Proverbs 13 (BOYCB)
1 Ọlọ́gbọ́n ọmọ gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀,ṣùgbọ́n ẹlẹ́gàn kò gbọ́ ìbáwí. 2 Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn ohun rere,ṣùgbọ́n, ìfẹ́ ọkàn aláìṣòótọ́ ní ìwà ipá. 3 Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́,ṣùgbọ́n ẹni tí ó ń sọ̀rọ̀ gbàù gbàù yóò parun. 4 Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkan kan,ṣùgbọ́n ọkàn àwọn ti kì í ṣe ọ̀lẹ rí ìtẹ́lọ́rùn. 5 Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́,ṣùgbọ́n ènìyàn búburú hu ìwà ìríra àti ìtìjú. 6 Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú,ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò. 7 Ènìyàn kan díbọ́n bí ẹni tí ó ní ọrọ̀ síbẹ̀ kò ní nǹkan kanẹlòmíràn díbọ́n bí i tálákà, síbẹ̀ ó ní ọrọ̀ púpọ̀. 8 Ọrọ̀ ènìyàn le è ra ẹ̀mí rẹ̀ṣùgbọ́n tálákà kì í gbọ́ ìdẹ́rùbà. 9 Ìmọ́lẹ̀ olódodo tàn roro,ṣùgbọ́n fìtílà ènìyàn búburú ni a pa kú. 10 Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ niṣùgbọ́n ọgbọ́n wà nínú àwọn tí ń gba ìmọ̀ràn. 11 Owó tí a fi ọ̀nà èrú kójọ yóò ṣí lọ,ṣùgbọ́n ẹni tí ń kó owó jọ díẹ̀díẹ̀ yóò pọ̀ sí i. 12 Ìrètí tí ń falẹ̀ máa ń mú kí ọkàn ṣàárẹ̀ṣùgbọ́n ìrètí tí a rí gbà jẹ́ igi ìyè. 13 Ẹni tí ó kẹ́gàn ẹ̀kọ́ yóò jìyà rẹ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ó pa àṣẹ mọ́ gba èrè rẹ̀. 14 Ìkọ́ni ọlọ́gbọ́n jẹ́ orísun ìyè,tí ń yí ènìyàn padà kúrò nínú ìdẹ̀kùn ikú. 15 Òye pípé ń mú ni rí ojúrere,ṣùgbọ́n ọ̀nà aláìṣòótọ́ kì í tọ́jọ́. 16 Gbogbo olóye ènìyàn máa ń hùwà pẹ̀lú ìmọ̀,ṣùgbọ́n aláìgbọ́n a fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn. 17 Ìránṣẹ́ búburú bọ́ sínú ìdààmúṣùgbọ́n aṣojú olóòtítọ́ mú ìwòsàn wá. 18 Ẹni tí ó kọ ìbáwí yóò di tálákà yóò sì rí ìtìjú,ṣùgbọ́n ẹni tí ó gbọ́ ìbáwí ni yóò rí ọlá. 19 Ìfẹ́ tí a mú ṣẹ dùn mọ́ ọkànṣùgbọ́n ìríra ni fún aṣiwèrè láti kúrò nínú ibi. 20 Ẹni tí ó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́nṣùgbọ́n ẹni tí ń bá aláìgbọ́n kẹ́gbẹ́ ń pa ara rẹ̀ lára. 21 Òsì a máa ta ẹlẹ́ṣẹ̀,ṣùgbọ́n ọrọ̀ ni èrè fún olódodo. 22 Ènìyàn rere a máa fi ogún sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀,ṣùgbọ́n, a kó ọrọ̀ àwọn tó dẹ́ṣẹ̀ pamọ́ fún àwọn olódodo. 23 Ilẹ̀ ẹ tálákà le è mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìre oko wáṣùgbọ́n àìṣòdodo gbá gbogbo rẹ̀ lọ. 24 Ẹni tí ó fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀ṣùgbọ́n ẹni tí ó fẹ́ràn ọmọ rẹ̀ yóò máa bá a wí. 25 Olódodo jẹ́wọ́ títí ó fi tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùnṣùgbọ́n ebi yóò máa pa ikùn ènìyàn búburú.
In Other Versions
Proverbs 13 in the ANGEFD
Proverbs 13 in the ANTPNG2D
Proverbs 13 in the AS21
Proverbs 13 in the BAGH
Proverbs 13 in the BBPNG
Proverbs 13 in the BBT1E
Proverbs 13 in the BDS
Proverbs 13 in the BEV
Proverbs 13 in the BHAD
Proverbs 13 in the BIB
Proverbs 13 in the BLPT
Proverbs 13 in the BNT
Proverbs 13 in the BNTABOOT
Proverbs 13 in the BNTLV
Proverbs 13 in the BOATCB
Proverbs 13 in the BOATCB2
Proverbs 13 in the BOBCV
Proverbs 13 in the BOCNT
Proverbs 13 in the BOECS
Proverbs 13 in the BOGWICC
Proverbs 13 in the BOHCB
Proverbs 13 in the BOHCV
Proverbs 13 in the BOHLNT
Proverbs 13 in the BOHNTLTAL
Proverbs 13 in the BOICB
Proverbs 13 in the BOILNTAP
Proverbs 13 in the BOITCV
Proverbs 13 in the BOKCV
Proverbs 13 in the BOKCV2
Proverbs 13 in the BOKHWOG
Proverbs 13 in the BOKSSV
Proverbs 13 in the BOLCB
Proverbs 13 in the BOLCB2
Proverbs 13 in the BOMCV
Proverbs 13 in the BONAV
Proverbs 13 in the BONCB
Proverbs 13 in the BONLT
Proverbs 13 in the BONUT2
Proverbs 13 in the BOPLNT
Proverbs 13 in the BOSCB
Proverbs 13 in the BOSNC
Proverbs 13 in the BOTLNT
Proverbs 13 in the BOVCB
Proverbs 13 in the BPBB
Proverbs 13 in the BPH
Proverbs 13 in the BSB
Proverbs 13 in the CCB
Proverbs 13 in the CUV
Proverbs 13 in the CUVS
Proverbs 13 in the DBT
Proverbs 13 in the DGDNT
Proverbs 13 in the DHNT
Proverbs 13 in the DNT
Proverbs 13 in the ELBE
Proverbs 13 in the EMTV
Proverbs 13 in the ESV
Proverbs 13 in the FBV
Proverbs 13 in the FEB
Proverbs 13 in the GGMNT
Proverbs 13 in the GNT
Proverbs 13 in the HARY
Proverbs 13 in the HNT
Proverbs 13 in the IRVA
Proverbs 13 in the IRVB
Proverbs 13 in the IRVG
Proverbs 13 in the IRVH
Proverbs 13 in the IRVK
Proverbs 13 in the IRVM
Proverbs 13 in the IRVM2
Proverbs 13 in the IRVO
Proverbs 13 in the IRVP
Proverbs 13 in the IRVT
Proverbs 13 in the IRVT2
Proverbs 13 in the IRVU
Proverbs 13 in the ISVN
Proverbs 13 in the JSNT
Proverbs 13 in the KAPI
Proverbs 13 in the KBT1ETNIK
Proverbs 13 in the KBV
Proverbs 13 in the KJV
Proverbs 13 in the KNFD
Proverbs 13 in the LBA
Proverbs 13 in the LBLA
Proverbs 13 in the LNT
Proverbs 13 in the LSV
Proverbs 13 in the MAAL
Proverbs 13 in the MBV
Proverbs 13 in the MBV2
Proverbs 13 in the MHNT
Proverbs 13 in the MKNFD
Proverbs 13 in the MNG
Proverbs 13 in the MNT
Proverbs 13 in the MNT2
Proverbs 13 in the MRS1T
Proverbs 13 in the NAA
Proverbs 13 in the NASB
Proverbs 13 in the NBLA
Proverbs 13 in the NBS
Proverbs 13 in the NBVTP
Proverbs 13 in the NET2
Proverbs 13 in the NIV11
Proverbs 13 in the NNT
Proverbs 13 in the NNT2
Proverbs 13 in the NNT3
Proverbs 13 in the PDDPT
Proverbs 13 in the PFNT
Proverbs 13 in the RMNT
Proverbs 13 in the SBIAS
Proverbs 13 in the SBIBS
Proverbs 13 in the SBIBS2
Proverbs 13 in the SBICS
Proverbs 13 in the SBIDS
Proverbs 13 in the SBIGS
Proverbs 13 in the SBIHS
Proverbs 13 in the SBIIS
Proverbs 13 in the SBIIS2
Proverbs 13 in the SBIIS3
Proverbs 13 in the SBIKS
Proverbs 13 in the SBIKS2
Proverbs 13 in the SBIMS
Proverbs 13 in the SBIOS
Proverbs 13 in the SBIPS
Proverbs 13 in the SBISS
Proverbs 13 in the SBITS
Proverbs 13 in the SBITS2
Proverbs 13 in the SBITS3
Proverbs 13 in the SBITS4
Proverbs 13 in the SBIUS
Proverbs 13 in the SBIVS
Proverbs 13 in the SBT
Proverbs 13 in the SBT1E
Proverbs 13 in the SCHL
Proverbs 13 in the SNT
Proverbs 13 in the SUSU
Proverbs 13 in the SUSU2
Proverbs 13 in the SYNO
Proverbs 13 in the TBIAOTANT
Proverbs 13 in the TBT1E
Proverbs 13 in the TBT1E2
Proverbs 13 in the TFTIP
Proverbs 13 in the TFTU
Proverbs 13 in the TGNTATF3T
Proverbs 13 in the THAI
Proverbs 13 in the TNFD
Proverbs 13 in the TNT
Proverbs 13 in the TNTIK
Proverbs 13 in the TNTIL
Proverbs 13 in the TNTIN
Proverbs 13 in the TNTIP
Proverbs 13 in the TNTIZ
Proverbs 13 in the TOMA
Proverbs 13 in the TTENT
Proverbs 13 in the UBG
Proverbs 13 in the UGV
Proverbs 13 in the UGV2
Proverbs 13 in the UGV3
Proverbs 13 in the VBL
Proverbs 13 in the VDCC
Proverbs 13 in the YALU
Proverbs 13 in the YAPE
Proverbs 13 in the YBVTP
Proverbs 13 in the ZBP