Revelation 20 (BOYCB)
1 Mo sì rí angẹli kan ń ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, ti òun ti kọ́kọ́rọ́ ọ̀gbun, àti ẹ̀wọ̀n ńlá kan ní ọwọ́ rẹ̀. 2 O sì di dragoni náà mú, ejò àtijọ́ nì, tí í ṣe èṣù, àti Satani, ó sì dè é ní ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún. 3 Ó sì gbé e sọ sínú ọ̀gbun náà, ó sì tì í, ó sì fi èdìdì dì í lórí rẹ̀, kí ó má ba à tan àwọn orílẹ̀-èdè jẹ mọ́ títí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún náà yóò fi pé. Lẹ́yìn èyí, a kò le ṣàì tú u sílẹ̀ fún ìgbà díẹ̀. 4 Mo sì rí àwọn ìtẹ́, wọ́n sì jókòó lórí wọn, a sì fi ìdájọ́ fún wọ́n, mo sì rí ọkàn àwọn tí a ti bẹ́ lórí nítorí ẹ̀rí Jesu, àti nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, àti àwọn tí kò sì foríbalẹ̀ fún ẹranko náà, àti fún àwòrán rẹ̀, tàbí tí kò sì gbà àmì rẹ̀ ní iwájú wọn àti ní ọwọ́ wọn; wọ́n sì wà láààyè, wọ́n sì jẹ ọba pẹ̀lú Kristi ní ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún. 5 (Àwọn òkú ìyókù kò wà láààyè mọ́ títí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún náà yóò fi pé). Èyí ni àjíǹde èkínní. 6 Ẹni ìbùkún àti mímọ́ ni ẹni tí ó ní ipa nínú àjíǹde èkínní náà. Lórí àwọn wọ̀nyí ikú ẹ̀ẹ̀kejì kò ní agbára, ṣùgbọ́n wọn ó jẹ́ àlùfáà Ọlọ́run àti ti Kristi, wọn ó sì máa jẹ ọba pẹ̀lú rẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún. 7 Nígbà tí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún náà bá sì pé, a ó tú Satani sílẹ̀ kúrò nínú túbú rẹ̀. 8 Yóò sì jáde lọ láti máa tan àwọn orílẹ̀-èdè tí ń bẹ ní igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé jẹ, Gogu àti Magogu, láti gbá wọn jọ sí ogun: àwọn tí iyè wọn dàbí iyanrìn Òkun. 9 Wọ́n sì gòkè lọ la ibú ayé já, wọ́n sì yí ibùdó àwọn ènìyàn mímọ́ ká àti ìlú àyànfẹ́ náà: iná sì ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, ó sì jó wọn run. 10 A sì wọ́ Èṣù tí ó tàn wọ́n jẹ lọ sínú adágún iná àti sulfuru, níbi tí ẹranko àti wòlíì èké nì gbé wà, a ó sì máa dá wọn lóró tọ̀sán tòru láé àti láéláé. 11 Mo sì rí ìtẹ́ funfun ńlá kan, àti ẹni tí ó jókòó lórí rẹ̀, níwájú ẹni tí ayé àti ọ̀run fò lọ; a kò sì rí ààyè fún wọn mọ́. 12 Mo sì rí àwọn òkú, àti èwe àti àgbà, wọn dúró níwájú ìtẹ́; a sì ṣí àwọn ìwé sílẹ̀; a sì ṣí àwọn ìwé mìíràn kan sílẹ̀ tí í ṣe ìwé ìyè: a sì ṣe ìdájọ́ fún àwọn òkú láti inú ohun tí a ti kọ sínú àwọn ìwé náà, gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn. 13 Òkun sì jọ̀wọ́ àwọn òkú tí ń bẹ nínú rẹ̀ lọ́wọ́; àti òkú àti ipò òkú sì jọ̀wọ́ òkú tí ó wà nínú wọn pẹ̀lú: a sì ṣe ìdájọ́ wọn, olúkúlùkù gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ wọn. 14 Àti ikú àti ipò òkú ni a sì sọ sínú adágún iná. Èyí ni ikú kejì. 15 Bí a bá sì rí ẹnikẹ́ni tí a kò kọ orúkọ rẹ̀ sínú ìwé ìyè, a ó sọ ọ́ sínú adágún iná.
In Other Versions
Revelation 20 in the ANGEFD
Revelation 20 in the ANTPNG2D
Revelation 20 in the AS21
Revelation 20 in the BAGH
Revelation 20 in the BBPNG
Revelation 20 in the BBT1E
Revelation 20 in the BDS
Revelation 20 in the BEV
Revelation 20 in the BHAD
Revelation 20 in the BIB
Revelation 20 in the BLPT
Revelation 20 in the BNT
Revelation 20 in the BNTABOOT
Revelation 20 in the BNTLV
Revelation 20 in the BOATCB
Revelation 20 in the BOATCB2
Revelation 20 in the BOBCV
Revelation 20 in the BOCNT
Revelation 20 in the BOECS
Revelation 20 in the BOGWICC
Revelation 20 in the BOHCB
Revelation 20 in the BOHCV
Revelation 20 in the BOHLNT
Revelation 20 in the BOHNTLTAL
Revelation 20 in the BOICB
Revelation 20 in the BOILNTAP
Revelation 20 in the BOITCV
Revelation 20 in the BOKCV
Revelation 20 in the BOKCV2
Revelation 20 in the BOKHWOG
Revelation 20 in the BOKSSV
Revelation 20 in the BOLCB
Revelation 20 in the BOLCB2
Revelation 20 in the BOMCV
Revelation 20 in the BONAV
Revelation 20 in the BONCB
Revelation 20 in the BONLT
Revelation 20 in the BONUT2
Revelation 20 in the BOPLNT
Revelation 20 in the BOSCB
Revelation 20 in the BOSNC
Revelation 20 in the BOTLNT
Revelation 20 in the BOVCB
Revelation 20 in the BPBB
Revelation 20 in the BPH
Revelation 20 in the BSB
Revelation 20 in the CCB
Revelation 20 in the CUV
Revelation 20 in the CUVS
Revelation 20 in the DBT
Revelation 20 in the DGDNT
Revelation 20 in the DHNT
Revelation 20 in the DNT
Revelation 20 in the ELBE
Revelation 20 in the EMTV
Revelation 20 in the ESV
Revelation 20 in the FBV
Revelation 20 in the FEB
Revelation 20 in the GGMNT
Revelation 20 in the GNT
Revelation 20 in the HARY
Revelation 20 in the HNT
Revelation 20 in the IRVA
Revelation 20 in the IRVB
Revelation 20 in the IRVG
Revelation 20 in the IRVH
Revelation 20 in the IRVK
Revelation 20 in the IRVM
Revelation 20 in the IRVM2
Revelation 20 in the IRVO
Revelation 20 in the IRVP
Revelation 20 in the IRVT
Revelation 20 in the IRVT2
Revelation 20 in the IRVU
Revelation 20 in the ISVN
Revelation 20 in the JSNT
Revelation 20 in the KAPI
Revelation 20 in the KBT1ETNIK
Revelation 20 in the KBV
Revelation 20 in the KJV
Revelation 20 in the KNFD
Revelation 20 in the LBA
Revelation 20 in the LBLA
Revelation 20 in the LNT
Revelation 20 in the LSV
Revelation 20 in the MAAL
Revelation 20 in the MBV
Revelation 20 in the MBV2
Revelation 20 in the MHNT
Revelation 20 in the MKNFD
Revelation 20 in the MNG
Revelation 20 in the MNT
Revelation 20 in the MNT2
Revelation 20 in the MRS1T
Revelation 20 in the NAA
Revelation 20 in the NASB
Revelation 20 in the NBLA
Revelation 20 in the NBS
Revelation 20 in the NBVTP
Revelation 20 in the NET2
Revelation 20 in the NIV11
Revelation 20 in the NNT
Revelation 20 in the NNT2
Revelation 20 in the NNT3
Revelation 20 in the PDDPT
Revelation 20 in the PFNT
Revelation 20 in the RMNT
Revelation 20 in the SBIAS
Revelation 20 in the SBIBS
Revelation 20 in the SBIBS2
Revelation 20 in the SBICS
Revelation 20 in the SBIDS
Revelation 20 in the SBIGS
Revelation 20 in the SBIHS
Revelation 20 in the SBIIS
Revelation 20 in the SBIIS2
Revelation 20 in the SBIIS3
Revelation 20 in the SBIKS
Revelation 20 in the SBIKS2
Revelation 20 in the SBIMS
Revelation 20 in the SBIOS
Revelation 20 in the SBIPS
Revelation 20 in the SBISS
Revelation 20 in the SBITS
Revelation 20 in the SBITS2
Revelation 20 in the SBITS3
Revelation 20 in the SBITS4
Revelation 20 in the SBIUS
Revelation 20 in the SBIVS
Revelation 20 in the SBT
Revelation 20 in the SBT1E
Revelation 20 in the SCHL
Revelation 20 in the SNT
Revelation 20 in the SUSU
Revelation 20 in the SUSU2
Revelation 20 in the SYNO
Revelation 20 in the TBIAOTANT
Revelation 20 in the TBT1E
Revelation 20 in the TBT1E2
Revelation 20 in the TFTIP
Revelation 20 in the TFTU
Revelation 20 in the TGNTATF3T
Revelation 20 in the THAI
Revelation 20 in the TNFD
Revelation 20 in the TNT
Revelation 20 in the TNTIK
Revelation 20 in the TNTIL
Revelation 20 in the TNTIN
Revelation 20 in the TNTIP
Revelation 20 in the TNTIZ
Revelation 20 in the TOMA
Revelation 20 in the TTENT
Revelation 20 in the UBG
Revelation 20 in the UGV
Revelation 20 in the UGV2
Revelation 20 in the UGV3
Revelation 20 in the VBL
Revelation 20 in the VDCC
Revelation 20 in the YALU
Revelation 20 in the YAPE
Revelation 20 in the YBVTP
Revelation 20 in the ZBP