Genesis 6 (BOYCB)
1 Nígbà tí ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí ní pọ̀ si ní orí ilẹ̀, wọ́n sí bí àwọn ọmọbìnrin. 2 Àwọn ọmọ Ọlọ́run rí i wí pé àwọn ọmọbìnrin ènìyàn lẹ́wà, wọ́n sì fẹ́ èyíkéyìí tí ó wù wọ́n ṣe aya. 3 Nígbà náà ni OLÚWA wí pé, “Èémí ìyè tí mo mí sínú ènìyàn kò ní máa gbé inú ènìyàn títí láé, nítorí ẹran-ara sá à ni òun, ọgọ́fà ọdún ni ọjọ́ rẹ̀ yóò jẹ́.” 4 Àwọn òmíràn wà láyé ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àti lẹ́yìn ìgbà náà; nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run lọ bá àwọn ọmọbìnrin ènìyàn lòpọ̀ tí wọ́n sì bímọ fún wọn. Àwọn náà ni ó di akọni àti olókìkí ìgbà náà. 5 OLÚWA sì rí bí ìwà búburú ènìyàn ti ń gbilẹ̀ si, àti pé gbogbo èrò inú rẹ̀ kìkì ibi ni, ní ìgbà gbogbo. 6 Inú OLÚWA sì bàjẹ́ gidigidi nítorí pé ó dá ènìyàn sí ayé, ọkàn rẹ̀ sì gbọgbẹ́. 7 Nítorí náà, OLÚWA wí pé, “Èmi yóò pa ènìyàn tí mo ti dá run kúrò lórí ilẹ̀, ènìyàn àti ẹranko, àti ohun tí ń rákò, àti ẹyẹ ojú ọ̀run, nítorí inú mi bàjẹ́ pé mo ti dá wọn.” 8 Ṣùgbọ́n, Noa rí ojúrere OLÚWA. 9 Wọ̀nyí ni ìtàn Noa. Noa nìkan ni ó jẹ́ olóòótọ́ ènìyàn àti ẹni tí ó pé ní ìgbà ayé rẹ̀, ó sì fi òtítọ́ bá Ọlọ́run rìn. 10 Noa sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta, Ṣemu, Hamu àti Jafeti. 11 Ayé sì kún fún ìbàjẹ́ gidigidi ní ojú Ọlọ́run, ó sì kún fún ìwà ipá pẹ̀lú. 12 Ọlọ́run sì rí bí ayé ti bàjẹ́ tó, nítorí àwọn ènìyàn inú ayé ti bá ara wọn jẹ́ ní gbogbo ọ̀nà wọn. 13 Ọlọ́run sì wí fún Noa pé, “Èmi yóò pa gbogbo ènìyàn run, nítorí ilẹ̀ ayé kún fún ìwà ipá nípasẹ̀ wọn. Èmi yóò pa wọ́n run àti ayé pẹ̀lú. 14 Nítorí náà fi igi ọ̀mọ̀ kan ọkọ̀, kí o sì yọ yàrá sí inú rẹ̀, kí o sì fi ọ̀dà ilẹ̀ rẹ́ ẹ tinú-tẹ̀yìn. 15 Báyìí ni ìwọ yóò ṣe kan ọkọ̀ náà: Gígùn rẹ̀ ní òró yóò jẹ́ ọ̀ọ́dúnrún (300) ìgbọ̀nwọ́, ìbú rẹ̀ yóò jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́, nígbà tí gíga rẹ̀ yóò jẹ́ ọgbọ̀n ìgbọ̀nwọ́. 16 Ṣe òrùlé sí orí ọkọ̀ náà ní ìgbọ̀nwọ́ kan, sì ṣe ọkọ̀ náà ní alájà mẹ́ta, ipá kan ní ìsàlẹ̀, ọ̀kan ní àárín àti ọ̀kan tí ó kù ní òkè, ẹ̀gbẹ́ ni kí ó ṣe ẹnu-ọ̀nà ọkọ̀ náà sí. 17 Èmi yóò mú ìkún omi wá sí ayé láti pa gbogbo ohun ẹlẹ́mìí run lábẹ́ ọ̀run. Gbogbo ẹ̀dá tí ó ní èémí ìyè ní inú. Gbogbo ohun tí ó wà nínú ayé yóò parun. 18 Ṣùgbọ́n èmi ó dá májẹ̀mú mi pẹ̀lú rẹ, ìwọ yóò sì wọ ọkọ̀, ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ pẹ̀lú aya rẹ. 19 Ìwọ yóò mú gbogbo ohun alààyè takọ tabo wá sí inú ọkọ̀, kí wọn le wà láààyè pẹ̀lú rẹ. 20 Mú onírúurú àwọn ẹyẹ, ẹranko àti àwọn ohun tí ń rákò ní méjì méjì, kí a bá lè pa wọ́n mọ́ láààyè. 21 Mú onírúurú oúnjẹ wá sínú ọkọ̀, kí o pa wọ́n mọ́ fún jíjẹ gbogbo ẹ̀yin tí ẹ wà nínú ọkọ̀ àti ènìyàn àti ẹranko.” 22 Noa sì ṣe ohun gbogbo bí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún un.
In Other Versions
Genesis 6 in the ANGEFD
Genesis 6 in the ANTPNG2D
Genesis 6 in the AS21
Genesis 6 in the BAGH
Genesis 6 in the BBPNG
Genesis 6 in the BBT1E
Genesis 6 in the BDS
Genesis 6 in the BEV
Genesis 6 in the BHAD
Genesis 6 in the BIB
Genesis 6 in the BLPT
Genesis 6 in the BNT
Genesis 6 in the BNTABOOT
Genesis 6 in the BNTLV
Genesis 6 in the BOATCB
Genesis 6 in the BOATCB2
Genesis 6 in the BOBCV
Genesis 6 in the BOCNT
Genesis 6 in the BOECS
Genesis 6 in the BOGWICC
Genesis 6 in the BOHCB
Genesis 6 in the BOHCV
Genesis 6 in the BOHLNT
Genesis 6 in the BOHNTLTAL
Genesis 6 in the BOICB
Genesis 6 in the BOILNTAP
Genesis 6 in the BOITCV
Genesis 6 in the BOKCV
Genesis 6 in the BOKCV2
Genesis 6 in the BOKHWOG
Genesis 6 in the BOKSSV
Genesis 6 in the BOLCB
Genesis 6 in the BOLCB2
Genesis 6 in the BOMCV
Genesis 6 in the BONAV
Genesis 6 in the BONCB
Genesis 6 in the BONLT
Genesis 6 in the BONUT2
Genesis 6 in the BOPLNT
Genesis 6 in the BOSCB
Genesis 6 in the BOSNC
Genesis 6 in the BOTLNT
Genesis 6 in the BOVCB
Genesis 6 in the BPBB
Genesis 6 in the BPH
Genesis 6 in the BSB
Genesis 6 in the CCB
Genesis 6 in the CUV
Genesis 6 in the CUVS
Genesis 6 in the DBT
Genesis 6 in the DGDNT
Genesis 6 in the DHNT
Genesis 6 in the DNT
Genesis 6 in the ELBE
Genesis 6 in the EMTV
Genesis 6 in the ESV
Genesis 6 in the FBV
Genesis 6 in the FEB
Genesis 6 in the GGMNT
Genesis 6 in the GNT
Genesis 6 in the HARY
Genesis 6 in the HNT
Genesis 6 in the IRVA
Genesis 6 in the IRVB
Genesis 6 in the IRVG
Genesis 6 in the IRVH
Genesis 6 in the IRVK
Genesis 6 in the IRVM
Genesis 6 in the IRVM2
Genesis 6 in the IRVO
Genesis 6 in the IRVP
Genesis 6 in the IRVT
Genesis 6 in the IRVT2
Genesis 6 in the IRVU
Genesis 6 in the ISVN
Genesis 6 in the JSNT
Genesis 6 in the KAPI
Genesis 6 in the KBT1ETNIK
Genesis 6 in the KBV
Genesis 6 in the KJV
Genesis 6 in the KNFD
Genesis 6 in the LBA
Genesis 6 in the LBLA
Genesis 6 in the LNT
Genesis 6 in the LSV
Genesis 6 in the MAAL
Genesis 6 in the MBV
Genesis 6 in the MBV2
Genesis 6 in the MHNT
Genesis 6 in the MKNFD
Genesis 6 in the MNG
Genesis 6 in the MNT
Genesis 6 in the MNT2
Genesis 6 in the MRS1T
Genesis 6 in the NAA
Genesis 6 in the NASB
Genesis 6 in the NBLA
Genesis 6 in the NBS
Genesis 6 in the NBVTP
Genesis 6 in the NET2
Genesis 6 in the NIV11
Genesis 6 in the NNT
Genesis 6 in the NNT2
Genesis 6 in the NNT3
Genesis 6 in the PDDPT
Genesis 6 in the PFNT
Genesis 6 in the RMNT
Genesis 6 in the SBIAS
Genesis 6 in the SBIBS
Genesis 6 in the SBIBS2
Genesis 6 in the SBICS
Genesis 6 in the SBIDS
Genesis 6 in the SBIGS
Genesis 6 in the SBIHS
Genesis 6 in the SBIIS
Genesis 6 in the SBIIS2
Genesis 6 in the SBIIS3
Genesis 6 in the SBIKS
Genesis 6 in the SBIKS2
Genesis 6 in the SBIMS
Genesis 6 in the SBIOS
Genesis 6 in the SBIPS
Genesis 6 in the SBISS
Genesis 6 in the SBITS
Genesis 6 in the SBITS2
Genesis 6 in the SBITS3
Genesis 6 in the SBITS4
Genesis 6 in the SBIUS
Genesis 6 in the SBIVS
Genesis 6 in the SBT
Genesis 6 in the SBT1E
Genesis 6 in the SCHL
Genesis 6 in the SNT
Genesis 6 in the SUSU
Genesis 6 in the SUSU2
Genesis 6 in the SYNO
Genesis 6 in the TBIAOTANT
Genesis 6 in the TBT1E
Genesis 6 in the TBT1E2
Genesis 6 in the TFTIP
Genesis 6 in the TFTU
Genesis 6 in the TGNTATF3T
Genesis 6 in the THAI
Genesis 6 in the TNFD
Genesis 6 in the TNT
Genesis 6 in the TNTIK
Genesis 6 in the TNTIL
Genesis 6 in the TNTIN
Genesis 6 in the TNTIP
Genesis 6 in the TNTIZ
Genesis 6 in the TOMA
Genesis 6 in the TTENT
Genesis 6 in the UBG
Genesis 6 in the UGV
Genesis 6 in the UGV2
Genesis 6 in the UGV3
Genesis 6 in the VBL
Genesis 6 in the VDCC
Genesis 6 in the YALU
Genesis 6 in the YAPE
Genesis 6 in the YBVTP
Genesis 6 in the ZBP