Psalms 71 (BOYCB)
1 Nínú rẹ, OLÚWA, ni mo ní ààbò;má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí. 2 Gbà mí kí o sì tú mi sílẹ̀ nínú òdodo rẹ;dẹ etí rẹ sí mi, kí o sì gbà mí. 3 Jẹ́ àpáta ààbò mi,níbi tí èmi lè máa lọ,pa àṣẹ láti gbà mí,nítorí ìwọ ni àpáta àti odi agbára mi. 4 Gbà mí, Ọlọ́run mi, lọ́wọ́ àwọn olùṣe búburú,ní ọwọ́ aláìṣòdodo àti ìkà ọkùnrin. 5 Nítorí ìwọ jẹ́ ìrètí mi, OLÚWA Olódùmarè,ìwọ ni ìgbẹ́kẹ̀lé mi láti ìgbà èwe. 6 Mo gbẹ́kẹ̀lé ọ láti ìgbà ìbí mi;Ìwọ mú mi jáde láti inú ìyá mi wáèmi ó máa yìn ọ́ títí láé. 7 Mo di àmì fún ọ̀pọ̀ ènìyàn,ṣùgbọ́n ìwọ ni ààbò mi tí ó lágbára. 8 Ìyìn rẹ̀ kún ẹnu mi,ó ń sọ ti ọlá rẹ ní ọjọ́ gbogbo. 9 Má ṣe ta mí nù ní ọjọ́ ogbó mi,má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ nígbà tí kò sí okun mọ́. 10 Nítorí àwọn ọ̀tá mi ń sọ̀rọ̀-òdì sí mi,àwọn tí wọn dúró láti pa mí gbìmọ̀ pọ̀. 11 Wọ́n wí pé, “Ọlọ́run ti kọ̀ ọ́ sílẹ̀;lépa rẹ̀ kí ẹ sì mu,nítorí kò sí ẹni tí yóò gbà á.” 12 Má ṣe jìnnà sí mi, Ọlọ́run;wa kánkán, Ọlọ́run mi, láti ràn mí lọ́wọ́. 13 Jẹ́ kí wọn kí ó dààmú,kí a sì run àwọn tí ń ṣe ọ̀tá ọkàn mikí a sì fi ẹ̀gàn àti àbùkùbo àwọn tí ń wá ìpalára mi. 14 Ṣùgbọ́n ní tèmi, ìgbà gbogbo ní ìrètí mi;èmi ó yìn ọ́ síwájú àti síwájú sí i. 15 Ẹnu mi yóò sọ nípa ti òdodo rẹ,ti ìgbàlà rẹ, ni gbogbo ọjọ́,lóòtítọ́, èmi kò mọ iye rẹ̀. 16 Èmi ó wá láti wá kéde agbára, OLÚWA Olódùmarè;èmi ó kéde òdodo rẹ̀ nìkan. 17 Láti ìgbà èwe, Ọlọ́run ni ìwọ ti kọ́ mitítí di òní ni mo ń sọ ti iṣẹ́ ìyanu rẹ. 18 Pẹ̀lúpẹ̀lú, nígbà tí èmi di arúgbó tán tí mo sì hewú,má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀, Ọlọ́run mi,títí èmi ó fi ipá rẹ han ìran tí ń bọ̀,àti agbára rẹ fún gbogbo àwọn tí ń bọ̀ lẹ́yìn. 19 Ọlọ́run, òdodo rẹ dé ọ̀run,ìwọ tí o ti ṣe ohun ńlá.Ta ni ó dàbí rẹ, Ọlọ́run? 20 Pẹ̀lúpẹ̀lú ìwọ ti mú mi rí ìdààmú, tí ó pọ̀ tí ó sì korò,ìwọ yóò tún sọ ayé mi jíìwọ yóò sì tún mú mi sọ sókèláti ọ̀gbun ilẹ̀ wá.Ìwọ yóò sọ ọlá mi di púpọ̀. 21 Ìwọ yóò fi kún ọwọ́ miìwọ yóò tù mí nínú ní ha gbogbo. 22 Èmi yóò fi dùùrù mi yìnfún òtítọ́ rẹ, Ọlọ́run mi;èmi ó kọrin ìyìn sí ọ pẹ̀lú dùùrùìwọ ẹni mímọ́ Israẹli. 23 Ètè mi yóò kígbe fún ìyìnnígbà tí mo bá kọrin ìyìn sí ọ:èmi, ẹni tí o rà padà. 24 Ahọ́n mi yóò sọ ti òdodo rẹ ní gbogbo ọjọ́,fún àwọn tí ó fẹ́ pa mí lára,a sì dójúti àwọn tí ń wá ìdààmú mi.
In Other Versions
Psalms 71 in the ANGEFD
Psalms 71 in the ANTPNG2D
Psalms 71 in the AS21
Psalms 71 in the BAGH
Psalms 71 in the BBPNG
Psalms 71 in the BBT1E
Psalms 71 in the BDS
Psalms 71 in the BEV
Psalms 71 in the BHAD
Psalms 71 in the BIB
Psalms 71 in the BLPT
Psalms 71 in the BNT
Psalms 71 in the BNTABOOT
Psalms 71 in the BNTLV
Psalms 71 in the BOATCB
Psalms 71 in the BOATCB2
Psalms 71 in the BOBCV
Psalms 71 in the BOCNT
Psalms 71 in the BOECS
Psalms 71 in the BOGWICC
Psalms 71 in the BOHCB
Psalms 71 in the BOHCV
Psalms 71 in the BOHLNT
Psalms 71 in the BOHNTLTAL
Psalms 71 in the BOICB
Psalms 71 in the BOILNTAP
Psalms 71 in the BOITCV
Psalms 71 in the BOKCV
Psalms 71 in the BOKCV2
Psalms 71 in the BOKHWOG
Psalms 71 in the BOKSSV
Psalms 71 in the BOLCB
Psalms 71 in the BOLCB2
Psalms 71 in the BOMCV
Psalms 71 in the BONAV
Psalms 71 in the BONCB
Psalms 71 in the BONLT
Psalms 71 in the BONUT2
Psalms 71 in the BOPLNT
Psalms 71 in the BOSCB
Psalms 71 in the BOSNC
Psalms 71 in the BOTLNT
Psalms 71 in the BOVCB
Psalms 71 in the BPBB
Psalms 71 in the BPH
Psalms 71 in the BSB
Psalms 71 in the CCB
Psalms 71 in the CUV
Psalms 71 in the CUVS
Psalms 71 in the DBT
Psalms 71 in the DGDNT
Psalms 71 in the DHNT
Psalms 71 in the DNT
Psalms 71 in the ELBE
Psalms 71 in the EMTV
Psalms 71 in the ESV
Psalms 71 in the FBV
Psalms 71 in the FEB
Psalms 71 in the GGMNT
Psalms 71 in the GNT
Psalms 71 in the HARY
Psalms 71 in the HNT
Psalms 71 in the IRVA
Psalms 71 in the IRVB
Psalms 71 in the IRVG
Psalms 71 in the IRVH
Psalms 71 in the IRVK
Psalms 71 in the IRVM
Psalms 71 in the IRVM2
Psalms 71 in the IRVO
Psalms 71 in the IRVP
Psalms 71 in the IRVT
Psalms 71 in the IRVT2
Psalms 71 in the IRVU
Psalms 71 in the ISVN
Psalms 71 in the JSNT
Psalms 71 in the KAPI
Psalms 71 in the KBT1ETNIK
Psalms 71 in the KBV
Psalms 71 in the KJV
Psalms 71 in the KNFD
Psalms 71 in the LBA
Psalms 71 in the LBLA
Psalms 71 in the LNT
Psalms 71 in the LSV
Psalms 71 in the MAAL
Psalms 71 in the MBV
Psalms 71 in the MBV2
Psalms 71 in the MHNT
Psalms 71 in the MKNFD
Psalms 71 in the MNG
Psalms 71 in the MNT
Psalms 71 in the MNT2
Psalms 71 in the MRS1T
Psalms 71 in the NAA
Psalms 71 in the NASB
Psalms 71 in the NBLA
Psalms 71 in the NBS
Psalms 71 in the NBVTP
Psalms 71 in the NET2
Psalms 71 in the NIV11
Psalms 71 in the NNT
Psalms 71 in the NNT2
Psalms 71 in the NNT3
Psalms 71 in the PDDPT
Psalms 71 in the PFNT
Psalms 71 in the RMNT
Psalms 71 in the SBIAS
Psalms 71 in the SBIBS
Psalms 71 in the SBIBS2
Psalms 71 in the SBICS
Psalms 71 in the SBIDS
Psalms 71 in the SBIGS
Psalms 71 in the SBIHS
Psalms 71 in the SBIIS
Psalms 71 in the SBIIS2
Psalms 71 in the SBIIS3
Psalms 71 in the SBIKS
Psalms 71 in the SBIKS2
Psalms 71 in the SBIMS
Psalms 71 in the SBIOS
Psalms 71 in the SBIPS
Psalms 71 in the SBISS
Psalms 71 in the SBITS
Psalms 71 in the SBITS2
Psalms 71 in the SBITS3
Psalms 71 in the SBITS4
Psalms 71 in the SBIUS
Psalms 71 in the SBIVS
Psalms 71 in the SBT
Psalms 71 in the SBT1E
Psalms 71 in the SCHL
Psalms 71 in the SNT
Psalms 71 in the SUSU
Psalms 71 in the SUSU2
Psalms 71 in the SYNO
Psalms 71 in the TBIAOTANT
Psalms 71 in the TBT1E
Psalms 71 in the TBT1E2
Psalms 71 in the TFTIP
Psalms 71 in the TFTU
Psalms 71 in the TGNTATF3T
Psalms 71 in the THAI
Psalms 71 in the TNFD
Psalms 71 in the TNT
Psalms 71 in the TNTIK
Psalms 71 in the TNTIL
Psalms 71 in the TNTIN
Psalms 71 in the TNTIP
Psalms 71 in the TNTIZ
Psalms 71 in the TOMA
Psalms 71 in the TTENT
Psalms 71 in the UBG
Psalms 71 in the UGV
Psalms 71 in the UGV2
Psalms 71 in the UGV3
Psalms 71 in the VBL
Psalms 71 in the VDCC
Psalms 71 in the YALU
Psalms 71 in the YAPE
Psalms 71 in the YBVTP
Psalms 71 in the ZBP