Isaiah 6 (BOYCB)
1 Ní ọdún tí ọba Ussiah kú, mo rí Olúwa tí ó jókòó lórí ìtẹ́ tí ó ga tí a gbé sókè, ìṣẹ́tí aṣọ ìgúnwà rẹ̀ sì kún inú tẹmpili. 2 Àwọn Serafu wà ní òkè rẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ìyẹ́ mẹ́fà, wọ́n fi ìyẹ́ méjì bo ojú wọn, wọ́n fi méjì bo ẹsẹ̀ wọn, wọ́n sí ń fi méjì fò. 3 Wọ́n sì ń kọ sí ara wọn wí pé,“Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogungbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀.” 4 Nípa ìró ohùn un wọn, òpó ìlẹ̀kùn àti gbogbo ògiri ilé náà sì mì tìtì, gbogbo inú tẹmpili sì kún fún èéfín. 5 Mo kígbe pé, “Ègbé ni fún mi! Mo ti gbé!” Nítorí mo jẹ́ ènìyàn aláìmọ́ ètè, mo sì ń gbé láàrín àwọn ènìyàn aláìmọ́ ètè, ojú mi sì ti rí ọba, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun jùlọ. 6 Nígbà náà ni ọ̀kan nínú àwọn Serafu wọ̀nyí fò wá sí ọ̀dọ̀ mi pẹ̀lú ẹ̀yín iná ní ọwọ́ rẹ̀, èyí tí ó ti fi ẹ̀mú mú ní orí pẹpẹ. 7 Èyí ni ó fi kàn mí ní ẹnu tí ó sì wí pé, “Wò ó, èyí ti kan ètè rẹ; a ti mú ẹ̀bi rẹ kúrò, a sì ti wẹ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ nù.” 8 Nígbà náà ni mo sì gbọ́ ohùn Olúwa wí pé, “Ta ni èmi yóò rán? Ta ni yóò sì lọ fún wa?”Nígbà náà ni èmi sì wí pé, “Èmi nìyí, rán mi!” 9 Òun sì wí pé, “Tọ àwọn ènìyàn yìí lọ kí o sì wí fún wọn pé,“ ‘Ní gbígbọ́ ẹ̀yin yóò gbọ́, kì yóò sì yé e yín;ní rí rí ẹ̀yin yóò ri, ẹ̀yin kì yóò mọ òye.’ 10 Mú kí àyà àwọn ènìyàn wọ̀nyí yigbì,mú kí etí wọn kí ó wúwo,kí o sì dìwọ́n ní ojú.Kí wọn kí ó má ba fi ojú wọn ríran,kí wọn kí ó má ba fi etí wọn gbọ́rọ̀,kí òye kí ó má ba yé ọkàn wọn,kí wọn kí ó má ba yípadàkí a má ba mú wọn ní ara dá.” 11 Nígbà náà ni mo wí pé, “Báwo ni yóò ti pẹ́ tó OLÚWA?”Òun sì dáhùn pé:“Títí àwọn ìlú ńlá yóò fi dahoro,láìsí olùgbé nínú rẹ̀ mọ́,títí tí àwọn ilé yóò fi wà láìsí ènìyàn,títí tí ilẹ̀ yóò fi dahoro pátápátá. 12 Títí tí OLÚWA yóò fi rán gbogbo wọn jìnnà rérétí ilẹ̀ náà sì di ìkọ̀sílẹ̀ pátápátá. 13 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdámẹ́wàá ṣẹ́kù lórí ilẹ̀ náà,yóò sì tún pàpà padà di rírun.Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí igi tẹrẹbinti àti igi óákù,ti í fi kùkùté sílẹ̀ nígbà tí a bá gé wọn lulẹ̀,bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni irúgbìn mímọ́ náà yóò di kùkùté ní ilẹ̀ náà.”
In Other Versions
Isaiah 6 in the ANGEFD
Isaiah 6 in the ANTPNG2D
Isaiah 6 in the AS21
Isaiah 6 in the BAGH
Isaiah 6 in the BBPNG
Isaiah 6 in the BBT1E
Isaiah 6 in the BDS
Isaiah 6 in the BEV
Isaiah 6 in the BHAD
Isaiah 6 in the BIB
Isaiah 6 in the BLPT
Isaiah 6 in the BNT
Isaiah 6 in the BNTABOOT
Isaiah 6 in the BNTLV
Isaiah 6 in the BOATCB
Isaiah 6 in the BOATCB2
Isaiah 6 in the BOBCV
Isaiah 6 in the BOCNT
Isaiah 6 in the BOECS
Isaiah 6 in the BOGWICC
Isaiah 6 in the BOHCB
Isaiah 6 in the BOHCV
Isaiah 6 in the BOHLNT
Isaiah 6 in the BOHNTLTAL
Isaiah 6 in the BOICB
Isaiah 6 in the BOILNTAP
Isaiah 6 in the BOITCV
Isaiah 6 in the BOKCV
Isaiah 6 in the BOKCV2
Isaiah 6 in the BOKHWOG
Isaiah 6 in the BOKSSV
Isaiah 6 in the BOLCB
Isaiah 6 in the BOLCB2
Isaiah 6 in the BOMCV
Isaiah 6 in the BONAV
Isaiah 6 in the BONCB
Isaiah 6 in the BONLT
Isaiah 6 in the BONUT2
Isaiah 6 in the BOPLNT
Isaiah 6 in the BOSCB
Isaiah 6 in the BOSNC
Isaiah 6 in the BOTLNT
Isaiah 6 in the BOVCB
Isaiah 6 in the BPBB
Isaiah 6 in the BPH
Isaiah 6 in the BSB
Isaiah 6 in the CCB
Isaiah 6 in the CUV
Isaiah 6 in the CUVS
Isaiah 6 in the DBT
Isaiah 6 in the DGDNT
Isaiah 6 in the DHNT
Isaiah 6 in the DNT
Isaiah 6 in the ELBE
Isaiah 6 in the EMTV
Isaiah 6 in the ESV
Isaiah 6 in the FBV
Isaiah 6 in the FEB
Isaiah 6 in the GGMNT
Isaiah 6 in the GNT
Isaiah 6 in the HARY
Isaiah 6 in the HNT
Isaiah 6 in the IRVA
Isaiah 6 in the IRVB
Isaiah 6 in the IRVG
Isaiah 6 in the IRVH
Isaiah 6 in the IRVK
Isaiah 6 in the IRVM
Isaiah 6 in the IRVM2
Isaiah 6 in the IRVO
Isaiah 6 in the IRVP
Isaiah 6 in the IRVT
Isaiah 6 in the IRVT2
Isaiah 6 in the IRVU
Isaiah 6 in the ISVN
Isaiah 6 in the JSNT
Isaiah 6 in the KAPI
Isaiah 6 in the KBT1ETNIK
Isaiah 6 in the KBV
Isaiah 6 in the KJV
Isaiah 6 in the KNFD
Isaiah 6 in the LBA
Isaiah 6 in the LBLA
Isaiah 6 in the LNT
Isaiah 6 in the LSV
Isaiah 6 in the MAAL
Isaiah 6 in the MBV
Isaiah 6 in the MBV2
Isaiah 6 in the MHNT
Isaiah 6 in the MKNFD
Isaiah 6 in the MNG
Isaiah 6 in the MNT
Isaiah 6 in the MNT2
Isaiah 6 in the MRS1T
Isaiah 6 in the NAA
Isaiah 6 in the NASB
Isaiah 6 in the NBLA
Isaiah 6 in the NBS
Isaiah 6 in the NBVTP
Isaiah 6 in the NET2
Isaiah 6 in the NIV11
Isaiah 6 in the NNT
Isaiah 6 in the NNT2
Isaiah 6 in the NNT3
Isaiah 6 in the PDDPT
Isaiah 6 in the PFNT
Isaiah 6 in the RMNT
Isaiah 6 in the SBIAS
Isaiah 6 in the SBIBS
Isaiah 6 in the SBIBS2
Isaiah 6 in the SBICS
Isaiah 6 in the SBIDS
Isaiah 6 in the SBIGS
Isaiah 6 in the SBIHS
Isaiah 6 in the SBIIS
Isaiah 6 in the SBIIS2
Isaiah 6 in the SBIIS3
Isaiah 6 in the SBIKS
Isaiah 6 in the SBIKS2
Isaiah 6 in the SBIMS
Isaiah 6 in the SBIOS
Isaiah 6 in the SBIPS
Isaiah 6 in the SBISS
Isaiah 6 in the SBITS
Isaiah 6 in the SBITS2
Isaiah 6 in the SBITS3
Isaiah 6 in the SBITS4
Isaiah 6 in the SBIUS
Isaiah 6 in the SBIVS
Isaiah 6 in the SBT
Isaiah 6 in the SBT1E
Isaiah 6 in the SCHL
Isaiah 6 in the SNT
Isaiah 6 in the SUSU
Isaiah 6 in the SUSU2
Isaiah 6 in the SYNO
Isaiah 6 in the TBIAOTANT
Isaiah 6 in the TBT1E
Isaiah 6 in the TBT1E2
Isaiah 6 in the TFTIP
Isaiah 6 in the TFTU
Isaiah 6 in the TGNTATF3T
Isaiah 6 in the THAI
Isaiah 6 in the TNFD
Isaiah 6 in the TNT
Isaiah 6 in the TNTIK
Isaiah 6 in the TNTIL
Isaiah 6 in the TNTIN
Isaiah 6 in the TNTIP
Isaiah 6 in the TNTIZ
Isaiah 6 in the TOMA
Isaiah 6 in the TTENT
Isaiah 6 in the UBG
Isaiah 6 in the UGV
Isaiah 6 in the UGV2
Isaiah 6 in the UGV3
Isaiah 6 in the VBL
Isaiah 6 in the VDCC
Isaiah 6 in the YALU
Isaiah 6 in the YAPE
Isaiah 6 in the YBVTP
Isaiah 6 in the ZBP