Job 4 (BOYCB)
1 Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani dáhùn wí pé, 2 “Bí àwa bá fi ẹnu lé e, láti bá ọ sọ̀rọ̀, ìwọ o ha banújẹ́?Ṣùgbọ́n ta ni ó lè pa ọ̀rọ̀ mọ́ ẹnu láìsọ? 3 Kíyèsi i, ìwọ sá ti kọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn,ìwọ ṣá ti mú ọwọ́ aláìlera le. 4 Ọ̀rọ̀ rẹ ti gbé àwọn tí ń ṣubú lọ dúró,ìwọ sì ti mú eékún àwọn tí ń wárìrì lera. 5 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí ó dé bá ọ, ó sì rẹ̀ ọ́, ó kọlù ọ́;ara rẹ kò lélẹ̀. 6 Ìbẹ̀rù Ọlọ́run rẹ kò ha jẹ́ ìgbẹ́kẹ̀lé rẹàti ìdúró ọ̀nà rẹ kò ha sì jẹ́ ìrètí rẹ? 7 “Èmi bẹ̀ ọ́ rántí, ta ni ó ṣègbé rí láìṣẹ̀?Tàbí níbo ni a gbé gé olódodo kúrò rí? 8 Àní bí èmi ti rí i pé, àwọn tí ń ṣe ìtulẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀,tí wọ́n sì fún irúgbìn ìwà búburú, wọn a sì ká èso rẹ̀ náà. 9 Nípa ìfẹ́ sí Ọlọ́run wọn a ṣègbé,nípa èémí ìbínú rẹ̀ wọn a parun. 10 Bíbú ramúramù kìnnìún àti ohùn òǹrorò kìnnìúnàti eyín àwọn ẹgbọrọ kìnnìún ní a ká. 11 Kìnnìún kígbe, nítorí àìrí ohun ọdẹ,àwọn ẹgbọrọ kìnnìún sísanra ni a túká kiri. 12 “Ǹjẹ́ nísinsin yìí a fi ohun àṣírí kan hàn fún mi,etí mi sì gbà díẹ̀ nínú rẹ̀. 13 Ní ìrò inú lójú ìran òru,nígbà tí oorun èjìká kùn ènìyàn. 14 Ẹ̀rù bà mí àti ìwárìrìtí ó mú gbogbo egungun mi jí pépé. 15 Nígbà náà ni ẹ̀mí kan kọjá lọ ní iwájú mi,irun ara mi dìde dúró ṣánṣán. 16 Ó dúró jẹ́ẹ́,ṣùgbọ́n èmi kò le wo àpẹẹrẹ ìrí rẹ̀,àwòrán kan hàn níwájú mi,ìdákẹ́rọ́rọ́ wà, mo sì gbóhùn kan wí pé, 17 ‘Ẹni kíkú le jẹ́ olódodo ju Ọlọ́run,ènìyàn ha le mọ́ ju ẹlẹ́dàá rẹ̀ bí? 18 Kíyèsi i, òun kò gbẹ́kẹ̀lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀,nínú àwọn angẹli rẹ̀ ní ó sì rí ẹ̀ṣẹ̀. 19 Mélòó mélòó àwọn tí ń gbé inú ilé amọ̀,ẹni tí ìpìlẹ̀ wọ́n jásí erùpẹ̀tí yóò di rírun kòkòrò. 20 A pa wọ́n run láàrín òwúrọ̀ àti àṣálẹ́wọ́n sì parun títí láé, láìrí ẹni kà á sí. 21 A kò ha ké okùn iye wọ́n kúrò bí?Wọ́n kú, àní láìlọ́gbọ́n?’
In Other Versions
Job 4 in the ANGEFD
Job 4 in the ANTPNG2D
Job 4 in the AS21
Job 4 in the BAGH
Job 4 in the BBPNG
Job 4 in the BBT1E
Job 4 in the BDS
Job 4 in the BEV
Job 4 in the BHAD
Job 4 in the BIB
Job 4 in the BLPT
Job 4 in the BNT
Job 4 in the BNTABOOT
Job 4 in the BNTLV
Job 4 in the BOATCB
Job 4 in the BOATCB2
Job 4 in the BOBCV
Job 4 in the BOCNT
Job 4 in the BOECS
Job 4 in the BOGWICC
Job 4 in the BOHCB
Job 4 in the BOHCV
Job 4 in the BOHLNT
Job 4 in the BOHNTLTAL
Job 4 in the BOICB
Job 4 in the BOILNTAP
Job 4 in the BOITCV
Job 4 in the BOKCV
Job 4 in the BOKCV2
Job 4 in the BOKHWOG
Job 4 in the BOKSSV
Job 4 in the BOLCB
Job 4 in the BOLCB2
Job 4 in the BOMCV
Job 4 in the BONAV
Job 4 in the BONCB
Job 4 in the BONLT
Job 4 in the BONUT2
Job 4 in the BOPLNT
Job 4 in the BOSCB
Job 4 in the BOSNC
Job 4 in the BOTLNT
Job 4 in the BOVCB
Job 4 in the BPBB
Job 4 in the BPH
Job 4 in the BSB
Job 4 in the CCB
Job 4 in the CUV
Job 4 in the CUVS
Job 4 in the DBT
Job 4 in the DGDNT
Job 4 in the DHNT
Job 4 in the DNT
Job 4 in the ELBE
Job 4 in the EMTV
Job 4 in the ESV
Job 4 in the FBV
Job 4 in the FEB
Job 4 in the GGMNT
Job 4 in the GNT
Job 4 in the HARY
Job 4 in the HNT
Job 4 in the IRVA
Job 4 in the IRVB
Job 4 in the IRVG
Job 4 in the IRVH
Job 4 in the IRVK
Job 4 in the IRVM
Job 4 in the IRVM2
Job 4 in the IRVO
Job 4 in the IRVP
Job 4 in the IRVT
Job 4 in the IRVT2
Job 4 in the IRVU
Job 4 in the ISVN
Job 4 in the JSNT
Job 4 in the KAPI
Job 4 in the KBT1ETNIK
Job 4 in the KBV
Job 4 in the KJV
Job 4 in the KNFD
Job 4 in the LBA
Job 4 in the LBLA
Job 4 in the LNT
Job 4 in the LSV
Job 4 in the MAAL
Job 4 in the MBV
Job 4 in the MBV2
Job 4 in the MHNT
Job 4 in the MKNFD
Job 4 in the MNG
Job 4 in the MNT
Job 4 in the MNT2
Job 4 in the MRS1T
Job 4 in the NAA
Job 4 in the NASB
Job 4 in the NBLA
Job 4 in the NBS
Job 4 in the NBVTP
Job 4 in the NET2
Job 4 in the NIV11
Job 4 in the NNT
Job 4 in the NNT2
Job 4 in the NNT3
Job 4 in the PDDPT
Job 4 in the PFNT
Job 4 in the RMNT
Job 4 in the SBIAS
Job 4 in the SBIBS
Job 4 in the SBIBS2
Job 4 in the SBICS
Job 4 in the SBIDS
Job 4 in the SBIGS
Job 4 in the SBIHS
Job 4 in the SBIIS
Job 4 in the SBIIS2
Job 4 in the SBIIS3
Job 4 in the SBIKS
Job 4 in the SBIKS2
Job 4 in the SBIMS
Job 4 in the SBIOS
Job 4 in the SBIPS
Job 4 in the SBISS
Job 4 in the SBITS
Job 4 in the SBITS2
Job 4 in the SBITS3
Job 4 in the SBITS4
Job 4 in the SBIUS
Job 4 in the SBIVS
Job 4 in the SBT
Job 4 in the SBT1E
Job 4 in the SCHL
Job 4 in the SNT
Job 4 in the SUSU
Job 4 in the SUSU2
Job 4 in the SYNO
Job 4 in the TBIAOTANT
Job 4 in the TBT1E
Job 4 in the TBT1E2
Job 4 in the TFTIP
Job 4 in the TFTU
Job 4 in the TGNTATF3T
Job 4 in the THAI
Job 4 in the TNFD
Job 4 in the TNT
Job 4 in the TNTIK
Job 4 in the TNTIL
Job 4 in the TNTIN
Job 4 in the TNTIP
Job 4 in the TNTIZ
Job 4 in the TOMA
Job 4 in the TTENT
Job 4 in the UBG
Job 4 in the UGV
Job 4 in the UGV2
Job 4 in the UGV3
Job 4 in the VBL
Job 4 in the VDCC
Job 4 in the YALU
Job 4 in the YAPE
Job 4 in the YBVTP
Job 4 in the ZBP