Isaiah 34 (BOYCB)
1 Súnmọ́ tòsí,ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti gbọ́,tẹ́tí sílẹ̀ ẹ̀yin ènìyànjẹ́ kí ayé gbọ́,àti ẹ̀kún rẹ̀,ayé àti ohun gbogbo tí ó ti inú rẹ̀ jáde. 2 Nítorí ìbínú OLÚWA ń bẹlára gbogbo orílẹ̀-èdè,àti ìrunú rẹ̀ lórí gbogbo ogun wọn:o ti fi wọ́n fún pípa. 3 Àwọn ti a pa nínú wọnni a ó sì jù sóde,òórùn wọn yóò ti inú òkú wọn jáde,àwọn òkè ńlá yóò sì yọ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ wọn. 4 Gbogbo àwọn ogun ọ̀run ni yóò di yíyọ́,a ó sì ká àwọn ọ̀run jọ bí i tákàdá,gbogbo ogun wọn yóò si ṣubú lulẹ̀,bí ewé ti n bọ́ kúrò lára àjàrà,àti bí i bíbọ́ èso lára igi ọ̀pọ̀tọ́. 5 Nítorí ti a rẹ idà mi ní ọ̀run,kíyèsi í, yóò sọ̀kalẹ̀ wá sórí Edomu,sórí àwọn ènìyàn tí mo ti parun fún ìdájọ́. 6 Idà OLÚWA kún fún ẹ̀jẹ̀a mú un sanra fún ọ̀rá,àti fún ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-àgùntàn àti ewúrẹ́,fún ọ̀rá ìwé àgbò—nítorí OLÚWA ni ìrúbọ kan ní Bosra,àti ìpakúpa ńlá kan ní ilẹ̀ Edomu. 7 Àti àwọn àgbáǹréré yóòba wọn sọ̀kalẹ̀ wá,àti àwọn ẹgbọrọ màlúùpẹ̀lú àwọn akọ màlúù,ilé wọn ni a ó fi ẹ̀jẹ̀ rin,a ó sì fi ọ̀rá sọ ekuru wọn di ọlọ́ràá. 8 Nítorí ọjọ́ ẹ̀san OLÚWA ni,àti ọdún ìsanpadà,nítorí ọ̀ràn Sioni. 9 Odò rẹ̀ ni a ó sì sọ di ọ̀dà,àti eruku rẹ̀ di imí-ọjọ́,ilẹ̀ rẹ̀ yóò sì di ọ̀dà tí ń jóná. 10 A kì yóò pa á ní òru tàbí ní ọ̀sán;èéfín rẹ̀ yóò gòkè láéláé:yóò dahoro láti ìran dé ìran,kò sí ẹnìkan tí yóò là á kọjá láé àti láéláé. 11 Òwìwí aginjù, àti àkàlà ni yóò ni ín,àti òwìwí àti ẹyẹ ìwò ni yóò máa gbé inú rẹ̀.Ọlọ́run yóò sì na sórí Edomuokùn ìwọ̀n ìparunàti òkúta òfo. 12 Ní ti àwọn ìjòyè rẹ̀ẹnìkan kì yóò sí níbẹ̀tiwọn ó pè wá sí ìjọba,gbogbo àwọn olórí i rẹ̀ yóò sì di asán. 13 Ẹ̀gún yóò sì hù jádenínú àwọn ààfin rẹ̀ wọ̀nyí,ẹ̀gún ọ̀gán nínú ìlú olódi rẹ̀.Yóò jẹ́ ibùgbé àwọn akátáàti àgbàlá fún àwọn òwìwí. 14 Àwọn ẹranko ijù àti àwọn ìkookò ni yóò pàdé,àti ewúrẹ́ igbó kan yóò máa kọ sí èkejì rẹ̀,iwin yóò máa gbé ibẹ̀ pẹ̀lú,yóò sì rí ibi ìsinmi fún ara rẹ̀. 15 Òwìwí yóò tẹ́ ìtẹ́ rẹ̀ síbẹ̀,yóò yé, yóò sì pa,yóò sì kójọ lábẹ́ òjìji rẹ̀:àwọn gúnnugún yóò péjọ síbẹ̀ pẹ̀lú,olúkúlùkù pẹ̀lú ẹnìkejì rẹ̀. 16 Ẹ wo ìwé OLÚWA, kí ẹ sì kà.Ọ̀kan nínú ìwọ̀nyí kì yóò yẹ̀,kò sí ọ̀kan tí yóò fẹ́ èkejì rẹ̀ kù:nítorí OLÚWA ti pàṣẹẹnu rẹ̀ ló sì fi kó wọn jọẸ̀mí rẹ̀ ló sì fi tò wọ́n jọ. 17 Ó ti di ìbò fún wọn,ọwọ́ rẹ̀ sì ti pín in fún wọnnípa títa okùn,wọn ó jogún rẹ̀ láéláé,láti ìran dé ìranni wọn ó máa gbé inú rẹ̀.
In Other Versions
Isaiah 34 in the ANGEFD
Isaiah 34 in the ANTPNG2D
Isaiah 34 in the AS21
Isaiah 34 in the BAGH
Isaiah 34 in the BBPNG
Isaiah 34 in the BBT1E
Isaiah 34 in the BDS
Isaiah 34 in the BEV
Isaiah 34 in the BHAD
Isaiah 34 in the BIB
Isaiah 34 in the BLPT
Isaiah 34 in the BNT
Isaiah 34 in the BNTABOOT
Isaiah 34 in the BNTLV
Isaiah 34 in the BOATCB
Isaiah 34 in the BOATCB2
Isaiah 34 in the BOBCV
Isaiah 34 in the BOCNT
Isaiah 34 in the BOECS
Isaiah 34 in the BOGWICC
Isaiah 34 in the BOHCB
Isaiah 34 in the BOHCV
Isaiah 34 in the BOHLNT
Isaiah 34 in the BOHNTLTAL
Isaiah 34 in the BOICB
Isaiah 34 in the BOILNTAP
Isaiah 34 in the BOITCV
Isaiah 34 in the BOKCV
Isaiah 34 in the BOKCV2
Isaiah 34 in the BOKHWOG
Isaiah 34 in the BOKSSV
Isaiah 34 in the BOLCB
Isaiah 34 in the BOLCB2
Isaiah 34 in the BOMCV
Isaiah 34 in the BONAV
Isaiah 34 in the BONCB
Isaiah 34 in the BONLT
Isaiah 34 in the BONUT2
Isaiah 34 in the BOPLNT
Isaiah 34 in the BOSCB
Isaiah 34 in the BOSNC
Isaiah 34 in the BOTLNT
Isaiah 34 in the BOVCB
Isaiah 34 in the BPBB
Isaiah 34 in the BPH
Isaiah 34 in the BSB
Isaiah 34 in the CCB
Isaiah 34 in the CUV
Isaiah 34 in the CUVS
Isaiah 34 in the DBT
Isaiah 34 in the DGDNT
Isaiah 34 in the DHNT
Isaiah 34 in the DNT
Isaiah 34 in the ELBE
Isaiah 34 in the EMTV
Isaiah 34 in the ESV
Isaiah 34 in the FBV
Isaiah 34 in the FEB
Isaiah 34 in the GGMNT
Isaiah 34 in the GNT
Isaiah 34 in the HARY
Isaiah 34 in the HNT
Isaiah 34 in the IRVA
Isaiah 34 in the IRVB
Isaiah 34 in the IRVG
Isaiah 34 in the IRVH
Isaiah 34 in the IRVK
Isaiah 34 in the IRVM
Isaiah 34 in the IRVM2
Isaiah 34 in the IRVO
Isaiah 34 in the IRVP
Isaiah 34 in the IRVT
Isaiah 34 in the IRVT2
Isaiah 34 in the IRVU
Isaiah 34 in the ISVN
Isaiah 34 in the JSNT
Isaiah 34 in the KAPI
Isaiah 34 in the KBT1ETNIK
Isaiah 34 in the KBV
Isaiah 34 in the KJV
Isaiah 34 in the KNFD
Isaiah 34 in the LBA
Isaiah 34 in the LBLA
Isaiah 34 in the LNT
Isaiah 34 in the LSV
Isaiah 34 in the MAAL
Isaiah 34 in the MBV
Isaiah 34 in the MBV2
Isaiah 34 in the MHNT
Isaiah 34 in the MKNFD
Isaiah 34 in the MNG
Isaiah 34 in the MNT
Isaiah 34 in the MNT2
Isaiah 34 in the MRS1T
Isaiah 34 in the NAA
Isaiah 34 in the NASB
Isaiah 34 in the NBLA
Isaiah 34 in the NBS
Isaiah 34 in the NBVTP
Isaiah 34 in the NET2
Isaiah 34 in the NIV11
Isaiah 34 in the NNT
Isaiah 34 in the NNT2
Isaiah 34 in the NNT3
Isaiah 34 in the PDDPT
Isaiah 34 in the PFNT
Isaiah 34 in the RMNT
Isaiah 34 in the SBIAS
Isaiah 34 in the SBIBS
Isaiah 34 in the SBIBS2
Isaiah 34 in the SBICS
Isaiah 34 in the SBIDS
Isaiah 34 in the SBIGS
Isaiah 34 in the SBIHS
Isaiah 34 in the SBIIS
Isaiah 34 in the SBIIS2
Isaiah 34 in the SBIIS3
Isaiah 34 in the SBIKS
Isaiah 34 in the SBIKS2
Isaiah 34 in the SBIMS
Isaiah 34 in the SBIOS
Isaiah 34 in the SBIPS
Isaiah 34 in the SBISS
Isaiah 34 in the SBITS
Isaiah 34 in the SBITS2
Isaiah 34 in the SBITS3
Isaiah 34 in the SBITS4
Isaiah 34 in the SBIUS
Isaiah 34 in the SBIVS
Isaiah 34 in the SBT
Isaiah 34 in the SBT1E
Isaiah 34 in the SCHL
Isaiah 34 in the SNT
Isaiah 34 in the SUSU
Isaiah 34 in the SUSU2
Isaiah 34 in the SYNO
Isaiah 34 in the TBIAOTANT
Isaiah 34 in the TBT1E
Isaiah 34 in the TBT1E2
Isaiah 34 in the TFTIP
Isaiah 34 in the TFTU
Isaiah 34 in the TGNTATF3T
Isaiah 34 in the THAI
Isaiah 34 in the TNFD
Isaiah 34 in the TNT
Isaiah 34 in the TNTIK
Isaiah 34 in the TNTIL
Isaiah 34 in the TNTIN
Isaiah 34 in the TNTIP
Isaiah 34 in the TNTIZ
Isaiah 34 in the TOMA
Isaiah 34 in the TTENT
Isaiah 34 in the UBG
Isaiah 34 in the UGV
Isaiah 34 in the UGV2
Isaiah 34 in the UGV3
Isaiah 34 in the VBL
Isaiah 34 in the VDCC
Isaiah 34 in the YALU
Isaiah 34 in the YAPE
Isaiah 34 in the YBVTP
Isaiah 34 in the ZBP