1 Timothy 4 (BOYCB)
1 Nísinsin yìí, èmi ń tẹnumọ́ ọ́ pé ní ìgbà ìkẹyìn àwọn mìíràn yóò kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọn yóò máa fiyèsí àwọn ẹ̀mí tí ń tannijẹ, àti ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù. 2 Nípa àgàbàgebè àwọn tí ń ṣèké, àwọn tí ọkàn tìkára wọn dàbí èyí tí a fi irin gbígbóná jó. 3 Àwọn tí ń dánilẹ́kun láti gbéyàwó tiwọn si ń pàṣẹ láti ka èèwọ̀ oúnjẹ ti Ọlọ́run ti dá fún ìtẹ́wọ́gbà pẹ̀lú ọpẹ́ àwọn onígbàgbọ́ àti àwọn ti ó mọ òtítọ́. 4 Nítorí gbogbo ohun ti Ọlọ́run dá ni ó dára, kò sí ọkàn tí ó yẹ kí a kọ̀, bí a bá fi ọpẹ́ gbà á. 5 Nítorí tí a fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run àti àdúrà yà sí mímọ́. 6 Bí ìwọ bá ń rán àwọn ará létí nǹkan wọ̀nyí, ìwọ ó jẹ́ ìránṣẹ́ rere ti Kristi Jesu, tí a fi ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ àti ẹ̀kọ́ rere bọ́, èyí ti ìwọ ti ń tẹ̀lé. 7 Ṣùgbọ́n kọ ọ̀rọ̀ asán àti ìtàn àwọn àgbà obìnrin, sì máa tọ́ ara rẹ sí ìwà-bí-Ọlọ́run. 8 Nítorí ṣíṣe eré-ìdárayá ni èrè fún ohun díẹ̀, ṣùgbọ́n ìwà-bí-Ọlọ́run ni èrè fún ohun gbogbo, ó ní ìlérí ti ìgbé ayé ìsinsin yìí àti ti èyí tí ń bọ̀. 9 Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ náà, ó sì yẹ fún ìtẹ́wọ́gbà gbogbo. 10 Nítorí fún èyí ni àwa ń ṣe làálàá tí a sì ń jìjàkadì, nítorí àwa ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, ẹni tí í ṣe Olùgbàlà gbogbo ènìyàn, pẹ̀lúpẹ̀lú ti àwọn ti ó gbàgbọ́. 11 Nǹkan wọ̀nyí ni kí ó máa paláṣẹ kí ó máa kọ́ni. 12 Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni gan ìgbà èwe rẹ; ṣùgbọ́n kì ìwọ jẹ́ àpẹẹrẹ fún àwọn tí ó gbàgbọ́, nínú ọ̀rọ̀, nínú ìwà híhù, nínú ìfẹ́, nínú ẹ̀mí, nínú ìgbàgbọ́, nínú ìwà mímọ́. 13 Títí èmi ó fi dé, máa fiyèsí kíkàwé àti ìgbaniníyànjú àti ìkọ́ni. 14 Má ṣe àìnání ẹ̀bùn tí ń bẹ lára rẹ, èyí tí a fi fún ọ nípa ìsọtẹ́lẹ̀ pẹ̀lú ìgbọ́wọ́lé àwọn alàgbà. 15 Máa fiyèsí nǹkan wọ̀nyí; fi ara rẹ fún wọn pátápátá; kí ìlọsíwájú rẹ lè hàn gbangba fún gbogbo ènìyàn. 16 Máa ṣe ìtọ́jú ará rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ; máa dúró láìyẹsẹ̀ nínú nǹkan wọ̀nyí; nítorí ní ṣíṣe èyí, ìwọ ó gba ara rẹ àti tí àwọn ti ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ là.
In Other Versions
1 Timothy 4 in the ANGEFD
1 Timothy 4 in the ANTPNG2D
1 Timothy 4 in the AS21
1 Timothy 4 in the BAGH
1 Timothy 4 in the BBPNG
1 Timothy 4 in the BBT1E
1 Timothy 4 in the BDS
1 Timothy 4 in the BEV
1 Timothy 4 in the BHAD
1 Timothy 4 in the BIB
1 Timothy 4 in the BLPT
1 Timothy 4 in the BNT
1 Timothy 4 in the BNTABOOT
1 Timothy 4 in the BNTLV
1 Timothy 4 in the BOATCB
1 Timothy 4 in the BOATCB2
1 Timothy 4 in the BOBCV
1 Timothy 4 in the BOCNT
1 Timothy 4 in the BOECS
1 Timothy 4 in the BOGWICC
1 Timothy 4 in the BOHCB
1 Timothy 4 in the BOHCV
1 Timothy 4 in the BOHLNT
1 Timothy 4 in the BOHNTLTAL
1 Timothy 4 in the BOICB
1 Timothy 4 in the BOILNTAP
1 Timothy 4 in the BOITCV
1 Timothy 4 in the BOKCV
1 Timothy 4 in the BOKCV2
1 Timothy 4 in the BOKHWOG
1 Timothy 4 in the BOKSSV
1 Timothy 4 in the BOLCB
1 Timothy 4 in the BOLCB2
1 Timothy 4 in the BOMCV
1 Timothy 4 in the BONAV
1 Timothy 4 in the BONCB
1 Timothy 4 in the BONLT
1 Timothy 4 in the BONUT2
1 Timothy 4 in the BOPLNT
1 Timothy 4 in the BOSCB
1 Timothy 4 in the BOSNC
1 Timothy 4 in the BOTLNT
1 Timothy 4 in the BOVCB
1 Timothy 4 in the BPBB
1 Timothy 4 in the BPH
1 Timothy 4 in the BSB
1 Timothy 4 in the CCB
1 Timothy 4 in the CUV
1 Timothy 4 in the CUVS
1 Timothy 4 in the DBT
1 Timothy 4 in the DGDNT
1 Timothy 4 in the DHNT
1 Timothy 4 in the DNT
1 Timothy 4 in the ELBE
1 Timothy 4 in the EMTV
1 Timothy 4 in the ESV
1 Timothy 4 in the FBV
1 Timothy 4 in the FEB
1 Timothy 4 in the GGMNT
1 Timothy 4 in the GNT
1 Timothy 4 in the HARY
1 Timothy 4 in the HNT
1 Timothy 4 in the IRVA
1 Timothy 4 in the IRVB
1 Timothy 4 in the IRVG
1 Timothy 4 in the IRVH
1 Timothy 4 in the IRVK
1 Timothy 4 in the IRVM
1 Timothy 4 in the IRVM2
1 Timothy 4 in the IRVO
1 Timothy 4 in the IRVP
1 Timothy 4 in the IRVT
1 Timothy 4 in the IRVT2
1 Timothy 4 in the IRVU
1 Timothy 4 in the ISVN
1 Timothy 4 in the JSNT
1 Timothy 4 in the KAPI
1 Timothy 4 in the KBT1ETNIK
1 Timothy 4 in the KBV
1 Timothy 4 in the KJV
1 Timothy 4 in the KNFD
1 Timothy 4 in the LBA
1 Timothy 4 in the LBLA
1 Timothy 4 in the LNT
1 Timothy 4 in the LSV
1 Timothy 4 in the MAAL
1 Timothy 4 in the MBV
1 Timothy 4 in the MBV2
1 Timothy 4 in the MHNT
1 Timothy 4 in the MKNFD
1 Timothy 4 in the MNG
1 Timothy 4 in the MNT
1 Timothy 4 in the MNT2
1 Timothy 4 in the MRS1T
1 Timothy 4 in the NAA
1 Timothy 4 in the NASB
1 Timothy 4 in the NBLA
1 Timothy 4 in the NBS
1 Timothy 4 in the NBVTP
1 Timothy 4 in the NET2
1 Timothy 4 in the NIV11
1 Timothy 4 in the NNT
1 Timothy 4 in the NNT2
1 Timothy 4 in the NNT3
1 Timothy 4 in the PDDPT
1 Timothy 4 in the PFNT
1 Timothy 4 in the RMNT
1 Timothy 4 in the SBIAS
1 Timothy 4 in the SBIBS
1 Timothy 4 in the SBIBS2
1 Timothy 4 in the SBICS
1 Timothy 4 in the SBIDS
1 Timothy 4 in the SBIGS
1 Timothy 4 in the SBIHS
1 Timothy 4 in the SBIIS
1 Timothy 4 in the SBIIS2
1 Timothy 4 in the SBIIS3
1 Timothy 4 in the SBIKS
1 Timothy 4 in the SBIKS2
1 Timothy 4 in the SBIMS
1 Timothy 4 in the SBIOS
1 Timothy 4 in the SBIPS
1 Timothy 4 in the SBISS
1 Timothy 4 in the SBITS
1 Timothy 4 in the SBITS2
1 Timothy 4 in the SBITS3
1 Timothy 4 in the SBITS4
1 Timothy 4 in the SBIUS
1 Timothy 4 in the SBIVS
1 Timothy 4 in the SBT
1 Timothy 4 in the SBT1E
1 Timothy 4 in the SCHL
1 Timothy 4 in the SNT
1 Timothy 4 in the SUSU
1 Timothy 4 in the SUSU2
1 Timothy 4 in the SYNO
1 Timothy 4 in the TBIAOTANT
1 Timothy 4 in the TBT1E
1 Timothy 4 in the TBT1E2
1 Timothy 4 in the TFTIP
1 Timothy 4 in the TFTU
1 Timothy 4 in the TGNTATF3T
1 Timothy 4 in the THAI
1 Timothy 4 in the TNFD
1 Timothy 4 in the TNT
1 Timothy 4 in the TNTIK
1 Timothy 4 in the TNTIL
1 Timothy 4 in the TNTIN
1 Timothy 4 in the TNTIP
1 Timothy 4 in the TNTIZ
1 Timothy 4 in the TOMA
1 Timothy 4 in the TTENT
1 Timothy 4 in the UBG
1 Timothy 4 in the UGV
1 Timothy 4 in the UGV2
1 Timothy 4 in the UGV3
1 Timothy 4 in the VBL
1 Timothy 4 in the VDCC
1 Timothy 4 in the YALU
1 Timothy 4 in the YAPE
1 Timothy 4 in the YBVTP
1 Timothy 4 in the ZBP