Psalms 40 (BOYCB)

undefined Fún adarí orin. Ti Dafidi. Saamu. 1 Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ dúró de OLÚWA;ó sì dẹtí sí mi, ó sì gbọ́ ẹkún mi. 2 Ó fà mí yọ gòkèláti inú ihò ìparun,láti inú ẹrẹ̀ pọ̀tọ̀pọ́tọ̀,ó sì fi ẹsẹ̀ mi lé orí àpáta,ó sì jẹ́ kí ìgbésẹ̀ mi wà láìfòyà. 3 Ó fi orin tuntun sí mi lẹ́nu,àní orin ìyìn sí Ọlọ́run wa.Ọ̀pọ̀ yóò rí i wọn yóò sì bẹ̀rù,wọn yóò sì gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA. 4 Ayọ̀ ni fún àwọn wọ̀n-ọn-nìtí ó fi OLÚWA ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé wọntí wọn kò sì yípadà sí agbéraga,tàbí àwọn tí ó yapalọ sí ọ̀dọ̀ ọlọ́run mìíràn. 5 OLÚWA Ọlọ́run mi,ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn iṣẹ́ ìyanu tí ìwọ ti ṣe.Àwọn ohun tí ìwọ ti ṣètò sílẹ̀ fún wa;ni ẹnikẹ́ni kò le kà wọ́n fún ọ lẹ́sẹẹsẹ,tí èmi yóò sì sọ̀rọ̀ wọn,wọ́n ju ohun tíènìyàn le è kà lọ. 6 Ẹbọ àti ẹran ẹbọ ni ìwọ kò fẹ́,ìwọ ti ṣí mi ní etí.Ọrẹ ẹbọ sísun àti ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ni ìwọ kò béèrè. 7 Nígbà náà ni mo wí pé,“Èmi nìyí;nínú ìwé kíká nia kọ ọ nípa tèmi wí pé. 8 Mo ní inú dídùnláti ṣe ìfẹ́ ẹ̀ rẹ,ìwọ Ọlọ́run mi,òfin rẹ̀ ń bẹ ní àyà mi.” 9 Èmi ti sọ ìròyìn ayọ̀ ti ìgbàlàláàrín àwùjọ ńlá;wò ó,èmi kò pa ètè mi mọ́,gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti mọ̀,ìwọ OLÚWA. 10 Èmi kò fi ìrànlọ́wọ́ ìgbàlà sin ní àyà mi;èmí ti sọ̀rọ̀ nípa òtítọ́ àti ìgbàlà rẹ.Èmi kò sì pa ìṣeun ìfẹ́ rẹ̀ àti òtítọ́ rẹ̀ mọ́kúrò láàrín àwọn ìjọ ńlá. 11 Ìwọ má ṣe, fa àánú rẹ tí ó rọ́nú sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi OLÚWA;jẹ́ kí ìṣeun ìfẹ́ rẹ àti òtítọ́ rẹkí ó máa pa mi mọ́ títí ayérayé. 12 Nítorí pé àìníye ibini ó yí mi káàkiri,ẹ̀ṣẹ̀ mi sì dì mọ́ mi,títí tí èmi kò fi ríran mọ́;wọ́n pọ̀ ju irun orí mi lọ,àti wí pé àyà mí ti kùnà. 13 Jẹ́ kí ó wù ọ́,ìwọ OLÚWA,láti gbà mí là; OLÚWA,yára láti ràn mí lọ́wọ́. 14 Gbogbo àwọn wọ̀n-ọn-nì ni kí ojú kí ó tìkí wọn kí ó sì dààmú;àwọn tí ń wá ọkàn mi láti parunjẹ́ kí a lé wọn padà sẹ́yìn kí a sì dójútì wọ́n,àwọn tí ń wá ìpalára mi. 15 Jẹ́ kí àwọn tí ó wí fún mi pé, “Háà! Háà!”ó di ẹni à fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nítorí ìtìjú wọn. 16 Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ń wá ọkí ó máa yọ̀kí inú wọn sì máa dùn sí ọ;kí gbogbo àwọn tí ó sì fẹ́ ìgbàlà rẹkí o máa wí nígbà gbogbo pé,“Gbígbéga ni OLÚWA!” 17 Bí ó ṣe ti èmi ni,tálákà àti aláìní ni èmi,ṣùgbọ́n Olúwa ń ṣe ìrántí mi.Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ miàti ìgbàlà mi;má ṣe jẹ́ kí ó pẹ́,ìwọ Ọlọ́run mi.

In Other Versions

Psalms 40 in the ANGEFD

Psalms 40 in the ANTPNG2D

Psalms 40 in the AS21

Psalms 40 in the BAGH

Psalms 40 in the BBPNG

Psalms 40 in the BBT1E

Psalms 40 in the BDS

Psalms 40 in the BEV

Psalms 40 in the BHAD

Psalms 40 in the BIB

Psalms 40 in the BLPT

Psalms 40 in the BNT

Psalms 40 in the BNTABOOT

Psalms 40 in the BNTLV

Psalms 40 in the BOATCB

Psalms 40 in the BOATCB2

Psalms 40 in the BOBCV

Psalms 40 in the BOCNT

Psalms 40 in the BOECS

Psalms 40 in the BOGWICC

Psalms 40 in the BOHCB

Psalms 40 in the BOHCV

Psalms 40 in the BOHLNT

Psalms 40 in the BOHNTLTAL

Psalms 40 in the BOICB

Psalms 40 in the BOILNTAP

Psalms 40 in the BOITCV

Psalms 40 in the BOKCV

Psalms 40 in the BOKCV2

Psalms 40 in the BOKHWOG

Psalms 40 in the BOKSSV

Psalms 40 in the BOLCB

Psalms 40 in the BOLCB2

Psalms 40 in the BOMCV

Psalms 40 in the BONAV

Psalms 40 in the BONCB

Psalms 40 in the BONLT

Psalms 40 in the BONUT2

Psalms 40 in the BOPLNT

Psalms 40 in the BOSCB

Psalms 40 in the BOSNC

Psalms 40 in the BOTLNT

Psalms 40 in the BOVCB

Psalms 40 in the BPBB

Psalms 40 in the BPH

Psalms 40 in the BSB

Psalms 40 in the CCB

Psalms 40 in the CUV

Psalms 40 in the CUVS

Psalms 40 in the DBT

Psalms 40 in the DGDNT

Psalms 40 in the DHNT

Psalms 40 in the DNT

Psalms 40 in the ELBE

Psalms 40 in the EMTV

Psalms 40 in the ESV

Psalms 40 in the FBV

Psalms 40 in the FEB

Psalms 40 in the GGMNT

Psalms 40 in the GNT

Psalms 40 in the HARY

Psalms 40 in the HNT

Psalms 40 in the IRVA

Psalms 40 in the IRVB

Psalms 40 in the IRVG

Psalms 40 in the IRVH

Psalms 40 in the IRVK

Psalms 40 in the IRVM

Psalms 40 in the IRVM2

Psalms 40 in the IRVO

Psalms 40 in the IRVP

Psalms 40 in the IRVT

Psalms 40 in the IRVT2

Psalms 40 in the IRVU

Psalms 40 in the ISVN

Psalms 40 in the JSNT

Psalms 40 in the KAPI

Psalms 40 in the KBT1ETNIK

Psalms 40 in the KBV

Psalms 40 in the KJV

Psalms 40 in the KNFD

Psalms 40 in the LBA

Psalms 40 in the LBLA

Psalms 40 in the LNT

Psalms 40 in the LSV

Psalms 40 in the MAAL

Psalms 40 in the MBV

Psalms 40 in the MBV2

Psalms 40 in the MHNT

Psalms 40 in the MKNFD

Psalms 40 in the MNG

Psalms 40 in the MNT

Psalms 40 in the MNT2

Psalms 40 in the MRS1T

Psalms 40 in the NAA

Psalms 40 in the NASB

Psalms 40 in the NBLA

Psalms 40 in the NBS

Psalms 40 in the NBVTP

Psalms 40 in the NET2

Psalms 40 in the NIV11

Psalms 40 in the NNT

Psalms 40 in the NNT2

Psalms 40 in the NNT3

Psalms 40 in the PDDPT

Psalms 40 in the PFNT

Psalms 40 in the RMNT

Psalms 40 in the SBIAS

Psalms 40 in the SBIBS

Psalms 40 in the SBIBS2

Psalms 40 in the SBICS

Psalms 40 in the SBIDS

Psalms 40 in the SBIGS

Psalms 40 in the SBIHS

Psalms 40 in the SBIIS

Psalms 40 in the SBIIS2

Psalms 40 in the SBIIS3

Psalms 40 in the SBIKS

Psalms 40 in the SBIKS2

Psalms 40 in the SBIMS

Psalms 40 in the SBIOS

Psalms 40 in the SBIPS

Psalms 40 in the SBISS

Psalms 40 in the SBITS

Psalms 40 in the SBITS2

Psalms 40 in the SBITS3

Psalms 40 in the SBITS4

Psalms 40 in the SBIUS

Psalms 40 in the SBIVS

Psalms 40 in the SBT

Psalms 40 in the SBT1E

Psalms 40 in the SCHL

Psalms 40 in the SNT

Psalms 40 in the SUSU

Psalms 40 in the SUSU2

Psalms 40 in the SYNO

Psalms 40 in the TBIAOTANT

Psalms 40 in the TBT1E

Psalms 40 in the TBT1E2

Psalms 40 in the TFTIP

Psalms 40 in the TFTU

Psalms 40 in the TGNTATF3T

Psalms 40 in the THAI

Psalms 40 in the TNFD

Psalms 40 in the TNT

Psalms 40 in the TNTIK

Psalms 40 in the TNTIL

Psalms 40 in the TNTIN

Psalms 40 in the TNTIP

Psalms 40 in the TNTIZ

Psalms 40 in the TOMA

Psalms 40 in the TTENT

Psalms 40 in the UBG

Psalms 40 in the UGV

Psalms 40 in the UGV2

Psalms 40 in the UGV3

Psalms 40 in the VBL

Psalms 40 in the VDCC

Psalms 40 in the YALU

Psalms 40 in the YAPE

Psalms 40 in the YBVTP

Psalms 40 in the ZBP