Ọlọ́run ń dán wa wò láti fihàn wá wí pé bí ẹranko ni ènìyàn rí. 19 Ó ní láti jẹ́ ohun ìrántí pé ìpín ènìyàn rí bí i tẹranko ìpín kan náà ń dúró dè wọ́n. Bí ọ̀kan ti ń kú náà ni èkejì yóò kú. Àwọn méjèèjì ni irú èémí kan náà, ènìyàn kò sàn ju ẹranko lọ, nítorí pé asán ni yíyè jẹ́ fún wọn. 20 Ibìkan náà ni gbogbo wọn ń lọ, wọ́n wá láti inú erùpẹ̀, inú erùpẹ̀ náà ni wọn yóò tún padà sí. 21 Ta ni ó mọ̀ bóyá ẹ̀mí ènìyàn ń lọ sí òkè tí ẹ̀mí ẹranko sì ń lọ sí ìsàlẹ̀ nínú ilẹ̀ ni?” 22 Nígbà náà, ni mo wá rí i wí pé, kò sí ohun tí ó sàn fún ènìyàn ju kí ó gbádùn iṣẹ́ rẹ̀, nítorí pé ìpín tirẹ̀ ni èyí. Tàbí ta ni ó le è mú kí ó rí ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀ kò sí!
In Other Versions
Ecclesiastes 3 in the ANGEFD
Ecclesiastes 3 in the ANTPNG2D
Ecclesiastes 3 in the AS21
Ecclesiastes 3 in the BAGH
Ecclesiastes 3 in the BBPNG
Ecclesiastes 3 in the BBT1E
Ecclesiastes 3 in the BDS
Ecclesiastes 3 in the BEV
Ecclesiastes 3 in the BHAD
Ecclesiastes 3 in the BIB
Ecclesiastes 3 in the BLPT
Ecclesiastes 3 in the BNT
Ecclesiastes 3 in the BNTABOOT
Ecclesiastes 3 in the BNTLV
Ecclesiastes 3 in the BOATCB
Ecclesiastes 3 in the BOATCB2
Ecclesiastes 3 in the BOBCV
Ecclesiastes 3 in the BOCNT
Ecclesiastes 3 in the BOECS
Ecclesiastes 3 in the BOGWICC
Ecclesiastes 3 in the BOHCB
Ecclesiastes 3 in the BOHCV
Ecclesiastes 3 in the BOHLNT
Ecclesiastes 3 in the BOHNTLTAL
Ecclesiastes 3 in the BOICB
Ecclesiastes 3 in the BOILNTAP
Ecclesiastes 3 in the BOITCV
Ecclesiastes 3 in the BOKCV
Ecclesiastes 3 in the BOKCV2
Ecclesiastes 3 in the BOKHWOG
Ecclesiastes 3 in the BOKSSV
Ecclesiastes 3 in the BOLCB
Ecclesiastes 3 in the BOLCB2
Ecclesiastes 3 in the BOMCV
Ecclesiastes 3 in the BONAV
Ecclesiastes 3 in the BONCB
Ecclesiastes 3 in the BONLT
Ecclesiastes 3 in the BONUT2
Ecclesiastes 3 in the BOPLNT
Ecclesiastes 3 in the BOSCB
Ecclesiastes 3 in the BOSNC
Ecclesiastes 3 in the BOTLNT
Ecclesiastes 3 in the BOVCB
Ecclesiastes 3 in the BPBB
Ecclesiastes 3 in the BPH
Ecclesiastes 3 in the BSB
Ecclesiastes 3 in the CCB
Ecclesiastes 3 in the CUV
Ecclesiastes 3 in the CUVS
Ecclesiastes 3 in the DBT
Ecclesiastes 3 in the DGDNT
Ecclesiastes 3 in the DHNT
Ecclesiastes 3 in the DNT
Ecclesiastes 3 in the ELBE
Ecclesiastes 3 in the EMTV
Ecclesiastes 3 in the ESV
Ecclesiastes 3 in the FBV
Ecclesiastes 3 in the FEB
Ecclesiastes 3 in the GGMNT
Ecclesiastes 3 in the GNT
Ecclesiastes 3 in the HARY
Ecclesiastes 3 in the HNT
Ecclesiastes 3 in the IRVA
Ecclesiastes 3 in the IRVB
Ecclesiastes 3 in the IRVG
Ecclesiastes 3 in the IRVH
Ecclesiastes 3 in the IRVK
Ecclesiastes 3 in the IRVM
Ecclesiastes 3 in the IRVM2
Ecclesiastes 3 in the IRVO
Ecclesiastes 3 in the IRVP
Ecclesiastes 3 in the IRVT
Ecclesiastes 3 in the IRVT2
Ecclesiastes 3 in the IRVU
Ecclesiastes 3 in the ISVN
Ecclesiastes 3 in the JSNT
Ecclesiastes 3 in the KAPI
Ecclesiastes 3 in the KBT1ETNIK
Ecclesiastes 3 in the KBV
Ecclesiastes 3 in the KJV
Ecclesiastes 3 in the KNFD
Ecclesiastes 3 in the LBA
Ecclesiastes 3 in the LBLA
Ecclesiastes 3 in the LNT
Ecclesiastes 3 in the LSV
Ecclesiastes 3 in the MAAL
Ecclesiastes 3 in the MBV
Ecclesiastes 3 in the MBV2
Ecclesiastes 3 in the MHNT
Ecclesiastes 3 in the MKNFD
Ecclesiastes 3 in the MNG
Ecclesiastes 3 in the MNT
Ecclesiastes 3 in the MNT2
Ecclesiastes 3 in the MRS1T
Ecclesiastes 3 in the NAA
Ecclesiastes 3 in the NASB
Ecclesiastes 3 in the NBLA
Ecclesiastes 3 in the NBS
Ecclesiastes 3 in the NBVTP
Ecclesiastes 3 in the NET2
Ecclesiastes 3 in the NIV11
Ecclesiastes 3 in the NNT
Ecclesiastes 3 in the NNT2
Ecclesiastes 3 in the NNT3
Ecclesiastes 3 in the PDDPT
Ecclesiastes 3 in the PFNT
Ecclesiastes 3 in the RMNT
Ecclesiastes 3 in the SBIAS
Ecclesiastes 3 in the SBIBS
Ecclesiastes 3 in the SBIBS2
Ecclesiastes 3 in the SBICS
Ecclesiastes 3 in the SBIDS
Ecclesiastes 3 in the SBIGS
Ecclesiastes 3 in the SBIHS
Ecclesiastes 3 in the SBIIS
Ecclesiastes 3 in the SBIIS2
Ecclesiastes 3 in the SBIIS3
Ecclesiastes 3 in the SBIKS
Ecclesiastes 3 in the SBIKS2
Ecclesiastes 3 in the SBIMS
Ecclesiastes 3 in the SBIOS
Ecclesiastes 3 in the SBIPS
Ecclesiastes 3 in the SBISS
Ecclesiastes 3 in the SBITS
Ecclesiastes 3 in the SBITS2
Ecclesiastes 3 in the SBITS3
Ecclesiastes 3 in the SBITS4
Ecclesiastes 3 in the SBIUS
Ecclesiastes 3 in the SBIVS
Ecclesiastes 3 in the SBT
Ecclesiastes 3 in the SBT1E
Ecclesiastes 3 in the SCHL
Ecclesiastes 3 in the SNT
Ecclesiastes 3 in the SUSU
Ecclesiastes 3 in the SUSU2
Ecclesiastes 3 in the SYNO
Ecclesiastes 3 in the TBIAOTANT
Ecclesiastes 3 in the TBT1E
Ecclesiastes 3 in the TBT1E2
Ecclesiastes 3 in the TFTIP
Ecclesiastes 3 in the TFTU
Ecclesiastes 3 in the TGNTATF3T
Ecclesiastes 3 in the THAI
Ecclesiastes 3 in the TNFD
Ecclesiastes 3 in the TNT
Ecclesiastes 3 in the TNTIK
Ecclesiastes 3 in the TNTIL
Ecclesiastes 3 in the TNTIN
Ecclesiastes 3 in the TNTIP
Ecclesiastes 3 in the TNTIZ
Ecclesiastes 3 in the TOMA
Ecclesiastes 3 in the TTENT
Ecclesiastes 3 in the UBG
Ecclesiastes 3 in the UGV
Ecclesiastes 3 in the UGV2
Ecclesiastes 3 in the UGV3
Ecclesiastes 3 in the VBL
Ecclesiastes 3 in the VDCC
Ecclesiastes 3 in the YALU
Ecclesiastes 3 in the YAPE
Ecclesiastes 3 in the YBVTP
Ecclesiastes 3 in the ZBP