Esther 6 (BOYCB)

1 Ní òru ọjọ́ náà ọba kò le è sùn; nítorí náà, ó pàṣẹ kí wọn mú ìwé ìrántí wá, àkọsílẹ̀ ìjọba rẹ̀, wọ́n mú un wá wọ́n sì kà á sí létí. 2 Wọ́n rí àkọsílẹ̀ níbẹ̀ pé Mordekai tí sọ àṣírí Bigitana àti Tereṣi, àwọn ìjòyè ọba méjì tí wọ́n ń ṣọ́ ẹnu-ọ̀nà, tí wọ́n ń gbèrò láti pa ọba Ahaswerusi. 3 Ọba béèrè pé, “Kí ni ọlá àti iyì tí Mordekai ti gbà fún èyí?”Àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì dáhùn pé, “Kò tí ì sí ohun tí a ṣe fún un.” 4 Ọba wí pé, “Ta ni ó wà nínú àgbàlá?” Nísinsin yìí, Hamani ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ àgbàlá ìta ààfin ni láti sọ fún ọba nípa síso Mordekai lórí igi tí ó ti rì fún un. 5 Àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì dáhùn pé, “Hamani ni ó wà níbẹ̀ ó dúró sí inú àgbàlá.”Ọba pàṣẹ pé, “Ẹ mú un wọlé wá.” 6 Nígbà tí Hamani wọlé, ọba béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni kí a ṣe fún ọkùnrin tí inú ọba dùn sí láti bu ọlá fún?”Nísinsin yìí Hamani sì ro èyí fúnra rẹ̀ pé, “Ta ni ó wà níbẹ̀ tí ọba fẹ́ dá lọ́lá ju èmi lọ?” 7 Nítorí náà Hamani dá ọba lóhùn pé, “Fún ọkùnrin tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá, 8 jẹ́ kí wọn kí ó mú aṣọ ọba èyí tí ọba ń wọ̀ àti ẹṣin tí ọba máa ń gùn, pẹ̀lú ọ̀kan lára adé ọba kí a fi dé e ní orí. 9 Jẹ́ kí a fi aṣọ àti ẹṣin lé ọ̀kan lára àwọn ìjòyè ọba tí ó ga jùlọ lọ́wọ́, kí wọn wọ aṣọ náà fún ọkùnrin tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá, kí wọn sì sìn ín gun ẹṣin jákèjádò gbogbo ìgboro ìlú, kí wọn máa kéde níwájú rẹ̀ pé, ‘Èyí ni a ṣe fún ọkùnrin náà ẹni tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá!’ ” 10 Ọba pàṣẹ fún Hamani pé, “Lọ lẹ́sẹ̀kan náà. Mú aṣọ náà àti ẹṣin kí o sì ṣe gẹ́gẹ́ bí o ṣe sọ fún Mordekai ará a Júù, ẹni tí ó jókòó sí ẹnu-ọ̀nà ọba. Má ṣe fi ohunkóhun sílẹ̀ nínú ohun tí o ti yàn.” 11 Bẹ́ẹ̀ ni Hamani ṣe mú aṣọ àti ẹṣin náà. Ó fi wọ Mordekai, Mordekai sì wà lórí ẹṣin jákèjádò gbogbo ìgboro ìlú, ó sì ń kéde níwájú rẹ̀ pé, “Èyí ni a ó ṣe fún ọkùnrin náà ẹni tí inú ọba dùn sí láti dá lọ́lá!” 12 Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí Mordekai padà sí ẹnu-ọ̀nà ọba. Ṣùgbọ́n Hamani sáré lọ ilé, ó sì bo orí rẹ̀ pẹ̀lú ìbànújẹ́, 13 Hamani sì sọ ohun gbogbo tí ó ṣẹlẹ̀ sí i fún Sereṣi ìyàwó rẹ̀ àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀.Àwọn olùbádámọ̀ràn rẹ̀ àti ìyàwó o rẹ̀ sọ fún un pé, “Níwọ́n ìgbà tí Mordekai ti jẹ́ ẹ̀yà Júù, níwájú ẹni tí ìṣubú rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀, ìwọ kò lè rí ẹ̀yìn in rẹ̀—dájúdájú ìwọ yóò parun!” 14 Bí wọ́n ṣe ń bá a sọ̀rọ̀, àwọn ìwẹ̀fà ọba wọlé, wọ́n sì kán Hamani lójú láti lọ sí ibi àsè tí Esteri ti pèsè.

In Other Versions

Esther 6 in the ANGEFD

Esther 6 in the ANTPNG2D

Esther 6 in the AS21

Esther 6 in the BAGH

Esther 6 in the BBPNG

Esther 6 in the BBT1E

Esther 6 in the BDS

Esther 6 in the BEV

Esther 6 in the BHAD

Esther 6 in the BIB

Esther 6 in the BLPT

Esther 6 in the BNT

Esther 6 in the BNTABOOT

Esther 6 in the BNTLV

Esther 6 in the BOATCB

Esther 6 in the BOATCB2

Esther 6 in the BOBCV

Esther 6 in the BOCNT

Esther 6 in the BOECS

Esther 6 in the BOGWICC

Esther 6 in the BOHCB

Esther 6 in the BOHCV

Esther 6 in the BOHLNT

Esther 6 in the BOHNTLTAL

Esther 6 in the BOICB

Esther 6 in the BOILNTAP

Esther 6 in the BOITCV

Esther 6 in the BOKCV

Esther 6 in the BOKCV2

Esther 6 in the BOKHWOG

Esther 6 in the BOKSSV

Esther 6 in the BOLCB

Esther 6 in the BOLCB2

Esther 6 in the BOMCV

Esther 6 in the BONAV

Esther 6 in the BONCB

Esther 6 in the BONLT

Esther 6 in the BONUT2

Esther 6 in the BOPLNT

Esther 6 in the BOSCB

Esther 6 in the BOSNC

Esther 6 in the BOTLNT

Esther 6 in the BOVCB

Esther 6 in the BPBB

Esther 6 in the BPH

Esther 6 in the BSB

Esther 6 in the CCB

Esther 6 in the CUV

Esther 6 in the CUVS

Esther 6 in the DBT

Esther 6 in the DGDNT

Esther 6 in the DHNT

Esther 6 in the DNT

Esther 6 in the ELBE

Esther 6 in the EMTV

Esther 6 in the ESV

Esther 6 in the FBV

Esther 6 in the FEB

Esther 6 in the GGMNT

Esther 6 in the GNT

Esther 6 in the HARY

Esther 6 in the HNT

Esther 6 in the IRVA

Esther 6 in the IRVB

Esther 6 in the IRVG

Esther 6 in the IRVH

Esther 6 in the IRVK

Esther 6 in the IRVM

Esther 6 in the IRVM2

Esther 6 in the IRVO

Esther 6 in the IRVP

Esther 6 in the IRVT

Esther 6 in the IRVT2

Esther 6 in the IRVU

Esther 6 in the ISVN

Esther 6 in the JSNT

Esther 6 in the KAPI

Esther 6 in the KBT1ETNIK

Esther 6 in the KBV

Esther 6 in the KJV

Esther 6 in the KNFD

Esther 6 in the LBA

Esther 6 in the LBLA

Esther 6 in the LNT

Esther 6 in the LSV

Esther 6 in the MAAL

Esther 6 in the MBV

Esther 6 in the MBV2

Esther 6 in the MHNT

Esther 6 in the MKNFD

Esther 6 in the MNG

Esther 6 in the MNT

Esther 6 in the MNT2

Esther 6 in the MRS1T

Esther 6 in the NAA

Esther 6 in the NASB

Esther 6 in the NBLA

Esther 6 in the NBS

Esther 6 in the NBVTP

Esther 6 in the NET2

Esther 6 in the NIV11

Esther 6 in the NNT

Esther 6 in the NNT2

Esther 6 in the NNT3

Esther 6 in the PDDPT

Esther 6 in the PFNT

Esther 6 in the RMNT

Esther 6 in the SBIAS

Esther 6 in the SBIBS

Esther 6 in the SBIBS2

Esther 6 in the SBICS

Esther 6 in the SBIDS

Esther 6 in the SBIGS

Esther 6 in the SBIHS

Esther 6 in the SBIIS

Esther 6 in the SBIIS2

Esther 6 in the SBIIS3

Esther 6 in the SBIKS

Esther 6 in the SBIKS2

Esther 6 in the SBIMS

Esther 6 in the SBIOS

Esther 6 in the SBIPS

Esther 6 in the SBISS

Esther 6 in the SBITS

Esther 6 in the SBITS2

Esther 6 in the SBITS3

Esther 6 in the SBITS4

Esther 6 in the SBIUS

Esther 6 in the SBIVS

Esther 6 in the SBT

Esther 6 in the SBT1E

Esther 6 in the SCHL

Esther 6 in the SNT

Esther 6 in the SUSU

Esther 6 in the SUSU2

Esther 6 in the SYNO

Esther 6 in the TBIAOTANT

Esther 6 in the TBT1E

Esther 6 in the TBT1E2

Esther 6 in the TFTIP

Esther 6 in the TFTU

Esther 6 in the TGNTATF3T

Esther 6 in the THAI

Esther 6 in the TNFD

Esther 6 in the TNT

Esther 6 in the TNTIK

Esther 6 in the TNTIL

Esther 6 in the TNTIN

Esther 6 in the TNTIP

Esther 6 in the TNTIZ

Esther 6 in the TOMA

Esther 6 in the TTENT

Esther 6 in the UBG

Esther 6 in the UGV

Esther 6 in the UGV2

Esther 6 in the UGV3

Esther 6 in the VBL

Esther 6 in the VDCC

Esther 6 in the YALU

Esther 6 in the YAPE

Esther 6 in the YBVTP

Esther 6 in the ZBP