Isaiah 27 (BOYCB)

1 Ní ọjọ́ náà, OLÚWA yóò fi idà rẹ̀ jẹ ni ní yàidà rẹ̀ a mú bí iná tí ó tóbi tí ó sì lágbáraLefitani ejò tí ń yọ̀ tẹ̀ẹ̀rẹ̀ n nì,Lefitani ejò tí ń lọ́ bìrìkìtì;Òun yóò sì pa ẹ̀mí búburú inú Òkun náà. 2 Ní ọjọ́ náà,“Kọrin nípa ọgbà àjàrà eléso kan. 3 Èmi OLÚWA ń bojútó o,Èmi ó bomirin ín láti ìgbàdégbà.Èmi ó ṣọ́ ọ tọ̀sán tòrukí ẹnikẹ́ni má ba à pa á lára. 4 Inú kò bí mi.Bí ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n bá dojú ìjà kọ mí!Èmi yóò dìde sí wọn ní ogun,Èmi yóò sì dáná sun gbogbo wọn. 5 Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jẹ́ kí wọn wá sọ́dọ̀ mi fún ààbò;jẹ́ kí wọ́n wá àlàáfíà pẹ̀lú mi,bẹ́ẹ̀ ni, jẹ́ kí wọn wá àlàáfíà pẹ̀lú mi.” 6 Ní ọjọ́ iwájú Jakọbu yóò ta gbòǹgbò,Israẹli yóò tanná yóò sì rudièso rẹ̀ yóò sì kún gbogbo ayé. 7 Ǹjẹ́ OLÚWA ti lù úgẹ́gẹ́ bí ó ti lu àwọn tí ó lù ú bolẹ̀?Ǹjẹ́ a ti pa ágẹ́gẹ́ bí a ti pa àwọn tí ó pa á? 8 Nípa ogun jíjà àti ìjìyà ti o le ni ófi dojúkọ ọ́pẹ̀lú ìjì gbígbóná ni ó lé e jáde,gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn fẹ́. 9 Nítorí èyí báyìí ni ètùtù yóò ṣe wàfún ẹ̀ṣẹ̀ Jakọbu,èyí ni yóò sì jẹ́ èso kíkún tiìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.Nígbà tí ó bá mú kí àwọn òkúta pẹpẹdàbí òkúta ẹfun tí a fọ́ sí wẹ́wẹ́,kì yóò sí ère Aṣerah tàbí pẹpẹ tùràrítí yóò wà ní ìdúró. 10 Ìlú olódi náà ti dahoro,ibùdó ìkọ̀sílẹ̀, tí a kọ̀ tìgẹ́gẹ́ bí aginjù;níbẹ̀ ni àwọn ọmọ màlúù ti ń jẹ okoníbẹ̀ ni wọn ń sùn sílẹ̀;wọn sì jẹ gbogbo ẹ̀ka rẹ̀ tán. 11 Nígbà tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ bá rọ, a ó ya wọn dànùàwọn obìnrin dé, wọ́n sì fi wọ́n dánánítorí aláìlóye ènìyàn ni wọn jẹ́,nítorí náà ni ẹni tí ó dá wọn kì yóò ṣàánú fún wọn;bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí ó mọ wọn kì yóò sì fi ojúrere wò wọ́n. 12 Ní ọjọ́ náà OLÚWA yóò sì kó oore láti ìṣàn omi odo Eufurate wá títí dé Wadi ti Ejibiti, àti ìwọ, ìwọ ọmọ Israẹli, ni a ó kójọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan. 13 Àti ní ọjọ́ náà, a ó fun fèrè ńlá kan. Gbogbo àwọn tí ń ṣègbé lọ ní Asiria àti àwọn tí ń ṣe àtìpó ní Ejibiti yóò wá sin OLÚWA ní òkè mímọ́ ní Jerusalẹmu.

In Other Versions

Isaiah 27 in the ANGEFD

Isaiah 27 in the ANTPNG2D

Isaiah 27 in the AS21

Isaiah 27 in the BAGH

Isaiah 27 in the BBPNG

Isaiah 27 in the BBT1E

Isaiah 27 in the BDS

Isaiah 27 in the BEV

Isaiah 27 in the BHAD

Isaiah 27 in the BIB

Isaiah 27 in the BLPT

Isaiah 27 in the BNT

Isaiah 27 in the BNTABOOT

Isaiah 27 in the BNTLV

Isaiah 27 in the BOATCB

Isaiah 27 in the BOATCB2

Isaiah 27 in the BOBCV

Isaiah 27 in the BOCNT

Isaiah 27 in the BOECS

Isaiah 27 in the BOGWICC

Isaiah 27 in the BOHCB

Isaiah 27 in the BOHCV

Isaiah 27 in the BOHLNT

Isaiah 27 in the BOHNTLTAL

Isaiah 27 in the BOICB

Isaiah 27 in the BOILNTAP

Isaiah 27 in the BOITCV

Isaiah 27 in the BOKCV

Isaiah 27 in the BOKCV2

Isaiah 27 in the BOKHWOG

Isaiah 27 in the BOKSSV

Isaiah 27 in the BOLCB

Isaiah 27 in the BOLCB2

Isaiah 27 in the BOMCV

Isaiah 27 in the BONAV

Isaiah 27 in the BONCB

Isaiah 27 in the BONLT

Isaiah 27 in the BONUT2

Isaiah 27 in the BOPLNT

Isaiah 27 in the BOSCB

Isaiah 27 in the BOSNC

Isaiah 27 in the BOTLNT

Isaiah 27 in the BOVCB

Isaiah 27 in the BPBB

Isaiah 27 in the BPH

Isaiah 27 in the BSB

Isaiah 27 in the CCB

Isaiah 27 in the CUV

Isaiah 27 in the CUVS

Isaiah 27 in the DBT

Isaiah 27 in the DGDNT

Isaiah 27 in the DHNT

Isaiah 27 in the DNT

Isaiah 27 in the ELBE

Isaiah 27 in the EMTV

Isaiah 27 in the ESV

Isaiah 27 in the FBV

Isaiah 27 in the FEB

Isaiah 27 in the GGMNT

Isaiah 27 in the GNT

Isaiah 27 in the HARY

Isaiah 27 in the HNT

Isaiah 27 in the IRVA

Isaiah 27 in the IRVB

Isaiah 27 in the IRVG

Isaiah 27 in the IRVH

Isaiah 27 in the IRVK

Isaiah 27 in the IRVM

Isaiah 27 in the IRVM2

Isaiah 27 in the IRVO

Isaiah 27 in the IRVP

Isaiah 27 in the IRVT

Isaiah 27 in the IRVT2

Isaiah 27 in the IRVU

Isaiah 27 in the ISVN

Isaiah 27 in the JSNT

Isaiah 27 in the KAPI

Isaiah 27 in the KBT1ETNIK

Isaiah 27 in the KBV

Isaiah 27 in the KJV

Isaiah 27 in the KNFD

Isaiah 27 in the LBA

Isaiah 27 in the LBLA

Isaiah 27 in the LNT

Isaiah 27 in the LSV

Isaiah 27 in the MAAL

Isaiah 27 in the MBV

Isaiah 27 in the MBV2

Isaiah 27 in the MHNT

Isaiah 27 in the MKNFD

Isaiah 27 in the MNG

Isaiah 27 in the MNT

Isaiah 27 in the MNT2

Isaiah 27 in the MRS1T

Isaiah 27 in the NAA

Isaiah 27 in the NASB

Isaiah 27 in the NBLA

Isaiah 27 in the NBS

Isaiah 27 in the NBVTP

Isaiah 27 in the NET2

Isaiah 27 in the NIV11

Isaiah 27 in the NNT

Isaiah 27 in the NNT2

Isaiah 27 in the NNT3

Isaiah 27 in the PDDPT

Isaiah 27 in the PFNT

Isaiah 27 in the RMNT

Isaiah 27 in the SBIAS

Isaiah 27 in the SBIBS

Isaiah 27 in the SBIBS2

Isaiah 27 in the SBICS

Isaiah 27 in the SBIDS

Isaiah 27 in the SBIGS

Isaiah 27 in the SBIHS

Isaiah 27 in the SBIIS

Isaiah 27 in the SBIIS2

Isaiah 27 in the SBIIS3

Isaiah 27 in the SBIKS

Isaiah 27 in the SBIKS2

Isaiah 27 in the SBIMS

Isaiah 27 in the SBIOS

Isaiah 27 in the SBIPS

Isaiah 27 in the SBISS

Isaiah 27 in the SBITS

Isaiah 27 in the SBITS2

Isaiah 27 in the SBITS3

Isaiah 27 in the SBITS4

Isaiah 27 in the SBIUS

Isaiah 27 in the SBIVS

Isaiah 27 in the SBT

Isaiah 27 in the SBT1E

Isaiah 27 in the SCHL

Isaiah 27 in the SNT

Isaiah 27 in the SUSU

Isaiah 27 in the SUSU2

Isaiah 27 in the SYNO

Isaiah 27 in the TBIAOTANT

Isaiah 27 in the TBT1E

Isaiah 27 in the TBT1E2

Isaiah 27 in the TFTIP

Isaiah 27 in the TFTU

Isaiah 27 in the TGNTATF3T

Isaiah 27 in the THAI

Isaiah 27 in the TNFD

Isaiah 27 in the TNT

Isaiah 27 in the TNTIK

Isaiah 27 in the TNTIL

Isaiah 27 in the TNTIN

Isaiah 27 in the TNTIP

Isaiah 27 in the TNTIZ

Isaiah 27 in the TOMA

Isaiah 27 in the TTENT

Isaiah 27 in the UBG

Isaiah 27 in the UGV

Isaiah 27 in the UGV2

Isaiah 27 in the UGV3

Isaiah 27 in the VBL

Isaiah 27 in the VDCC

Isaiah 27 in the YALU

Isaiah 27 in the YAPE

Isaiah 27 in the YBVTP

Isaiah 27 in the ZBP