Jeremiah 28 (BOYCB)
1 Ní oṣù karùn-ún ní ọdún kan náà, ọdún kẹrin ní ìbẹ̀rẹ̀ ìṣèjọba Sedekiah ọba Juda, wòlíì Hananiah ọmọ Assuri, tí ó wá láti Gibeoni, sọ fún mi ní ilé OLÚWA tí ó wà ní iwájú àwọn àlùfáà àti gbogbo ènìyàn: 2 “Èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Israẹli wí: ‘Èmi yóò mú àjàgà ọba Babeli rọrùn. 3 Láàrín ọdún méjì, Èmi yóò mú gbogbo ohun èlò tí ọba Nebukadnessari; ọba Babeli kó kúrò ní ilé OLÚWA tí ó sì kó lọ sí Babeli padà wá. 4 Èmi á tún mú ààyè Jekoniah ọmọ Jehoiakimu ọba Juda padà, àti gbogbo àwọn tí ń ṣe àtìpó láti Juda ní Babeli,’ èyí ni ọ̀rọ̀ OLÚWA pé, ‘àjàgà yín láti ọwọ́ ọba Babeli yóò rọrùn.’ ” 5 Wòlíì Jeremiah wí fún wòlíì Hananiah ní iwájú ọmọ àlùfáà àti àwọn ènìyàn tí wọ́n dúró ní ilé OLÚWA. 6 Jeremiah wòlíì wí pé, “Àmín! Kí OLÚWA kí ó ṣe bẹ́ẹ̀! Kí OLÚWA kí ó mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ tí ìwọ sọ àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ, láti mú ohun èlò ilé OLÚWA àti gbogbo àwọn ìgbèkùn láti ilẹ̀ Babeli padà wá sí ibí yìí. 7 Nísinsin yìí, ìwọ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí tí mo sọ sí etí rẹ àti sí etí gbogbo ènìyàn. 8 Ní ìbẹ̀rẹ̀ àwọn wòlíì tí ó ṣáájú rẹ àti èmi ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ ogun, ibi àti àjàkálẹ̀ sí ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè. 9 Ṣùgbọ́n, àwọn wòlíì tí ó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ àlàáfíà ni a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí wòlíì olóòtítọ́ tí OLÚWA rán, tí àsọtẹ́lẹ̀ rẹ bá wá sí ìmúṣẹ.” 10 Wòlíì Hananiah gbé àjàgà ọrùn wòlíì Jeremiah kúrò, ó sì fọ́ ọ. 11 Hananiah sọ níwájú gbogbo ènìyàn wí pé, “Èyí ni ohun tí OLÚWA wí: ‘Bákan náà ni Èmi yóò fọ́ àjàgà ọrùn Nebukadnessari, ọba Babeli láàrín ọdún méjì.’ ” Wòlíì Jeremiah sì bá ọ̀nà tirẹ̀ lọ. 12 Láìpẹ́ ni ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ Jeremiah wòlíì wá lẹ́yìn ìgbà tí wòlíì Hananiah ti gbé àjàgà kúrò ní ọrùn wòlíì Jeremiah wí pé: 13 “Lọ sọ fún Hananiah, ‘Èyí ni ohun tí OLÚWA wí, ìwọ ti wó àjàgà onígi, ṣùgbọ́n ní ààyè wọn, wà á bá àjàgà onírin. 14 Èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Israẹli wí: Èmi yóò fi àjàgà onírin sí ọrùn gbogbo orílẹ̀-èdè láti lè máa sin Nebukadnessari ọba Babeli, àti pé gbogbo yín ni ẹ̀ ó máa sìn ín. Èmi yóò tún fún un ní àṣẹ lórí àwọn ẹranko búburú.’ ” 15 Wòlíì Jeremiah sọ fún wòlíì Hananiah pé, “Gbọ́ ọ, Hananiah! OLÚWA kò rán ọ, síbẹ̀, ìwọ jẹ́ kí orílẹ̀-èdè yìí gba irọ́ gbọ́. 16 Nítorí náà, èyí ni ohun tí OLÚWA wí: ‘Mo ṣetán láti mú ọ kúrò nínú ayé, ní ọdún yìí ni ìwọ yóò kú nítorí o ti wàásù ọ̀tẹ̀ sí OLÚWA.’ ” 17 Ní oṣù keje ọdún yìí ni Hananiah wòlíì kú.
In Other Versions
Jeremiah 28 in the ANGEFD
Jeremiah 28 in the ANTPNG2D
Jeremiah 28 in the AS21
Jeremiah 28 in the BAGH
Jeremiah 28 in the BBPNG
Jeremiah 28 in the BBT1E
Jeremiah 28 in the BDS
Jeremiah 28 in the BEV
Jeremiah 28 in the BHAD
Jeremiah 28 in the BIB
Jeremiah 28 in the BLPT
Jeremiah 28 in the BNT
Jeremiah 28 in the BNTABOOT
Jeremiah 28 in the BNTLV
Jeremiah 28 in the BOATCB
Jeremiah 28 in the BOATCB2
Jeremiah 28 in the BOBCV
Jeremiah 28 in the BOCNT
Jeremiah 28 in the BOECS
Jeremiah 28 in the BOGWICC
Jeremiah 28 in the BOHCB
Jeremiah 28 in the BOHCV
Jeremiah 28 in the BOHLNT
Jeremiah 28 in the BOHNTLTAL
Jeremiah 28 in the BOICB
Jeremiah 28 in the BOILNTAP
Jeremiah 28 in the BOITCV
Jeremiah 28 in the BOKCV
Jeremiah 28 in the BOKCV2
Jeremiah 28 in the BOKHWOG
Jeremiah 28 in the BOKSSV
Jeremiah 28 in the BOLCB
Jeremiah 28 in the BOLCB2
Jeremiah 28 in the BOMCV
Jeremiah 28 in the BONAV
Jeremiah 28 in the BONCB
Jeremiah 28 in the BONLT
Jeremiah 28 in the BONUT2
Jeremiah 28 in the BOPLNT
Jeremiah 28 in the BOSCB
Jeremiah 28 in the BOSNC
Jeremiah 28 in the BOTLNT
Jeremiah 28 in the BOVCB
Jeremiah 28 in the BPBB
Jeremiah 28 in the BPH
Jeremiah 28 in the BSB
Jeremiah 28 in the CCB
Jeremiah 28 in the CUV
Jeremiah 28 in the CUVS
Jeremiah 28 in the DBT
Jeremiah 28 in the DGDNT
Jeremiah 28 in the DHNT
Jeremiah 28 in the DNT
Jeremiah 28 in the ELBE
Jeremiah 28 in the EMTV
Jeremiah 28 in the ESV
Jeremiah 28 in the FBV
Jeremiah 28 in the FEB
Jeremiah 28 in the GGMNT
Jeremiah 28 in the GNT
Jeremiah 28 in the HARY
Jeremiah 28 in the HNT
Jeremiah 28 in the IRVA
Jeremiah 28 in the IRVB
Jeremiah 28 in the IRVG
Jeremiah 28 in the IRVH
Jeremiah 28 in the IRVK
Jeremiah 28 in the IRVM
Jeremiah 28 in the IRVM2
Jeremiah 28 in the IRVO
Jeremiah 28 in the IRVP
Jeremiah 28 in the IRVT
Jeremiah 28 in the IRVT2
Jeremiah 28 in the IRVU
Jeremiah 28 in the ISVN
Jeremiah 28 in the JSNT
Jeremiah 28 in the KAPI
Jeremiah 28 in the KBT1ETNIK
Jeremiah 28 in the KBV
Jeremiah 28 in the KJV
Jeremiah 28 in the KNFD
Jeremiah 28 in the LBA
Jeremiah 28 in the LBLA
Jeremiah 28 in the LNT
Jeremiah 28 in the LSV
Jeremiah 28 in the MAAL
Jeremiah 28 in the MBV
Jeremiah 28 in the MBV2
Jeremiah 28 in the MHNT
Jeremiah 28 in the MKNFD
Jeremiah 28 in the MNG
Jeremiah 28 in the MNT
Jeremiah 28 in the MNT2
Jeremiah 28 in the MRS1T
Jeremiah 28 in the NAA
Jeremiah 28 in the NASB
Jeremiah 28 in the NBLA
Jeremiah 28 in the NBS
Jeremiah 28 in the NBVTP
Jeremiah 28 in the NET2
Jeremiah 28 in the NIV11
Jeremiah 28 in the NNT
Jeremiah 28 in the NNT2
Jeremiah 28 in the NNT3
Jeremiah 28 in the PDDPT
Jeremiah 28 in the PFNT
Jeremiah 28 in the RMNT
Jeremiah 28 in the SBIAS
Jeremiah 28 in the SBIBS
Jeremiah 28 in the SBIBS2
Jeremiah 28 in the SBICS
Jeremiah 28 in the SBIDS
Jeremiah 28 in the SBIGS
Jeremiah 28 in the SBIHS
Jeremiah 28 in the SBIIS
Jeremiah 28 in the SBIIS2
Jeremiah 28 in the SBIIS3
Jeremiah 28 in the SBIKS
Jeremiah 28 in the SBIKS2
Jeremiah 28 in the SBIMS
Jeremiah 28 in the SBIOS
Jeremiah 28 in the SBIPS
Jeremiah 28 in the SBISS
Jeremiah 28 in the SBITS
Jeremiah 28 in the SBITS2
Jeremiah 28 in the SBITS3
Jeremiah 28 in the SBITS4
Jeremiah 28 in the SBIUS
Jeremiah 28 in the SBIVS
Jeremiah 28 in the SBT
Jeremiah 28 in the SBT1E
Jeremiah 28 in the SCHL
Jeremiah 28 in the SNT
Jeremiah 28 in the SUSU
Jeremiah 28 in the SUSU2
Jeremiah 28 in the SYNO
Jeremiah 28 in the TBIAOTANT
Jeremiah 28 in the TBT1E
Jeremiah 28 in the TBT1E2
Jeremiah 28 in the TFTIP
Jeremiah 28 in the TFTU
Jeremiah 28 in the TGNTATF3T
Jeremiah 28 in the THAI
Jeremiah 28 in the TNFD
Jeremiah 28 in the TNT
Jeremiah 28 in the TNTIK
Jeremiah 28 in the TNTIL
Jeremiah 28 in the TNTIN
Jeremiah 28 in the TNTIP
Jeremiah 28 in the TNTIZ
Jeremiah 28 in the TOMA
Jeremiah 28 in the TTENT
Jeremiah 28 in the UBG
Jeremiah 28 in the UGV
Jeremiah 28 in the UGV2
Jeremiah 28 in the UGV3
Jeremiah 28 in the VBL
Jeremiah 28 in the VDCC
Jeremiah 28 in the YALU
Jeremiah 28 in the YAPE
Jeremiah 28 in the YBVTP
Jeremiah 28 in the ZBP