1 Samuel 31 (BOYCB)
1 Nísinsin yìí, àwọn ará Filistini dojú ìjà kọ Israẹli, àwọn ará Israẹli sì sálọ kúrò níwájú wọn, a sì pa ọ̀pọ̀ wọn sí orí òkè Gilboa. 2 Àwọn Filistini sì ń lépa Saulu àti àwọn ọmọ rẹ̀ kíkan; àwọn Filistini sì pa Jonatani àti Abinadabu, àti Malikiṣua, àwọn ọmọ Saulu. 3 Ìjà náà sì burú fún Saulu gidigidi, àwọn tafàtafà si ta á ní ọfà, o sì fi ara pa púpọ̀ lọ́wọ́ àwọn tafàtafà. 4 Saulu sì wí fún ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ pé, “Fa idà rẹ yọ, kí ìwọ sì fi gún mi, kí àwọn aláìkọlà wọ̀nyí má ba à wá gún mi, àti kí wọn kí ó má bá à fi mí ṣe ẹlẹ́yà.”Ṣùgbọ́n ẹni tí ó rú ẹ̀rù ìhámọ́ra rẹ̀ kò fẹ́ ṣe bẹ́ẹ̀, nítorí pé ẹ̀rù bà á gidigidi. Nígbà náà ni Saulu mú idà, ó sì ṣubú lù ú. 5 Nígbà tí ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀ si rí i pé Saulu kú, òun náà sì fi idà rẹ̀ pa ara rẹ̀, ó sì kú pẹ̀lú rẹ̀. 6 Saulu sì kú, àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta, àti ẹni tí ó ru ìhámọ́ra rẹ̀, àti gbogbo àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ ní ọjọ́ kan náà. 7 Nígbà ti àwọn ọkùnrin Israẹli tí ó wà lápá kejì àfonífojì náà, àti àwọn ẹni tí ó wà lápá kejì Jordani, rí pé àwọn ọkùnrin Israẹli sá, àti pé Saulu àti àwọn ọmọkùnrin rẹ ti kú, wọ́n sì fi ìlú sílẹ̀, wọ́n sì sá, àwọn Filistini sì wá, wọ́n sì jókòó si ìlú wọn. 8 Ní ọjọ́ kejì, nígbà tí àwọn Filistini dé láti bọ́ nǹkan tí ń bẹ lára àwọn tí ó kù, wọ́n sì rí pé, Saulu àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta ṣubú ni òkè Gilboa. 9 Wọ́n sì gé orí rẹ̀, wọ́n sì bọ ìhámọ́ra rẹ̀, wọ́n sì ránṣẹ́ lọ ilẹ̀ Filistini káàkiri, láti máa sọ ọ́ ní gbangba ni ilé òrìṣà wọn, àti láàrín àwọn ènìyàn. 10 Wọ́n sì fi ìhámọ́ra rẹ̀ sí ilé Aṣtoreti: wọ́n sì kan òkú rẹ̀ mọ́ odi Beti-Ṣani. 11 Nígbà tí àwọn ará Jabesi Gileadi sì gbọ́ èyí tí àwọn Filistini ṣe sí Saulu. 12 Gbogbo àwọn ọkùnrin alágbára sì dìde, wọ́n sì fi gbogbo òru náà rìn, wọ́n sì gbé òkú Saulu, àti òkú àwọn ọmọ bíbí rẹ̀ kúrò lára odi Beti-Ṣani, wọ́n sì wá sí Jabesi, wọ́n sì sun wọ́n níbẹ̀. 13 Wọ́n sì kó egungun wọn, wọ́n sì sin wọ́n lábẹ́ igi tamariski ní Jabesi, wọ́n sì gbààwẹ̀ ní ọjọ́ méje.
In Other Versions
1 Samuel 31 in the ANGEFD
1 Samuel 31 in the ANTPNG2D
1 Samuel 31 in the AS21
1 Samuel 31 in the BAGH
1 Samuel 31 in the BBPNG
1 Samuel 31 in the BBT1E
1 Samuel 31 in the BDS
1 Samuel 31 in the BEV
1 Samuel 31 in the BHAD
1 Samuel 31 in the BIB
1 Samuel 31 in the BLPT
1 Samuel 31 in the BNT
1 Samuel 31 in the BNTABOOT
1 Samuel 31 in the BNTLV
1 Samuel 31 in the BOATCB
1 Samuel 31 in the BOATCB2
1 Samuel 31 in the BOBCV
1 Samuel 31 in the BOCNT
1 Samuel 31 in the BOECS
1 Samuel 31 in the BOGWICC
1 Samuel 31 in the BOHCB
1 Samuel 31 in the BOHCV
1 Samuel 31 in the BOHLNT
1 Samuel 31 in the BOHNTLTAL
1 Samuel 31 in the BOICB
1 Samuel 31 in the BOILNTAP
1 Samuel 31 in the BOITCV
1 Samuel 31 in the BOKCV
1 Samuel 31 in the BOKCV2
1 Samuel 31 in the BOKHWOG
1 Samuel 31 in the BOKSSV
1 Samuel 31 in the BOLCB
1 Samuel 31 in the BOLCB2
1 Samuel 31 in the BOMCV
1 Samuel 31 in the BONAV
1 Samuel 31 in the BONCB
1 Samuel 31 in the BONLT
1 Samuel 31 in the BONUT2
1 Samuel 31 in the BOPLNT
1 Samuel 31 in the BOSCB
1 Samuel 31 in the BOSNC
1 Samuel 31 in the BOTLNT
1 Samuel 31 in the BOVCB
1 Samuel 31 in the BPBB
1 Samuel 31 in the BPH
1 Samuel 31 in the BSB
1 Samuel 31 in the CCB
1 Samuel 31 in the CUV
1 Samuel 31 in the CUVS
1 Samuel 31 in the DBT
1 Samuel 31 in the DGDNT
1 Samuel 31 in the DHNT
1 Samuel 31 in the DNT
1 Samuel 31 in the ELBE
1 Samuel 31 in the EMTV
1 Samuel 31 in the ESV
1 Samuel 31 in the FBV
1 Samuel 31 in the FEB
1 Samuel 31 in the GGMNT
1 Samuel 31 in the GNT
1 Samuel 31 in the HARY
1 Samuel 31 in the HNT
1 Samuel 31 in the IRVA
1 Samuel 31 in the IRVB
1 Samuel 31 in the IRVG
1 Samuel 31 in the IRVH
1 Samuel 31 in the IRVK
1 Samuel 31 in the IRVM
1 Samuel 31 in the IRVM2
1 Samuel 31 in the IRVO
1 Samuel 31 in the IRVP
1 Samuel 31 in the IRVT
1 Samuel 31 in the IRVT2
1 Samuel 31 in the IRVU
1 Samuel 31 in the ISVN
1 Samuel 31 in the JSNT
1 Samuel 31 in the KAPI
1 Samuel 31 in the KBT1ETNIK
1 Samuel 31 in the KBV
1 Samuel 31 in the KJV
1 Samuel 31 in the KNFD
1 Samuel 31 in the LBA
1 Samuel 31 in the LBLA
1 Samuel 31 in the LNT
1 Samuel 31 in the LSV
1 Samuel 31 in the MAAL
1 Samuel 31 in the MBV
1 Samuel 31 in the MBV2
1 Samuel 31 in the MHNT
1 Samuel 31 in the MKNFD
1 Samuel 31 in the MNG
1 Samuel 31 in the MNT
1 Samuel 31 in the MNT2
1 Samuel 31 in the MRS1T
1 Samuel 31 in the NAA
1 Samuel 31 in the NASB
1 Samuel 31 in the NBLA
1 Samuel 31 in the NBS
1 Samuel 31 in the NBVTP
1 Samuel 31 in the NET2
1 Samuel 31 in the NIV11
1 Samuel 31 in the NNT
1 Samuel 31 in the NNT2
1 Samuel 31 in the NNT3
1 Samuel 31 in the PDDPT
1 Samuel 31 in the PFNT
1 Samuel 31 in the RMNT
1 Samuel 31 in the SBIAS
1 Samuel 31 in the SBIBS
1 Samuel 31 in the SBIBS2
1 Samuel 31 in the SBICS
1 Samuel 31 in the SBIDS
1 Samuel 31 in the SBIGS
1 Samuel 31 in the SBIHS
1 Samuel 31 in the SBIIS
1 Samuel 31 in the SBIIS2
1 Samuel 31 in the SBIIS3
1 Samuel 31 in the SBIKS
1 Samuel 31 in the SBIKS2
1 Samuel 31 in the SBIMS
1 Samuel 31 in the SBIOS
1 Samuel 31 in the SBIPS
1 Samuel 31 in the SBISS
1 Samuel 31 in the SBITS
1 Samuel 31 in the SBITS2
1 Samuel 31 in the SBITS3
1 Samuel 31 in the SBITS4
1 Samuel 31 in the SBIUS
1 Samuel 31 in the SBIVS
1 Samuel 31 in the SBT
1 Samuel 31 in the SBT1E
1 Samuel 31 in the SCHL
1 Samuel 31 in the SNT
1 Samuel 31 in the SUSU
1 Samuel 31 in the SUSU2
1 Samuel 31 in the SYNO
1 Samuel 31 in the TBIAOTANT
1 Samuel 31 in the TBT1E
1 Samuel 31 in the TBT1E2
1 Samuel 31 in the TFTIP
1 Samuel 31 in the TFTU
1 Samuel 31 in the TGNTATF3T
1 Samuel 31 in the THAI
1 Samuel 31 in the TNFD
1 Samuel 31 in the TNT
1 Samuel 31 in the TNTIK
1 Samuel 31 in the TNTIL
1 Samuel 31 in the TNTIN
1 Samuel 31 in the TNTIP
1 Samuel 31 in the TNTIZ
1 Samuel 31 in the TOMA
1 Samuel 31 in the TTENT
1 Samuel 31 in the UBG
1 Samuel 31 in the UGV
1 Samuel 31 in the UGV2
1 Samuel 31 in the UGV3
1 Samuel 31 in the VBL
1 Samuel 31 in the VDCC
1 Samuel 31 in the YALU
1 Samuel 31 in the YAPE
1 Samuel 31 in the YBVTP
1 Samuel 31 in the ZBP