Matthew 28 (BOYCB)

1 Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kìn-ín-ní ọ̀sẹ̀, bí ilẹ̀ ti ń mọ́, Maria Magdalene àti Maria kejì lọ sí ibojì. 2 Wọ́n rí i pé, ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá ṣẹ̀ tí ó mú gbogbo ilẹ̀ mì tìtì. Nítorí angẹli Olúwa ti sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run. Ó ti yí òkúta ibojì kúrò. Ó sì jókòó lé e lórí. 3 Ojú rẹ̀ tàn bí mọ̀nàmọ́ná. Aṣọ rẹ̀ sì jẹ́ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwú. 4 Ẹ̀rù ba àwọn olùṣọ́, wọ́n sì wárìrì wọn sì dàbí òkú. 5 Nígbà náà ni angẹli náà wí fún àwọn obìnrin náà pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù. Mo mọ̀ pé ẹ̀yin ń wá Jesu tí a kàn mọ́ àgbélébùú. 6 Ṣùgbọ́n kò sí níhìn-ín. Nítorí pé ó ti jíǹde, gẹ́gẹ́ bí òun ti wí. Ẹ wọlé wá wo ibi ti wọ́n tẹ́ ẹ sí. 7 Nísinsin yìí, ẹ lọ kíákíá láti sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, ‘Ó ti jíǹde kúrò nínú òkú. Àti pé òun ń lọ sí Galili síwájú yín, níbẹ̀ ni ẹ̀yin yóò gbé rí i,’ wò ó, o ti sọ fún yin.” 8 Àwọn obìnrin náà sáré kúrò ní ibojì pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ayọ̀ ńlá. Wọ́n sáré láti sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn nípa ìròyìn tí angẹli náà fi fún wọn. 9 Bí wọ́n ti ń sáré lọ lójijì Jesu pàdé wọn. Ó wí pé, “Àlàáfíà”, wọ́n wólẹ̀ níwájú rẹ̀. Wọ́n gbá a ní ẹsẹ̀ mú. Wọ́n sì foríbalẹ̀ fún un. 10 Nígbà náà, Jesu wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù. Ẹ lọ sọ fún àwọn arákùnrin mi pé, ‘Kí wọ́n lọ tààrà sí Galili níbẹ̀ ni wọn yóò gbé rí mi.’ ” 11 Bí àwọn obìnrin náà sì ti ń lọ sí ìlú, díẹ̀ nínú àwọn olùṣọ́ tí wọ́n ti ń ṣọ́ ibojì lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà. 12 Wọ́n sì pe ìpàdé àwọn àgbàgbà Júù. Wọ́n sì fohùn ṣọ̀kan láti fi owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fún àwọn olùṣọ́. 13 Wọ́n wí pé, “Ẹ sọ fún àwọn ènìyàn pé, ‘Gbogbo yín sùn nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu wá lóru láti jí òkú rẹ̀.’ 14 Bí Pilatu bá sì mọ̀ nípa rẹ̀, àwa yóò ṣe àlàyé tí yóò tẹ́ ẹ lọ́rùn fún un, tí ọ̀rọ̀ náà kì yóò fi lè kó bá yín.” 15 Àwọn olùṣọ́ sì gba owó náà. Wọ́n sì ṣe gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti darí wọn. Ìtàn yìí sì tàn ká kíákíá láàrín àwọn Júù. Wọ́n sì gba ìtàn náà gbọ́ títí di òní yìí. 16 Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mọ́kànlá náà lọ sí Galili ní orí òkè níbi tí Jesu sọ pé wọn yóò ti rí òun. 17 Nígbà tí wọ́n sì rí i, wọ́n foríbalẹ̀ fún un. Ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú wọn ṣe iyèméjì bóyá Jesu ni tàbí òun kọ́. 18 Nígbà náà ni Jesu wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Gbogbo agbára ni ọ̀run àti ní ayé ni a ti fi fún mi. 19 Nítorí náà, ẹ lọ, ẹ sọ wọ́n di ọmọ-ẹ̀yìn orílẹ̀-èdè gbogbo, ẹ máa bamitiisi wọn ní orúkọ Baba àti ti Ọmọ àti ti Ẹ̀mí Mímọ́. 20 Ẹ kọ́ wọn láti máa kíyèsi ohun gbogbo èyí tí mo ti pàṣẹ fún yín. Nítorí èmi wà pẹ̀lú yín ní ìgbà gbogbo títí tí ó fi dé òpin ayé.”

In Other Versions

Matthew 28 in the ANGEFD

Matthew 28 in the ANTPNG2D

Matthew 28 in the AS21

Matthew 28 in the BAGH

Matthew 28 in the BBPNG

Matthew 28 in the BBT1E

Matthew 28 in the BDS

Matthew 28 in the BEV

Matthew 28 in the BHAD

Matthew 28 in the BIB

Matthew 28 in the BLPT

Matthew 28 in the BNT

Matthew 28 in the BNTABOOT

Matthew 28 in the BNTLV

Matthew 28 in the BOATCB

Matthew 28 in the BOATCB2

Matthew 28 in the BOBCV

Matthew 28 in the BOCNT

Matthew 28 in the BOECS

Matthew 28 in the BOGWICC

Matthew 28 in the BOHCB

Matthew 28 in the BOHCV

Matthew 28 in the BOHLNT

Matthew 28 in the BOHNTLTAL

Matthew 28 in the BOICB

Matthew 28 in the BOILNTAP

Matthew 28 in the BOITCV

Matthew 28 in the BOKCV

Matthew 28 in the BOKCV2

Matthew 28 in the BOKHWOG

Matthew 28 in the BOKSSV

Matthew 28 in the BOLCB

Matthew 28 in the BOLCB2

Matthew 28 in the BOMCV

Matthew 28 in the BONAV

Matthew 28 in the BONCB

Matthew 28 in the BONLT

Matthew 28 in the BONUT2

Matthew 28 in the BOPLNT

Matthew 28 in the BOSCB

Matthew 28 in the BOSNC

Matthew 28 in the BOTLNT

Matthew 28 in the BOVCB

Matthew 28 in the BPBB

Matthew 28 in the BPH

Matthew 28 in the BSB

Matthew 28 in the CCB

Matthew 28 in the CUV

Matthew 28 in the CUVS

Matthew 28 in the DBT

Matthew 28 in the DGDNT

Matthew 28 in the DHNT

Matthew 28 in the DNT

Matthew 28 in the ELBE

Matthew 28 in the EMTV

Matthew 28 in the ESV

Matthew 28 in the FBV

Matthew 28 in the FEB

Matthew 28 in the GGMNT

Matthew 28 in the GNT

Matthew 28 in the HARY

Matthew 28 in the HNT

Matthew 28 in the IRVA

Matthew 28 in the IRVB

Matthew 28 in the IRVG

Matthew 28 in the IRVH

Matthew 28 in the IRVK

Matthew 28 in the IRVM

Matthew 28 in the IRVM2

Matthew 28 in the IRVO

Matthew 28 in the IRVP

Matthew 28 in the IRVT

Matthew 28 in the IRVT2

Matthew 28 in the IRVU

Matthew 28 in the ISVN

Matthew 28 in the JSNT

Matthew 28 in the KAPI

Matthew 28 in the KBT1ETNIK

Matthew 28 in the KBV

Matthew 28 in the KJV

Matthew 28 in the KNFD

Matthew 28 in the LBA

Matthew 28 in the LBLA

Matthew 28 in the LNT

Matthew 28 in the LSV

Matthew 28 in the MAAL

Matthew 28 in the MBV

Matthew 28 in the MBV2

Matthew 28 in the MHNT

Matthew 28 in the MKNFD

Matthew 28 in the MNG

Matthew 28 in the MNT

Matthew 28 in the MNT2

Matthew 28 in the MRS1T

Matthew 28 in the NAA

Matthew 28 in the NASB

Matthew 28 in the NBLA

Matthew 28 in the NBS

Matthew 28 in the NBVTP

Matthew 28 in the NET2

Matthew 28 in the NIV11

Matthew 28 in the NNT

Matthew 28 in the NNT2

Matthew 28 in the NNT3

Matthew 28 in the PDDPT

Matthew 28 in the PFNT

Matthew 28 in the RMNT

Matthew 28 in the SBIAS

Matthew 28 in the SBIBS

Matthew 28 in the SBIBS2

Matthew 28 in the SBICS

Matthew 28 in the SBIDS

Matthew 28 in the SBIGS

Matthew 28 in the SBIHS

Matthew 28 in the SBIIS

Matthew 28 in the SBIIS2

Matthew 28 in the SBIIS3

Matthew 28 in the SBIKS

Matthew 28 in the SBIKS2

Matthew 28 in the SBIMS

Matthew 28 in the SBIOS

Matthew 28 in the SBIPS

Matthew 28 in the SBISS

Matthew 28 in the SBITS

Matthew 28 in the SBITS2

Matthew 28 in the SBITS3

Matthew 28 in the SBITS4

Matthew 28 in the SBIUS

Matthew 28 in the SBIVS

Matthew 28 in the SBT

Matthew 28 in the SBT1E

Matthew 28 in the SCHL

Matthew 28 in the SNT

Matthew 28 in the SUSU

Matthew 28 in the SUSU2

Matthew 28 in the SYNO

Matthew 28 in the TBIAOTANT

Matthew 28 in the TBT1E

Matthew 28 in the TBT1E2

Matthew 28 in the TFTIP

Matthew 28 in the TFTU

Matthew 28 in the TGNTATF3T

Matthew 28 in the THAI

Matthew 28 in the TNFD

Matthew 28 in the TNT

Matthew 28 in the TNTIK

Matthew 28 in the TNTIL

Matthew 28 in the TNTIN

Matthew 28 in the TNTIP

Matthew 28 in the TNTIZ

Matthew 28 in the TOMA

Matthew 28 in the TTENT

Matthew 28 in the UBG

Matthew 28 in the UGV

Matthew 28 in the UGV2

Matthew 28 in the UGV3

Matthew 28 in the VBL

Matthew 28 in the VDCC

Matthew 28 in the YALU

Matthew 28 in the YAPE

Matthew 28 in the YBVTP

Matthew 28 in the ZBP