Hosea 9 (BOYCB)
1 Má ṣe yọ̀, ìwọ Israẹli;má ṣe hó ìhó ayọ̀ bí àwọn orílẹ̀-èdè yòókù.Nítorí ẹ ti jẹ́ aláìṣòótọ́ si Ọlọ́run yín.Ẹ fẹ́ràn láti gba owó iṣẹ́ àgbèrèní gbogbo ilẹ̀ ìpakà. 2 Àwọn ilẹ̀ ìpakà àti ilé ìfun wáìnì kò ní fún àwọn ènìyàn lóúnjẹwáìnì tuntun yóò tàn láìròtẹ́lẹ̀. 3 Wọn kò ní ṣẹ́kù sí ilé OLÚWAEfraimu yóò padà sí Ejibiti,yóò sì jẹ oúnjẹ àìmọ́ ní Asiria. 4 Wọn kò ní fi ọrẹ ohun mímu fún OLÚWA.Bẹ́ẹ̀ ni ìrúbọ wọn kò ní mú, inú rẹ̀ dùn.Ìrú ẹbọ bẹ́ẹ̀ yóò dàbí oúnjẹ àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀.Gbogbo àwọn tó bá sì jẹ ẹ́ yóò di aláìmọ́.Oúnjẹ yìí yóò wà fún wọn fúnra wọnkò ní wá sí orí tẹmpili OLÚWA. 5 Kí ni ẹ̀yin ó ṣe ní ọjọ́ àjọ̀dún tí a yànní àwọn ọjọ́ àjọ̀dún OLÚWA? 6 Bí wọ́n tilẹ̀ yọ́ kúrò lọ́wọ́ ìparunEjibiti yóò kó wọn jọ,Memfisi yóò sì sin wọ́n.Ibi ìsọjọ̀ fàdákà wọn ni ẹ̀gún yóò jogún,Ẹ̀gún yóò bo àpótí ìṣúra fàdákà wọn.Ẹ̀gún yóò sì bogbogbo àgọ́ wọn. 7 Àwọn ọjọ́ ìjìyà ń bọ̀;àwọn ọjọ́ ìṣirò iṣẹ́ ti dé.Jẹ́ kí Israẹli mọ èyí.Nítorí pé ẹ̀ṣẹ̀ yín pọ̀ìkórìíra yín sì pọ̀ gan an ni.A ka àwọn wòlíì sí òmùgọ̀,a ka ẹni ìmísí sí asínwín. 8 Wòlíì, papọ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run,ni olùṣọ́ ọ Efraimu.Síbẹ̀ ìdẹ̀kùn dúró dè é ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀àti ìkórìíra ní ilé Ọlọ́run rẹ̀. 9 Wọ́n ti gbilẹ̀ nínú ìwà ìbàjẹ́gẹ́gẹ́ bí i ọjọ́ GibeahỌlọ́run yóò rántí ìwà búburú wọnyóò sì jẹ wọ́n ní yà fún ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 10 “Mo rí Israẹli bí èso àjàrà ní aginjù.Mo rí àwọn baba yín,bí àkọ́pọ́n nínú igi ọ̀pọ̀tọ́ ní àkọ́so rẹ̀.Ṣùgbọ́n wọ́n tọ Baali-Peori lọ,wọ́n yà wọn sọ́tọ̀ fún òrìṣà tó ń mú ìtìjú bá ni,ohun ìríra wọn sì rí gẹ́gẹ́ bí wọn ti fẹ́. 11 Ògo Efraimu yóò fò lọ bí ẹyẹkò ní sí ìfẹ́rakù, ìlóyún àti ìbímọ. 12 Bí wọ́n tilẹ̀ tọ́ ọmọ dàgbà.Èmi yóò mú wọn ṣọ̀fọ̀ lórí gbogbo wọn.Ègbé ni fún wọn,nígbà tí mo yípadà kúrò lọ́dọ̀ wọn! 13 Mo rí Efraimu bí ìlú Tiretí a tẹ̀dó sí ibi dáradáraṣùgbọ́n Efraimu yóò kó àwọnọmọ rẹ̀ jáde fún àwọn apànìyàn.” 14 Fún wọn, OLÚWA!Kí ni ìwọ yóò fún wọn?Fún wọn ní inú tí ń ba oyún jẹ́àti ọyàn gbígbẹ. 15 “Nítorí gbogbo ìwà búburú tí wọ́n hù ní Gilgali,Mo kórìíra wọn níbẹ̀,nítorí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.Èmi yóò lé wọn jáde ní ilé mi,Èmi kò ní ní ìfẹ́ wọn mọ́ọlọ̀tẹ̀ ni gbogbo olórí wọn. 16 Efraimu ti rẹ̀ dànùgbogbo rẹ̀ sì ti rọ,kò sì so èso.Bí wọ́n tilẹ̀ bímọ.Èmi ó pa àwọn ọmọ wọn tí wọ́n fẹ́ràn jùlọ.” 17 Ọlọ́run mi yóò kọ̀ wọ́n sílẹ̀nítorí pé wọn kò gbọ́rọ̀ sí i;wọn yóò sì di alárìnkiri láàrín àwọn orílẹ̀-èdè.
In Other Versions
Hosea 9 in the ANGEFD
Hosea 9 in the ANTPNG2D
Hosea 9 in the AS21
Hosea 9 in the BAGH
Hosea 9 in the BBPNG
Hosea 9 in the BBT1E
Hosea 9 in the BDS
Hosea 9 in the BEV
Hosea 9 in the BHAD
Hosea 9 in the BIB
Hosea 9 in the BLPT
Hosea 9 in the BNT
Hosea 9 in the BNTABOOT
Hosea 9 in the BNTLV
Hosea 9 in the BOATCB
Hosea 9 in the BOATCB2
Hosea 9 in the BOBCV
Hosea 9 in the BOCNT
Hosea 9 in the BOECS
Hosea 9 in the BOGWICC
Hosea 9 in the BOHCB
Hosea 9 in the BOHCV
Hosea 9 in the BOHLNT
Hosea 9 in the BOHNTLTAL
Hosea 9 in the BOICB
Hosea 9 in the BOILNTAP
Hosea 9 in the BOITCV
Hosea 9 in the BOKCV
Hosea 9 in the BOKCV2
Hosea 9 in the BOKHWOG
Hosea 9 in the BOKSSV
Hosea 9 in the BOLCB
Hosea 9 in the BOLCB2
Hosea 9 in the BOMCV
Hosea 9 in the BONAV
Hosea 9 in the BONCB
Hosea 9 in the BONLT
Hosea 9 in the BONUT2
Hosea 9 in the BOPLNT
Hosea 9 in the BOSCB
Hosea 9 in the BOSNC
Hosea 9 in the BOTLNT
Hosea 9 in the BOVCB
Hosea 9 in the BPBB
Hosea 9 in the BPH
Hosea 9 in the BSB
Hosea 9 in the CCB
Hosea 9 in the CUV
Hosea 9 in the CUVS
Hosea 9 in the DBT
Hosea 9 in the DGDNT
Hosea 9 in the DHNT
Hosea 9 in the DNT
Hosea 9 in the ELBE
Hosea 9 in the EMTV
Hosea 9 in the ESV
Hosea 9 in the FBV
Hosea 9 in the FEB
Hosea 9 in the GGMNT
Hosea 9 in the GNT
Hosea 9 in the HARY
Hosea 9 in the HNT
Hosea 9 in the IRVA
Hosea 9 in the IRVB
Hosea 9 in the IRVG
Hosea 9 in the IRVH
Hosea 9 in the IRVK
Hosea 9 in the IRVM
Hosea 9 in the IRVM2
Hosea 9 in the IRVO
Hosea 9 in the IRVP
Hosea 9 in the IRVT
Hosea 9 in the IRVT2
Hosea 9 in the IRVU
Hosea 9 in the ISVN
Hosea 9 in the JSNT
Hosea 9 in the KAPI
Hosea 9 in the KBT1ETNIK
Hosea 9 in the KBV
Hosea 9 in the KJV
Hosea 9 in the KNFD
Hosea 9 in the LBA
Hosea 9 in the LBLA
Hosea 9 in the LNT
Hosea 9 in the LSV
Hosea 9 in the MAAL
Hosea 9 in the MBV
Hosea 9 in the MBV2
Hosea 9 in the MHNT
Hosea 9 in the MKNFD
Hosea 9 in the MNG
Hosea 9 in the MNT
Hosea 9 in the MNT2
Hosea 9 in the MRS1T
Hosea 9 in the NAA
Hosea 9 in the NASB
Hosea 9 in the NBLA
Hosea 9 in the NBS
Hosea 9 in the NBVTP
Hosea 9 in the NET2
Hosea 9 in the NIV11
Hosea 9 in the NNT
Hosea 9 in the NNT2
Hosea 9 in the NNT3
Hosea 9 in the PDDPT
Hosea 9 in the PFNT
Hosea 9 in the RMNT
Hosea 9 in the SBIAS
Hosea 9 in the SBIBS
Hosea 9 in the SBIBS2
Hosea 9 in the SBICS
Hosea 9 in the SBIDS
Hosea 9 in the SBIGS
Hosea 9 in the SBIHS
Hosea 9 in the SBIIS
Hosea 9 in the SBIIS2
Hosea 9 in the SBIIS3
Hosea 9 in the SBIKS
Hosea 9 in the SBIKS2
Hosea 9 in the SBIMS
Hosea 9 in the SBIOS
Hosea 9 in the SBIPS
Hosea 9 in the SBISS
Hosea 9 in the SBITS
Hosea 9 in the SBITS2
Hosea 9 in the SBITS3
Hosea 9 in the SBITS4
Hosea 9 in the SBIUS
Hosea 9 in the SBIVS
Hosea 9 in the SBT
Hosea 9 in the SBT1E
Hosea 9 in the SCHL
Hosea 9 in the SNT
Hosea 9 in the SUSU
Hosea 9 in the SUSU2
Hosea 9 in the SYNO
Hosea 9 in the TBIAOTANT
Hosea 9 in the TBT1E
Hosea 9 in the TBT1E2
Hosea 9 in the TFTIP
Hosea 9 in the TFTU
Hosea 9 in the TGNTATF3T
Hosea 9 in the THAI
Hosea 9 in the TNFD
Hosea 9 in the TNT
Hosea 9 in the TNTIK
Hosea 9 in the TNTIL
Hosea 9 in the TNTIN
Hosea 9 in the TNTIP
Hosea 9 in the TNTIZ
Hosea 9 in the TOMA
Hosea 9 in the TTENT
Hosea 9 in the UBG
Hosea 9 in the UGV
Hosea 9 in the UGV2
Hosea 9 in the UGV3
Hosea 9 in the VBL
Hosea 9 in the VDCC
Hosea 9 in the YALU
Hosea 9 in the YAPE
Hosea 9 in the YBVTP
Hosea 9 in the ZBP