Jeremiah 43 (BOYCB)
1 Nígbà tí Jeremiah parí sísọ ọ̀rọ̀ tí OLÚWA Ọlọ́run rán an sí wọn tan. 2 Asariah ọmọ Hoṣaiah àti Johanani ọmọ Karea, àti gbogbo àwọn agbéraga ọkùnrin sọ fún Jeremiah pé, “Ìwọ ń pa irọ́! OLÚWA Ọlọ́run wa kò rán ọ láti sọ pé, ‘Ẹ má lọ sí Ejibiti láti ṣàtìpó níbẹ̀.’ 3 Ṣùgbọ́n Baruku, ọmọ Neriah, ni ó fi ọ̀rọ̀ sí ọ lẹ́nu sí wa, láti fà wá lé àwọn ará Babeli lọ́wọ́, láti pa wá àti láti kó wa ní ìgbèkùn lọ sí Babeli.” 4 Nítorí náà, Johanani ti Karea àti gbogbo àwọn olórí ogun, àti gbogbo àwọn ènìyàn tàpá sí àṣẹ OLÚWA nípa dídúró sí Juda. 5 Dípò bẹ́ẹ̀, Johanani ọmọ Karea àti gbogbo àwọn olórí ogun sì ko àwọn àjẹkù Juda tí wọ́n wá láti gbé ilẹ̀ Juda láti orílẹ̀-èdè gbogbo tí wọ́n ti tú wọn ká. 6 Wọ́n tún kó àwọn ọkùnrin, àwọn obìnrin àti àwọn ọmọdé, àti àwọn ọmọ ọba tí ó jẹ́ obìnrin èyí tí Nebusaradani balógun ẹ̀ṣọ́ ti fi sílẹ̀ pẹ̀lú Gedaliah ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, àti Jeremiah wòlíì náà àti Baruku ọmọ Neriah. 7 Nítorí náà, wọn wọ Ejibiti pẹ̀lú àìgbọ́ràn sí àṣẹ OLÚWA, wọ́n sì lọ títí dé Tafanesi. 8 Ní Tafanesi ọ̀rọ̀ OLÚWA tọ Jeremiah wá: 9 “Nígbà tí àwọn Júù ń wòye mú àwọn òkúta pẹ̀lú rẹ, kí o sì rì wọ́n mọ́ inú amọ̀ tí ó wà nínú bíríkì tí ó wà níbi pèpéle ẹnu-ọ̀nà ààfin Farao ní Tafanesi. 10 Báyìí kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí. Èmi yóò ránṣẹ́ sí ìránṣẹ́ mi Nebukadnessari ọba Babeli, Èmi yóò gbé ìjọba rẹ̀ ka orí àwọn òkúta; èyí tí mo ti rì sí ibí yìí, yóò tan ìjọba rẹ̀ jù wọ́n lọ. 11 Yóò gbé ogun sí Ejibiti; yóò mú ikú bá àwọn tí ó yan ikú; ìgbèkùn fún àwọn tí ó ti yan ìgbèkùn, àti idà fún àwọn tí ó yan idà. 12 Yóò dá, iná sun tẹmpili àwọn òrìṣà Ejibiti, yóò sun tẹmpili àwọn òrìṣà Ejibiti, yóò sì mú wọn lọ ìgbèkùn. Gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn, yóò ró aṣọ rẹ̀ mọ́ra, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni yóò ró Ejibiti òun yóò sì lọ kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà. 13 Ní tẹmpili ni yóò ti fọ́ ère ilé oòrùn tí ó wà ní ilẹ̀ Ejibiti túútúú, yóò sì sun àwọn tẹmpili àwọn òrìṣà Ejibiti.’ ”
In Other Versions
Jeremiah 43 in the ANGEFD
Jeremiah 43 in the ANTPNG2D
Jeremiah 43 in the AS21
Jeremiah 43 in the BAGH
Jeremiah 43 in the BBPNG
Jeremiah 43 in the BBT1E
Jeremiah 43 in the BDS
Jeremiah 43 in the BEV
Jeremiah 43 in the BHAD
Jeremiah 43 in the BIB
Jeremiah 43 in the BLPT
Jeremiah 43 in the BNT
Jeremiah 43 in the BNTABOOT
Jeremiah 43 in the BNTLV
Jeremiah 43 in the BOATCB
Jeremiah 43 in the BOATCB2
Jeremiah 43 in the BOBCV
Jeremiah 43 in the BOCNT
Jeremiah 43 in the BOECS
Jeremiah 43 in the BOGWICC
Jeremiah 43 in the BOHCB
Jeremiah 43 in the BOHCV
Jeremiah 43 in the BOHLNT
Jeremiah 43 in the BOHNTLTAL
Jeremiah 43 in the BOICB
Jeremiah 43 in the BOILNTAP
Jeremiah 43 in the BOITCV
Jeremiah 43 in the BOKCV
Jeremiah 43 in the BOKCV2
Jeremiah 43 in the BOKHWOG
Jeremiah 43 in the BOKSSV
Jeremiah 43 in the BOLCB
Jeremiah 43 in the BOLCB2
Jeremiah 43 in the BOMCV
Jeremiah 43 in the BONAV
Jeremiah 43 in the BONCB
Jeremiah 43 in the BONLT
Jeremiah 43 in the BONUT2
Jeremiah 43 in the BOPLNT
Jeremiah 43 in the BOSCB
Jeremiah 43 in the BOSNC
Jeremiah 43 in the BOTLNT
Jeremiah 43 in the BOVCB
Jeremiah 43 in the BPBB
Jeremiah 43 in the BPH
Jeremiah 43 in the BSB
Jeremiah 43 in the CCB
Jeremiah 43 in the CUV
Jeremiah 43 in the CUVS
Jeremiah 43 in the DBT
Jeremiah 43 in the DGDNT
Jeremiah 43 in the DHNT
Jeremiah 43 in the DNT
Jeremiah 43 in the ELBE
Jeremiah 43 in the EMTV
Jeremiah 43 in the ESV
Jeremiah 43 in the FBV
Jeremiah 43 in the FEB
Jeremiah 43 in the GGMNT
Jeremiah 43 in the GNT
Jeremiah 43 in the HARY
Jeremiah 43 in the HNT
Jeremiah 43 in the IRVA
Jeremiah 43 in the IRVB
Jeremiah 43 in the IRVG
Jeremiah 43 in the IRVH
Jeremiah 43 in the IRVK
Jeremiah 43 in the IRVM
Jeremiah 43 in the IRVM2
Jeremiah 43 in the IRVO
Jeremiah 43 in the IRVP
Jeremiah 43 in the IRVT
Jeremiah 43 in the IRVT2
Jeremiah 43 in the IRVU
Jeremiah 43 in the ISVN
Jeremiah 43 in the JSNT
Jeremiah 43 in the KAPI
Jeremiah 43 in the KBT1ETNIK
Jeremiah 43 in the KBV
Jeremiah 43 in the KJV
Jeremiah 43 in the KNFD
Jeremiah 43 in the LBA
Jeremiah 43 in the LBLA
Jeremiah 43 in the LNT
Jeremiah 43 in the LSV
Jeremiah 43 in the MAAL
Jeremiah 43 in the MBV
Jeremiah 43 in the MBV2
Jeremiah 43 in the MHNT
Jeremiah 43 in the MKNFD
Jeremiah 43 in the MNG
Jeremiah 43 in the MNT
Jeremiah 43 in the MNT2
Jeremiah 43 in the MRS1T
Jeremiah 43 in the NAA
Jeremiah 43 in the NASB
Jeremiah 43 in the NBLA
Jeremiah 43 in the NBS
Jeremiah 43 in the NBVTP
Jeremiah 43 in the NET2
Jeremiah 43 in the NIV11
Jeremiah 43 in the NNT
Jeremiah 43 in the NNT2
Jeremiah 43 in the NNT3
Jeremiah 43 in the PDDPT
Jeremiah 43 in the PFNT
Jeremiah 43 in the RMNT
Jeremiah 43 in the SBIAS
Jeremiah 43 in the SBIBS
Jeremiah 43 in the SBIBS2
Jeremiah 43 in the SBICS
Jeremiah 43 in the SBIDS
Jeremiah 43 in the SBIGS
Jeremiah 43 in the SBIHS
Jeremiah 43 in the SBIIS
Jeremiah 43 in the SBIIS2
Jeremiah 43 in the SBIIS3
Jeremiah 43 in the SBIKS
Jeremiah 43 in the SBIKS2
Jeremiah 43 in the SBIMS
Jeremiah 43 in the SBIOS
Jeremiah 43 in the SBIPS
Jeremiah 43 in the SBISS
Jeremiah 43 in the SBITS
Jeremiah 43 in the SBITS2
Jeremiah 43 in the SBITS3
Jeremiah 43 in the SBITS4
Jeremiah 43 in the SBIUS
Jeremiah 43 in the SBIVS
Jeremiah 43 in the SBT
Jeremiah 43 in the SBT1E
Jeremiah 43 in the SCHL
Jeremiah 43 in the SNT
Jeremiah 43 in the SUSU
Jeremiah 43 in the SUSU2
Jeremiah 43 in the SYNO
Jeremiah 43 in the TBIAOTANT
Jeremiah 43 in the TBT1E
Jeremiah 43 in the TBT1E2
Jeremiah 43 in the TFTIP
Jeremiah 43 in the TFTU
Jeremiah 43 in the TGNTATF3T
Jeremiah 43 in the THAI
Jeremiah 43 in the TNFD
Jeremiah 43 in the TNT
Jeremiah 43 in the TNTIK
Jeremiah 43 in the TNTIL
Jeremiah 43 in the TNTIN
Jeremiah 43 in the TNTIP
Jeremiah 43 in the TNTIZ
Jeremiah 43 in the TOMA
Jeremiah 43 in the TTENT
Jeremiah 43 in the UBG
Jeremiah 43 in the UGV
Jeremiah 43 in the UGV2
Jeremiah 43 in the UGV3
Jeremiah 43 in the VBL
Jeremiah 43 in the VDCC
Jeremiah 43 in the YALU
Jeremiah 43 in the YAPE
Jeremiah 43 in the YBVTP
Jeremiah 43 in the ZBP