Nehemiah 1 (BOYCB)
1 Ọ̀rọ̀ Nehemiah ọmọ Hakaliah. Ní oṣù Kisleu ní ogún ọdún (ìjọba Ahaswerusi ọba Persia) nígbà tí mo wà ní ààfin Susa, 2 Hanani, ọ̀kan nínú àwọn arákùnrin mi wá láti Juda pẹ̀lú àwọn ọkùnrin kan, mo sì béèrè lọ́wọ́ wọn nípa àwọn Júù tí ó ṣẹ́kù tí wọn kò kó ní ìgbèkùn, àti nípa Jerusalẹmu. 3 Wọ́n sọ fún mi pé, “Àwọn tí ó kù tí a kó ní ìgbèkùn tí wọ́n sì padà sí agbègbè ìjọba wà nínú wàhálà púpọ̀ àti ẹ̀gàn. Odi Jerusalẹmu ti wó lulẹ̀ a sì ti fi iná sun ẹnu ibodè rẹ̀.” 4 Nígbà tí mo gbọ́ àwọn nǹkan wọ̀nyí, mo jókòó mo sì sọkún. Mo ṣọ̀fọ̀, mo gbààwẹ̀, mo sì gbàdúrà fún ọjọ́ díẹ̀ níwájú Ọlọ́run ọ̀run. 5 Nígbà náà ni mo wí pé:“OLÚWA, Ọlọ́run ọ̀run, Ọlọ́run tí ó tóbi tí ó sì ní ẹ̀rù, tí ó ń pa májẹ̀mú ìfẹ́ rẹ̀ mọ́ pẹ̀lú wọn tí ó fẹ́ ẹ tí wọ́n sì ń pa àṣẹ mọ́. 6 Jẹ́ kí etí rẹ kí ó ṣí sílẹ̀, kí ojú ù rẹ kí ó sì ṣí sílẹ̀ láti gbọ́ àdúrà tí ìránṣẹ́ rẹ ń gbà ní iwájú rẹ ní ọ̀sán àti ní òru fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ, àwọn ènìyàn Israẹli. Mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àwa ọmọ Israẹli àti tèmi àti ti ilé baba mi, tí a ti ṣẹ̀ sí ọ. 7 Àwa ti ṣe búburú sí ọ. A kò sì pa àṣẹ ìlànà àti òfin tí ìwọ fún Mose ìránṣẹ́ rẹ mọ́. 8 “Rántí ìlànà tí o fún Mose ìránṣẹ́ rẹ, wí pé, ‘Bí ìwọ bá jẹ́ aláìṣòótọ́, èmi yóò fọ́n yín ká sí àárín àwọn orílẹ̀-èdè. 9 Ṣùgbọ́n tí ẹ̀yin bá yípadà sí mi, tí ẹ bá sì pa àṣẹ mi mọ́, nígbà náà bí àwọn ènìyàn yín tí a kó ní ìgbèkùn tilẹ̀ wà ní jìnnà réré ìpẹ̀kun ọ̀run, èmi yóò kó wọn jọ láti ibẹ̀, èmi yóò sì mú wọn wá, sí ibi tí èmi ti yàn bí i ibùgbé fún orúkọ mi.’ 10 “Àwọn ni ìránṣẹ́ rẹ àti ènìyàn rẹ àwọn tí ìwọ rà padà pẹ̀lú agbára ńlá rẹ àti ọwọ́ agbára ńlá rẹ. 11 OLÚWA, jẹ́ kí etí rẹ ṣí sílẹ̀ sí àdúrà ìránṣẹ́ rẹ yìí, àti sí àdúrà àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ní inú dídùn láti bọ̀wọ̀ fún orúkọ rẹ. Fún ìránṣẹ́ rẹ ní àṣeyọrí lónìí kí o sì síjú àánú wò ó níwájú ọkùnrin yìí.”Nítorí tí mo jẹ́ agbọ́tí ọba nígbà náà.
In Other Versions
Nehemiah 1 in the ANGEFD
Nehemiah 1 in the ANTPNG2D
Nehemiah 1 in the AS21
Nehemiah 1 in the BAGH
Nehemiah 1 in the BBPNG
Nehemiah 1 in the BBT1E
Nehemiah 1 in the BDS
Nehemiah 1 in the BEV
Nehemiah 1 in the BHAD
Nehemiah 1 in the BIB
Nehemiah 1 in the BLPT
Nehemiah 1 in the BNT
Nehemiah 1 in the BNTABOOT
Nehemiah 1 in the BNTLV
Nehemiah 1 in the BOATCB
Nehemiah 1 in the BOATCB2
Nehemiah 1 in the BOBCV
Nehemiah 1 in the BOCNT
Nehemiah 1 in the BOECS
Nehemiah 1 in the BOGWICC
Nehemiah 1 in the BOHCB
Nehemiah 1 in the BOHCV
Nehemiah 1 in the BOHLNT
Nehemiah 1 in the BOHNTLTAL
Nehemiah 1 in the BOICB
Nehemiah 1 in the BOILNTAP
Nehemiah 1 in the BOITCV
Nehemiah 1 in the BOKCV
Nehemiah 1 in the BOKCV2
Nehemiah 1 in the BOKHWOG
Nehemiah 1 in the BOKSSV
Nehemiah 1 in the BOLCB
Nehemiah 1 in the BOLCB2
Nehemiah 1 in the BOMCV
Nehemiah 1 in the BONAV
Nehemiah 1 in the BONCB
Nehemiah 1 in the BONLT
Nehemiah 1 in the BONUT2
Nehemiah 1 in the BOPLNT
Nehemiah 1 in the BOSCB
Nehemiah 1 in the BOSNC
Nehemiah 1 in the BOTLNT
Nehemiah 1 in the BOVCB
Nehemiah 1 in the BPBB
Nehemiah 1 in the BPH
Nehemiah 1 in the BSB
Nehemiah 1 in the CCB
Nehemiah 1 in the CUV
Nehemiah 1 in the CUVS
Nehemiah 1 in the DBT
Nehemiah 1 in the DGDNT
Nehemiah 1 in the DHNT
Nehemiah 1 in the DNT
Nehemiah 1 in the ELBE
Nehemiah 1 in the EMTV
Nehemiah 1 in the ESV
Nehemiah 1 in the FBV
Nehemiah 1 in the FEB
Nehemiah 1 in the GGMNT
Nehemiah 1 in the GNT
Nehemiah 1 in the HARY
Nehemiah 1 in the HNT
Nehemiah 1 in the IRVA
Nehemiah 1 in the IRVB
Nehemiah 1 in the IRVG
Nehemiah 1 in the IRVH
Nehemiah 1 in the IRVK
Nehemiah 1 in the IRVM
Nehemiah 1 in the IRVM2
Nehemiah 1 in the IRVO
Nehemiah 1 in the IRVP
Nehemiah 1 in the IRVT
Nehemiah 1 in the IRVT2
Nehemiah 1 in the IRVU
Nehemiah 1 in the ISVN
Nehemiah 1 in the JSNT
Nehemiah 1 in the KAPI
Nehemiah 1 in the KBT1ETNIK
Nehemiah 1 in the KBV
Nehemiah 1 in the KJV
Nehemiah 1 in the KNFD
Nehemiah 1 in the LBA
Nehemiah 1 in the LBLA
Nehemiah 1 in the LNT
Nehemiah 1 in the LSV
Nehemiah 1 in the MAAL
Nehemiah 1 in the MBV
Nehemiah 1 in the MBV2
Nehemiah 1 in the MHNT
Nehemiah 1 in the MKNFD
Nehemiah 1 in the MNG
Nehemiah 1 in the MNT
Nehemiah 1 in the MNT2
Nehemiah 1 in the MRS1T
Nehemiah 1 in the NAA
Nehemiah 1 in the NASB
Nehemiah 1 in the NBLA
Nehemiah 1 in the NBS
Nehemiah 1 in the NBVTP
Nehemiah 1 in the NET2
Nehemiah 1 in the NIV11
Nehemiah 1 in the NNT
Nehemiah 1 in the NNT2
Nehemiah 1 in the NNT3
Nehemiah 1 in the PDDPT
Nehemiah 1 in the PFNT
Nehemiah 1 in the RMNT
Nehemiah 1 in the SBIAS
Nehemiah 1 in the SBIBS
Nehemiah 1 in the SBIBS2
Nehemiah 1 in the SBICS
Nehemiah 1 in the SBIDS
Nehemiah 1 in the SBIGS
Nehemiah 1 in the SBIHS
Nehemiah 1 in the SBIIS
Nehemiah 1 in the SBIIS2
Nehemiah 1 in the SBIIS3
Nehemiah 1 in the SBIKS
Nehemiah 1 in the SBIKS2
Nehemiah 1 in the SBIMS
Nehemiah 1 in the SBIOS
Nehemiah 1 in the SBIPS
Nehemiah 1 in the SBISS
Nehemiah 1 in the SBITS
Nehemiah 1 in the SBITS2
Nehemiah 1 in the SBITS3
Nehemiah 1 in the SBITS4
Nehemiah 1 in the SBIUS
Nehemiah 1 in the SBIVS
Nehemiah 1 in the SBT
Nehemiah 1 in the SBT1E
Nehemiah 1 in the SCHL
Nehemiah 1 in the SNT
Nehemiah 1 in the SUSU
Nehemiah 1 in the SUSU2
Nehemiah 1 in the SYNO
Nehemiah 1 in the TBIAOTANT
Nehemiah 1 in the TBT1E
Nehemiah 1 in the TBT1E2
Nehemiah 1 in the TFTIP
Nehemiah 1 in the TFTU
Nehemiah 1 in the TGNTATF3T
Nehemiah 1 in the THAI
Nehemiah 1 in the TNFD
Nehemiah 1 in the TNT
Nehemiah 1 in the TNTIK
Nehemiah 1 in the TNTIL
Nehemiah 1 in the TNTIN
Nehemiah 1 in the TNTIP
Nehemiah 1 in the TNTIZ
Nehemiah 1 in the TOMA
Nehemiah 1 in the TTENT
Nehemiah 1 in the UBG
Nehemiah 1 in the UGV
Nehemiah 1 in the UGV2
Nehemiah 1 in the UGV3
Nehemiah 1 in the VBL
Nehemiah 1 in the VDCC
Nehemiah 1 in the YALU
Nehemiah 1 in the YAPE
Nehemiah 1 in the YBVTP
Nehemiah 1 in the ZBP