Psalms 35 (BOYCB)
undefined Ti Dafidi. 1 OLÚWA, gbógun ti àwọn tí ń gbóguntì mí;kí o sì kọ ojú ìjà sí àwọn tí ó ń bá mi í jà! 2 Di asà àti àpáta mú,kí o sì dìde fún ìrànlọ́wọ́ mi! 3 Fa idà àti ọ̀kọ̀ yọkí o sì dojúkọ àwọn tí ń lé mi.Sọ fún ọkàn mi pé,“Èmi ni ìgbàlà rẹ.” 4 Kí wọn kí ó dààmú,kí a sì ti àwọn tí ń lépa ọkàn mi lójú;kí a sì mú wọn padà,kí a sì dààmú àwọn tí ń gbèrò ìpalára mi. 5 Jẹ́ kí wọn dàbí ìyàngbò níwájú afẹ́fẹ́,kí angẹli OLÚWA kí ó máa lé wọn kiri. 6 Jẹ́ kí ọ̀nà wọn kí ó ṣókùnkùn, kí ó sì máa yọ́,kí angẹli OLÚWA kí ó máa lépa wọn! 7 Nítorí pé, ní àìnídìí ni wọ́n dẹ àwọ̀n wọn sílẹ̀ fún mi,ní àìnídìí ni wọ́n wa kòtò sílẹ̀ fún ọkàn mi. 8 Kí ìparun kí ó wá sí orí rẹ̀ ní òjijì.Àwọ̀n rẹ̀ tí ó dẹ, kí ó mú òun tìkára rẹ̀;kí wọn ṣubú sínú kòtò sí ìparun ara rẹ̀. 9 Nígbà náà ni ọkàn mi yóò yọ̀ nínú OLÚWA,àní, yóò sì máa yọ̀ nínú ìgbàlà rẹ̀. 10 Gbogbo egungun mi yóò wí pé,“Ta ni ó dàbí ì ìwọ OLÚWA?O gba tálákà lọ́wọ́ àwọn tí ó lágbára jù ú lọ,tálákà àti aláìní lọ́wọ́ ẹni tí ń fi ṣe ìkógun?” 11 Àwọn ẹlẹ́rìí èké dìde;wọ́n ń bi mi ní ohun tí èmi kò mọ̀. 12 Wọ́n fi búburú san ìre fún mi;láti sọ ọkàn mi di òfo. 13 Ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti èmi ni, nígbà tí wọn ń ṣe àìsàn, mo wọ aṣọ ọ̀fọ̀;mo fi àwẹ̀ pọ́n ara mi lójú.Mo gba àdúrà pẹ̀lú ìtẹríba ní oókan àyà mi; 14 èmí ń lọ kiri bí ẹni ń ṣọ̀fọ̀bí i ẹni wí pé fún ọ̀rẹ́ tàbí ẹ̀gbọ́n mi ni.Èmí tẹríba nínú ìbànújẹ́bí ẹni tí ń ṣọ̀fọ̀ ìyà rẹ̀. 15 Ṣùgbọ́n nínú ìkọ̀sẹ̀ mi wọ́n sì yọ̀, wọ́n sì kó ara wọn jọ;wọ́n kó ara wọn jọ sí mi; àní àwọn tí èmi kò mọ̀.Wọ́n fà mí ya wọ́n kò sì dákẹ́. 16 Bí àwọn àgàbàgebè tí ń ṣe ẹlẹ́yà ní àpèjẹwọ́n pa eyín wọn keke sí mi. 17 Yóò ti pẹ́ tó OLÚWA, tí ìwọ yóò máa wò wọ́n lọ?Yọ mí kúrò nínú ìparun wọn,àní ẹ̀mí ì mi kúrò lọ́wọ́ kìnnìún. 18 Nígbà náà ni èmi yóò ṣọpẹ́ fún Ọ nínú àjọ ńlá;èmi yóò máa yìn Ọ́ ní àwùjọ ọ̀pọ̀ ènìyàn. 19 Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mikí ó yọ̀ lórí ì mi;bẹ́ẹ̀ ni kí o má ṣe àwọn tí ó kórìíra miní àìnídìí máa ṣẹ́jú sí mi. 20 Nítorí pé wọn kò sọ ọ̀rọ̀ àlàáfíà,ṣùgbọ́n wọ́n lóyún ọ̀rọ̀ ẹ̀tànsí àwọn ènìyàn dídákẹ́ ilẹ̀ náà. 21 Wọ́n ya ẹnu wọn gbòòrò sí mi; wọ́n wí pé, “Háà! Háà!Ojú wa sì ti rí i.” 22 Ìwọ́ ti rí i OLÚWA; má ṣe dákẹ́!Olúwa má ṣe jìnnà sí mi! 23 Dìde! ru ara rẹ̀ sókè fún ààbò mi,àti sí ọ̀ràn mi, Ọlọ́run mi àti Olúwa mi! 24 Ṣe ìdájọ́ mi, OLÚWA Ọlọ́run mi, gẹ́gẹ́ bí òdodo rẹ,kí o má sì ṣe jẹ́ kí wọn kí ó yọ̀ lórí mi! 25 Má ṣe jẹ́ kí wọn wí nínú ara wọn pé, “Háà! A ti rí ohun tí ọkàn wa ń fẹ́!”Má ṣe jẹ́ kí wọn kí ó wí pé, “A ti gbé e mì.” 26 Kí ojú kí ó tì wọ́n,kí wọn kí ó sì dààmú pọ̀,àní àwọn tí ń yọ̀ sí ìyọnu mikí a fi ìtìjú àti àbùkù wọ̀ wọ́n ní aṣọ tí ń gbéraga sí mi. 27 Jẹ́ kí àwọn tí ó fẹ́ ìdáláre mifò fún ayọ̀ àti ìdùnnú;kí wọn máa sọ ọ́ títí lọ, “Pé gbígbéga ni OLÚWA,sí àlàáfíà ìránṣẹ́ rẹ̀.” 28 Nígbà náà ni ahọ́n mi yóò máa sọ̀rọ̀ òdodo rẹ,àti ìyìn rẹ ní gbogbo ọjọ́.
In Other Versions
Psalms 35 in the ANGEFD
Psalms 35 in the ANTPNG2D
Psalms 35 in the AS21
Psalms 35 in the BAGH
Psalms 35 in the BBPNG
Psalms 35 in the BBT1E
Psalms 35 in the BDS
Psalms 35 in the BEV
Psalms 35 in the BHAD
Psalms 35 in the BIB
Psalms 35 in the BLPT
Psalms 35 in the BNT
Psalms 35 in the BNTABOOT
Psalms 35 in the BNTLV
Psalms 35 in the BOATCB
Psalms 35 in the BOATCB2
Psalms 35 in the BOBCV
Psalms 35 in the BOCNT
Psalms 35 in the BOECS
Psalms 35 in the BOGWICC
Psalms 35 in the BOHCB
Psalms 35 in the BOHCV
Psalms 35 in the BOHLNT
Psalms 35 in the BOHNTLTAL
Psalms 35 in the BOICB
Psalms 35 in the BOILNTAP
Psalms 35 in the BOITCV
Psalms 35 in the BOKCV
Psalms 35 in the BOKCV2
Psalms 35 in the BOKHWOG
Psalms 35 in the BOKSSV
Psalms 35 in the BOLCB
Psalms 35 in the BOLCB2
Psalms 35 in the BOMCV
Psalms 35 in the BONAV
Psalms 35 in the BONCB
Psalms 35 in the BONLT
Psalms 35 in the BONUT2
Psalms 35 in the BOPLNT
Psalms 35 in the BOSCB
Psalms 35 in the BOSNC
Psalms 35 in the BOTLNT
Psalms 35 in the BOVCB
Psalms 35 in the BPBB
Psalms 35 in the BPH
Psalms 35 in the BSB
Psalms 35 in the CCB
Psalms 35 in the CUV
Psalms 35 in the CUVS
Psalms 35 in the DBT
Psalms 35 in the DGDNT
Psalms 35 in the DHNT
Psalms 35 in the DNT
Psalms 35 in the ELBE
Psalms 35 in the EMTV
Psalms 35 in the ESV
Psalms 35 in the FBV
Psalms 35 in the FEB
Psalms 35 in the GGMNT
Psalms 35 in the GNT
Psalms 35 in the HARY
Psalms 35 in the HNT
Psalms 35 in the IRVA
Psalms 35 in the IRVB
Psalms 35 in the IRVG
Psalms 35 in the IRVH
Psalms 35 in the IRVK
Psalms 35 in the IRVM
Psalms 35 in the IRVM2
Psalms 35 in the IRVO
Psalms 35 in the IRVP
Psalms 35 in the IRVT
Psalms 35 in the IRVT2
Psalms 35 in the IRVU
Psalms 35 in the ISVN
Psalms 35 in the JSNT
Psalms 35 in the KAPI
Psalms 35 in the KBT1ETNIK
Psalms 35 in the KBV
Psalms 35 in the KJV
Psalms 35 in the KNFD
Psalms 35 in the LBA
Psalms 35 in the LBLA
Psalms 35 in the LNT
Psalms 35 in the LSV
Psalms 35 in the MAAL
Psalms 35 in the MBV
Psalms 35 in the MBV2
Psalms 35 in the MHNT
Psalms 35 in the MKNFD
Psalms 35 in the MNG
Psalms 35 in the MNT
Psalms 35 in the MNT2
Psalms 35 in the MRS1T
Psalms 35 in the NAA
Psalms 35 in the NASB
Psalms 35 in the NBLA
Psalms 35 in the NBS
Psalms 35 in the NBVTP
Psalms 35 in the NET2
Psalms 35 in the NIV11
Psalms 35 in the NNT
Psalms 35 in the NNT2
Psalms 35 in the NNT3
Psalms 35 in the PDDPT
Psalms 35 in the PFNT
Psalms 35 in the RMNT
Psalms 35 in the SBIAS
Psalms 35 in the SBIBS
Psalms 35 in the SBIBS2
Psalms 35 in the SBICS
Psalms 35 in the SBIDS
Psalms 35 in the SBIGS
Psalms 35 in the SBIHS
Psalms 35 in the SBIIS
Psalms 35 in the SBIIS2
Psalms 35 in the SBIIS3
Psalms 35 in the SBIKS
Psalms 35 in the SBIKS2
Psalms 35 in the SBIMS
Psalms 35 in the SBIOS
Psalms 35 in the SBIPS
Psalms 35 in the SBISS
Psalms 35 in the SBITS
Psalms 35 in the SBITS2
Psalms 35 in the SBITS3
Psalms 35 in the SBITS4
Psalms 35 in the SBIUS
Psalms 35 in the SBIVS
Psalms 35 in the SBT
Psalms 35 in the SBT1E
Psalms 35 in the SCHL
Psalms 35 in the SNT
Psalms 35 in the SUSU
Psalms 35 in the SUSU2
Psalms 35 in the SYNO
Psalms 35 in the TBIAOTANT
Psalms 35 in the TBT1E
Psalms 35 in the TBT1E2
Psalms 35 in the TFTIP
Psalms 35 in the TFTU
Psalms 35 in the TGNTATF3T
Psalms 35 in the THAI
Psalms 35 in the TNFD
Psalms 35 in the TNT
Psalms 35 in the TNTIK
Psalms 35 in the TNTIL
Psalms 35 in the TNTIN
Psalms 35 in the TNTIP
Psalms 35 in the TNTIZ
Psalms 35 in the TOMA
Psalms 35 in the TTENT
Psalms 35 in the UBG
Psalms 35 in the UGV
Psalms 35 in the UGV2
Psalms 35 in the UGV3
Psalms 35 in the VBL
Psalms 35 in the VDCC
Psalms 35 in the YALU
Psalms 35 in the YAPE
Psalms 35 in the YBVTP
Psalms 35 in the ZBP