Jeremiah 9 (BOYCB)

1 Háà! Orí ìbá jẹ́ orísun omikí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé!Èmi yóò sì sọkún tọ̀sán tòrunítorí ìparun àwọn ènìyàn mi. 2 Háà, èmi ìbá ní ni aginjùilé àgbàwọ̀ fún àwọn arìnrìn-àjò,kí n ba à lè fi àwọn ènìyàn mi sílẹ̀kí n sì lọ kúrò lọ́dọ̀ wọn:nítorí gbogbo wọn jẹ́ panṣágààjọ aláìṣòótọ́ ènìyàn. 3 Wọ́n ti pèsè ahọ́n wọn sílẹ̀bí ọfà láti fi pa irọ́;kì í ṣe nípa òtítọ́ni wọ́n fi borí ní ilẹ̀ náà.Wọ́n ń lọ láti inú ẹ̀ṣẹ̀ kan sí òmíràn;wọn kò sì náání mi,ní OLÚWA wí. 4 “Ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ;má ṣe gbẹ́kẹ̀lé àwọn arákùnrin rẹ.Nítorí pé oníkálùkù arákùnrin jẹ́ atannijẹ,oníkálùkù ọ̀rẹ́ sì jẹ́ abanijẹ́. 5 Ọ̀rẹ́ ń dalẹ̀ ọ̀rẹ́. Kò sì ṣí ẹnitó sọ òtítọ́, wọ́n ti kọ́ ahọ́n wọnláti máa purọ́. Wọ́n sọ ara wọndi onírẹ̀wẹ̀sì pẹ̀lú ẹ̀ṣẹ̀ 6 Ó ń gbé ní àárín ẹ̀tàn;wọ́n kọ̀ láti mọ̀ mí nínú ẹ̀tàn wọn,”ni OLÚWA wí. 7 Nítorí náà, èyí ni ohun tí OLÚWA Ọlọ́run Àwọn ọmọ-ogun wí:“Wò ó, èmi dán wọn wo;nítorí pé kí ni èmi tún le è ṣe?Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ènìyàn mi? 8 Ahọ́n wọn dàbí ọfà olóró;ó ń sọ ẹ̀tàn.Oníkálùkù sì ń fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ àlàáfíà sí aládùúgbò rẹ̀,ní inú ọkàn rẹ̀, ó dẹ tàkúté sílẹ̀. 9 Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n nítorí èyí?”ni OLÚWA wí.“Èmi kì yóò ha gbẹ̀san arami lórí irú orílẹ̀-èdè yìí bí?” 10 Èmi yóò sì sọkún, pohùnréré ẹkún fún àwọn òkèàti ẹkún ìrora lórí pápá oko aginjù wọ̀n-ọn-nì.Nítorí wọ́n di ahoro, wọn kò sì kọjá ní ibẹ̀.A kò sì gbọ́ igbe ẹran ọ̀sìn.Àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ti sálọ,bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ẹranko sì ti lọ. 11 “Èmi yóò sì sọ Jerusalẹmu di òkìtìàlàpà àti ihò àwọn ìkookò.Èmi ó sì sọ ìlú Juda di ahorotí ẹnikẹ́ni kò sì ní le è gbé.” 12 Ta ni ẹni náà tí ó ní ọgbọ́n láti mòye nǹkan wọ̀nyí? Ta ni OLÚWA ti sọ èyí fún, tí ó sì lè ṣàlàyé rẹ̀? Èéṣe tí ilẹ̀ náà fi ṣègbé bí aginjù, tí ẹnìkankan kò sì le là á kọjá? 13 OLÚWA sì wí pé, nítorí pé wọ́n ti kọ òfin mi sílẹ̀, èyí tí mo gbé kalẹ̀ níwájú wọn, wọn ṣe àìgbọ́ràn sí wọn, wọn kò sì rìn nínú òfin mi. 14 Dípò èyí, wọ́n ti tẹ̀lé agídí ọkàn wọn, wọ́n ti tẹ̀lé Baali gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wọn ṣe kọ́ wọn. 15 Nítorí náà, èyí ni ohun tí OLÚWA àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí, “Wò ó, Èmi yóò mú kí àwọn ènìyàn wọ̀nyí jẹ oúnjẹ kíkorò àti láti mu omi májèlé. 16 Èmi yóò sì tú wọn ká láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, nínú èyí tí àwọn tàbí àwọn baba wọn kò mọ̀. Èmi yóò sì lépa wọn pẹ̀lú idà títí èmi yóò fi pa wọ́n run.” 17 Èyí sì ni ohun tí OLÚWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí:“Sá à wò ó nísinsin yìí! Ké sí obìnrin ti ń ṣọ̀fọ̀ nì kí ó wá;sì ránṣẹ́ pe àwọn tí ó mòye nínú wọn. 18 Jẹ́ kí wọn wá kíákíá,kí wọn wá pohùnréré ẹkúnlé wa lórí títí ojú wa yóòfi sàn fún omijé tí omi yóò sì máa sàn àwọn ìpéǹpéjú wa. 19 A gbọ́ igbe ìpohùnréréẹkún ní Sioni:‘Àwa ti ṣègbé tó!A gbọdọ̀ fi ilẹ̀ wa sílẹ̀,nítorí pé àwọn ilé wa ti parun.’ ” 20 Nísinsin yìí, ẹ̀yin obìnrin ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA;ṣí etí yín sí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ.Kọ́ àwọn ọmọbìnrin yín ní ìpohùnréré ẹkún,kí ẹ sì kọ́ ara yín ní arò. 21 Ikú ti gba ojú fèrèsé wa wọléó sì ti wọ odi alágbára waó ti ké àwọn ọmọ kúrò ní àdúgbòàti àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin kúrò ní gbọ̀ngàn ìta gbangba. 22 Sọ pé, “Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“ ‘Òkú àwọn ènìyàn yóò ṣubúbí ààtàn ní oko gbangbaàti bí ìbùkúnwọ́ lẹ́yìn olùkórèláìsí ẹnìkankan láti kó wọn jọ.’ ” 23 Èyí ni ohun tí OLÚWA wí:“Má ṣe jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n yangàn nítorí agbára ọgbọ́n rẹ̀,tàbí alágbára nítorí agbára rẹ̀,tàbí ọlọ́rọ̀ nítorí ọrọ̀ rẹ̀. 24 Ẹ jẹ́ kí ẹni tí ń ṣògo nípa èyí nì wí pé:òun ní òye, òun sì mọ̀ mí wí pé,Èmi ni OLÚWA tí ń ṣe òtítọ́,ìdájọ́ àti òdodo ní ayé,nínú èyí ni mo ní inú dídùn sí,” OLÚWA wí. 25 “Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLÚWA wí, “tí Èmi yóò fi ìyà jẹ gbogbo àwọn tí a kọ ilà fún nínú ara nìkan. 26 Ejibiti, Juda, Edomu, Ammoni, Moabu àti gbogbo àwọn tí ń gbé ní ọ̀nà jíjìn réré ní aginjù. Nítorí pé gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí jẹ́ aláìkọlà gbogbo àwọn ará ilé Israẹli sì jẹ́ aláìkọlà ọkàn.”

In Other Versions

Jeremiah 9 in the ANGEFD

Jeremiah 9 in the ANTPNG2D

Jeremiah 9 in the AS21

Jeremiah 9 in the BAGH

Jeremiah 9 in the BBPNG

Jeremiah 9 in the BBT1E

Jeremiah 9 in the BDS

Jeremiah 9 in the BEV

Jeremiah 9 in the BHAD

Jeremiah 9 in the BIB

Jeremiah 9 in the BLPT

Jeremiah 9 in the BNT

Jeremiah 9 in the BNTABOOT

Jeremiah 9 in the BNTLV

Jeremiah 9 in the BOATCB

Jeremiah 9 in the BOATCB2

Jeremiah 9 in the BOBCV

Jeremiah 9 in the BOCNT

Jeremiah 9 in the BOECS

Jeremiah 9 in the BOGWICC

Jeremiah 9 in the BOHCB

Jeremiah 9 in the BOHCV

Jeremiah 9 in the BOHLNT

Jeremiah 9 in the BOHNTLTAL

Jeremiah 9 in the BOICB

Jeremiah 9 in the BOILNTAP

Jeremiah 9 in the BOITCV

Jeremiah 9 in the BOKCV

Jeremiah 9 in the BOKCV2

Jeremiah 9 in the BOKHWOG

Jeremiah 9 in the BOKSSV

Jeremiah 9 in the BOLCB

Jeremiah 9 in the BOLCB2

Jeremiah 9 in the BOMCV

Jeremiah 9 in the BONAV

Jeremiah 9 in the BONCB

Jeremiah 9 in the BONLT

Jeremiah 9 in the BONUT2

Jeremiah 9 in the BOPLNT

Jeremiah 9 in the BOSCB

Jeremiah 9 in the BOSNC

Jeremiah 9 in the BOTLNT

Jeremiah 9 in the BOVCB

Jeremiah 9 in the BPBB

Jeremiah 9 in the BPH

Jeremiah 9 in the BSB

Jeremiah 9 in the CCB

Jeremiah 9 in the CUV

Jeremiah 9 in the CUVS

Jeremiah 9 in the DBT

Jeremiah 9 in the DGDNT

Jeremiah 9 in the DHNT

Jeremiah 9 in the DNT

Jeremiah 9 in the ELBE

Jeremiah 9 in the EMTV

Jeremiah 9 in the ESV

Jeremiah 9 in the FBV

Jeremiah 9 in the FEB

Jeremiah 9 in the GGMNT

Jeremiah 9 in the GNT

Jeremiah 9 in the HARY

Jeremiah 9 in the HNT

Jeremiah 9 in the IRVA

Jeremiah 9 in the IRVB

Jeremiah 9 in the IRVG

Jeremiah 9 in the IRVH

Jeremiah 9 in the IRVK

Jeremiah 9 in the IRVM

Jeremiah 9 in the IRVM2

Jeremiah 9 in the IRVO

Jeremiah 9 in the IRVP

Jeremiah 9 in the IRVT

Jeremiah 9 in the IRVT2

Jeremiah 9 in the IRVU

Jeremiah 9 in the ISVN

Jeremiah 9 in the JSNT

Jeremiah 9 in the KAPI

Jeremiah 9 in the KBT1ETNIK

Jeremiah 9 in the KBV

Jeremiah 9 in the KJV

Jeremiah 9 in the KNFD

Jeremiah 9 in the LBA

Jeremiah 9 in the LBLA

Jeremiah 9 in the LNT

Jeremiah 9 in the LSV

Jeremiah 9 in the MAAL

Jeremiah 9 in the MBV

Jeremiah 9 in the MBV2

Jeremiah 9 in the MHNT

Jeremiah 9 in the MKNFD

Jeremiah 9 in the MNG

Jeremiah 9 in the MNT

Jeremiah 9 in the MNT2

Jeremiah 9 in the MRS1T

Jeremiah 9 in the NAA

Jeremiah 9 in the NASB

Jeremiah 9 in the NBLA

Jeremiah 9 in the NBS

Jeremiah 9 in the NBVTP

Jeremiah 9 in the NET2

Jeremiah 9 in the NIV11

Jeremiah 9 in the NNT

Jeremiah 9 in the NNT2

Jeremiah 9 in the NNT3

Jeremiah 9 in the PDDPT

Jeremiah 9 in the PFNT

Jeremiah 9 in the RMNT

Jeremiah 9 in the SBIAS

Jeremiah 9 in the SBIBS

Jeremiah 9 in the SBIBS2

Jeremiah 9 in the SBICS

Jeremiah 9 in the SBIDS

Jeremiah 9 in the SBIGS

Jeremiah 9 in the SBIHS

Jeremiah 9 in the SBIIS

Jeremiah 9 in the SBIIS2

Jeremiah 9 in the SBIIS3

Jeremiah 9 in the SBIKS

Jeremiah 9 in the SBIKS2

Jeremiah 9 in the SBIMS

Jeremiah 9 in the SBIOS

Jeremiah 9 in the SBIPS

Jeremiah 9 in the SBISS

Jeremiah 9 in the SBITS

Jeremiah 9 in the SBITS2

Jeremiah 9 in the SBITS3

Jeremiah 9 in the SBITS4

Jeremiah 9 in the SBIUS

Jeremiah 9 in the SBIVS

Jeremiah 9 in the SBT

Jeremiah 9 in the SBT1E

Jeremiah 9 in the SCHL

Jeremiah 9 in the SNT

Jeremiah 9 in the SUSU

Jeremiah 9 in the SUSU2

Jeremiah 9 in the SYNO

Jeremiah 9 in the TBIAOTANT

Jeremiah 9 in the TBT1E

Jeremiah 9 in the TBT1E2

Jeremiah 9 in the TFTIP

Jeremiah 9 in the TFTU

Jeremiah 9 in the TGNTATF3T

Jeremiah 9 in the THAI

Jeremiah 9 in the TNFD

Jeremiah 9 in the TNT

Jeremiah 9 in the TNTIK

Jeremiah 9 in the TNTIL

Jeremiah 9 in the TNTIN

Jeremiah 9 in the TNTIP

Jeremiah 9 in the TNTIZ

Jeremiah 9 in the TOMA

Jeremiah 9 in the TTENT

Jeremiah 9 in the UBG

Jeremiah 9 in the UGV

Jeremiah 9 in the UGV2

Jeremiah 9 in the UGV3

Jeremiah 9 in the VBL

Jeremiah 9 in the VDCC

Jeremiah 9 in the YALU

Jeremiah 9 in the YAPE

Jeremiah 9 in the YBVTP

Jeremiah 9 in the ZBP