Ezekiel 25 (BOYCB)

1 Ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ̀ mí wá wí pé: 2 “Ọmọ ènìyàn, kọ ojú rẹ sí àwọn ará Ammoni kí ó sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí wọn. 3 Sì wí fún àwọn ará Ammoni pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA Olódùmarè tí ó wí pé. Nítorí tí ìwọ wí pé, “Á hà!” Sí ibi mímọ́ mi nígbà tí ó di àìlọ́wọ̀ àti sí orí ilẹ̀ Israẹli nígbà tí ó di ahoro; àti sí ilẹ̀ Juda, nígbà tí wọ́n lọ sí ìgbèkùn, 4 kíyèsi i, nítorí náà ni èmi yóò fi fi ọ lé àwọn ènìyàn ìlà-oòrùn lọ́wọ́ ni ohun ìní. Wọn yóò sì gbé ààfin wọn kalẹ̀ nínú rẹ, wọn yóò sì gbé ibùgbé wọn nínú rẹ, wọn yóò jẹ èso rẹ, wọn yóò sì mu wàrà rẹ. 5 Èmi yóò sì sọ Rabba di ibùjẹ, fún àwọn ìbákasẹ àti àwọn ọmọ Ammoni di ibùsùn fún agbo ẹran. Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé, Èmi ni OLÚWA. 6 Nítorí báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí. Nítorí pé ìwọ pàtẹ́wọ́, ìwọ sì jan ẹsẹ̀ mọ́lẹ̀, tí ìwọ ń yọ̀ pẹ̀lú gbogbo àrankàn rẹ sí ilẹ̀ Israẹli 7 nítorí náà, èmi yóò na ọwọ́ mi lé ọ, èmi yóò sì fi ọ fún àwọn aláìkọlà fún ìkógun. Èmi yóò sì gé ọ kúrò láàrín àwọn ènìyàn, èmi yóò sì jẹ́ kí o parun kúrò ni ilẹ̀ gbogbo. Èmi yóò sì pa ọ́ run, ìwọ yóò sì mọ̀ pé èmi ni OLÚWA.’ ” 8 “Báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí: ‘Nítorí pé Moabu àti Seiri sọ wí pé, “Wò ó, ilé Juda ti dàbí gbogbo àwọn kèfèrí,” 9 nítorí náà, Èmi yóò ṣí Moabu sílẹ̀ láti àwọn ìlú gbogbo tí ó wà ní ààlà rẹ̀, ògo ilẹ̀ náà, Beti-Jeṣimoti, Baali-Meoni àti Kiriataimu. 10 Èmi yóò fi Moabu pẹ̀lú àwọn ará Ammoni lé àwọn ènìyàn ìlà-oòrùn ní ìní, kí a má bà á lè rántí àwọn ará Ammoni láàrín orílẹ̀-èdè gbogbo. 11 Èmi yóò sì mú ìdájọ́ sẹ sí Moabu lára, wọn yóò sì mọ̀ pé èmi ni OLÚWA.’ ” 12 “Báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí pé: ‘Nítorí pé Edomu gbẹ̀san lára ilé Juda, ó sì jẹ̀bi gidigidi nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀, 13 nítorí náà báyìí ní OLÚWA Olódùmarè wí pé: Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Edomu èmi yóò sì pa àwọn ènìyàn àti àwọn ẹranko rẹ̀. Èmi yóò fi ṣófo láti Temani dé Dedani yóò ti ipa idà ṣubú. 14 Èmi yóò gbẹ̀san lára Edomu láti ọwọ́ àwọn ènìyàn mi Israẹli, wọn sì ṣe sí Edomu gẹ́gẹ́ bí ìbínú àti ìrunú mi, wọn yóò mọ̀ ìgbẹ̀san mi ní OLÚWA Olódùmarè wí.’ ” 15 “Báyìí ni OLÚWA Olódùmarè wí pé: ‘Nítorí tí àwọn ará Filistini hùwà ẹ̀san tí wọ́n sì gbẹ̀san pẹ̀lú odì ní ọkàn wọn, àti pẹ̀lú ìkórìíra gbangba àtijọ́ ní wíwá ọ̀nà láti pa Juda run, 16 nítorí náà báyìí ní OLÚWA Olódùmarè wí pé, “Èmi ti ṣetán láti na ọwọ́ mi jáde sí àwọn ará Filistini, èmi yóò sì ké àwọn ará Kereti kúrò, èmi yóò sì pa àwọn tí ó kù ní etí kún run. 17 Èmi yóò sì gbẹ̀san ńlá lára wọn nípa ìbáwí gbígbóná; wọn yóò sì mọ̀ wí pé, Èmi ni OLÚWA. Nígbà tí èmi yóò gba ẹ̀san lára wọn.” ’ ”

In Other Versions

Ezekiel 25 in the ANGEFD

Ezekiel 25 in the ANTPNG2D

Ezekiel 25 in the AS21

Ezekiel 25 in the BAGH

Ezekiel 25 in the BBPNG

Ezekiel 25 in the BBT1E

Ezekiel 25 in the BDS

Ezekiel 25 in the BEV

Ezekiel 25 in the BHAD

Ezekiel 25 in the BIB

Ezekiel 25 in the BLPT

Ezekiel 25 in the BNT

Ezekiel 25 in the BNTABOOT

Ezekiel 25 in the BNTLV

Ezekiel 25 in the BOATCB

Ezekiel 25 in the BOATCB2

Ezekiel 25 in the BOBCV

Ezekiel 25 in the BOCNT

Ezekiel 25 in the BOECS

Ezekiel 25 in the BOGWICC

Ezekiel 25 in the BOHCB

Ezekiel 25 in the BOHCV

Ezekiel 25 in the BOHLNT

Ezekiel 25 in the BOHNTLTAL

Ezekiel 25 in the BOICB

Ezekiel 25 in the BOILNTAP

Ezekiel 25 in the BOITCV

Ezekiel 25 in the BOKCV

Ezekiel 25 in the BOKCV2

Ezekiel 25 in the BOKHWOG

Ezekiel 25 in the BOKSSV

Ezekiel 25 in the BOLCB

Ezekiel 25 in the BOLCB2

Ezekiel 25 in the BOMCV

Ezekiel 25 in the BONAV

Ezekiel 25 in the BONCB

Ezekiel 25 in the BONLT

Ezekiel 25 in the BONUT2

Ezekiel 25 in the BOPLNT

Ezekiel 25 in the BOSCB

Ezekiel 25 in the BOSNC

Ezekiel 25 in the BOTLNT

Ezekiel 25 in the BOVCB

Ezekiel 25 in the BPBB

Ezekiel 25 in the BPH

Ezekiel 25 in the BSB

Ezekiel 25 in the CCB

Ezekiel 25 in the CUV

Ezekiel 25 in the CUVS

Ezekiel 25 in the DBT

Ezekiel 25 in the DGDNT

Ezekiel 25 in the DHNT

Ezekiel 25 in the DNT

Ezekiel 25 in the ELBE

Ezekiel 25 in the EMTV

Ezekiel 25 in the ESV

Ezekiel 25 in the FBV

Ezekiel 25 in the FEB

Ezekiel 25 in the GGMNT

Ezekiel 25 in the GNT

Ezekiel 25 in the HARY

Ezekiel 25 in the HNT

Ezekiel 25 in the IRVA

Ezekiel 25 in the IRVB

Ezekiel 25 in the IRVG

Ezekiel 25 in the IRVH

Ezekiel 25 in the IRVK

Ezekiel 25 in the IRVM

Ezekiel 25 in the IRVM2

Ezekiel 25 in the IRVO

Ezekiel 25 in the IRVP

Ezekiel 25 in the IRVT

Ezekiel 25 in the IRVT2

Ezekiel 25 in the IRVU

Ezekiel 25 in the ISVN

Ezekiel 25 in the JSNT

Ezekiel 25 in the KAPI

Ezekiel 25 in the KBT1ETNIK

Ezekiel 25 in the KBV

Ezekiel 25 in the KJV

Ezekiel 25 in the KNFD

Ezekiel 25 in the LBA

Ezekiel 25 in the LBLA

Ezekiel 25 in the LNT

Ezekiel 25 in the LSV

Ezekiel 25 in the MAAL

Ezekiel 25 in the MBV

Ezekiel 25 in the MBV2

Ezekiel 25 in the MHNT

Ezekiel 25 in the MKNFD

Ezekiel 25 in the MNG

Ezekiel 25 in the MNT

Ezekiel 25 in the MNT2

Ezekiel 25 in the MRS1T

Ezekiel 25 in the NAA

Ezekiel 25 in the NASB

Ezekiel 25 in the NBLA

Ezekiel 25 in the NBS

Ezekiel 25 in the NBVTP

Ezekiel 25 in the NET2

Ezekiel 25 in the NIV11

Ezekiel 25 in the NNT

Ezekiel 25 in the NNT2

Ezekiel 25 in the NNT3

Ezekiel 25 in the PDDPT

Ezekiel 25 in the PFNT

Ezekiel 25 in the RMNT

Ezekiel 25 in the SBIAS

Ezekiel 25 in the SBIBS

Ezekiel 25 in the SBIBS2

Ezekiel 25 in the SBICS

Ezekiel 25 in the SBIDS

Ezekiel 25 in the SBIGS

Ezekiel 25 in the SBIHS

Ezekiel 25 in the SBIIS

Ezekiel 25 in the SBIIS2

Ezekiel 25 in the SBIIS3

Ezekiel 25 in the SBIKS

Ezekiel 25 in the SBIKS2

Ezekiel 25 in the SBIMS

Ezekiel 25 in the SBIOS

Ezekiel 25 in the SBIPS

Ezekiel 25 in the SBISS

Ezekiel 25 in the SBITS

Ezekiel 25 in the SBITS2

Ezekiel 25 in the SBITS3

Ezekiel 25 in the SBITS4

Ezekiel 25 in the SBIUS

Ezekiel 25 in the SBIVS

Ezekiel 25 in the SBT

Ezekiel 25 in the SBT1E

Ezekiel 25 in the SCHL

Ezekiel 25 in the SNT

Ezekiel 25 in the SUSU

Ezekiel 25 in the SUSU2

Ezekiel 25 in the SYNO

Ezekiel 25 in the TBIAOTANT

Ezekiel 25 in the TBT1E

Ezekiel 25 in the TBT1E2

Ezekiel 25 in the TFTIP

Ezekiel 25 in the TFTU

Ezekiel 25 in the TGNTATF3T

Ezekiel 25 in the THAI

Ezekiel 25 in the TNFD

Ezekiel 25 in the TNT

Ezekiel 25 in the TNTIK

Ezekiel 25 in the TNTIL

Ezekiel 25 in the TNTIN

Ezekiel 25 in the TNTIP

Ezekiel 25 in the TNTIZ

Ezekiel 25 in the TOMA

Ezekiel 25 in the TTENT

Ezekiel 25 in the UBG

Ezekiel 25 in the UGV

Ezekiel 25 in the UGV2

Ezekiel 25 in the UGV3

Ezekiel 25 in the VBL

Ezekiel 25 in the VDCC

Ezekiel 25 in the YALU

Ezekiel 25 in the YAPE

Ezekiel 25 in the YBVTP

Ezekiel 25 in the ZBP