Ephesians 1 (BOYCB)
1 Paulu, aposteli Jesu Kristi nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, Sí àwọn ènìyàn mímọ́ tí ó wà ní Efesu, àti sí àwọn olóòtítọ́ nínú Kristi Jesu: 2 Oore-ọ̀fẹ́ sí yín àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wá àti Jesu Kristi Olúwa. 3 Ògo ni fún Ọlọ́run àti Baba Jesu Kristi Olúwa wa, ẹni tí ó ti bùkún wa láti inú ọ̀run wá pẹ̀lú àwọn ìbùkún ẹ̀mí gbogbo nínú Kristi. 4 Àní, gẹ́gẹ́ bí o ti yàn wá nínú rẹ̀ ṣáájú ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé, láti jẹ́ mímọ́ àti aláìlábùkù níwájú rẹ̀ nínú ìfẹ́ 5 ẹni tí ò ti yàn wá tẹ́lẹ̀ sí ìsọdọmọ nípa Jesu Kristi fún ara rẹ̀, ní ìbámu ìdùnnú ìfẹ́ rẹ̀, 6 fún ìyìn ògo oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀, èyí tí ò ti fi fún wa nínú Àyànfẹ́ rẹ̀. 7 Nínú rẹ̀ ni àwa rí ìràpadà gba nípa ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ àti ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa, ní ìbámu pẹ̀lú ọrọ̀ oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run 8 èyí tí ó fún wa lọ́pọ̀lọ́pọ̀ pẹ̀lú gbogbo ọgbọ́n àti ìmòye, 9 Ó ti sọ ohun ìjìnlẹ̀ ìfẹ́ rẹ̀ di mí mọ̀ fún wa gẹ́gẹ́ bí ìdùnnú rere rẹ̀, èyí ti o pinnu nínú Kristi, 10 èyí tí yóò jẹ jáde ní kíkún àkókò, láti ṣe àkójọpọ̀ àwọn ohun tí ọ̀run àti ti ayé lábẹ́ Kristi. 11 Nínú rẹ̀ ni a yàn wá fẹ́ lẹ́yìn tí ó ti yàn wá tẹ́lẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpinnu ẹni tí ń ṣiṣẹ́ ohun gbogbo ní ìbámu ìfẹ́ rẹ̀, 12 kí àwa kí ó le wà fún ìyìn ògo rẹ̀, àwa tí a ti ni ìrètí ṣáájú nínú Kristi. 13 Àti ẹ̀yin pẹ̀lú darapọ̀ nínú Kristi nígbà tí ẹ̀yin gbọ́ ọ̀rọ̀ òtítọ́ náà àní ìyìnrere ìgbàlà yin. Nígbà tí ẹ̀yin gbàgbọ́, a fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe èdìdì ayé yin nínú rẹ, èyí tí a ti ṣe ìlérí rẹ̀ tẹ́lẹ̀, 14 èyí tí ó jẹ́ ìdánilójú àṣansílẹ̀ ogún wa títí yóò fi di àkókò ìràpadà àwọn tí í ṣe ti Ọlọ́run sí ìyìn ògo rẹ̀. 15 Nítorí ìdí èyí, nígbà tí mo ti gbúròó ìgbàgbọ́ ti ń bẹ láàrín yín nínú Jesu Olúwa, àti ìfẹ́ yín sí gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. 16 Èmi kò sì sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, àti láti máa rántí yín nínú àdúrà mi. 17 Mo sì ń béèrè nígbà gbogbo pé kí Ọlọ́run Jesu Kristi Olúwa wa, Baba ògo, lè fún yín ni Ẹ̀mí nípa ti ọgbọ́n àti ti ìfihàn kí ẹ̀yin kí ó tún lè mọ̀ ọ́n sí i. 18 Mo tún ń gbàdúrà bákan náà wí pé kí ojú ọkàn yín lè mọ́lẹ̀; kí ẹ̀yin lè mọ ohun tí ìrètí ìpè rẹ̀ jẹ́, àti ọrọ̀ ògo rẹ̀ èyí tí í ṣe ogún àwọn ènìyàn mímọ́, 19 àti aláìlẹ́gbẹ́ títóbi agbára rẹ̀ fún àwa tí a gbàgbọ́. Gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ agbára rẹ̀, 20 èyí tí ó fi sínú Kristi, nígbà tí o ti jí dìde kúrò nínú òkú, tí ó sì mú un jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún nínú àwọn ọ̀run. 21 Ó gbéga ju gbogbo ìjọba, àti àṣẹ, àti agbára, àti òye àti gbogbo orúkọ tí a ń dá, kì í ṣe ni ayé yìí nìkan, ṣùgbọ́n ni èyí tí ń bọ̀ pẹ̀lú. 22 Ọlọ́run sì ti fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì fi í ṣe orí lórí ohun gbogbo fún ìjọ, 23 èyí tí i ṣe ara rẹ̀, ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹni tí ó kún ohun gbogbo ní gbogbo ọ̀nà.
In Other Versions
Ephesians 1 in the ANGEFD
Ephesians 1 in the ANTPNG2D
Ephesians 1 in the AS21
Ephesians 1 in the BAGH
Ephesians 1 in the BBPNG
Ephesians 1 in the BBT1E
Ephesians 1 in the BDS
Ephesians 1 in the BEV
Ephesians 1 in the BHAD
Ephesians 1 in the BIB
Ephesians 1 in the BLPT
Ephesians 1 in the BNT
Ephesians 1 in the BNTABOOT
Ephesians 1 in the BNTLV
Ephesians 1 in the BOATCB
Ephesians 1 in the BOATCB2
Ephesians 1 in the BOBCV
Ephesians 1 in the BOCNT
Ephesians 1 in the BOECS
Ephesians 1 in the BOGWICC
Ephesians 1 in the BOHCB
Ephesians 1 in the BOHCV
Ephesians 1 in the BOHLNT
Ephesians 1 in the BOHNTLTAL
Ephesians 1 in the BOICB
Ephesians 1 in the BOILNTAP
Ephesians 1 in the BOITCV
Ephesians 1 in the BOKCV
Ephesians 1 in the BOKCV2
Ephesians 1 in the BOKHWOG
Ephesians 1 in the BOKSSV
Ephesians 1 in the BOLCB
Ephesians 1 in the BOLCB2
Ephesians 1 in the BOMCV
Ephesians 1 in the BONAV
Ephesians 1 in the BONCB
Ephesians 1 in the BONLT
Ephesians 1 in the BONUT2
Ephesians 1 in the BOPLNT
Ephesians 1 in the BOSCB
Ephesians 1 in the BOSNC
Ephesians 1 in the BOTLNT
Ephesians 1 in the BOVCB
Ephesians 1 in the BPBB
Ephesians 1 in the BPH
Ephesians 1 in the BSB
Ephesians 1 in the CCB
Ephesians 1 in the CUV
Ephesians 1 in the CUVS
Ephesians 1 in the DBT
Ephesians 1 in the DGDNT
Ephesians 1 in the DHNT
Ephesians 1 in the DNT
Ephesians 1 in the ELBE
Ephesians 1 in the EMTV
Ephesians 1 in the ESV
Ephesians 1 in the FBV
Ephesians 1 in the FEB
Ephesians 1 in the GGMNT
Ephesians 1 in the GNT
Ephesians 1 in the HARY
Ephesians 1 in the HNT
Ephesians 1 in the IRVA
Ephesians 1 in the IRVB
Ephesians 1 in the IRVG
Ephesians 1 in the IRVH
Ephesians 1 in the IRVK
Ephesians 1 in the IRVM
Ephesians 1 in the IRVM2
Ephesians 1 in the IRVO
Ephesians 1 in the IRVP
Ephesians 1 in the IRVT
Ephesians 1 in the IRVT2
Ephesians 1 in the IRVU
Ephesians 1 in the ISVN
Ephesians 1 in the JSNT
Ephesians 1 in the KAPI
Ephesians 1 in the KBT1ETNIK
Ephesians 1 in the KBV
Ephesians 1 in the KJV
Ephesians 1 in the KNFD
Ephesians 1 in the LBA
Ephesians 1 in the LBLA
Ephesians 1 in the LNT
Ephesians 1 in the LSV
Ephesians 1 in the MAAL
Ephesians 1 in the MBV
Ephesians 1 in the MBV2
Ephesians 1 in the MHNT
Ephesians 1 in the MKNFD
Ephesians 1 in the MNG
Ephesians 1 in the MNT
Ephesians 1 in the MNT2
Ephesians 1 in the MRS1T
Ephesians 1 in the NAA
Ephesians 1 in the NASB
Ephesians 1 in the NBLA
Ephesians 1 in the NBS
Ephesians 1 in the NBVTP
Ephesians 1 in the NET2
Ephesians 1 in the NIV11
Ephesians 1 in the NNT
Ephesians 1 in the NNT2
Ephesians 1 in the NNT3
Ephesians 1 in the PDDPT
Ephesians 1 in the PFNT
Ephesians 1 in the RMNT
Ephesians 1 in the SBIAS
Ephesians 1 in the SBIBS
Ephesians 1 in the SBIBS2
Ephesians 1 in the SBICS
Ephesians 1 in the SBIDS
Ephesians 1 in the SBIGS
Ephesians 1 in the SBIHS
Ephesians 1 in the SBIIS
Ephesians 1 in the SBIIS2
Ephesians 1 in the SBIIS3
Ephesians 1 in the SBIKS
Ephesians 1 in the SBIKS2
Ephesians 1 in the SBIMS
Ephesians 1 in the SBIOS
Ephesians 1 in the SBIPS
Ephesians 1 in the SBISS
Ephesians 1 in the SBITS
Ephesians 1 in the SBITS2
Ephesians 1 in the SBITS3
Ephesians 1 in the SBITS4
Ephesians 1 in the SBIUS
Ephesians 1 in the SBIVS
Ephesians 1 in the SBT
Ephesians 1 in the SBT1E
Ephesians 1 in the SCHL
Ephesians 1 in the SNT
Ephesians 1 in the SUSU
Ephesians 1 in the SUSU2
Ephesians 1 in the SYNO
Ephesians 1 in the TBIAOTANT
Ephesians 1 in the TBT1E
Ephesians 1 in the TBT1E2
Ephesians 1 in the TFTIP
Ephesians 1 in the TFTU
Ephesians 1 in the TGNTATF3T
Ephesians 1 in the THAI
Ephesians 1 in the TNFD
Ephesians 1 in the TNT
Ephesians 1 in the TNTIK
Ephesians 1 in the TNTIL
Ephesians 1 in the TNTIN
Ephesians 1 in the TNTIP
Ephesians 1 in the TNTIZ
Ephesians 1 in the TOMA
Ephesians 1 in the TTENT
Ephesians 1 in the UBG
Ephesians 1 in the UGV
Ephesians 1 in the UGV2
Ephesians 1 in the UGV3
Ephesians 1 in the VBL
Ephesians 1 in the VDCC
Ephesians 1 in the YALU
Ephesians 1 in the YAPE
Ephesians 1 in the YBVTP
Ephesians 1 in the ZBP