Joshua 23 (BOYCB)
1 Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, nígbà tí OLÚWA sì ti fún Israẹli ní ìsinmi kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn tí ó yí wọn ká, nígbà náà Joṣua sì ti di arúgbó. 2 Ó sì pe gbogbo Israẹli jọ: àgbàgbà wọn, olórí wọn, adájọ́ àti àwọn ìjòyè, ó sì sọ fún wọn pé, “Èmi ti pọ̀ ní ọdún èmi ti di arúgbó. 3 Ẹ̀yin tìkára yín sì ti rí ohun gbogbo tí OLÚWA Ọlọ́run yín ti ṣe sí gbogbo orílẹ̀-èdè wọ̀nyí nítorí yín, OLÚWA Ọlọ́run yín ni ó jà fún yín. 4 Ẹ rántí bí mo ṣe pín ogún ìní fún àwọn ẹ̀yà yín ní ilẹ̀ orílẹ̀-èdè gbogbo tí ó kù; àwọn orílẹ̀-èdè tí mo ti ṣẹ́gun ní àárín Jordani àti Òkun Ńlá ní ìwọ̀-oòrùn. 5 OLÚWA Ọlọ́run yín fúnra rẹ̀ yóò lé wọn jáde kúrò ní ọ̀nà yín, yóò sì tì wọ́n jáde ní iwájú yín, ẹ̀yin yóò sì gba ilẹ̀ ìní wọn, gẹ́gẹ́ bí OLÚWA Ọlọ́run ti ṣe ìlérí fún yín. 6 “Ẹ jẹ́ alágbára gidigidi, kí ẹ sì ṣọ́ra láti ṣe ìgbọ́ràn sí ohun tí a kọ sí inú ìwé òfin Mose, láìyí padà sí ọ̀tún tàbí sí òsì. 7 Ẹ má ṣe ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tí ó ṣẹ́kù láàrín yín; ẹ má ṣe pe orúkọ òrìṣà wọn tàbí kí ẹ fi wọ́n búra. Ẹ kò gbọdọ̀ sìn wọ́n tàbí ki ẹ tẹríba fún wọn. 8 Ṣùgbọ́n ẹ di OLÚWA Ọlọ́run yín mú ṣinṣin gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ń ṣe tẹ́lẹ̀ títí di àkókò yìí. 9 “OLÚWA ti lé àwọn orílẹ̀-èdè ńlá àti alágbára kúrò níwájú yín; títí di òní yìí kò sí ẹnìkan tí ó le dojúkọ yín. 10 Ọ̀kan nínú yín lé ẹgbẹ̀rún (1,000) ọ̀tá, nítorí tí OLÚWA Ọlọ́run yín jà fún yín gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ìlérí. 11 Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ ṣọ́ra gidigidi láti fẹ́ràn OLÚWA Ọlọ́run yín. 12 “Ṣùgbọ́n bí ẹ bá yí padà, tí ẹ sì gba ìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó ṣẹ́kù lára àwọn orílẹ̀-èdè tí ó kù láàrín yín, tí ẹ sì ń fọmọ fún ara yín ní ìyàwó, tí ẹ sì bá wọn ní àjọṣepọ̀. 13 Nígbà náà ni ẹ ó mọ̀ dájú pé OLÚWA Ọlọ́run yín kì yóò lé àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí jáde mọ́ kúrò níwájú yín. Dípò èyí, wọn yóò jẹ́ ìkẹ́kùn àti tàkúté fún un yín, pàṣán ní ẹ̀yin yín àti ẹ̀gún ní ojú yín, títí ẹ ó fi ṣègbé kúrò ní ilẹ̀ dáradára yí, èyí tí OLÚWA Ọlọ́run yín ti fi fún yín. 14 “Nísinsin yìí èmi ti fẹ́ máa lọ sí ibi tí àwọn àgbà ń rè. Ẹ mọ̀ pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti àyà yín pé, kò sí ohun kan tí ó kùnà nínú àwọn ìlérí rere gbogbo tí OLÚWA Ọlọ́run yín fi fún un yín. Gbogbo ìlérí tó ti ṣe kò sí ọ̀kan tí ó kùnà. 15 Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìlérí dáradára gbogbo ti OLÚWA Ọlọ́run yín ti wá sí ìmúṣẹ, bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA yóò mú ibi gbogbo tí ó ti kìlọ̀ wá sí orí yín, títí yóò fi pa yín run kúrò ní ilẹ̀ dáradára tí ó ti fi fún un yín. 16 Bí ẹ bá sẹ̀ sí májẹ̀mú OLÚWA Ọlọ́run yín, èyí tí ó pàṣẹ fún un yín, tí ẹ bá sì lọ tí ẹ sì sin àwọn òrìṣà tí ẹ sì tẹ orí ba fún wọn, ìbínú gbígbóná OLÚWA yóò wá sórí i yín, ẹ̀yin yóò sì ṣègbé kíákíá kúrò ní ilẹ̀ dáradára tí ó ti fi fún un yín.”
In Other Versions
Joshua 23 in the ANGEFD
Joshua 23 in the ANTPNG2D
Joshua 23 in the AS21
Joshua 23 in the BAGH
Joshua 23 in the BBPNG
Joshua 23 in the BBT1E
Joshua 23 in the BDS
Joshua 23 in the BEV
Joshua 23 in the BHAD
Joshua 23 in the BIB
Joshua 23 in the BLPT
Joshua 23 in the BNT
Joshua 23 in the BNTABOOT
Joshua 23 in the BNTLV
Joshua 23 in the BOATCB
Joshua 23 in the BOATCB2
Joshua 23 in the BOBCV
Joshua 23 in the BOCNT
Joshua 23 in the BOECS
Joshua 23 in the BOGWICC
Joshua 23 in the BOHCB
Joshua 23 in the BOHCV
Joshua 23 in the BOHLNT
Joshua 23 in the BOHNTLTAL
Joshua 23 in the BOICB
Joshua 23 in the BOILNTAP
Joshua 23 in the BOITCV
Joshua 23 in the BOKCV
Joshua 23 in the BOKCV2
Joshua 23 in the BOKHWOG
Joshua 23 in the BOKSSV
Joshua 23 in the BOLCB
Joshua 23 in the BOLCB2
Joshua 23 in the BOMCV
Joshua 23 in the BONAV
Joshua 23 in the BONCB
Joshua 23 in the BONLT
Joshua 23 in the BONUT2
Joshua 23 in the BOPLNT
Joshua 23 in the BOSCB
Joshua 23 in the BOSNC
Joshua 23 in the BOTLNT
Joshua 23 in the BOVCB
Joshua 23 in the BPBB
Joshua 23 in the BPH
Joshua 23 in the BSB
Joshua 23 in the CCB
Joshua 23 in the CUV
Joshua 23 in the CUVS
Joshua 23 in the DBT
Joshua 23 in the DGDNT
Joshua 23 in the DHNT
Joshua 23 in the DNT
Joshua 23 in the ELBE
Joshua 23 in the EMTV
Joshua 23 in the ESV
Joshua 23 in the FBV
Joshua 23 in the FEB
Joshua 23 in the GGMNT
Joshua 23 in the GNT
Joshua 23 in the HARY
Joshua 23 in the HNT
Joshua 23 in the IRVA
Joshua 23 in the IRVB
Joshua 23 in the IRVG
Joshua 23 in the IRVH
Joshua 23 in the IRVK
Joshua 23 in the IRVM
Joshua 23 in the IRVM2
Joshua 23 in the IRVO
Joshua 23 in the IRVP
Joshua 23 in the IRVT
Joshua 23 in the IRVT2
Joshua 23 in the IRVU
Joshua 23 in the ISVN
Joshua 23 in the JSNT
Joshua 23 in the KAPI
Joshua 23 in the KBT1ETNIK
Joshua 23 in the KBV
Joshua 23 in the KJV
Joshua 23 in the KNFD
Joshua 23 in the LBA
Joshua 23 in the LBLA
Joshua 23 in the LNT
Joshua 23 in the LSV
Joshua 23 in the MAAL
Joshua 23 in the MBV
Joshua 23 in the MBV2
Joshua 23 in the MHNT
Joshua 23 in the MKNFD
Joshua 23 in the MNG
Joshua 23 in the MNT
Joshua 23 in the MNT2
Joshua 23 in the MRS1T
Joshua 23 in the NAA
Joshua 23 in the NASB
Joshua 23 in the NBLA
Joshua 23 in the NBS
Joshua 23 in the NBVTP
Joshua 23 in the NET2
Joshua 23 in the NIV11
Joshua 23 in the NNT
Joshua 23 in the NNT2
Joshua 23 in the NNT3
Joshua 23 in the PDDPT
Joshua 23 in the PFNT
Joshua 23 in the RMNT
Joshua 23 in the SBIAS
Joshua 23 in the SBIBS
Joshua 23 in the SBIBS2
Joshua 23 in the SBICS
Joshua 23 in the SBIDS
Joshua 23 in the SBIGS
Joshua 23 in the SBIHS
Joshua 23 in the SBIIS
Joshua 23 in the SBIIS2
Joshua 23 in the SBIIS3
Joshua 23 in the SBIKS
Joshua 23 in the SBIKS2
Joshua 23 in the SBIMS
Joshua 23 in the SBIOS
Joshua 23 in the SBIPS
Joshua 23 in the SBISS
Joshua 23 in the SBITS
Joshua 23 in the SBITS2
Joshua 23 in the SBITS3
Joshua 23 in the SBITS4
Joshua 23 in the SBIUS
Joshua 23 in the SBIVS
Joshua 23 in the SBT
Joshua 23 in the SBT1E
Joshua 23 in the SCHL
Joshua 23 in the SNT
Joshua 23 in the SUSU
Joshua 23 in the SUSU2
Joshua 23 in the SYNO
Joshua 23 in the TBIAOTANT
Joshua 23 in the TBT1E
Joshua 23 in the TBT1E2
Joshua 23 in the TFTIP
Joshua 23 in the TFTU
Joshua 23 in the TGNTATF3T
Joshua 23 in the THAI
Joshua 23 in the TNFD
Joshua 23 in the TNT
Joshua 23 in the TNTIK
Joshua 23 in the TNTIL
Joshua 23 in the TNTIN
Joshua 23 in the TNTIP
Joshua 23 in the TNTIZ
Joshua 23 in the TOMA
Joshua 23 in the TTENT
Joshua 23 in the UBG
Joshua 23 in the UGV
Joshua 23 in the UGV2
Joshua 23 in the UGV3
Joshua 23 in the VBL
Joshua 23 in the VDCC
Joshua 23 in the YALU
Joshua 23 in the YAPE
Joshua 23 in the YBVTP
Joshua 23 in the ZBP