Isaiah 17 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Damasku:“Kíyèsi i, Damasku kò ní jẹ́ ìlú mọ́ṣùgbọ́n yóò padà di ààtàn. 2 Àwọn ìlú Aroeri ni a ó kọ̀sílẹ̀fún àwọn agbo ẹran tí yóò máa sùn síbẹ̀,láìsí ẹni tí yóò dẹ́rùbà wọ́n. 3 Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Efraimu,àti agbára ọba kúrò ní Damasku;àwọn àṣẹ́kù Aramu yóò dágẹ́gẹ́ bí ògo ti àwọn Israẹli,”ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí. 4 “Ní ọjọ́ náà ni ògo Jakọbu yóò sá;ọ̀rá ara rẹ̀ yóò ṣòfò dànù. 5 Yóò sì dàbí ìgbà tí olùkórè kó àwọnirúgbìn tí ó dúró jọtí ó sì ń kórè irúgbìn pẹ̀lú apá rẹ̀—àti gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí ènìyàn pa ọkà ní àfonífojì ti Refaimu. 6 Síbẹ̀síbẹ̀ irúgbìn díẹ̀ yóò ṣẹ́kù,gẹ́gẹ́ bí ìgbà tí a gbọn igi olifi,tí èso olifi méjì tàbí mẹ́ta ṣẹ́kùsórí ẹ̀ka tí ó ga jùlọ,mẹ́rin tàbí márùn-ún lórí ẹ̀ka tí ó so jù,”ni OLÚWA wí, àní Ọlọ́run Israẹli. 7 Ní ọjọ́ náà, àwọn ènìyàn yóò gbójú sókè sí Ẹlẹ́dàá wọn,wọn yóò sì síjú wo Ẹni Mímọ́ Israẹli. 8 Wọn kò ní wo àwọn pẹpẹ mọ́,èyí tí í ṣe iṣẹ́ ọwọ́ wọn,wọn kò sì ní kọbi ara sí ère Aṣerah mọ́tàbí pẹpẹ tùràrí tí ìka ọwọ́ wọn ti ṣe. 9 Ní ọjọ́ náà àwọn ìlú alágbára rẹ̀, yóò dàbí ẹ̀ka ìkọ̀sílẹ̀, àti ẹ̀ka téńté òkè tí wọ́n fi sílẹ̀ nítorí àwọn ọmọ Israẹli. Gbogbo wọn yóò sì di ahoro. 10 Nítorí ìwọ ti gbàgbé Ọlọ́run ìgbàlà rẹ;tí ìwọ kò sì náání àpáta ìgbàlà rẹ̀,nítorí náà ni ìwọ ti gbin ọ̀gbìn dáradáraìwọ sì tọ́ àjèjì ẹ̀ka sínú rẹ̀. 11 Nítorí náà, bí ẹ tilẹ̀ mú àṣàyàn igi tí ẹ sì gbin àjàrà tí ó ti òkèrè wá,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọjọ́ tí ẹ kó wọn jáde ẹ mú wọn hù jáde,àti ní òwúrọ̀ tí ẹ gbìn wọ́nẹ mú kí wọ́n rúdí,síbẹ̀síbẹ̀ ìkórè kò ní mú nǹkan wání ọjọ́ ààrùn àti ìrora tí kò gbóògùn. 12 Kíyèsi i, ìrunú àwọn orílẹ̀-èdè—wọ́n ń runú bí ìgbì Òkun!Kíyèsi i, rògbòdìyàn tí ogunlọ́gọ̀ ènìyànwọ́n bú ramúramù gẹ́gẹ́ bí ariwo odò ńlá! 13 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ènìyàn ń búramúramù gẹ́gẹ́ bí ìrúmi odò,nígbà tí ó bá wọn wí wọ́n sálọ jìnnà réré,a tì wọ́n lọ gẹ́gẹ́ bí ìyàngbò ní orí òkè,àti gẹ́gẹ́ bí ewéko níwájú ìjì líle. 14 Ní aginjù, ìpayà òjijì!Kí ó tó di òwúrọ̀, a ò rí wọn mọ́!Èyí ni ìpín àwọn tí ó jí wa lẹ́rù,àti ìpín àwọn tí ó fi ogun kó wa.
In Other Versions
Isaiah 17 in the ANGEFD
Isaiah 17 in the ANTPNG2D
Isaiah 17 in the AS21
Isaiah 17 in the BAGH
Isaiah 17 in the BBPNG
Isaiah 17 in the BBT1E
Isaiah 17 in the BDS
Isaiah 17 in the BEV
Isaiah 17 in the BHAD
Isaiah 17 in the BIB
Isaiah 17 in the BLPT
Isaiah 17 in the BNT
Isaiah 17 in the BNTABOOT
Isaiah 17 in the BNTLV
Isaiah 17 in the BOATCB
Isaiah 17 in the BOATCB2
Isaiah 17 in the BOBCV
Isaiah 17 in the BOCNT
Isaiah 17 in the BOECS
Isaiah 17 in the BOGWICC
Isaiah 17 in the BOHCB
Isaiah 17 in the BOHCV
Isaiah 17 in the BOHLNT
Isaiah 17 in the BOHNTLTAL
Isaiah 17 in the BOICB
Isaiah 17 in the BOILNTAP
Isaiah 17 in the BOITCV
Isaiah 17 in the BOKCV
Isaiah 17 in the BOKCV2
Isaiah 17 in the BOKHWOG
Isaiah 17 in the BOKSSV
Isaiah 17 in the BOLCB
Isaiah 17 in the BOLCB2
Isaiah 17 in the BOMCV
Isaiah 17 in the BONAV
Isaiah 17 in the BONCB
Isaiah 17 in the BONLT
Isaiah 17 in the BONUT2
Isaiah 17 in the BOPLNT
Isaiah 17 in the BOSCB
Isaiah 17 in the BOSNC
Isaiah 17 in the BOTLNT
Isaiah 17 in the BOVCB
Isaiah 17 in the BPBB
Isaiah 17 in the BPH
Isaiah 17 in the BSB
Isaiah 17 in the CCB
Isaiah 17 in the CUV
Isaiah 17 in the CUVS
Isaiah 17 in the DBT
Isaiah 17 in the DGDNT
Isaiah 17 in the DHNT
Isaiah 17 in the DNT
Isaiah 17 in the ELBE
Isaiah 17 in the EMTV
Isaiah 17 in the ESV
Isaiah 17 in the FBV
Isaiah 17 in the FEB
Isaiah 17 in the GGMNT
Isaiah 17 in the GNT
Isaiah 17 in the HARY
Isaiah 17 in the HNT
Isaiah 17 in the IRVA
Isaiah 17 in the IRVB
Isaiah 17 in the IRVG
Isaiah 17 in the IRVH
Isaiah 17 in the IRVK
Isaiah 17 in the IRVM
Isaiah 17 in the IRVM2
Isaiah 17 in the IRVO
Isaiah 17 in the IRVP
Isaiah 17 in the IRVT
Isaiah 17 in the IRVT2
Isaiah 17 in the IRVU
Isaiah 17 in the ISVN
Isaiah 17 in the JSNT
Isaiah 17 in the KAPI
Isaiah 17 in the KBT1ETNIK
Isaiah 17 in the KBV
Isaiah 17 in the KJV
Isaiah 17 in the KNFD
Isaiah 17 in the LBA
Isaiah 17 in the LBLA
Isaiah 17 in the LNT
Isaiah 17 in the LSV
Isaiah 17 in the MAAL
Isaiah 17 in the MBV
Isaiah 17 in the MBV2
Isaiah 17 in the MHNT
Isaiah 17 in the MKNFD
Isaiah 17 in the MNG
Isaiah 17 in the MNT
Isaiah 17 in the MNT2
Isaiah 17 in the MRS1T
Isaiah 17 in the NAA
Isaiah 17 in the NASB
Isaiah 17 in the NBLA
Isaiah 17 in the NBS
Isaiah 17 in the NBVTP
Isaiah 17 in the NET2
Isaiah 17 in the NIV11
Isaiah 17 in the NNT
Isaiah 17 in the NNT2
Isaiah 17 in the NNT3
Isaiah 17 in the PDDPT
Isaiah 17 in the PFNT
Isaiah 17 in the RMNT
Isaiah 17 in the SBIAS
Isaiah 17 in the SBIBS
Isaiah 17 in the SBIBS2
Isaiah 17 in the SBICS
Isaiah 17 in the SBIDS
Isaiah 17 in the SBIGS
Isaiah 17 in the SBIHS
Isaiah 17 in the SBIIS
Isaiah 17 in the SBIIS2
Isaiah 17 in the SBIIS3
Isaiah 17 in the SBIKS
Isaiah 17 in the SBIKS2
Isaiah 17 in the SBIMS
Isaiah 17 in the SBIOS
Isaiah 17 in the SBIPS
Isaiah 17 in the SBISS
Isaiah 17 in the SBITS
Isaiah 17 in the SBITS2
Isaiah 17 in the SBITS3
Isaiah 17 in the SBITS4
Isaiah 17 in the SBIUS
Isaiah 17 in the SBIVS
Isaiah 17 in the SBT
Isaiah 17 in the SBT1E
Isaiah 17 in the SCHL
Isaiah 17 in the SNT
Isaiah 17 in the SUSU
Isaiah 17 in the SUSU2
Isaiah 17 in the SYNO
Isaiah 17 in the TBIAOTANT
Isaiah 17 in the TBT1E
Isaiah 17 in the TBT1E2
Isaiah 17 in the TFTIP
Isaiah 17 in the TFTU
Isaiah 17 in the TGNTATF3T
Isaiah 17 in the THAI
Isaiah 17 in the TNFD
Isaiah 17 in the TNT
Isaiah 17 in the TNTIK
Isaiah 17 in the TNTIL
Isaiah 17 in the TNTIN
Isaiah 17 in the TNTIP
Isaiah 17 in the TNTIZ
Isaiah 17 in the TOMA
Isaiah 17 in the TTENT
Isaiah 17 in the UBG
Isaiah 17 in the UGV
Isaiah 17 in the UGV2
Isaiah 17 in the UGV3
Isaiah 17 in the VBL
Isaiah 17 in the VDCC
Isaiah 17 in the YALU
Isaiah 17 in the YAPE
Isaiah 17 in the YBVTP
Isaiah 17 in the ZBP